Colossians 2 (BOYCB)
1 Mo fẹ́ kí ẹ mọ bí mo ti ń jìjàkadì fún un yín àti fún àwọn ará Laodikea àti fún ọ̀pọ̀ ènìyàn mìíràn tí wọn kò ì tí ì rí mi sójú rí. 2 Ohun tí mo ń béèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run fún un yín nínú àdúrà mi ni pé, kí a lè mú yín lọ́kàn le, kí a sì lè so yín pọ̀ pẹ̀lú ìfẹ́ to lágbára, kí ẹ le ní àṣírí ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run lẹ́kùnrẹ́rẹ́. Àṣírí ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run náà ni Kristi fúnra rẹ̀. 3 Nínú ẹni tí a fi gbogbo ìṣúra ìjìnlẹ̀ ọgbọ́n àti ìmọ̀ pamọ́ sí. 4 Mo sọ èyí fún un yín kí ẹnikẹ́ni ma ba à fi ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn mú yín ṣìnà. 5 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé èmi kò sí i lọ́dọ̀ yín nínú ara, ṣùgbọ́n mo wà lọ́dọ̀ yín nínú ẹ̀mí, bẹ́ẹ̀ ni mo sì ń yọ̀ láti kíyèsi ètò yín àti bí ìdúró ṣinṣin yín nínú Kristi ti rí. 6 Nítorí náà, bí ẹ̀yin ti gba Jesu Kristi gẹ́gẹ́ bí Olúwa, bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ̀yin máa gbé nínú rẹ̀. 7 Ẹ fi gbòǹgbò múlẹ̀, kí a sì gbé yín ró nínú rẹ̀, kí ẹ sì fi ẹsẹ̀ múlẹ̀ nínú ìgbàgbọ́ yín, bí a ti kọ́ yín, àti kí ẹ sì máa pọ̀ nínú rẹ̀ pẹ̀lú ọpẹ́. 8 Ẹ rí dájú pé ẹnikẹ́ni kò mú yin ní ìgbèkùn pẹ̀lú ẹ̀kọ́ àròsọ àti ìmọ̀ ẹ̀tàn, èyí tí ó gbára lé ìlànà ti ènìyàn àti àgbékalẹ̀ àwọn ẹ̀mí ayé yìí tí ó yàtọ̀ sí ti Kristi. 9 Nítorí nínú Kristi ni ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìwàláàyè Ọlọ́run gbé ní ara, 10 ẹ̀yin sì ní ohun gbogbo ní kíkún nínú Kristi, ẹni tí i ṣe orí fún gbogbo agbára àti àṣẹ. 11 Nínú ẹni tí a kò fi ìkọlà tí a fi ọwọ́ kọ kọ yín ní ilà, ni bíbọ ara ẹ̀ṣẹ̀ sílẹ̀, nínú ìkọlà Kristi. 12 Bí a ti sin yín pọ̀ pẹ̀lú rẹ̀ nínú ìtẹ̀bọmi, tí a sì ti jí yín dìde pẹ̀lú rẹ̀ nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ yín nínú agbára Ọlọ́run, ẹni tí ó jí dìde kúrò nínú òkú. 13 Àti ẹ̀yin, ẹni tí ó ti kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ yín àti àìkọlà ará yín, mo ní, ẹ̀yin ni ó sì ti sọ di ààyè pọ̀ pẹ̀lú rẹ̀, ó sì ti dárí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ yín jì yín; 14 Ó sì ti pa ìwé májẹ̀mú nì rẹ́, tí ó lòdì sí wa, tí a kọ nínú òfin, èyí tí o lòdì sí wa: òun ni ó sì ti mú kúrò lójú ọ̀nà, ó sì kàn án mọ àgbélébùú. 15 Ó sì ti gba agbára kúrò lọ́wọ́ àwọn ìjọba ẹ̀mí búburú àti àwọn alágbára gbogbo, ó sì ti dójútì wọn ní gbangba, bí ó ti ń yọ̀ fún ìṣẹ́gun lórí wọn. 16 Nítorí náà ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni ṣe ìdájọ́ yín ní ti jíjẹ, tàbí ní ti mímu, tàbí ní ti ọjọ́ àsè, tàbí oṣù tuntun, àti ọjọ́ ìsinmi. 