Genesis 14 (BOYCB)
1 Ní àsìkò yìí ni Amrafeli ọba Ṣinari, Arioku ọba Ellasari, Kedorlaomeri ọba Elamu àti Tidali ọba Goyimu 2 jáde lọ láti bá Bera ọba Sodomu, Birṣa ọba Gomorra, Ṣenabu ọba Adma, Ṣemeberi ọba Seboimu àti ọba Bela (èyí ni Soari) jagun. 3 Gbogbo àwọn ọba wọ̀nyí ni ó kó ogun wọn jọ pọ̀ sí àfonífojì Siddimu (ti o túmọ̀ sí Òkun Iyọ̀). 4 Fún ọdún méjìlá gbáko ni wọ́n ti ń sin Kedorlaomeri bí ẹrú. Ṣùgbọ́n nígbà tí ó di ọdún kẹtàlá wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i. 5 Ní ọdún kẹrìnlá, ni Kedorlaomeri àti àwọn ọba tí wọ́n ti jọ ni májẹ̀mú àṣepọ̀ wá, wọ́n ṣígun, wọ́n sì ṣẹ́gun ará Refaimu ní Aṣteroti-Karnaimu, àwọn ará Susimu ni Hamu, àwọn ará Emimu ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Kiriataimu, 6 àti àwọn ará Hori ní orí òkè wọ̀n-ọn-nì Seiri, títí ó fi dé Eli-Parani ní etí ijù. 7 Wọ́n sì tún yípadà lọ sí En-Miṣpati (ti o túmọ̀ sí Kadeṣi), wọ́n sì ṣẹ́gun gbogbo ilẹ̀ àwọn Amaleki, àti àwọn ará Amori tí ó tẹ̀dó sí Hasason Tamari pẹ̀lú. 8 Nígbà náà ni ọba Sodomu, ọba Gomorra, ọba Adma, ọba Seboimu àti ọba Bela (èyí ni Soari), kó àwọn ọmọ-ogun wọn, wọ́n sì pa ibùdó ogun wọn sí Àfonífojì Siddimu, 9 láti kojú ìjà sí Kedorlaomeri ọba Elamu, Tidali ọba Goyimu, Amrafeli ọba Ṣinari àti Arioku ọba Ellasari (ọba mẹ́rin kọjú ìjà sí ọba márùn-ún). 10 Àfonífojì Siddimu sì kún fún kòtò ọ̀dà ilẹ̀, nígbà tí ọba Sodomu àti ọba Gomorra sì sá, díẹ̀ nínú àwọn ọkùnrin ogun náà ṣubú sínú àwọn kòtò náà, àwọn tókù sì sálọ sì orí òkè. 11 Àwọn ọba mẹ́rẹ̀ẹ̀rin náà sì kó gbogbo ẹrù Sodomu àti Gomorra àti oúnjẹ wọn; wọ́n sì lọ. 12 Wọ́n sì mú Lọti ọmọ arákùnrin Abramu tí ń gbé ní Sodomu àti gbogbo ohun ìní rẹ̀. 13 Ẹnìkan tí ó sá àsálà sì wá ròyìn fún Abramu, ará Heberu ni. Abramu sá ti tẹ̀dó sí ẹ̀gbẹ́ igi ńlá igbó Mamre ará Amori, arákùnrin Eṣkolu àti Aneri: àwọn ẹni tí ó ń bá Abramu ní àṣepọ̀. 14 Nígbà tí Abramu gbọ́ wí pé, a di Lọti ní ìgbèkùn, ó kó àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ tí a bí sí ilẹ̀ rẹ̀ tí ó sì ti kọ́ ni ogun jíjà jáde, wọ́n jẹ́ okòó lé lọ́ọ̀dúnrún ó dín méjì (318) ènìyàn, ó sì lépa wọn títí dé Dani. 15 Ní ọ̀gànjọ́ òru, Abramu pín àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ sí méjì, ó sì kọlù wọ́n, ó sì ṣẹ́gun wọn, ó sì lé wọn títí dé Hoba tí ó wà ní apá òsì Damasku. 16 Gbogbo ìkógun ni ó rí gbà padà àti ọmọ arákùnrin rẹ̀, Lọti pẹ̀lú ohun ìní rẹ̀, àti àwọn obìnrin pẹ̀lú àwọn ènìyàn tókù. 17 Nígbà tí Abramu ti ṣẹ́gun Kedorlaomeri àti àwọn ọba tí ó pẹ̀lú rẹ̀, ọba Sodomu lọ pàdé rẹ̀ ní àfonífojì Ṣafe (èyí ni àfonífojì Ọba). 