Isaiah 33 (BOYCB)
1 Ègbé ni fún ọ, ìwọ apanirun,ìwọ tí a kò tí ì parun!Ègbé ni fún ọ, ìwọ ọ̀dàlẹ̀,ìwọ tí a kò tí ì dà ọ́!Nígbà tí o bá dẹ́kun à ń pa ni run;a ó pa ìwọ náà run,nígbà tí o bá dẹ́kun à ń dani,a ó da ìwọ náà. 2 OLÚWA ṣàánú fún waàwa ń ṣàfẹ́rí i rẹ.Máa jẹ́ agbára wa ní òròòwúrọ̀ìgbàlà wa ní àsìkò ìpọ́njú. 3 Ní ìkérara ohùn rẹ, àwọn ènìyàn sá,nígbà tí o dìde sókè, àwọn orílẹ̀-èdè fọ́nká. 4 Ìkógun rẹ, ìwọ orílẹ̀-èdè ni a kórègẹ́gẹ́ bí i ti ọ̀dọ́ eṣú;gẹ́gẹ́ bí àkójọpọ̀ eṣú, àwọn ènìyàn wọ ibẹ̀. 5 A gbé OLÚWA ga, nítorí pé ó ń gbé ibi gíga,Òun yóò kún Sioni pẹ̀lú ẹ̀tọ́ àti òdodo. 6 Òun yóò jẹ́ ìpìlẹ̀ tí ó dájú fún àkókò rẹibùjókòó ìgbàlà kíkún àti ọgbọ́n òun ìmọ̀;ìbẹ̀rù OLÚWA ni kọ́kọ́rọ́ sí ìṣúra yìí. 7 Wò ó, àwọn onígboyà ọkùnrin wọn pohùnréréẹkún ní òpópónà;àwọn ikọ̀ àlàáfíà sọkún kíkorò. 8 Àwọn ojú ọ̀nà ńlá ni a ṣá tì,kò sí arìnrìn-àjò kankan ní ojú ọ̀nà.A ti ba àdéhùn jẹ́,a kẹ́gàn àwọn ẹlẹ́rìí,a kò bu ọlá fún ẹnikẹ́ni. 9 Ilẹ̀ ṣọ̀fọ̀ ó sì ṣòfò dànù,ojú ti Lebanoni ó sì sáṢaroni sì dàbí aginjù,àti Baṣani òun Karmeli rẹ àwọn èwe wọn. 10 “Ní ìsinsin yìí ni èmi yóò dìde,” ni OLÚWA wí.“Ní ìsinsin yìí ni a ó gbé mi ga,ní ìsinsin yìí ni a ó gbé mi sókè. 11 Ìwọ lóyún ìyàngbò,o sì bí koríko;èémí yín bí iná tí yóò jẹ yín run. 12 A ó jó àwọn ènìyàn run bí eérú;bí igbó ẹ̀gún tí a gé la ó dáná sí wọn.” 13 Ìwọ tí ó wà lọ́nà jíjìn, gbọ́ ohun tí mo ti ṣe;ìwọ tí ò ń bẹ nítòsí, jẹ́rìí agbára mi! 14 Ẹ̀rù ba àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní Sioni;ìwárìrì bá àwọn tí kò gba Ọlọ́run gbọ́:“Ta ni nínú wa lólè gbé pẹ̀lú iná ajónirun?Ta ni nínú wa lólè gbé pẹ̀lú iná àìnípẹ̀kun?” 15 Ẹni tí ó ń rìn lódodotí ó ń sọ ohun tí ó tọ́,tí ó kọ èrè tí ó ti ibi ìlọ́nilọ́wọ́gbà wá,tí ó sì pa ọwọ́ rẹ̀ mọ́ kúrò nínú gbígba àbẹ̀tẹ́lẹ̀,tí ó di etí rẹ̀ sí ọ̀tẹ̀ láti pànìyàntí ó sì di ojú rẹ̀ sí à ti pète ibi, 16 Òun náà yóò gbé ní ibi gíga,ibi ààbò rẹ̀ yóò jẹ́ òkè ńlá olódi.A ó mú oúnjẹ fún un,omi rẹ̀ yóò sì dájú. 17 Ojú rẹ yóò rí ọba nínú ẹwà rẹ̀yóò sì rí ilẹ̀ kan tí ó tẹ́ lọ rẹrẹẹrẹ. 