Proverbs 19 (BOYCB)

1 Ó sàn kí ènìyàn jẹ́ tálákà tí ìrìn rẹ̀ kò lábùkùju aláìgbọ́n tí ètè rẹ̀ jẹ́ àyídáyidà. 2 Kò dára láti ní ìtara láìní ìmọ̀,tàbí kí ènìyàn kánjú kí ó sì ṣìnà. 3 Ìwà òmùgọ̀ ènìyàn fúnra rẹ̀ a pa ẹ̀mí rẹ̀ run;síbẹ̀ ọkàn rẹ̀ yóò máa bínú sí OLÚWA. 4 Ọrọ̀ máa ń fa ọ̀rẹ́ púpọ̀;ṣùgbọ́n ọ̀rẹ́ tálákà tún kọ̀ ọ́ sílẹ̀. 5 Ajẹ́rìí èké kò ní lọ láìjìyà,ẹni tí ó sì ń tú irọ́ jáde kò ní lọ lọ́fẹ̀ẹ́. 6 Ọ̀pọ̀ ń wá ojúrere olórí;gbogbo ènìyàn sì ni ọ̀rẹ́ ẹni tí ó lawọ́. 7 Gbogbo ará ilé e tálákà ni ó pa á tì,mélòó mélòó ni ti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ tí ń sá fún un!Bí ó tilẹ̀ ń lé wọn kiri pẹ̀lú ẹ̀bẹ̀,kò tilẹ̀ le rí wọn rárá. 8 Ẹni tí ó gba ọgbọ́n fẹ́ràn ọkàn ara rẹ̀;ẹni tí ó bá káràmáṣìkí òye yóò gbèrú. 9 Ajẹ́rìí èké kì yóò lọ láìjìyàẹni tí ó sì ń tú irọ́ jáde yóò parun. 10 Kò yẹ aláìgbọ́n láti máa gbé nínú ọláńlá,mélòó mélòó bí ó ti burú tó fún ẹrú láti jẹ ọba lórí ọmọ-aládé. 11 Ọgbọ́n ènìyàn a máa fún un ní sùúrù;fún ògo rẹ̀ ni láti fojú fo àṣìṣe dá. 12 Ìbínú ọba dàbí kíké e kìnnìún,ṣùgbọ́n ojúrere rẹ̀ dàbí ìrì lára koríko. 13 Aṣiwèrè ọmọ jẹ́ ìparun baba rẹ̀,aya tí ó máa ń jà sì dàbí ọ̀ṣọ̀ọ̀rọ̀ òjò. 14 A máa ń jogún ilé àti ọrọ̀ lọ́dọ̀ òbí,ṣùgbọ́n aya olóye láti ọ̀dọ̀ OLÚWA ni. 15 Ọ̀lẹ ṣíṣe máa ń fa oorun sísùn fọnfọn,ebi yóò sì máa pa ènìyàn tí ó lọ́ra. 16 Ẹnikẹ́ni tí ó gbọ́ ẹ̀kọ́ pa ẹnu rẹ̀ mọ́,ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá kẹ́gàn ọ̀nà rẹ̀ yóò kú. 17 Ẹni tí ó ṣàánú tálákà, OLÚWA ní ó yá,yóò sì pín in lérè ohun tí ó ti ṣe. 18 Bá ọmọ rẹ wí nítorí nínú ìyẹn ni ìrètí wà;àìṣe bẹ́ẹ̀ ìwọ lọ́wọ́ nínú ìparun un rẹ̀. 19 Ènìyàn onínú-fùfù gbọdọ̀ gba èrè ìwà rẹ̀;bí ìwọ bá gbà á là, ìwọ yóò tún ní láti ṣe é lẹ́ẹ̀kan sí i. 20 Fetí sí ìmọ̀ràn kí o sì gba ẹ̀kọ́,ní ìgbẹ̀yìn gbẹ́yín ìwọ yóò di ọlọ́gbọ́n. 21 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ète inú ọkàn ènìyàn,ṣùgbọ́n ìfẹ́ OLÚWA ní ó máa ń borí. 22 Ohun tí ènìyàn ń fẹ́ ni ìfẹ́ tí kì í yẹ̀;ó sàn láti jẹ́ tálákà ju òpùrọ́ lọ. 23 Ìbẹ̀rù OLÚWA ń mú ìyè wá;nígbà náà ọkàn ń balẹ̀, láìsí ewu. 24 Ọ̀lẹ ki ọwọ́ rẹ̀ bọ inú àwo oúnjẹ;kò tilẹ̀ ní mú u padà wá sí ẹnu rẹ̀. 25 Na ẹlẹ́gàn, òpè yóò sì kọ́gbọ́n;bá olóye ènìyàn wí, yóò sì ní ìmọ̀ sí i. 26 Ẹni tí ó ṣìkà sí baba rẹ̀, tí ó sì lé ìyá rẹ̀ jádeòun ni ọmọ tí ń ṣe ìtìjú, tí ó sì mú ẹ̀gàn wá. 27 Ọmọ mi, dẹ́kun láti tẹ́tí sí ẹ̀kọ́,tí í mú ni ṣìnà kúrò nínú ọ̀rọ̀-ìmọ̀. 28 Ẹlẹ́rìí búburú fi ìdájọ́ ṣẹ̀sín,ẹnu ènìyàn búburú sì ń gbé ibi mì. 29 A ti pèsè ìjìyà sílẹ̀ fún ẹlẹ́gàn;àti pàṣán fún ẹ̀yìn àwọn aṣiwèrè.

