Job 41 (BOYCB)

1 “Ǹjẹ́ ìwọ le è fi ìwọ̀ fa Lefitani jáde?Tàbí ìwọ lè fi okùn so ahọ́n rẹ̀ mọ́lẹ̀? 2 Ìwọ lè fi okùn bọ̀ ọ́ ní í mú,tàbí fi ìwọ̀ ẹ̀gún gun ní ẹ̀rẹ̀kẹ́? 3 Òun ha jẹ́ bẹ ẹ̀bẹ̀ fún àánú lọ́dọ̀rẹ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ bí òun ha bá ọ sọ̀rọ̀ pẹ̀lẹ́? 4 Òun ha bá ọ dá májẹ̀mú bí?Ìwọ ó ha máa mú ṣe ẹrú láéláé bí? 5 Ìwọ ha lè ba sáré bí ẹni pé ẹyẹ ni,tàbí ìwọ ó dè é fún àwọn ọmọbìnrin ìránṣẹ́ rẹ̀? 6 Ẹgbẹ́ àwọn apẹja yóò ha máa tà á bí?Wọn ó ha pín láàrín àwọn oníṣòwò? 7 Ìwọ ha lè fi ọ̀kọ̀-irin gun awọ rẹ̀,tàbí orí rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀kọ̀ ìpẹja. 8 Fi ọwọ́ rẹ lé e lára,ìwọ ó rántí ìjà náà, ìwọ kì yóò sì ṣe bẹ́ẹ̀ mọ́. 9 Kíyèsi, ìgbìyànjú láti mú un ní asán;ní kìkì ìrí rẹ̀ ara kì yóò ha rọ̀ ọ́ wẹ̀sì? 10 Kò sí ẹni aláyà lílé tí ó lè ru sókè.Ǹjẹ́ ta ni ó lè dúró níwájú mi. 11 Ta ni ó kọ́kọ́ ṣe fún mi, tí èmi ìbá fi san án fún un?Ohunkóhun ti ń bẹ lábẹ́ ọ̀run gbogbo, tèmi ni. 12 “Èmi kì yóò fi ẹ̀yà ara Lefitani,tàbí ipá rẹ, tàbí ìhámọ́ra rẹ tí ó ní ẹwà pamọ́. 13 Ta ni yóò lè rídìí aṣọ àpáta rẹ̀?Tàbí ta ni ó lè súnmọ́ ọ̀nà méjì eyín rẹ̀? 14 Ta ni ó lè ṣí ìlẹ̀kùn iwájú rẹ̀?Àyíká ẹ̀yin rẹ ni ìbẹ̀rù ńlá. 15 Ìpẹ́ lílé ní ìgbéraga rẹ̀;ó pàdé pọ̀ tímọ́tímọ́ bí àmì èdìdì. 16 Èkínní fi ara mọ́ èkejì tó bẹ́ẹ̀tí afẹ́fẹ́ kò lè wọ àárín wọn. 17 Èkínní fi ara mọ́ èkejì rẹ̀;wọ́n lè wọ́n pọ̀ tí a kò lè mọ̀ wọ́n. 18 Nípa sí sin rẹ̀ ìmọ́lẹ̀ á mọ́,ojú rẹ̀ a sì dàbí ìpéǹpéjú òwúrọ̀. 19 Láti ẹnu rẹ ni ọ̀wọ́-iná ti jáde wá,ìpẹ́pẹ́ iná a sì ta jáde. 20 Láti ihò imú rẹ ni èéfín ti jáde wá,bí ẹni pé láti inú ìkòkò tí a fẹ́ iná ìfèéfèé lábẹ́ rẹ̀. 21 Èémí rẹ̀ tiná bọ ẹ̀yin iná,ọ̀wọ́-iná sì ti ẹnu rẹ̀ jáde. 22 Ní ọrùn rẹ̀ ní agbára kù sí,àti ìbànújẹ́ àyà sì padà di ayọ̀ níwájú rẹ̀. 23 Jabajaba ẹran rẹ̀ dìjọ pọ̀,wọ́n múra gírí fún ara wọn, a kò lè sí wọn ní ipò. 24 Àyà rẹ̀ dúró gbagidi bí òkúta,àní, ó le bi ìyá ọlọ. 25 Nígbà tí ó bá gbé ara rẹ̀ sókè, àwọn alágbára bẹ̀rù;nítorí ìbẹ̀rù ńlá, wọ́n dààmú. 26 Ọ̀kọ̀ tàbí idà, tàbí ọfà,ẹni tí ó ṣá a kò lè rán an. 27 Ó ká irin sí ibi koríko gbígbẹàti idẹ si bi igi híhù. 28 Ọfà kò lè mú un sá;òkúta kànnakánná lọ́dọ̀ rẹ̀ dàbí àgékù koríko. 29 Ó ka ẹṣin sí bí àgékù ìdì koríko;ó rẹ́rìn-ín sí mímì ọ̀kọ̀. 30 Òkúta mímú ń bẹ nísàlẹ̀ abẹ́ rẹ̀,ó sì tẹ́ ohun mímú ṣóńṣó sórí ẹrẹ̀. 31 Ó mú ibú omi hó bí ìkòkò;ó sọ̀ agbami òkun dàbí kólòbó ìkunra. 32 Ó mú ipa ọ̀nà tan lẹ́yìn rẹ̀;ènìyàn a máa ka ibú sí ewú arúgbó. 33 Lórí ilẹ̀ ayé kò sí ẹni tí ó dàbí rẹ̀,tí a dá láìní ìbẹ̀rù. 34 Ó bojú wo ohun gíga gbogbo,ó sì nìkan jásí ọba lórí gbogbo àwọn ọmọ ìgbéraga.”

