Hebrews 8 (BOYCB)

1 Nísinsin yìí, kókó ohun tí à ń sọ nìyí. Àwa ní irú olórí àlùfáà bẹ́ẹ̀, tí ó jókòó lọ́wọ́ ọ̀tún ìtẹ́ Ọláńlá nínú àwọn ọ̀run, 2 Ìránṣẹ́ ibi mímọ́, àti ti àgọ́ tòótọ́, tí Olúwa pa, kì í ṣe ènìyàn. 3 Nítorí a fi olórí àlùfáà kọ̀ọ̀kan jẹ láti máa mú ẹ̀bùn wá láti máa rú ẹbọ, nítorí náà ó ṣe pàtàkì fún eléyìí náà láti ní nǹkan tí ó máa fi sílẹ̀. 4 Tí ó bá jẹ́ pé ó wà ní ayé ni, òun kì bá ti jẹ́ àlùfáà, nítorí pé àwọn ọkùnrin tí ó ń fi ẹ̀bùn sílẹ̀ ti wà bí òfin ṣe là á sílẹ̀. 5 Àwọn ẹni tí ń jọ́sìn nínú pẹpẹ kan tí ó jẹ́ àpẹẹrẹ àti òjìji ohun tí ń bẹ ní ọ̀run. Ìdí abájọ nìyí tí a fi kìlọ̀ fún Mose nígbà tí ó fẹ́ kọ́ àgọ́, nítorí ó wí pé, “Kíyèsí i, kí ìwọ kí ó ṣe wọ́n gẹ́gẹ́ bí àpẹẹrẹ wọn, ti a fi hàn ọ́ ni orí òkè.” 6 Ṣùgbọ́n nísinsin yìí o ti gba iṣẹ́ ìránṣẹ́ tí ó ni ọlá jù, níwọ̀n bí o ti jẹ pé alárinà májẹ̀mú tí o dára jù ní i ṣe, èyí tí a fi ṣe òfin lórí ìlérí tí o sàn jù bẹ́ẹ̀ lọ. 7 Nítorí ìbá ṣe pé májẹ̀mú ìṣáájú nì kò ní àbùkù, ǹjẹ́ a kì bá ti wá ààyè fún èkejì. 8 Nítorí tí ó rí àbùkù lára wọn, ó wí pé,“Ìgbà kan ń bọ̀, ni Olúwa wí,tí Èmi yóò bá ilé Israẹliàti ilé Juda dá májẹ̀mú tuntun. 9 Kì í ṣe gẹ́gẹ́ bí májẹ̀mútí mo ti bá àwọn baba baba wọn dá,nígbà tí mo fà wọ́n lọ́wọ́ láti mú wọn jádekúrò ní ilẹ̀ Ejibiti, nítorí wọn kò jẹ́ olóòtítọ́ sí májẹ̀mú mièmi kò sì ta wọ́n nu, ni Olúwa wí. 10 Nítorí èyí ni májẹ̀mú tí èmi yóò bá ilé Israẹlidá lẹ́yìn àwọn ọjọ́ wọ̀nyí, ni Olúwa wí.Èmi ó fi òfin mi sí inú wọn,èmi ó sì kọ wọ́n sí ọkàn wọn,èmi ó sì máa jẹ́ Ọlọ́run fún wọn,wọn ó sì máa jẹ́ ènìyàn fún mi. 11 Olúkúlùkù kò ní tún máa kọ́ ara ìlú rẹ̀,tàbí olúkúlùkù arákùnrin rẹ̀, pé, ‘Mọ Olúwa,’nítorí pé gbogbo wọn ni yóò mọ̀ mí,láti kékeré dé àgbà. 12 Nítorí pé èmi ó ṣàánú fún àìṣòdodo wọn,àti ẹ̀ṣẹ̀ wọn àti àìṣedéédéé wọn lèmi ki yóò sì rántí mọ́.” 13 Ní èyí tí ó wí pé, májẹ̀mú títún ó ti sọ ti ìṣáájú di ti láéláé. Ṣùgbọ́n èyí tí ó ń di i ti láéláé tí ó sì ń gbó, o múra àti di asán.

