Habakkuk 3 (BOYCB)
1 Àdúrà wòlíì Habakuku gẹ́gẹ́ bí sígónótì. Ohun èlò orin. 2 OLÚWA mo tí gbọ́ ohùn rẹ;ẹ̀rù sì ba mi fún iṣẹ́ rẹ OLÚWAsọ wọn di ọ̀tún ní ọjọ́ ti wa,ní àkókò tiwa, jẹ́ kó di mí mọ̀;ni ìbínú, rántí àánú. 3 Ọlọ́run yóò wa láti Temani,ibi mímọ́ jùlọ láti òkè Paraniògo rẹ̀ sí bo àwọn ọ̀run,ilé ayé sì kún fún ìyìn rẹ. 4 Dídán rẹ sí dàbí ìmọ́lẹ̀ oòrùnìtànṣán ìmọ́lẹ̀ jáde wa láti ọwọ́ rẹ,níbi tí wọn fi agbára rẹ̀ pamọ́ sí. 5 Àjàkálẹ̀-ààrùn ń lọ ni iwájú rẹ;ìyọnu sí ń tọ ẹsẹ̀ rẹ lọ. 6 Ó dúró, ó sì mi ayé;ó wò, ó sì mú àwọn orílẹ̀-èdè wárìrìa sì tú àwọn òkè ńlá ayérayé ká,àwọn òkè kéékèèké ayérayé sì tẹríba:ọ̀nà rẹ ayérayé ni. 7 Mo rí àgọ́ Kuṣani nínú ìpọ́njúàti àwọn ibùgbé Midiani nínú ìrora. 8 Ǹjẹ́ ìwọ ha ń bínú sí àwọn odò nì, OLÚWA?Ǹjẹ́ ìbínú rẹ wa lórí àwọn odò ṣíṣàn bí?Ìbínú rẹ ha wá sórí Òkuntí ìwọ fi ń gun ẹṣin,àti kẹ̀kẹ́ ìgbàlà rẹ? 9 A ṣí ọrun rẹ sílẹ̀ pátápátá,gẹ́gẹ́ bí ìbúra àwọn ẹ̀yà, àní ọ̀rọ̀ rẹ,ìwọ sì fi odò pín ilẹ̀ ayé. 10 Àwọn òkè ńlá ri ọ wọn sì wárìrìàgbàrá òjò ń sàn án kọjá lọ;ibú ń ké ramúramùó sì gbé irú omi sókè. 11 Òòrùn àti Òṣùpá dúró jẹ́ẹ́jẹ́ ni ibùgbé wọn,pẹ̀lú ìmọ́lẹ̀ ọfà rẹ ni wọn yára lọ,àti ni dídán ọ̀kọ̀ rẹ ti ń kọ mànà. 12 Ní ìrunú ni ìwọ rin ilẹ̀ náà já,ní ìbínú ni ìwọ tí tẹ́ àwọn orílẹ̀-èdè rẹ. 13 Ìwọ jáde lọ láti tú àwọn ènìyàn rẹ sílẹ̀,àti láti gba ẹni àmì òróró rẹ là,Ìwọ ti run àwọn olórí kúrò nínú ilẹ̀ àwọn ènìyàn búburú,ó sì bọ ìhámọ́ra rẹ láti orí de ẹsẹ̀. 14 Pẹ̀lú ọ̀kọ̀ rẹ̀ kí ó fi gún orí rẹnígbà tí àwọn jagunjagun rẹ̀jáde láti tú wá ká,ayọ̀ wọn sì ni láti jẹ tálákà run ní ìkọ̀kọ̀. 15 Ìwọ fi ẹṣin rẹ rìn Òkun já,ó sì da àwọn omi ńlá ru. 16 Mo gbọ́, ọkàn mi sì wárìrì,ètè mi sì gbọ̀n sí ìró náà;ìbàjẹ́ sì wọ inú egungun mi lọ,ẹsẹ̀ mi sì wárìrì,mo dúró ni ìdákẹ́ jẹ́ẹ́ fún ọjọ́ ìdààmúláti de sórí àwọn ènìyàn tó ń dojúkọ wá. 17 Bí igi ọ̀pọ̀tọ́ ko tilẹ̀ tanná,tí èso kò sí nínú àjàrà;tí igi olifi ko le so,àwọn oko ko sì mú oúnjẹ wá;tí a sì ké agbo ẹran kúrò nínú agbo,tí kò sì sí ọwọ́ ẹran ni ibùso mọ́, 18 síbẹ̀, èmi ó láyọ̀ nínú OLÚWA,èmi yóò sí máa yọ nínú Ọlọ́run ìgbàlà mi. 19 OLÚWA Olódùmarè ni agbára mi,òun yóò sí ṣe ẹsẹ̀ mi bí ẹsẹ̀ abo àgbọ̀nrín,yóò sí mú mi rìn lórí ibi gíga.Sí olórí akọrin lórí ohun èlò orin olókùn mi.