18 Melkisedeki ọba Salẹmu sì mú oúnjẹ àti ọtí wáìnì jáde wá. Òun ni àlùfáà Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo. 19 Ó sì súre fún Abramu, wí pé,“Ìbùkún ni fún Abramu ti Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo,Ẹni tí ó dá ọ̀run òun ayé. 20 Ìbùkún sì ni fún Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo jùlọ,tí ó fi àwọn ọ̀tá rẹ lé ọ lọ́wọ́.”Abramu sì fún un ní ìdámẹ́wàá ohun gbogbo. 21 Ọba Sodomu sì wí fún Abramu pé, “Kó àwọn ènìyàn mi fún mi, ṣùgbọ́n mú àwọn ẹrù fún ara rẹ.” 22 Ṣùgbọ́n Abramu dá ọba Sodomu lóhùn pé, “Mo ti búra fún OLÚWA, Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo, tí ó dá ọ̀run àti ayé, mo sì ti gbọ́wọ́ sókè, 23 pé, èmi kì yóò mú láti fọ́nrán òwú títí dé okùn bàtà, àti pé, èmi kí yóò mú ohun kan tí ṣe tìrẹ, kí ìwọ kí ó má ba à wí pé, ‘Mo sọ Abramu di ọlọ́rọ̀.’ 24 Èmi kì yóò gba ohunkóhun yàtọ̀ sí ohun tí àwọn ọkùnrin mi ti jẹ́, ṣùgbọ́n fi ìpín fún àwọn ọkùnrin tí ó bá mi lọ, Aneri, Eṣkolu àti Mamre. Jẹ́ kí wọn kí ó gba ìpín wọn.”
In Other Versions
Genesis 14 in the ANGEFD
Genesis 14 in the ANTPNG2D
Genesis 14 in the AS21
Genesis 14 in the BAGH
Genesis 14 in the BBPNG
Genesis 14 in the BBT1E
Genesis 14 in the BDS
Genesis 14 in the BEV
Genesis 14 in the BHAD
Genesis 14 in the BIB
Genesis 14 in the BLPT
Genesis 14 in the BNT
Genesis 14 in the BNTABOOT
Genesis 14 in the BNTLV
Genesis 14 in the BOATCB
Genesis 14 in the BOATCB2
Genesis 14 in the BOBCV
Genesis 14 in the BOCNT
Genesis 14 in the BOECS
Genesis 14 in the BOGWICC
Genesis 14 in the BOHCB
Genesis 14 in the BOHCV
Genesis 14 in the BOHLNT
Genesis 14 in the BOHNTLTAL
Genesis 14 in the BOICB
Genesis 14 in the BOILNTAP
Genesis 14 in the BOITCV
Genesis 14 in the BOKCV
Genesis 14 in the BOKCV2
Genesis 14 in the BOKHWOG
Genesis 14 in the BOKSSV
Genesis 14 in the BOLCB
Genesis 14 in the BOLCB2
Genesis 14 in the BOMCV
Genesis 14 in the BONAV
Genesis 14 in the BONCB
Genesis 14 in the BONLT
Genesis 14 in the BONUT2
Genesis 14 in the BOPLNT
Genesis 14 in the BOSCB
Genesis 14 in the BOSNC
Genesis 14 in the BOTLNT
Genesis 14 in the BOVCB
Genesis 14 in the BPBB
Genesis 14 in the BPH
Genesis 14 in the BSB
Genesis 14 in the CCB
Genesis 14 in the CUV
Genesis 14 in the CUVS
Genesis 14 in the DBT
Genesis 14 in the DGDNT
Genesis 14 in the DHNT
Genesis 14 in the DNT
Genesis 14 in the ELBE
Genesis 14 in the EMTV
Genesis 14 in the ESV
Genesis 14 in the FBV