In Other Versions

Proverbs 19 in the ANGEFD

Proverbs 19 in the ANTPNG2D

Proverbs 19 in the AS21

Proverbs 19 in the BAGH

Proverbs 19 in the BBPNG

Proverbs 19 in the BBT1E

Proverbs 19 in the BDS

Proverbs 19 in the BEV

Proverbs 19 in the BHAD

Proverbs 19 in the BIB

Proverbs 19 in the BLPT

Proverbs 19 in the BNT

Proverbs 19 in the BNTABOOT

Proverbs 19 in the BNTLV

Proverbs 19 in the BOATCB

Proverbs 19 in the BOATCB2

Proverbs 19 in the BOBCV

Proverbs 19 in the BOCNT

Proverbs 19 in the BOECS

Proverbs 19 in the BOGWICC

Proverbs 19 in the BOHCB

Proverbs 19 in the BOHCV

Proverbs 19 in the BOHLNT

Proverbs 19 in the BOHNTLTAL

Proverbs 19 in the BOICB

Proverbs 19 in the BOILNTAP

Proverbs 19 in the BOITCV

Proverbs 19 in the BOKCV

Proverbs 19 in the BOKCV2

Proverbs 19 in the BOKHWOG

Proverbs 19 in the BOKSSV

Proverbs 19 in the BOLCB

Proverbs 19 in the BOLCB2

Proverbs 19 in the BOMCV

Proverbs 19 in the BONAV

Proverbs 19 in the BONCB

Proverbs 19 in the BONLT

Proverbs 19 in the BONUT2

Proverbs 19 in the BOPLNT

Proverbs 19 in the BOSCB

Proverbs 19 in the BOSNC

Proverbs 19 in the BOTLNT

Proverbs 19 in the BOVCB

Proverbs 19 in the BPBB

Proverbs 19 in the BPH

Proverbs 19 in the BSB

Proverbs 19 in the CCB

Proverbs 19 in the CUV

Proverbs 19 in the CUVS

Proverbs 19 in the DBT

Proverbs 19 in the DGDNT

Proverbs 19 in the DHNT

Proverbs 19 in the DNT

Proverbs 19 in the ELBE

Proverbs 19 in the EMTV

Proverbs 19 in the ESV

Proverbs 19 in the FBV

Proverbs 19 in the FEB

Proverbs 19 in the GGMNT

Proverbs 19 in the GNT

Proverbs 19 in the HARY

Proverbs 19 in the HNT

Proverbs 19 in the IRVA

Proverbs 19 in the IRVB

Proverbs 19 in the IRVG

Proverbs 19 in the IRVH

Proverbs 19 in the IRVK

Proverbs 19 in the IRVM

Proverbs 19 in the IRVM2

Proverbs 19 in the IRVO

Proverbs 19 in the IRVP

Proverbs 19 in the IRVT

Proverbs 19 in the IRVT2

Proverbs 19 in the IRVU

Proverbs 19 in the ISVN

Proverbs 19 in the JSNT

Proverbs 19 in the KAPI

Proverbs 19 in the KBT1ETNIK

Proverbs 19 in the KBV

Proverbs 19 in the KJV