In Other Versions
Habakkuk 3 in the ANGEFD
Habakkuk 3 in the ANTPNG2D
Habakkuk 3 in the AS21
Habakkuk 3 in the BAGH
Habakkuk 3 in the BBPNG
Habakkuk 3 in the BBT1E
Habakkuk 3 in the BDS
Habakkuk 3 in the BEV
Habakkuk 3 in the BHAD
Habakkuk 3 in the BIB
Habakkuk 3 in the BLPT
Habakkuk 3 in the BNT
Habakkuk 3 in the BNTABOOT
Habakkuk 3 in the BNTLV
Habakkuk 3 in the BOATCB
Habakkuk 3 in the BOATCB2
Habakkuk 3 in the BOBCV
Habakkuk 3 in the BOCNT
Habakkuk 3 in the BOECS
Habakkuk 3 in the BOGWICC
Habakkuk 3 in the BOHCB
Habakkuk 3 in the BOHCV
Habakkuk 3 in the BOHLNT
Habakkuk 3 in the BOHNTLTAL
Habakkuk 3 in the BOICB
Habakkuk 3 in the BOILNTAP
Habakkuk 3 in the BOITCV
Habakkuk 3 in the BOKCV
Habakkuk 3 in the BOKCV2
Habakkuk 3 in the BOKHWOG
Habakkuk 3 in the BOKSSV
Habakkuk 3 in the BOLCB
Habakkuk 3 in the BOLCB2
Habakkuk 3 in the BOMCV
Habakkuk 3 in the BONAV
Habakkuk 3 in the BONCB
Habakkuk 3 in the BONLT
Habakkuk 3 in the BONUT2
Habakkuk 3 in the BOPLNT
Habakkuk 3 in the BOSCB
Habakkuk 3 in the BOSNC
Habakkuk 3 in the BOTLNT
Habakkuk 3 in the BOVCB
Habakkuk 3 in the BPBB
Habakkuk 3 in the BPH
Habakkuk 3 in the BSB
Habakkuk 3 in the CCB
Habakkuk 3 in the CUV
Habakkuk 3 in the CUVS
Habakkuk 3 in the DBT
Habakkuk 3 in the DGDNT
Habakkuk 3 in the DHNT
Habakkuk 3 in the DNT
Habakkuk 3 in the ELBE
Habakkuk 3 in the EMTV
Habakkuk 3 in the ESV
Habakkuk 3 in the FBV
Habakkuk 3 in the FEB
Habakkuk 3 in the GGMNT
Habakkuk 3 in the GNT
Habakkuk 3 in the HARY
Habakkuk 3 in the HNT
Habakkuk 3 in the IRVA
Habakkuk 3 in the IRVB
Habakkuk 3 in the IRVG
Habakkuk 3 in the IRVH
Habakkuk 3 in the IRVK
Habakkuk 3 in the IRVM
Habakkuk 3 in the IRVM2
Habakkuk 3 in the IRVO
Habakkuk 3 in the IRVP
Habakkuk 3 in the IRVT
Habakkuk 3 in the IRVT2
Habakkuk 3 in the IRVU
Habakkuk 3 in the ISVN
Habakkuk 3 in the JSNT
Habakkuk 3 in the KAPI
Habakkuk 3 in the KBT1ETNIK
Habakkuk 3 in the KBV
Habakkuk 3 in the KJV