In Other Versions

Hebrews 8 in the ANGEFD

Hebrews 8 in the ANTPNG2D

Hebrews 8 in the AS21

Hebrews 8 in the BAGH

Hebrews 8 in the BBPNG

Hebrews 8 in the BBT1E

Hebrews 8 in the BDS

Hebrews 8 in the BEV

Hebrews 8 in the BHAD

Hebrews 8 in the BIB

Hebrews 8 in the BLPT

Hebrews 8 in the BNT

Hebrews 8 in the BNTABOOT

Hebrews 8 in the BNTLV

Hebrews 8 in the BOATCB

Hebrews 8 in the BOATCB2

Hebrews 8 in the BOBCV

Hebrews 8 in the BOCNT

Hebrews 8 in the BOECS

Hebrews 8 in the BOGWICC

Hebrews 8 in the BOHCB

Hebrews 8 in the BOHCV

Hebrews 8 in the BOHLNT

Hebrews 8 in the BOHNTLTAL

Hebrews 8 in the BOICB

Hebrews 8 in the BOILNTAP

Hebrews 8 in the BOITCV

Hebrews 8 in the BOKCV

Hebrews 8 in the BOKCV2

Hebrews 8 in the BOKHWOG

Hebrews 8 in the BOKSSV

Hebrews 8 in the BOLCB

Hebrews 8 in the BOLCB2

Hebrews 8 in the BOMCV

Hebrews 8 in the BONAV

Hebrews 8 in the BONCB

Hebrews 8 in the BONLT

Hebrews 8 in the BONUT2

Hebrews 8 in the BOPLNT

Hebrews 8 in the BOSCB

Hebrews 8 in the BOSNC

Hebrews 8 in the BOTLNT

Hebrews 8 in the BOVCB

Hebrews 8 in the BPBB

Hebrews 8 in the BPH

Hebrews 8 in the BSB

Hebrews 8 in the CCB

Hebrews 8 in the CUV

Hebrews 8 in the CUVS

Hebrews 8 in the DBT

Hebrews 8 in the DGDNT

Hebrews 8 in the DHNT

Hebrews 8 in the DNT

Hebrews 8 in the ELBE

Hebrews 8 in the EMTV

Hebrews 8 in the ESV

Hebrews 8 in the FBV

Hebrews 8 in the FEB

Hebrews 8 in the GGMNT

Hebrews 8 in the GNT

Hebrews 8 in the HARY

Hebrews 8 in the HNT

Hebrews 8 in the IRVA

Hebrews 8 in the IRVB

Hebrews 8 in the IRVG

Hebrews 8 in the IRVH

Hebrews 8 in the IRVK

Hebrews 8 in the IRVM

Hebrews 8 in the IRVM2

Hebrews 8 in the IRVO

Hebrews 8 in the IRVP

Hebrews 8 in the IRVT

Hebrews 8 in the IRVT2

Hebrews 8 in the IRVU

Hebrews 8 in the ISVN

Hebrews 8 in the JSNT

Hebrews 8 in the KAPI

Hebrews 8 in the KBT1ETNIK

Hebrews 8 in the KBV

Hebrews 8 in the KJV

Hebrews 8 in the KNFD

Hebrews 8 in the LBA

Hebrews 8 in the LBLA

Hebrews 8 in the LNT

Hebrews 8 in the LSV

Hebrews 8 in the MAAL

Hebrews 8 in the MBV

Hebrews 8 in the MBV2

Hebrews 8 in the MHNT

Hebrews 8 in the MKNFD

Hebrews 8 in the MNG

Hebrews 8 in the MNT

Hebrews 8 in the MNT2

Hebrews 8 in the MRS1T

Hebrews 8 in the NAA

Hebrews 8 in the NASB

Hebrews 8 in the NBLA

Hebrews 8 in the NBS

Hebrews 8 in the NBVTP

Hebrews 8 in the NET2

Hebrews 8 in the NIV11

Hebrews 8 in the NNT

Hebrews 8 in the NNT2

Hebrews 8 in the NNT3

Hebrews 8 in the PDDPT

Hebrews 8 in the PFNT

Hebrews 8 in the RMNT

Hebrews 8 in the SBIAS

Hebrews 8 in the SBIBS

Hebrews 8 in the SBIBS2

Hebrews 8 in the SBICS

Hebrews 8 in the SBIDS

Hebrews 8 in the SBIGS

Hebrews 8 in the SBIHS

Hebrews 8 in the SBIIS

Hebrews 8 in the SBIIS2

Hebrews 8 in the SBIIS3

Hebrews 8 in the SBIKS

Hebrews 8 in the SBIKS2

Hebrews 8 in the SBIMS

Hebrews 8 in the SBIOS

Hebrews 8 in the SBIPS

Hebrews 8 in the SBISS

Hebrews 8 in the SBITS

Hebrews 8 in the SBITS2

Hebrews 8 in the SBITS3

Hebrews 8 in the SBITS4

Hebrews 8 in the SBIUS

Hebrews 8 in the SBIVS

Hebrews 8 in the SBT

Hebrews 8 in the SBT1E

Hebrews 8 in the SCHL

Hebrews 8 in the SNT

Hebrews 8 in the SUSU

Hebrews 8 in the SUSU2

Hebrews 8 in the SYNO

Hebrews 8 in the TBIAOTANT

Hebrews 8 in the TBT1E

Hebrews 8 in the TBT1E2

Hebrews 8 in the TFTIP

Hebrews 8 in the TFTU

Hebrews 8 in the TGNTATF3T

Hebrews 8 in the THAI

Hebrews 8 in the TNFD

Hebrews 8 in the TNT

Hebrews 8 in the TNTIK

Hebrews 8 in the TNTIL

Hebrews 8 in the TNTIN

Hebrews 8 in the TNTIP

Hebrews 8 in the TNTIZ

Hebrews 8 in the TOMA

Hebrews 8 in the TTENT

Hebrews 8 in the UBG

Hebrews 8 in the UGV

Hebrews 8 in the UGV2

Hebrews 8 in the UGV3

Hebrews 8 in the VBL

Hebrews 8 in the VDCC

Hebrews 8 in the YALU

Hebrews 8 in the YAPE

Hebrews 8 in the YBVTP

Hebrews 8 in the ZBP