18 Nínú èrò rẹ ìwọ yóò rántí ẹ̀rù rẹ àtẹ̀yìnwá:“Níbo ni ọ̀gá àgbà náà wà?Níbo ni ẹni tí ń gba owó òde wà?Níbo ni òṣìṣẹ́ ti ó ń mójútó ilé ìṣọ́ wà?” 19 Ìwọ kì yóò rí àwọn agbéraga ènìyàn mọ́,àwọn ènìyàn tí èdè wọn fi ara sin,pẹ̀lú ahọ́n tí ó ṣàjèjì tí kò sì yé ni. 20 Gbójú sókè sí Sioni, ìlú àjọ̀dún wa,ojú rẹ yóò rí Jerusalẹmu,ibùgbé àlàáfíà n nì, àgọ́ tí a kò ní yí padà;àwọn òpó rẹ̀ ni a kì yóò fàtutàbí èyíkéyìí nínú okùn rẹ̀ kí já. 21 Níbẹ̀ ni OLÚWA yóò ti jẹ́ alágbára kan fún wa.Yóò sì dàbí ibi àwọn odò ńlá ńlá àti odò kéékèèké.Kì yóò sí ọkọ̀ ojú omi pẹ̀lú tí yóò kọjá lórí i wọn,ọkọ̀ ojú omi ńlá ni a kì yóò tù lórí wọn. 22 Nítorí OLÚWA ni onídàájọ́ wa, OLÚWA ni onídàájọ́ wa, OLÚWA òun ni ọba wa;òun ni ẹni tí yóò gbà wá là. 23 Gbogbo okùn rẹ ni ó ti dẹ̀:Ìgbókùnró kò fìdímúlẹ̀,wọn kò taṣọ agbọ́kọ̀rìn,lẹ́yìn náà, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìkógun ni a ó pínàní arọ pẹ̀lú yóò ru ìkógun lọ. 24 Kò sí ẹnikẹ́ni tí ó ń gbé Sioni tí yóò wí pé, “Ara mi kò yá,”a ó dárí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ènìyàn tí ń gbé ibẹ̀ jì wọ́n.
In Other Versions
Isaiah 33 in the ANGEFD
Isaiah 33 in the ANTPNG2D
Isaiah 33 in the AS21
Isaiah 33 in the BAGH
Isaiah 33 in the BBPNG
Isaiah 33 in the BBT1E
Isaiah 33 in the BDS
Isaiah 33 in the BEV
Isaiah 33 in the BHAD
Isaiah 33 in the BIB
Isaiah 33 in the BLPT
Isaiah 33 in the BNT
Isaiah 33 in the BNTABOOT
Isaiah 33 in the BNTLV
Isaiah 33 in the BOATCB
Isaiah 33 in the BOATCB2
Isaiah 33 in the BOBCV
Isaiah 33 in the BOCNT
Isaiah 33 in the BOECS
Isaiah 33 in the BOGWICC
Isaiah 33 in the BOHCB
Isaiah 33 in the BOHCV
Isaiah 33 in the BOHLNT
Isaiah 33 in the BOHNTLTAL
Isaiah 33 in the BOICB
Isaiah 33 in the BOILNTAP
Isaiah 33 in the BOITCV
Isaiah 33 in the BOKCV
Isaiah 33 in the BOKCV2
Isaiah 33 in the BOKHWOG
Isaiah 33 in the BOKSSV
Isaiah 33 in the BOLCB
Isaiah 33 in the BOLCB2
Isaiah 33 in the BOMCV
Isaiah 33 in the BONAV
Isaiah 33 in the BONCB
Isaiah 33 in the BONLT
Isaiah 33 in the BONUT2
Isaiah 33 in the BOPLNT
Isaiah 33 in the BOSCB
Isaiah 33 in the BOSNC
Isaiah 33 in the BOTLNT
Isaiah 33 in the BOVCB
Isaiah 33 in the BPBB
Isaiah 33 in the BPH
Isaiah 33 in the BSB
Isaiah 33 in the CCB
Isaiah 33 in the CUV
Isaiah 33 in the CUVS
Isaiah 33 in the DBT
Isaiah 33 in the DGDNT
Isaiah 33 in the DHNT
Isaiah 33 in the DNT
Isaiah 33 in the ELBE
Isaiah 33 in the EMTV
Isaiah 33 in the ESV
Isaiah 33 in the FBV
Isaiah 33 in the FEB
Isaiah 33 in the GGMNT
Isaiah 33 in the GNT
Isaiah 33 in the HARY