Genesis 14 in the FEB
Genesis 14 in the GGMNT
Genesis 14 in the GNT
Genesis 14 in the HARY
Genesis 14 in the HNT
Genesis 14 in the IRVA
Genesis 14 in the IRVB
Genesis 14 in the IRVG
Genesis 14 in the IRVH
Genesis 14 in the IRVK
Genesis 14 in the IRVM
Genesis 14 in the IRVM2
Genesis 14 in the IRVO
Genesis 14 in the IRVP
Genesis 14 in the IRVT
Genesis 14 in the IRVT2
Genesis 14 in the IRVU
Genesis 14 in the ISVN
Genesis 14 in the JSNT
Genesis 14 in the KAPI
Genesis 14 in the KBT1ETNIK
Genesis 14 in the KBV
Genesis 14 in the KJV
Genesis 14 in the KNFD
Genesis 14 in the LBA
Genesis 14 in the LBLA
Genesis 14 in the LNT
Genesis 14 in the LSV
Genesis 14 in the MAAL
Genesis 14 in the MBV
Genesis 14 in the MBV2
Genesis 14 in the MHNT
Genesis 14 in the MKNFD
Genesis 14 in the MNG
Genesis 14 in the MNT
Genesis 14 in the MNT2
Genesis 14 in the MRS1T
Genesis 14 in the NAA
Genesis 14 in the NASB
Genesis 14 in the NBLA
Genesis 14 in the NBS
Genesis 14 in the NBVTP
Genesis 14 in the NET2
Genesis 14 in the NIV11
Genesis 14 in the NNT
Genesis 14 in the NNT2
Genesis 14 in the NNT3
Genesis 14 in the PDDPT
Genesis 14 in the PFNT
Genesis 14 in the RMNT
Genesis 14 in the SBIAS
Genesis 14 in the SBIBS
Genesis 14 in the SBIBS2
Genesis 14 in the SBICS
Genesis 14 in the SBIDS
Genesis 14 in the SBIGS
Genesis 14 in the SBIHS
Genesis 14 in the SBIIS
Genesis 14 in the SBIIS2
Genesis 14 in the SBIIS3
Genesis 14 in the SBIKS
Genesis 14 in the SBIKS2
Genesis 14 in the SBIMS
Genesis 14 in the SBIOS
Genesis 14 in the SBIPS
Genesis 14 in the SBISS
Genesis 14 in the SBITS
Genesis 14 in the SBITS2
Genesis 14 in the SBITS3
Genesis 14 in the SBITS4
Genesis 14 in the SBIUS
Genesis 14 in the SBIVS
Genesis 14 in the SBT
Genesis 14 in the SBT1E
Genesis 14 in the SCHL
Genesis 14 in the SNT
Genesis 14 in the SUSU
Genesis 14 in the SUSU2
Genesis 14 in the SYNO
Genesis 14 in the TBIAOTANT
Genesis 14 in the TBT1E
Genesis 14 in the TBT1E2
Genesis 14 in the TFTIP
Genesis 14 in the TFTU
Genesis 14 in the TGNTATF3T
Genesis 14 in the THAI
Genesis 14 in the TNFD
Genesis 14 in the TNT
Genesis 14 in the TNTIK
Genesis 14 in the TNTIL
Genesis 14 in the TNTIN
Genesis 14 in the TNTIP
Genesis 14 in the TNTIZ
Genesis 14 in the TOMA
Genesis 14 in the TTENT
Genesis 14 in the UBG
Genesis 14 in the UGV
Genesis 14 in the UGV2
Genesis 14 in the UGV3
Genesis 14 in the VBL
Genesis 14 in the VDCC
Genesis 14 in the YALU
Genesis 14 in the YAPE
Genesis 14 in the YBVTP
Genesis 14 in the ZBP