Ecclesiastes 4 (BOYCB)

1 Mo sì tún wò ó, mo sì rí gbogbo ìnilára tí ó ń ṣẹlẹ̀ lábẹ́ oòrùn,mo rí ẹkún àwọn tí ara ń ni,wọn kò sì ní olùtùnú kankan,agbára wà ní ìkápá àwọn tí ó ń ni wọ́n lára,wọn kò sì ní olùtùnú kankan. 2 Mo jowú àwọn tí wọ́n ti kútí wọ́n sì ti lọ,ó sàn fún wọn ju àwọntí wọ́n sì wà láààyè lọ. 3 Nítòótọ́, ẹni tí kò tí ì sí sàn juàwọn méjèèjì lọ:ẹni tí kò tí ì rí iṣẹ́ búburútí ó ń lọ ní abẹ́ oòrùn. 4 Mo sì tún mọ̀ pẹ̀lú, ìdí tí ènìyàn fi ń ṣiṣẹ́ tagbára tagbára láti ṣe àṣeyọrí, nítorí pé wọn ń jowú àwọn aládùúgbò wọn ni. Ṣùgbọ́n, asán ni, ó dàbí ẹni ń gbìyànjú àti mú afẹ́fẹ́. 5 Aṣiwèrè ká ọwọ́ rẹ̀ kòó sì ba tara rẹ̀ jẹ́. 6 Oúnjẹ ẹ̀kúnwọ́ kan pẹ̀lú ìdákẹ́ jẹ́ẹ́jẹ́ sàn ju ẹ̀kúnwọ́ méjì pẹ̀lú wàhálà,àti gbígba ìyànjú àti lé afẹ́fẹ́ lọ. 7 Lẹ́ẹ̀kan sí i, mo tún rí ohun asán kan lábẹ́ oòrùn. 8 Ọkùnrin kan ṣoṣo dá wà;kò ní ọmọkùnrin kankan tàbí ẹbí.Kò sí òpin nínú làálàá rẹ̀ gbogbo,síbẹ̀, ọrọ̀ kò tẹ́ ojú rẹ̀ lọ́rùn.Bẹ́ẹ̀ ni kò sì wí pé, “Nítorí ta ni èmí ṣe ń ṣe làálàá,àti wí pé, èétiṣe tí mo fi ń fi ìgbádùn du ara mi?”Eléyìí náà asán ni,iṣẹ́ òsì! 9 Ẹni méjì sàn ju ẹnìkan,nítorí wọ́n ní èrè rere fún làálàá wọn. 10 Tí ọ̀kan bá ṣubú lulẹ̀,ọ̀rẹ́ rẹ̀ le è ràn án lọ́wọ́ kí ó fà á sókè,ṣùgbọ́n ìyọnu ni fún ọkùnrin náà tí ó ṣubútí kò sì ní ẹni tí ó le è ràn án lọ́wọ́! 11 Àti pẹ̀lú pé, bí ẹni méjì bá sùn pọ̀, wọn yóò móoru.Ṣùgbọ́n báwo ni ẹnìkan ṣe le è dá nìkan móoru? 12 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, a le è kojú ogun ẹnìkan,àwọn méjì le è gbìjà ara wọn,ìkọ́ okùn mẹ́ta kì í dùn ún yára fà já. 13 Òtòṣì ìpẹ́ẹ̀rẹ̀ tí ó ṣe ọlọ́gbọ́n, ó sàn ju arúgbó àti aṣiwèrè ọba lọ tí kò mọ bí yóò ti ṣe gba ìmọ̀ràn. 14 Nítorí pé láti inú túbú ni ó ti jáde láti jẹ ọba, bí a tilẹ̀ bí i ní tálákà ní ìjọba rẹ̀. 15 Mo rí gbogbo alààyè tí ń rìn lábẹ́ oòrùn, pẹ̀lú ìpẹ́ẹ̀rẹ̀ kejì tí yóò gba ipò ọba yìí. 16 Gbogbo àwọn tí ó wà níwájú wọn kò sì lópin, ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ àwọn ènìyàn ní ó jẹ ọba lé lórí, ẹni tí ó wà ní ipò yìí kò dùn mọ́ àwọn tí ó tẹ̀lé wọn nínú. Asán ni eléyìí pẹ̀lú jẹ́, ó dàbí ẹni ń gbìyànjú àti mú afẹ́fẹ́ ni.