Isaiah 33 in the HNT
Isaiah 33 in the IRVA
Isaiah 33 in the IRVB
Isaiah 33 in the IRVG
Isaiah 33 in the IRVH
Isaiah 33 in the IRVK
Isaiah 33 in the IRVM
Isaiah 33 in the IRVM2
Isaiah 33 in the IRVO
Isaiah 33 in the IRVP
Isaiah 33 in the IRVT
Isaiah 33 in the IRVT2
Isaiah 33 in the IRVU
Isaiah 33 in the ISVN
Isaiah 33 in the JSNT
Isaiah 33 in the KAPI
Isaiah 33 in the KBT1ETNIK
Isaiah 33 in the KBV
Isaiah 33 in the KJV
Isaiah 33 in the KNFD
Isaiah 33 in the LBA
Isaiah 33 in the LBLA
Isaiah 33 in the LNT
Isaiah 33 in the LSV
Isaiah 33 in the MAAL
Isaiah 33 in the MBV
Isaiah 33 in the MBV2
Isaiah 33 in the MHNT
Isaiah 33 in the MKNFD
Isaiah 33 in the MNG
Isaiah 33 in the MNT
Isaiah 33 in the MNT2
Isaiah 33 in the MRS1T
Isaiah 33 in the NAA
Isaiah 33 in the NASB
Isaiah 33 in the NBLA
Isaiah 33 in the NBS
Isaiah 33 in the NBVTP
Isaiah 33 in the NET2
Isaiah 33 in the NIV11
Isaiah 33 in the NNT
Isaiah 33 in the NNT2
Isaiah 33 in the NNT3
Isaiah 33 in the PDDPT
Isaiah 33 in the PFNT
Isaiah 33 in the RMNT
Isaiah 33 in the SBIAS
Isaiah 33 in the SBIBS
Isaiah 33 in the SBIBS2
Isaiah 33 in the SBICS
Isaiah 33 in the SBIDS
Isaiah 33 in the SBIGS
Isaiah 33 in the SBIHS
Isaiah 33 in the SBIIS
Isaiah 33 in the SBIIS2
Isaiah 33 in the SBIIS3
Isaiah 33 in the SBIKS
Isaiah 33 in the SBIKS2
Isaiah 33 in the SBIMS
Isaiah 33 in the SBIOS
Isaiah 33 in the SBIPS
Isaiah 33 in the SBISS
Isaiah 33 in the SBITS
Isaiah 33 in the SBITS2
Isaiah 33 in the SBITS3
Isaiah 33 in the SBITS4
Isaiah 33 in the SBIUS
Isaiah 33 in the SBIVS
Isaiah 33 in the SBT
Isaiah 33 in the SBT1E
Isaiah 33 in the SCHL
Isaiah 33 in the SNT
Isaiah 33 in the SUSU
Isaiah 33 in the SUSU2
Isaiah 33 in the SYNO
Isaiah 33 in the TBIAOTANT
Isaiah 33 in the TBT1E
Isaiah 33 in the TBT1E2
Isaiah 33 in the TFTIP
Isaiah 33 in the TFTU
Isaiah 33 in the TGNTATF3T
Isaiah 33 in the THAI
Isaiah 33 in the TNFD
Isaiah 33 in the TNT
Isaiah 33 in the TNTIK
Isaiah 33 in the TNTIL
Isaiah 33 in the TNTIN
Isaiah 33 in the TNTIP
Isaiah 33 in the TNTIZ
Isaiah 33 in the TOMA
Isaiah 33 in the TTENT
Isaiah 33 in the UBG
Isaiah 33 in the UGV
Isaiah 33 in the UGV2
Isaiah 33 in the UGV3
Isaiah 33 in the VBL
Isaiah 33 in the VDCC
Isaiah 33 in the YALU
Isaiah 33 in the YAPE
Isaiah 33 in the YBVTP
Isaiah 33 in the ZBP