17 Àwọn tí í ṣe òjìji ohun tí ń bọ̀; ṣùgbọ́n ní ti òtítọ́, nínú Kristi ni àti mu wọn ṣẹ. 18 Ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni tí ó ní inú dídùn nínú ìrẹ̀lẹ̀ èké àti bíbọ àwọn angẹli lọ́ èrè yín gbà lọ́wọ́ yín, ẹni tí ń dúró lórí nǹkan wọ̀n-ọn-nì tí ó ti rí, tí ó ń ṣe féfé asán nípa èrò ti ọkàn ara rẹ̀. 19 Wọn ti sọ ìdàpọ̀ wọn pẹ̀lú ẹni tí i ṣe orí nu, láti ọ̀dọ̀ ẹni tí a ń ti ipa oríkèé àti iṣan pèsè fún gbogbo ara, ti a sì ń so ó ṣọ̀kan pọ̀, tí ó sì ń dàgbà nípa ìmísí Ọlọ́run. 20 Bí ẹ̀yin bá ti kú pẹ̀lú Kristi si àwọn agbára ìlànà ayé yìí, kín ló dé tí ẹ̀yin ń tẹríba fún òfin bí ẹni pé ẹ̀yin wà nínú ayé. 21 Má ṣe dìímú, má ṣe tọ́ ọ wò, má ṣe fi ọwọ́ bà á. 22 Gbogbo èyí tí yóò ti ipa lílo run, gẹ́gẹ́ bí òfin àti ẹ̀kọ́ ènìyàn? 23 Àwọn nǹkan tí ó ní àfarawé ọgbọ́n nítòótọ́, nípasẹ̀ àdábọwọ́ ìsìn, àti ìrẹ̀lẹ̀, àti ìpọ́nra-ẹni-lójú, ṣùgbọ́n tí kò ni èrè láti di ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara ku.
In Other Versions
Colossians 2 in the ANGEFD
Colossians 2 in the ANTPNG2D
Colossians 2 in the AS21
Colossians 2 in the BAGH
Colossians 2 in the BBPNG
Colossians 2 in the BBT1E
Colossians 2 in the BDS
Colossians 2 in the BEV
Colossians 2 in the BHAD
Colossians 2 in the BIB
Colossians 2 in the BLPT
Colossians 2 in the BNT
Colossians 2 in the BNTABOOT
Colossians 2 in the BNTLV
Colossians 2 in the BOATCB
Colossians 2 in the BOATCB2
Colossians 2 in the BOBCV
Colossians 2 in the BOCNT
Colossians 2 in the BOECS
Colossians 2 in the BOGWICC
Colossians 2 in the BOHCB
Colossians 2 in the BOHCV
Colossians 2 in the BOHLNT
Colossians 2 in the BOHNTLTAL
Colossians 2 in the BOICB
Colossians 2 in the BOILNTAP
Colossians 2 in the BOITCV
Colossians 2 in the BOKCV
Colossians 2 in the BOKCV2
Colossians 2 in the BOKHWOG
Colossians 2 in the BOKSSV
Colossians 2 in the BOLCB
Colossians 2 in the BOLCB2
Colossians 2 in the BOMCV
Colossians 2 in the BONAV
Colossians 2 in the BONCB
Colossians 2 in the BONLT
Colossians 2 in the BONUT2
Colossians 2 in the BOPLNT
Colossians 2 in the BOSCB
Colossians 2 in the BOSNC
Colossians 2 in the BOTLNT
Colossians 2 in the BOVCB
Colossians 2 in the BPBB
Colossians 2 in the BPH
Colossians 2 in the BSB
Colossians 2 in the CCB
Colossians 2 in the CUV
Colossians 2 in the CUVS
Colossians 2 in the DBT
Colossians 2 in the DGDNT
Colossians 2 in the DHNT
Colossians 2 in the DNT
Colossians 2 in the ELBE
Colossians 2 in the EMTV
Colossians 2 in the ESV
Colossians 2 in the FBV
Colossians 2 in the FEB
Colossians 2 in the GGMNT
Colossians 2 in the GNT
Colossians 2 in the HARY
Colossians 2 in the HNT