In Other Versions

Ecclesiastes 4 in the ANGEFD

Ecclesiastes 4 in the ANTPNG2D

Ecclesiastes 4 in the AS21

Ecclesiastes 4 in the BAGH

Ecclesiastes 4 in the BBPNG

Ecclesiastes 4 in the BBT1E

Ecclesiastes 4 in the BDS

Ecclesiastes 4 in the BEV

Ecclesiastes 4 in the BHAD

Ecclesiastes 4 in the BIB

Ecclesiastes 4 in the BLPT

Ecclesiastes 4 in the BNT

Ecclesiastes 4 in the BNTABOOT

Ecclesiastes 4 in the BNTLV

Ecclesiastes 4 in the BOATCB

Ecclesiastes 4 in the BOATCB2

Ecclesiastes 4 in the BOBCV

Ecclesiastes 4 in the BOCNT

Ecclesiastes 4 in the BOECS

Ecclesiastes 4 in the BOGWICC

Ecclesiastes 4 in the BOHCB

Ecclesiastes 4 in the BOHCV

Ecclesiastes 4 in the BOHLNT

Ecclesiastes 4 in the BOHNTLTAL

Ecclesiastes 4 in the BOICB

Ecclesiastes 4 in the BOILNTAP

Ecclesiastes 4 in the BOITCV

Ecclesiastes 4 in the BOKCV

Ecclesiastes 4 in the BOKCV2

Ecclesiastes 4 in the BOKHWOG

Ecclesiastes 4 in the BOKSSV

Ecclesiastes 4 in the BOLCB

Ecclesiastes 4 in the BOLCB2

Ecclesiastes 4 in the BOMCV

Ecclesiastes 4 in the BONAV

Ecclesiastes 4 in the BONCB

Ecclesiastes 4 in the BONLT

Ecclesiastes 4 in the BONUT2

Ecclesiastes 4 in the BOPLNT

Ecclesiastes 4 in the BOSCB

Ecclesiastes 4 in the BOSNC

Ecclesiastes 4 in the BOTLNT

Ecclesiastes 4 in the BOVCB

Ecclesiastes 4 in the BPBB

Ecclesiastes 4 in the BPH

Ecclesiastes 4 in the BSB

Ecclesiastes 4 in the CCB

Ecclesiastes 4 in the CUV

Ecclesiastes 4 in the CUVS

Ecclesiastes 4 in the DBT

Ecclesiastes 4 in the DGDNT

Ecclesiastes 4 in the DHNT

Ecclesiastes 4 in the DNT

Ecclesiastes 4 in the ELBE

Ecclesiastes 4 in the EMTV

Ecclesiastes 4 in the ESV

Ecclesiastes 4 in the FBV

Ecclesiastes 4 in the FEB

Ecclesiastes 4 in the GGMNT

Ecclesiastes 4 in the GNT

Ecclesiastes 4 in the HARY

Ecclesiastes 4 in the HNT

Ecclesiastes 4 in the IRVA

Ecclesiastes 4 in the IRVB

Ecclesiastes 4 in the IRVG

Ecclesiastes 4 in the IRVH

Ecclesiastes 4 in the IRVK

Ecclesiastes 4 in the IRVM

Ecclesiastes 4 in the IRVM2

Ecclesiastes 4 in the IRVO

Ecclesiastes 4 in the IRVP

Ecclesiastes 4 in the IRVT

Ecclesiastes 4 in the IRVT2

Ecclesiastes 4 in the IRVU

Ecclesiastes 4 in the ISVN

Ecclesiastes 4 in the JSNT

Ecclesiastes 4 in the KAPI

Ecclesiastes 4 in the KBT1ETNIK

Ecclesiastes 4 in the KBV

Ecclesiastes 4 in the KJV

