Matthew 1 (BOYCB)

1 Ìwé ìran Jesu Kristi, ẹni tí í ṣe ọmọ Dafidi, ọmọ Abrahamu: 2 Abrahamu ni baba Isaaki;Isaaki ni baba Jakọbu;Jakọbu ni baba Juda àti àwọn arákùnrin rẹ̀, 3 Juda ni baba Peresi àti Sera,Tamari sì ni ìyá rẹ̀,Peresi ni baba Hesroni:Hesroni ni baba Ramu; 4 Ramu ni baba Amminadabu;Amminadabu ni baba Nahiṣoni;Nahiṣoni ni baba Salmoni; 5 Salmoni ni baba Boasi, Rahabu sí ni ìyá rẹ̀;Boasi ni baba Obedi, Rutu sí ni ìyá rẹ̀;Obedi sì ni baba Jese; 6 Jese ni baba Dafidi ọba. Dafidi ni baba Solomoni, ẹni tí ìyá rẹ̀ jẹ́ aya Uriah tẹ́lẹ̀ rí. 7 Solomoni ni baba Rehoboamu,Rehoboamu ni baba Abijah,Abijah ni baba Asa, 8 Asa ni baba Jehoṣafati;Jehoṣafati ni baba Jehoramu;Jehoramu ni baba Ussiah; 9 Ussiah ni baba Jotamu;Jotamu ni baba Ahaṣi;Ahaṣi ni baba Hesekiah; 10 Hesekiah ni baba Manase;Manase ni baba Amoni;Amoni ni baba Josiah; 11 Josiah sì ni baba Jekoniah àti àwọn arákùnrin rẹ̀ ní àkókò ìkólọ sí Babeli. 12 Lẹ́yìn ìkólọ sí Babeli:Jekoniah ni baba Ṣealitieli;Ṣealitieli ni baba Serubbabeli; 13 Serubbabeli ni baba Abihudi;Abihudi ni baba Eliakimu;Eliakimu ni baba Asori; 14 Asori ni baba Sadoku;Sadoku ni baba Akimu;Akimu ni baba Elihudi; 15 Elihudi ni baba Eleasari;Eleasari ni baba Mattani;Mattani ni baba Jakọbu; 16 Jakọbu ni baba Josẹfu, ẹni tí ń ṣe ọkọ Maria, ìyá Jesu, ẹni tí í ṣe Kristi. 17 Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo wọ́n jẹ́ ìran mẹ́rìnlá láti orí Abrahamu dé orí Dafidi, ìran mẹ́rìnlá á láti orí Dafidi títí dé ìkólọ sí Babeli, àti ìran mẹ́rìnlá láti ìkólọ títí dé orí Kristi. 18 Bí a ṣe bí Jesu Kristi nìyí, ní àkókò ti àdéhùn ìgbéyàwó ti parí láàrín Maria ìyá rẹ̀ àti Josẹfu, ṣùgbọ́n kí wọn tó pàdé, a rí i ó lóyún láti ọwọ́ Ẹ̀mí Mímọ́. 19 Nítorí Josẹfu ọkọ rẹ̀ tí í ṣe olóòtítọ́ ènìyàn kò fẹ́ dójútì í ní gbangba, ó ní èrò láti kọ̀ ọ́ sílẹ̀ ní ìkọ̀kọ̀. 20 Ṣùgbọ́n nígbà tí ó ro èrò yìí tán, angẹli Olúwa yọ sí i ní ojú àlá, ó wí pé, “Josẹfu, ọmọ Dafidi, má fòyà láti fi Maria ṣe aya rẹ, nítorí oyún tí ó wà nínú rẹ̀ láti ọwọ́ Ẹ̀mí Mímọ́ ni. 21 Òun yóò sì bí ọmọkùnrin, ìwọ yóò sì pe orúkọ rẹ̀ ní Jesu, nítorí òun ni yóò gba àwọn ènìyàn rẹ̀ là kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ wọn.” 22 Gbogbo nǹkan wọ̀nyí sì ṣẹ láti mú ọ̀rọ̀ Olúwa ṣẹ èyí tí a sọ láti ẹnu wòlíì rẹ̀ wá pé: 23 “Wúńdíá kan yóò lóyún, yóò sì bí ọmọkùnrin kan, yóò sì pe orúkọ rẹ̀ ní Emmanueli,” (èyí tí ó túmọ̀ sí “Ọlọ́run wà pẹ̀lú wa”). 24 Nígbà tí Josẹfu jí lójú oorun rẹ̀, òun ṣe gẹ́gẹ́ bí angẹli Olúwa ti pàṣẹ fún un. Ó mú Maria wá sílé rẹ̀ ní aya. 25 Ṣùgbọ́n òun kò mọ̀ ọ́n títí tí ó fi bí ọmọkùnrin, òun sì sọ orúkọ rẹ̀ ní Jesu.