In Other Versions

Job 41 in the ANGEFD

Job 41 in the ANTPNG2D

Job 41 in the AS21

Job 41 in the BAGH

Job 41 in the BBPNG

Job 41 in the BBT1E

Job 41 in the BDS

Job 41 in the BEV

Job 41 in the BHAD

Job 41 in the BIB

Job 41 in the BLPT

Job 41 in the BNT

Job 41 in the BNTABOOT

Job 41 in the BNTLV

Job 41 in the BOATCB

Job 41 in the BOATCB2

Job 41 in the BOBCV

Job 41 in the BOCNT

Job 41 in the BOECS

Job 41 in the BOGWICC

Job 41 in the BOHCB

Job 41 in the BOHCV

Job 41 in the BOHLNT

Job 41 in the BOHNTLTAL

Job 41 in the BOICB

Job 41 in the BOILNTAP

Job 41 in the BOITCV

Job 41 in the BOKCV

Job 41 in the BOKCV2

Job 41 in the BOKHWOG

Job 41 in the BOKSSV

Job 41 in the BOLCB

Job 41 in the BOLCB2

Job 41 in the BOMCV

Job 41 in the BONAV

Job 41 in the BONCB

Job 41 in the BONLT

Job 41 in the BONUT2

Job 41 in the BOPLNT

Job 41 in the BOSCB

Job 41 in the BOSNC

Job 41 in the BOTLNT

Job 41 in the BOVCB

Job 41 in the BPBB

Job 41 in the BPH

Job 41 in the BSB

Job 41 in the CCB

Job 41 in the CUV

Job 41 in the CUVS

Job 41 in the DBT

Job 41 in the DGDNT

Job 41 in the DHNT

Job 41 in the DNT

Job 41 in the ELBE

Job 41 in the EMTV

Job 41 in the ESV

Job 41 in the FBV

Job 41 in the FEB

Job 41 in the GGMNT

Job 41 in the GNT

Job 41 in the HARY

Job 41 in the HNT

Job 41 in the IRVA

Job 41 in the IRVB

Job 41 in the IRVG

Job 41 in the IRVH

Job 41 in the IRVK

Job 41 in the IRVM

Job 41 in the IRVM2

Job 41 in the IRVO

Job 41 in the IRVP

Job 41 in the IRVT

Job 41 in the IRVT2

Job 41 in the IRVU

Job 41 in the ISVN

Job 41 in the JSNT

Job 41 in the KAPI

Job 41 in the KBT1ETNIK

Job 41 in the KBV

Job 41 in the KJV

Job 41 in the KNFD

Job 41 in the LBA

Job 41 in the LBLA

Job 41 in the LNT

Job 41 in the LSV

Job 41 in the MAAL

Job 41 in the MBV

Job 41 in the MBV2

Job 41 in the MHNT

Job 41 in the MKNFD

Job 41 in the MNG

Job 41 in the MNT

Job 41 in the MNT2

Job 41 in the MRS1T

Job 41 in the NAA

Job 41 in the NASB

Job 41 in the NBLA

Job 41 in the NBS

Job 41 in the NBVTP

Job 41 in the NET2

Job 41 in the NIV11

Job 41 in the NNT

Job 41 in the NNT2

Job 41 in the NNT3

Job 41 in the PDDPT

Job 41 in the PFNT

Job 41 in the RMNT

Job 41 in the SBIAS

Job 41 in the SBIBS

Job 41 in the SBIBS2

Job 41 in the SBICS

Job 41 in the SBIDS

Job 41 in the SBIGS

Job 41 in the SBIHS

Job 41 in the SBIIS

Job 41 in the SBIIS2

Job 41 in the SBIIS3

Job 41 in the SBIKS

Job 41 in the SBIKS2

Job 41 in the SBIMS

Job 41 in the SBIOS

Job 41 in the SBIPS

Job 41 in the SBISS

Job 41 in the SBITS

Job 41 in the SBITS2

Job 41 in the SBITS3

Job 41 in the SBITS4

Job 41 in the SBIUS

Job 41 in the SBIVS

Job 41 in the SBT

Job 41 in the SBT1E

Job 41 in the SCHL

Job 41 in the SNT

Job 41 in the SUSU

Job 41 in the SUSU2

Job 41 in the SYNO

Job 41 in the TBIAOTANT

Job 41 in the TBT1E

Job 41 in the TBT1E2

Job 41 in the TFTIP

Job 41 in the TFTU

Job 41 in the TGNTATF3T

Job 41 in the THAI

Job 41 in the TNFD

Job 41 in the TNT

Job 41 in the TNTIK

Job 41 in the TNTIL

Job 41 in the TNTIN

Job 41 in the TNTIP

Job 41 in the TNTIZ

Job 41 in the TOMA

Job 41 in the TTENT

Job 41 in the UBG

Job 41 in the UGV

Job 41 in the UGV2

Job 41 in the UGV3

Job 41 in the VBL

Job 41 in the VDCC

Job 41 in the YALU

Job 41 in the YAPE

Job 41 in the YBVTP

Job 41 in the ZBP