Job 37 (BOYCB)

1 “Àyà sì fò mi sí èyí pẹ̀lú,ó sì kúrò ní ipò rẹ̀. 2 Fetísílẹ̀! Fetísílẹ̀, kí ẹ sì gbọ́ ìró ohùn rẹ̀,àti èyí tí ó ti ẹnu rẹ̀ jáde wá. 3 Ó ṣe ìlànà rẹ̀ ní ìsàlẹ̀ ọ̀run gbogbo,mọ̀nàmọ́ná rẹ̀ ni ó sì jọ̀wọ́ rẹ̀ lọ́wọ́ dé òpin ilẹ̀ ayé. 4 Lẹ́yìn mọ̀nàmọ́ná ohùn kan fọ̀ ramúramù;ó sì fi ohùn ọláńlá rẹ̀ sán àrá.Òhun kì yóò sì dá àrá dúró,nígbà tí ó bá ń gbọ́ ohùn rẹ̀. 5 Ọlọ́run fi ohùn rẹ̀ sán àrá ní ọ̀nà ìyanu;ohùn ńlá ńlá ni í ṣe tí àwa kò le mọ̀. 6 Nítorí tí ó wí fún yìnyín pé, ‘Ìwọ rọ̀ sílẹ̀ ayé,’àti pẹ̀lú fún ọwọ́ òjò, ‘Fún òjò ńlá agbára rẹ̀.’ 7 Ó fi èdìdì di ọwọ́ gbogbo ènìyàn kí gbogbo wọn kí ó lè mọ iṣẹ́ rẹ̀,ó sì tún dá olúkúlùkù ènìyàn dúró lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀. 8 Nígbà náà ní àwọn ẹranko wọ inú ihò lọ,wọn a sì wà ni ipò wọn. 9 Láti ìhà gúúsù ni ìjì àjàyíká tí jáde wá,àti òtútù láti inú afẹ́fẹ́ ti tú àwọsánmọ̀ ká. 10 Nípa ẹ̀mí Ọlọ́run a fi ìdí omi fún ni,ibú omi á sì súnkì. 11 Pẹ̀lúpẹ̀lú ó fi omi púpọ̀ mú àwọsánmọ̀ wúwo,a sì tú àwọsánmọ̀ ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ ká ara wọn. 12 Àwọn wọ̀nyí yí káàkiri nípa ìlànà rẹ̀,kí wọn kí ó lè ṣe ohunkóhuntí ó pàṣẹ fún wọn lórí ilẹ̀ ayé. 13 Ó mú àwọsánmọ̀ wá, ìbá ṣe fún ìkìlọ̀,tàbí omi wá sí ayé láti fi ìfẹ́ rẹ̀ hàn. 14 “Jobu, dẹtí sílẹ̀ sí èyí;dúró jẹ́ẹ́ kí o sì ro iṣẹ́ ìyanu Ọlọ́run. 15 Ṣe ìwọ mọ àkókò ìgbà tí Ọlọ́run ṣe wọ́n lọ́jọ̀,tí ó sì mú ìmọ́lẹ̀ àwọsánmọ̀ rẹ̀ dán? 16 Ṣé ìwọ mọ ìgbà tí àwọsánmọ̀ í fò lọ,iṣẹ́ ìyanu ẹni tí ó pé ní ìmọ̀? 17 Ìwọ ẹni ti aṣọ rẹ̀ ti máa n gbóná,nígbà tí ó fi atẹ́gùn ìhà gúúsù mú ayé dákẹ́. 18 Ìwọ ha ba tẹ́ pẹpẹ ojú ọ̀run, tí ó dúró ṣinṣin,tí ó sì dàbí dígí tí ó yọ̀ dà? 19 “Kọ́ wa ní èyí tí a lè wí fún un;nítorí pé àwa kò le wádìí ọ̀rọ̀ náà nítorí òkùnkùn wa. 20 A ó ha wí fún un pé, èmi fẹ́ sọ̀rọ̀?Tàbí ẹnìkan lè wí pé, ìfẹ́ mi ni pé kí a gbé mi mì? 21 Síbẹ̀ nísinsin yìí ènìyàn kò ríoòrùn tí ń dán nínú àwọsánmọ̀,ṣùgbọ́n afẹ́fẹ́ ń kọjá, a sì gbá wọn mọ́. 22 Wúrà dídán ti inú ìhà àríwá jáde wá;lọ́dọ̀ Ọlọ́run ni ọláńlá ẹ̀rù ńlá wa. 23 Nípa ti Olódùmarè àwa kò le wádìí rẹ̀, ó rékọjá ní ipá;nínú ìdájọ́ àti títí bi òun kì í ba ẹ̀tọ́ àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ òtítọ́ jẹ́. 24 Nítorí náà ènìyàn ha máa bẹ̀rù rẹ̀,òun kì í ṣe ojú sájú ẹnikẹ́ni tí ó gbọ́n ní ayé?”

