Isaiah 10 (BOYCB)

1 Ègbé ni fún àwọn ti ń ṣe òfin àìṣòdodo, 2 láti dún àwọn aláìní ní ẹ̀tọ́ wọnàti láti fa ọwọ́ ìdájọ́ sẹ́yìn kúrò níwájú àwọn olùpọ́njú ènìyàn mi,wọ́n sọ àwọn ọ̀pọ̀ di ìjẹ fún wọn,wọ́n sì ń ja àwọn aláìní baba lólè. 3 Kí ni ìwọ yóò ṣe ní ọjọ́ ìṣirònígbà tí ìparun bá ti ọ̀nà jíjìn wá?Ta ni ìwọ yóò sá tọ̀ fún ìrànlọ́wọ́?Níbo ni ìwọ yóò fi ọrọ̀ rẹ sí? 4 Ohunkóhun kò ní ṣẹ́kù mọ́ bí kò ṣe láti tẹ̀ ba láàrín àwọn ìgbèkùntàbí kí o ṣubú sáàrín àwọn tí a pa. Pẹ̀lú gbogbo nǹkan wọ̀nyí, ìbínú rẹ̀ kò kúrò,ọwọ́ rẹ̀ sì tún gbé sókè. 5 “Ègbé ni fún àwọn ará Asiria, ọ̀gọ ìbínú mi,ní ọwọ́ ẹni tí kùmọ̀ ìbínú mi wà! 6 Mo rán an sí orílẹ̀-èdè aláìní Ọlọ́run,mo dojú rẹ̀ kọ àwọn ènìyàn tí ó mú mi bínúláti já ẹrù gbà, àti láti kó ìkógunláti tẹ̀ mọ́lẹ̀ bí amọ̀ ní ojú òpópó. 7 Ṣùgbọ́n, èyí kì í ṣe ohun tí ó fẹ́ ṣe,èyí kọ́ ni ohun tí ó ní lọ́kàn;èrò rẹ̀ ni láti parun,láti fi òpin sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè. 8 ‘Kì í ha ṣe pé ọba ni gbogbo àwọn aláṣẹ mi?’ ni Olúwa wí. 9 ‘Kì í ha ṣe pé Kalno dàbí i Karkemiṣi?Hamati kò ha dàbí i Arpadi,àti Samaria bí i Damasku? 10 Gẹ́gẹ́ bí ọwọ́ mi ti gbá ìjọba àwọn òrìṣà mú,ìjọba tí ère rẹ̀ pọ̀ ju ti Jerusalẹmu àti Samaria lọ. 11 Èmi kì yóò a bá Jerusalẹmu wí àti àwọn ère rẹ̀?’ ”Gẹ́gẹ́ bí mo ṣe ṣe sí Samaria àti àwọn ère rẹ̀? 12 Nígbà tí Olúwa ti ṣe iṣẹ́ rẹ̀ sí òkè Sioni àti Jerusalẹmu, yóò sọ wí pé, “Èmi yóò fi ìyà jẹ ọba Asiria nítorí gààrù àyà rẹ̀ àti ìgbéraga ojú rẹ̀. 13 Nítorí ó sọ pé:“ ‘Pẹ̀lú agbára ọwọ́ mi ni mo fi ṣe èyíàti pẹ̀lú ọgbọ́n ọ̀n mi, nítorí mo ní òye.Mo mú ààlà àwọn orílẹ̀-èdè kúrò,mo sì ti kó ìṣúra wọn.Gẹ́gẹ́ bí alágbára kan, mo borí àwọn ọba wọn. 14 Bí ènìyàn ti í tọwọ́ bọ ìtẹ́ ẹyẹ,bẹ́ẹ̀ ni ọwọ́ mi tẹ ọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè.Bí ènìyàn ti í kó ẹyin tí a kọ̀sílẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni mo kó àwọn orílẹ̀-èdèkò sí èyí tí ó fi apá lu apá,tàbí kí ó ya ẹnu láti dún.’ ” 15 Ǹjẹ́ àáké le gbé ara rẹ̀ sókè kọjá ẹni tí ó ń fì í,tàbí kí ayùn fọ́nnu sí ẹni tí ó ń lò ó?Àfi bí ẹni pé ọ̀pá ó na ẹni tí ó gbé e sókè,tàbí kí kùmọ̀ lu èyí tí kì í ṣe igi. 16 Nítorí náà, ni Olúwa, OLÚWA àwọn ọmọ-ogun,yóò rán ààrùn ìrẹ̀dànù sóríàwọn akíkanjú jagunjagun,lábẹ́ ògo rẹ̀ ni iná kan yóò ti sọgẹ́gẹ́ bí iná ajónirun. 