Colossians 2 in the IRVA
Colossians 2 in the IRVB
Colossians 2 in the IRVG
Colossians 2 in the IRVH
Colossians 2 in the IRVK
Colossians 2 in the IRVM
Colossians 2 in the IRVM2
Colossians 2 in the IRVO
Colossians 2 in the IRVP
Colossians 2 in the IRVT
Colossians 2 in the IRVT2
Colossians 2 in the IRVU
Colossians 2 in the ISVN
Colossians 2 in the JSNT
Colossians 2 in the KAPI
Colossians 2 in the KBT1ETNIK
Colossians 2 in the KBV
Colossians 2 in the KJV
Colossians 2 in the KNFD
Colossians 2 in the LBA
Colossians 2 in the LBLA
Colossians 2 in the LNT
Colossians 2 in the LSV
Colossians 2 in the MAAL
Colossians 2 in the MBV
Colossians 2 in the MBV2
Colossians 2 in the MHNT
Colossians 2 in the MKNFD
Colossians 2 in the MNG
Colossians 2 in the MNT
Colossians 2 in the MNT2
Colossians 2 in the MRS1T
Colossians 2 in the NAA
Colossians 2 in the NASB
Colossians 2 in the NBLA
Colossians 2 in the NBS
Colossians 2 in the NBVTP
Colossians 2 in the NET2
Colossians 2 in the NIV11
Colossians 2 in the NNT
Colossians 2 in the NNT2
Colossians 2 in the NNT3
Colossians 2 in the PDDPT
Colossians 2 in the PFNT
Colossians 2 in the RMNT
Colossians 2 in the SBIAS
Colossians 2 in the SBIBS
Colossians 2 in the SBIBS2
Colossians 2 in the SBICS
Colossians 2 in the SBIDS
Colossians 2 in the SBIGS
Colossians 2 in the SBIHS
Colossians 2 in the SBIIS
Colossians 2 in the SBIIS2
Colossians 2 in the SBIIS3
Colossians 2 in the SBIKS
Colossians 2 in the SBIKS2
Colossians 2 in the SBIMS
Colossians 2 in the SBIOS
Colossians 2 in the SBIPS
Colossians 2 in the SBISS
Colossians 2 in the SBITS
Colossians 2 in the SBITS2
Colossians 2 in the SBITS3
Colossians 2 in the SBITS4
Colossians 2 in the SBIUS
Colossians 2 in the SBIVS
Colossians 2 in the SBT
Colossians 2 in the SBT1E
Colossians 2 in the SCHL
Colossians 2 in the SNT
Colossians 2 in the SUSU
Colossians 2 in the SUSU2
Colossians 2 in the SYNO
Colossians 2 in the TBIAOTANT
Colossians 2 in the TBT1E
Colossians 2 in the TBT1E2
Colossians 2 in the TFTIP
Colossians 2 in the TFTU
Colossians 2 in the TGNTATF3T
Colossians 2 in the THAI
Colossians 2 in the TNFD
Colossians 2 in the TNT
Colossians 2 in the TNTIK
Colossians 2 in the TNTIL
Colossians 2 in the TNTIN
Colossians 2 in the TNTIP
Colossians 2 in the TNTIZ
Colossians 2 in the TOMA
Colossians 2 in the TTENT
Colossians 2 in the UBG
Colossians 2 in the UGV
Colossians 2 in the UGV2
Colossians 2 in the UGV3
Colossians 2 in the VBL
Colossians 2 in the VDCC
Colossians 2 in the YALU
Colossians 2 in the YAPE
Colossians 2 in the YBVTP
Colossians 2 in the ZBP