Habakkuk 3 in the KNFD
Habakkuk 3 in the LBA
Habakkuk 3 in the LBLA
Habakkuk 3 in the LNT
Habakkuk 3 in the LSV
Habakkuk 3 in the MAAL
Habakkuk 3 in the MBV
Habakkuk 3 in the MBV2
Habakkuk 3 in the MHNT
Habakkuk 3 in the MKNFD
Habakkuk 3 in the MNG
Habakkuk 3 in the MNT
Habakkuk 3 in the MNT2
Habakkuk 3 in the MRS1T
Habakkuk 3 in the NAA
Habakkuk 3 in the NASB
Habakkuk 3 in the NBLA
Habakkuk 3 in the NBS
Habakkuk 3 in the NBVTP
Habakkuk 3 in the NET2
Habakkuk 3 in the NIV11
Habakkuk 3 in the NNT
Habakkuk 3 in the NNT2
Habakkuk 3 in the NNT3
Habakkuk 3 in the PDDPT
Habakkuk 3 in the PFNT
Habakkuk 3 in the RMNT
Habakkuk 3 in the SBIAS
Habakkuk 3 in the SBIBS
Habakkuk 3 in the SBIBS2
Habakkuk 3 in the SBICS
Habakkuk 3 in the SBIDS
Habakkuk 3 in the SBIGS
Habakkuk 3 in the SBIHS
Habakkuk 3 in the SBIIS
Habakkuk 3 in the SBIIS2
Habakkuk 3 in the SBIIS3
Habakkuk 3 in the SBIKS
Habakkuk 3 in the SBIKS2
Habakkuk 3 in the SBIMS
Habakkuk 3 in the SBIOS
Habakkuk 3 in the SBIPS
Habakkuk 3 in the SBISS
Habakkuk 3 in the SBITS
Habakkuk 3 in the SBITS2
Habakkuk 3 in the SBITS3
Habakkuk 3 in the SBITS4
Habakkuk 3 in the SBIUS
Habakkuk 3 in the SBIVS
Habakkuk 3 in the SBT
Habakkuk 3 in the SBT1E
Habakkuk 3 in the SCHL
Habakkuk 3 in the SNT
Habakkuk 3 in the SUSU
Habakkuk 3 in the SUSU2
Habakkuk 3 in the SYNO
Habakkuk 3 in the TBIAOTANT
Habakkuk 3 in the TBT1E
Habakkuk 3 in the TBT1E2
Habakkuk 3 in the TFTIP
Habakkuk 3 in the TFTU
Habakkuk 3 in the TGNTATF3T
Habakkuk 3 in the THAI
Habakkuk 3 in the TNFD
Habakkuk 3 in the TNT
Habakkuk 3 in the TNTIK
Habakkuk 3 in the TNTIL
Habakkuk 3 in the TNTIN
Habakkuk 3 in the TNTIP
Habakkuk 3 in the TNTIZ
Habakkuk 3 in the TOMA
Habakkuk 3 in the TTENT
Habakkuk 3 in the UBG
Habakkuk 3 in the UGV
Habakkuk 3 in the UGV2
Habakkuk 3 in the UGV3
Habakkuk 3 in the VBL
Habakkuk 3 in the VDCC
Habakkuk 3 in the YALU
Habakkuk 3 in the YAPE
Habakkuk 3 in the YBVTP
Habakkuk 3 in the ZBP