In Other Versions

Matthew 1 in the ANGEFD

Matthew 1 in the ANTPNG2D

Matthew 1 in the AS21

Matthew 1 in the BAGH

Matthew 1 in the BBPNG

Matthew 1 in the BBT1E

Matthew 1 in the BDS

Matthew 1 in the BEV

Matthew 1 in the BHAD

Matthew 1 in the BIB

Matthew 1 in the BLPT

Matthew 1 in the BNT

Matthew 1 in the BNTABOOT

Matthew 1 in the BNTLV

Matthew 1 in the BOATCB

Matthew 1 in the BOATCB2

Matthew 1 in the BOBCV

Matthew 1 in the BOCNT

Matthew 1 in the BOECS

Matthew 1 in the BOGWICC

Matthew 1 in the BOHCB

Matthew 1 in the BOHCV

Matthew 1 in the BOHLNT

Matthew 1 in the BOHNTLTAL

Matthew 1 in the BOICB

Matthew 1 in the BOILNTAP

Matthew 1 in the BOITCV

Matthew 1 in the BOKCV

Matthew 1 in the BOKCV2

Matthew 1 in the BOKHWOG

Matthew 1 in the BOKSSV

Matthew 1 in the BOLCB

Matthew 1 in the BOLCB2

Matthew 1 in the BOMCV

Matthew 1 in the BONAV

Matthew 1 in the BONCB

Matthew 1 in the BONLT

Matthew 1 in the BONUT2

Matthew 1 in the BOPLNT

Matthew 1 in the BOSCB

Matthew 1 in the BOSNC

Matthew 1 in the BOTLNT

Matthew 1 in the BOVCB

Matthew 1 in the BPBB

Matthew 1 in the BPH

Matthew 1 in the BSB

Matthew 1 in the CCB

Matthew 1 in the CUV

Matthew 1 in the CUVS

Matthew 1 in the DBT

Matthew 1 in the DGDNT

Matthew 1 in the DHNT

Matthew 1 in the DNT

Matthew 1 in the ELBE

Matthew 1 in the EMTV

Matthew 1 in the ESV

Matthew 1 in the FBV

Matthew 1 in the FEB

Matthew 1 in the GGMNT

Matthew 1 in the GNT

Matthew 1 in the HARY

Matthew 1 in the HNT

Matthew 1 in the IRVA

Matthew 1 in the IRVB

Matthew 1 in the IRVG

Matthew 1 in the IRVH

Matthew 1 in the IRVK

Matthew 1 in the IRVM

Matthew 1 in the IRVM2

Matthew 1 in the IRVO

Matthew 1 in the IRVP

Matthew 1 in the IRVT

Matthew 1 in the IRVT2

Matthew 1 in the IRVU

Matthew 1 in the ISVN

Matthew 1 in the JSNT

Matthew 1 in the KAPI

Matthew 1 in the KBT1ETNIK

Matthew 1 in the KBV

Matthew 1 in the KJV

Matthew 1 in the KNFD

Matthew 1 in the LBA

Matthew 1 in the LBLA

Matthew 1 in the LNT

Matthew 1 in the LSV

Matthew 1 in the MAAL

Matthew 1 in the MBV

Matthew 1 in the MBV2

Matthew 1 in the MHNT

Matthew 1 in the MKNFD

Matthew 1 in the MNG

Matthew 1 in the MNT

Matthew 1 in the MNT2

Matthew 1 in the MRS1T

Matthew 1 in the NAA

Matthew 1 in the NASB

Matthew 1 in the NBLA

Matthew 1 in the NBS

Matthew 1 in the NBVTP

Matthew 1 in the NET2

Matthew 1 in the NIV11

Matthew 1 in the NNT

Matthew 1 in the NNT2

Matthew 1 in the NNT3

Matthew 1 in the PDDPT

Matthew 1 in the PFNT

Matthew 1 in the RMNT

Matthew 1 in the SBIAS

Matthew 1 in the SBIBS

Matthew 1 in the SBIBS2

Matthew 1 in the SBICS

Matthew 1 in the SBIDS

Matthew 1 in the SBIGS

Matthew 1 in the SBIHS

Matthew 1 in the SBIIS

Matthew 1 in the SBIIS2

Matthew 1 in the SBIIS3

Matthew 1 in the SBIKS

Matthew 1 in the SBIKS2

Matthew 1 in the SBIMS

Matthew 1 in the SBIOS

Matthew 1 in the SBIPS

Matthew 1 in the SBISS

Matthew 1 in the SBITS

Matthew 1 in the SBITS2

Matthew 1 in the SBITS3

Matthew 1 in the SBITS4

Matthew 1 in the SBIUS

Matthew 1 in the SBIVS

Matthew 1 in the SBT

Matthew 1 in the SBT1E

Matthew 1 in the SCHL

Matthew 1 in the SNT

Matthew 1 in the SUSU

Matthew 1 in the SUSU2

Matthew 1 in the SYNO

Matthew 1 in the TBIAOTANT

Matthew 1 in the TBT1E

Matthew 1 in the TBT1E2

Matthew 1 in the TFTIP

Matthew 1 in the TFTU

Matthew 1 in the TGNTATF3T

Matthew 1 in the THAI

Matthew 1 in the TNFD

Matthew 1 in the TNT

Matthew 1 in the TNTIK

Matthew 1 in the TNTIL

Matthew 1 in the TNTIN

Matthew 1 in the TNTIP

Matthew 1 in the TNTIZ

Matthew 1 in the TOMA

Matthew 1 in the TTENT

Matthew 1 in the UBG

Matthew 1 in the UGV

Matthew 1 in the UGV2

Matthew 1 in the UGV3

Matthew 1 in the VBL

Matthew 1 in the VDCC

Matthew 1 in the YALU

Matthew 1 in the YAPE

Matthew 1 in the YBVTP

Matthew 1 in the ZBP