17 Ìmọ́lẹ̀ Israẹli yóò di iná,Ẹni Mímọ́ rẹ̀ yóò jẹ́ ọ̀wọ́-iná,ní ọjọ́ kan ṣoṣo yóò jó yóò sì runàti ẹ̀gún àti ẹ̀wọ̀n. 18 Gbogbo ẹwà igbó o rẹ̀, àti àwọn pápá ọlọ́ràágbogbo rẹ̀ ni yóò run pátápátá,gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó ṣàìsàn ti í ṣòfò dànù. 19 Àwọn igi tí yóò kù nínú igbó o rẹ̀yóò kéré níye,tí ọ̀dọ́mọdé yóò fi le kọ̀ wọ́n sílẹ̀. 20 Ní ọjọ́ náà, àwọn tí ó ṣẹ́kù ní Israẹli,àwọn tí ó yè ní ilé e Jakọbu,kò ní gbẹ́kẹ̀lé ẹni náàtí ó lù wọ́n bolẹ̀,ṣùgbọ́n ní òtítọ́ yóò gbẹ́kẹ̀lé OLÚWA,Ẹni Mímọ́ Israẹli. 21 Àwọn ìyókù yóò padà, àwọn ìyókù ti Jakọbuyóò padà sí ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Alágbára. 22 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ènìyàn rẹ, ìwọ Israẹli dàbí yanrìn ní Òkun,ẹni díẹ̀ ni yóò padà.A ti pàṣẹ ìparun,àkúnwọ́sílẹ̀ àti òdodo. 23 Olúwa, OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ni yóò mú un ṣẹ,ìparun tí a ti pàṣẹ rẹ̀ lórí gbogbo ilẹ̀ náà. 24 Nítorí náà, báyìí ni Olúwa, OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí,“Ẹ̀yin ènìyàn mi tí ó ń gbé Sioni,ẹ má ṣe bẹ̀rù àwọn Asiria,tí ó ń fi ọ̀pá lù yín,tí wọ́n sì ń gbé ọ̀gọ tì yín bíEjibiti ti ṣe. 25 Láìpẹ́, ìbínú mi sí i yín yóò wá sí òpinn ó sì dojú ìrunú mi kọ wọ́n, fún ìparun wọn.” 26 OLÚWA àwọn ọmọ-ogun yóò nà wọ́n ní ẹgba.Gẹ́gẹ́ bí ó ṣe lu Midiani ní òkè Orebu,yóò sì gbé ọ̀pá rẹ̀ lé orí omigẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe ní Ejibiti. 27 Ní ọjọ́ náà, a ó gbé ẹrù wọn kúrò ní èjìká a yín,àti àjàgà a wọn kúrò ní ọrùn un yína ó fọ́ àjàgà náà,nítorí pé ẹ̀yin ó ti sanra. 28 Wọ́n wọ Aiati,wọ́n gba Migroni kọjá,wọ́n kó nǹkan pamọ́ sí Mikmasi. 29 Wọ́n ti rékọjá ọ̀nà, wọ́n wí pé,“Àwa ó tẹ̀dó sí Geba lóru yìí.”Rama mì tìtìGibeah ti Saulu sálọ. 30 Gbé ohùn rẹ sókè, ìwọ ọmọbìnrin Galimu!Dẹ etí sílẹ̀, ìwọ Laiṣa!Ìwọ òtòṣì Anatoti! 31 Madmena ti fẹsẹ̀ fẹ́ ẹ,àwọn ènìyàn Gebimu ti fi ara pamọ́. 32 Ní ọjọ́ yìí, wọn yóò dúró ní Nobuwọn yóò kan sáárá,ní òkè ọmọbìnrin Sioniní òkè Jerusalẹmu. 33 Wò ó, Olúwa, OLÚWA àwọn ọmọ-ogun,yóò kán ẹ̀ka náà sọnù pẹ̀lú agbára.Àwọn igi ọlọ́lá ni a ó gé lulẹ̀àwọn tí ó ga gogoro ni a ó rẹ̀ sílẹ̀. 34 Òun yóò gé igbó dídí pẹ̀lú àáké,Lebanoni yóò ṣubú níwájú Alágbára náà.