Ecclesiastes 4 in the KNFD

Ecclesiastes 4 in the LBA

Ecclesiastes 4 in the LBLA

Ecclesiastes 4 in the LNT

Ecclesiastes 4 in the LSV

Ecclesiastes 4 in the MAAL

Ecclesiastes 4 in the MBV

Ecclesiastes 4 in the MBV2

Ecclesiastes 4 in the MHNT

Ecclesiastes 4 in the MKNFD

Ecclesiastes 4 in the MNG

Ecclesiastes 4 in the MNT

Ecclesiastes 4 in the MNT2

Ecclesiastes 4 in the MRS1T

Ecclesiastes 4 in the NAA

Ecclesiastes 4 in the NASB

Ecclesiastes 4 in the NBLA

Ecclesiastes 4 in the NBS

Ecclesiastes 4 in the NBVTP

Ecclesiastes 4 in the NET2

Ecclesiastes 4 in the NIV11

Ecclesiastes 4 in the NNT

Ecclesiastes 4 in the NNT2

Ecclesiastes 4 in the NNT3

Ecclesiastes 4 in the PDDPT

Ecclesiastes 4 in the PFNT

Ecclesiastes 4 in the RMNT

Ecclesiastes 4 in the SBIAS

Ecclesiastes 4 in the SBIBS

Ecclesiastes 4 in the SBIBS2

Ecclesiastes 4 in the SBICS

Ecclesiastes 4 in the SBIDS

Ecclesiastes 4 in the SBIGS

Ecclesiastes 4 in the SBIHS

Ecclesiastes 4 in the SBIIS

Ecclesiastes 4 in the SBIIS2

Ecclesiastes 4 in the SBIIS3

Ecclesiastes 4 in the SBIKS

Ecclesiastes 4 in the SBIKS2

Ecclesiastes 4 in the SBIMS

Ecclesiastes 4 in the SBIOS

Ecclesiastes 4 in the SBIPS

Ecclesiastes 4 in the SBISS

Ecclesiastes 4 in the SBITS

Ecclesiastes 4 in the SBITS2

Ecclesiastes 4 in the SBITS3

Ecclesiastes 4 in the SBITS4

Ecclesiastes 4 in the SBIUS

Ecclesiastes 4 in the SBIVS

Ecclesiastes 4 in the SBT

Ecclesiastes 4 in the SBT1E

Ecclesiastes 4 in the SCHL

Ecclesiastes 4 in the SNT

Ecclesiastes 4 in the SUSU

Ecclesiastes 4 in the SUSU2

Ecclesiastes 4 in the SYNO

Ecclesiastes 4 in the TBIAOTANT

Ecclesiastes 4 in the TBT1E

Ecclesiastes 4 in the TBT1E2

Ecclesiastes 4 in the TFTIP

Ecclesiastes 4 in the TFTU

Ecclesiastes 4 in the TGNTATF3T

Ecclesiastes 4 in the THAI

Ecclesiastes 4 in the TNFD

Ecclesiastes 4 in the TNT

Ecclesiastes 4 in the TNTIK

Ecclesiastes 4 in the TNTIL

Ecclesiastes 4 in the TNTIN

Ecclesiastes 4 in the TNTIP

Ecclesiastes 4 in the TNTIZ

Ecclesiastes 4 in the TOMA

Ecclesiastes 4 in the TTENT

Ecclesiastes 4 in the UBG

Ecclesiastes 4 in the UGV

Ecclesiastes 4 in the UGV2

Ecclesiastes 4 in the UGV3

Ecclesiastes 4 in the VBL

Ecclesiastes 4 in the VDCC

Ecclesiastes 4 in the YALU

Ecclesiastes 4 in the YAPE

Ecclesiastes 4 in the YBVTP

Ecclesiastes 4 in the ZBP