In Other Versions

Job 37 in the ANGEFD

Job 37 in the ANTPNG2D

Job 37 in the AS21

Job 37 in the BAGH

Job 37 in the BBPNG

Job 37 in the BBT1E

Job 37 in the BDS

Job 37 in the BEV

Job 37 in the BHAD

Job 37 in the BIB

Job 37 in the BLPT

Job 37 in the BNT

Job 37 in the BNTABOOT

Job 37 in the BNTLV

Job 37 in the BOATCB

Job 37 in the BOATCB2

Job 37 in the BOBCV

Job 37 in the BOCNT

Job 37 in the BOECS

Job 37 in the BOGWICC

Job 37 in the BOHCB

Job 37 in the BOHCV

Job 37 in the BOHLNT

Job 37 in the BOHNTLTAL

Job 37 in the BOICB

Job 37 in the BOILNTAP

Job 37 in the BOITCV

Job 37 in the BOKCV

Job 37 in the BOKCV2

Job 37 in the BOKHWOG

Job 37 in the BOKSSV

Job 37 in the BOLCB

Job 37 in the BOLCB2

Job 37 in the BOMCV

Job 37 in the BONAV

Job 37 in the BONCB

Job 37 in the BONLT

Job 37 in the BONUT2

Job 37 in the BOPLNT

Job 37 in the BOSCB

Job 37 in the BOSNC

Job 37 in the BOTLNT

Job 37 in the BOVCB

Job 37 in the BPBB

Job 37 in the BPH

Job 37 in the BSB

Job 37 in the CCB

Job 37 in the CUV

Job 37 in the CUVS

Job 37 in the DBT

Job 37 in the DGDNT

Job 37 in the DHNT

Job 37 in the DNT

Job 37 in the ELBE

Job 37 in the EMTV

Job 37 in the ESV

Job 37 in the FBV

Job 37 in the FEB

Job 37 in the GGMNT

Job 37 in the GNT

Job 37 in the HARY

Job 37 in the HNT

Job 37 in the IRVA

Job 37 in the IRVB

Job 37 in the IRVG

Job 37 in the IRVH

Job 37 in the IRVK

Job 37 in the IRVM

Job 37 in the IRVM2

Job 37 in the IRVO

Job 37 in the IRVP

Job 37 in the IRVT

Job 37 in the IRVT2

Job 37 in the IRVU

Job 37 in the ISVN

Job 37 in the JSNT

Job 37 in the KAPI

Job 37 in the KBT1ETNIK

Job 37 in the KBV

Job 37 in the KJV

Job 37 in the KNFD

Job 37 in the LBA

Job 37 in the LBLA

Job 37 in the LNT

Job 37 in the LSV

Job 37 in the MAAL

Job 37 in the MBV

Job 37 in the MBV2

Job 37 in the MHNT

Job 37 in the MKNFD

Job 37 in the MNG

Job 37 in the MNT

Job 37 in the MNT2

Job 37 in the MRS1T

Job 37 in the NAA

Job 37 in the NASB

Job 37 in the NBLA

Job 37 in the NBS

Job 37 in the NBVTP

Job 37 in the NET2

Job 37 in the NIV11

Job 37 in the NNT

Job 37 in the NNT2

Job 37 in the NNT3

Job 37 in the PDDPT

Job 37 in the PFNT

Job 37 in the RMNT

Job 37 in the SBIAS

Job 37 in the SBIBS

Job 37 in the SBIBS2

Job 37 in the SBICS

Job 37 in the SBIDS

Job 37 in the SBIGS

Job 37 in the SBIHS

Job 37 in the SBIIS

Job 37 in the SBIIS2

Job 37 in the SBIIS3

Job 37 in the SBIKS

Job 37 in the SBIKS2

Job 37 in the SBIMS

Job 37 in the SBIOS

Job 37 in the SBIPS

Job 37 in the SBISS

Job 37 in the SBITS

Job 37 in the SBITS2

Job 37 in the SBITS3

Job 37 in the SBITS4

Job 37 in the SBIUS

Job 37 in the SBIVS

Job 37 in the SBT

Job 37 in the SBT1E

Job 37 in the SCHL

Job 37 in the SNT

Job 37 in the SUSU

Job 37 in the SUSU2

Job 37 in the SYNO

Job 37 in the TBIAOTANT

Job 37 in the TBT1E

Job 37 in the TBT1E2

Job 37 in the TFTIP

Job 37 in the TFTU

Job 37 in the TGNTATF3T

Job 37 in the THAI

Job 37 in the TNFD

Job 37 in the TNT

Job 37 in the TNTIK

Job 37 in the TNTIL

Job 37 in the TNTIN

Job 37 in the TNTIP

Job 37 in the TNTIZ

Job 37 in the TOMA

Job 37 in the TTENT

Job 37 in the UBG

Job 37 in the UGV

Job 37 in the UGV2

Job 37 in the UGV3

Job 37 in the VBL

Job 37 in the VDCC

Job 37 in the YALU

Job 37 in the YAPE

Job 37 in the YBVTP

Job 37 in the ZBP