Proverbs 19 in the KNFD

Proverbs 19 in the LBA

Proverbs 19 in the LBLA

Proverbs 19 in the LNT

Proverbs 19 in the LSV

Proverbs 19 in the MAAL

Proverbs 19 in the MBV

Proverbs 19 in the MBV2

Proverbs 19 in the MHNT

Proverbs 19 in the MKNFD

Proverbs 19 in the MNG

Proverbs 19 in the MNT

Proverbs 19 in the MNT2

Proverbs 19 in the MRS1T

Proverbs 19 in the NAA

Proverbs 19 in the NASB

Proverbs 19 in the NBLA

Proverbs 19 in the NBS

Proverbs 19 in the NBVTP

Proverbs 19 in the NET2

Proverbs 19 in the NIV11

Proverbs 19 in the NNT

Proverbs 19 in the NNT2

Proverbs 19 in the NNT3

Proverbs 19 in the PDDPT

Proverbs 19 in the PFNT

Proverbs 19 in the RMNT

Proverbs 19 in the SBIAS

Proverbs 19 in the SBIBS

Proverbs 19 in the SBIBS2

Proverbs 19 in the SBICS

Proverbs 19 in the SBIDS

Proverbs 19 in the SBIGS

Proverbs 19 in the SBIHS

Proverbs 19 in the SBIIS

Proverbs 19 in the SBIIS2

Proverbs 19 in the SBIIS3

Proverbs 19 in the SBIKS

Proverbs 19 in the SBIKS2

Proverbs 19 in the SBIMS

Proverbs 19 in the SBIOS

Proverbs 19 in the SBIPS

Proverbs 19 in the SBISS

Proverbs 19 in the SBITS

Proverbs 19 in the SBITS2

Proverbs 19 in the SBITS3

Proverbs 19 in the SBITS4

Proverbs 19 in the SBIUS

Proverbs 19 in the SBIVS

Proverbs 19 in the SBT

Proverbs 19 in the SBT1E

Proverbs 19 in the SCHL

Proverbs 19 in the SNT

Proverbs 19 in the SUSU

Proverbs 19 in the SUSU2

Proverbs 19 in the SYNO

Proverbs 19 in the TBIAOTANT

Proverbs 19 in the TBT1E

Proverbs 19 in the TBT1E2

Proverbs 19 in the TFTIP

Proverbs 19 in the TFTU

Proverbs 19 in the TGNTATF3T

Proverbs 19 in the THAI

Proverbs 19 in the TNFD

Proverbs 19 in the TNT

Proverbs 19 in the TNTIK

Proverbs 19 in the TNTIL

Proverbs 19 in the TNTIN

Proverbs 19 in the TNTIP

Proverbs 19 in the TNTIZ

Proverbs 19 in the TOMA

Proverbs 19 in the TTENT

Proverbs 19 in the UBG

Proverbs 19 in the UGV

Proverbs 19 in the UGV2

Proverbs 19 in the UGV3

Proverbs 19 in the VBL

Proverbs 19 in the VDCC

Proverbs 19 in the YALU

Proverbs 19 in the YAPE

Proverbs 19 in the YBVTP

Proverbs 19 in the ZBP