In Other Versions

Isaiah 10 in the ANGEFD

Isaiah 10 in the ANTPNG2D

Isaiah 10 in the AS21

Isaiah 10 in the BAGH

Isaiah 10 in the BBPNG

Isaiah 10 in the BBT1E

Isaiah 10 in the BDS

Isaiah 10 in the BEV

Isaiah 10 in the BHAD

Isaiah 10 in the BIB

Isaiah 10 in the BLPT

Isaiah 10 in the BNT

Isaiah 10 in the BNTABOOT

Isaiah 10 in the BNTLV

Isaiah 10 in the BOATCB

Isaiah 10 in the BOATCB2

Isaiah 10 in the BOBCV

Isaiah 10 in the BOCNT

Isaiah 10 in the BOECS

Isaiah 10 in the BOGWICC

Isaiah 10 in the BOHCB

Isaiah 10 in the BOHCV

Isaiah 10 in the BOHLNT

Isaiah 10 in the BOHNTLTAL

Isaiah 10 in the BOICB

Isaiah 10 in the BOILNTAP

Isaiah 10 in the BOITCV

Isaiah 10 in the BOKCV

Isaiah 10 in the BOKCV2

Isaiah 10 in the BOKHWOG

Isaiah 10 in the BOKSSV

Isaiah 10 in the BOLCB

Isaiah 10 in the BOLCB2

Isaiah 10 in the BOMCV

Isaiah 10 in the BONAV

Isaiah 10 in the BONCB

Isaiah 10 in the BONLT

Isaiah 10 in the BONUT2

Isaiah 10 in the BOPLNT

Isaiah 10 in the BOSCB

Isaiah 10 in the BOSNC

Isaiah 10 in the BOTLNT

Isaiah 10 in the BOVCB

Isaiah 10 in the BPBB

Isaiah 10 in the BPH

Isaiah 10 in the BSB

Isaiah 10 in the CCB

Isaiah 10 in the CUV

Isaiah 10 in the CUVS

Isaiah 10 in the DBT

Isaiah 10 in the DGDNT

Isaiah 10 in the DHNT

Isaiah 10 in the DNT

Isaiah 10 in the ELBE

Isaiah 10 in the EMTV

Isaiah 10 in the ESV

Isaiah 10 in the FBV

Isaiah 10 in the FEB

Isaiah 10 in the GGMNT

Isaiah 10 in the GNT

Isaiah 10 in the HARY

Isaiah 10 in the HNT

Isaiah 10 in the IRVA

Isaiah 10 in the IRVB

Isaiah 10 in the IRVG

Isaiah 10 in the IRVH

Isaiah 10 in the IRVK

Isaiah 10 in the IRVM

Isaiah 10 in the IRVM2

Isaiah 10 in the IRVO

Isaiah 10 in the IRVP

Isaiah 10 in the IRVT

Isaiah 10 in the IRVT2

Isaiah 10 in the IRVU

Isaiah 10 in the ISVN

Isaiah 10 in the JSNT

Isaiah 10 in the KAPI

Isaiah 10 in the KBT1ETNIK

Isaiah 10 in the KBV

Isaiah 10 in the KJV

Isaiah 10 in the KNFD

Isaiah 10 in the LBA

Isaiah 10 in the LBLA

Isaiah 10 in the LNT

Isaiah 10 in the LSV

Isaiah 10 in the MAAL

Isaiah 10 in the MBV

Isaiah 10 in the MBV2

Isaiah 10 in the MHNT

Isaiah 10 in the MKNFD

Isaiah 10 in the MNG

Isaiah 10 in the MNT

Isaiah 10 in the MNT2

Isaiah 10 in the MRS1T

Isaiah 10 in the NAA

Isaiah 10 in the NASB

Isaiah 10 in the NBLA

Isaiah 10 in the NBS

Isaiah 10 in the NBVTP

Isaiah 10 in the NET2

Isaiah 10 in the NIV11

Isaiah 10 in the NNT

Isaiah 10 in the NNT2

Isaiah 10 in the NNT3

Isaiah 10 in the PDDPT

Isaiah 10 in the PFNT

Isaiah 10 in the RMNT

Isaiah 10 in the SBIAS

Isaiah 10 in the SBIBS

Isaiah 10 in the SBIBS2

Isaiah 10 in the SBICS

Isaiah 10 in the SBIDS

Isaiah 10 in the SBIGS

Isaiah 10 in the SBIHS

Isaiah 10 in the SBIIS

Isaiah 10 in the SBIIS2

Isaiah 10 in the SBIIS3

Isaiah 10 in the SBIKS

Isaiah 10 in the SBIKS2

Isaiah 10 in the SBIMS

Isaiah 10 in the SBIOS

Isaiah 10 in the SBIPS

Isaiah 10 in the SBISS

Isaiah 10 in the SBITS

Isaiah 10 in the SBITS2

Isaiah 10 in the SBITS3

Isaiah 10 in the SBITS4

Isaiah 10 in the SBIUS

Isaiah 10 in the SBIVS

Isaiah 10 in the SBT

Isaiah 10 in the SBT1E

Isaiah 10 in the SCHL

Isaiah 10 in the SNT

Isaiah 10 in the SUSU

Isaiah 10 in the SUSU2

Isaiah 10 in the SYNO

Isaiah 10 in the TBIAOTANT

Isaiah 10 in the TBT1E

Isaiah 10 in the TBT1E2

Isaiah 10 in the TFTIP

Isaiah 10 in the TFTU

Isaiah 10 in the TGNTATF3T

Isaiah 10 in the THAI

Isaiah 10 in the TNFD

Isaiah 10 in the TNT

Isaiah 10 in the TNTIK

Isaiah 10 in the TNTIL

Isaiah 10 in the TNTIN

Isaiah 10 in the TNTIP

Isaiah 10 in the TNTIZ

Isaiah 10 in the TOMA

Isaiah 10 in the TTENT

Isaiah 10 in the UBG

Isaiah 10 in the UGV

Isaiah 10 in the UGV2

Isaiah 10 in the UGV3

Isaiah 10 in the VBL

Isaiah 10 in the VDCC

Isaiah 10 in the YALU

Isaiah 10 in the YAPE

Isaiah 10 in the YBVTP

Isaiah 10 in the ZBP