Psalms 69 (BOYCB)
undefined Fún adarí orin. Tí ohùn “Àwọn Lílì.” Ti Dafidi. 1 Gbà mí, Ọlọ́run,nítorí omi ti kún dé ọrùn mi. 2 Mo ń rì nínú irà jíjìn,níbi tí kò sí ibi ìfẹsẹ̀lé.Mo ti wá sínú omi jíjìn;ìkún omi bò mí mọ́lẹ̀. 3 Agara dá mi, mo ń pè fún ìrànlọ́wọ́;ọ̀fun mí gbẹ, ojú mi ṣú,nígbà tí èmi dúró de Ọlọ́run mi. 4 Àwọn tí ó kórìíra mi láìnídìíwọ́n ju irun orí mi lọ,púpọ̀ ni àwọn ọ̀tá mi láìnídìí,àwọn tí ń wá láti pa mí run.A fi ipá mú miláti san ohun tí èmi kò jí. 5 Ìwọ mọ òmùgọ̀ mi, Ọlọ́run;ẹ̀bi mi kò pamọ́ lójú rẹ. 6 Má ṣe dójútì àwọn tí ó ní ìrètí nínú rẹ nítorí mi,Olúwa, OLÚWA àwọn ọmọ-ogun;má ṣe jẹ́ kí àwọn tó ń wá ọ dààmú nítorí mi,Ọlọ́run Israẹli. 7 Nítorí rẹ ni mo ń ru ẹ̀gàn,ìtìjú sì bo ojú mi. 8 Mo jẹ́ àjèjì si àwọn arákùnrin mi;àlejò sí àwọn arákùnrin ìyá mi; 9 nítorí ìtara ilé rẹ jẹ mí run,àti ẹ̀gàn àwọn tí ń gàn ọ́ ṣubú lù mí. 10 Nígbà tí mo sọkúntí mo sì ń fi àwẹ̀ jẹ ara mi ní ìyàèyí náà sì dín ẹ̀gàn mi kù; 11 nígbà tí mo wọ aṣọ àkísà,àwọn ènìyàn ń pa òwe mọ́ mi. 12 Àwọn tí ó jókòó ní ẹnu ibodè ń bú mi,mo sì di orin àwọn ọ̀mùtí. 13 Ṣùgbọ́n bí ó ṣe ti èmi niìwọ ni èmi ń gbàdúrà mi sí OLÚWA,ní ìgbà ìtẹ́wọ́gbàỌlọ́run, nínú ìfẹ́ títóbi rẹ,dá mi lóhùn pẹ̀lú ìgbàlà rẹ tí ó dájú. 14 Gbà mí kúrò nínú ẹrẹ̀,má ṣe jẹ́ kí n rì;gbà mí lọ́wọ́ àwọn tí ó kórìíra mi,kúrò nínú ibú omi. 15 Má ṣe jẹ́ kí ìkún omi bò mí mọ́lẹ̀bẹ́ẹ̀ ni má ṣe jẹ́ kí ọ̀gbìn gbé mi mìkí o má sì ṣe jẹ́ kí ihò pa ẹnu rẹ̀ dé mọ́ mi. 16 Dá mí lóhùn, OLÚWA, nínú ìṣeun ìfẹ́ rẹ;nínú ọ̀pọ̀ àánú rẹ yípadà sí mi. 17 Má ṣe pa ojú rẹ mọ́ fún ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ:yára dá mi lóhùn, nítorí mo wà nínú ìpọ́njú. 18 Súnmọ́ tòsí kí o sì gbà mí là;rà mí padà nítorí àwọn ọ̀tá mi. 19 Ìwọ ti mọ ẹ̀gàn mi, ìtìjú mi àti àìlọ́lá;gbogbo àwọn ọ̀tá mi wà níwájú rẹ. 20 Ẹ̀gàn ba ọkàn mi jẹ́,wọ́n fi mí sílẹ̀ láìsí ìrànlọ́wọ́;mo ń wá aláàánú, ṣùgbọ́n kò sí,mo ń wá olùtùnú, ṣùgbọ́n n kò rí ẹnìkankan. 21 Wọ́n fi òróró fún mi pẹ̀lú ohun jíjẹ mi,àti ní òùngbẹ mi, wọ́n fi ọtí kíkan fún mi. 22 Jẹ́ kí tábìlì wọn kí ó di ìkẹ́kùnní iwájú wọn, kí ó sì di okùn dídẹfún àwọn tó wà ní àlàáfíà. 23 Kí ojú wọn kì í ó ṣókùnkùn, kí wọn má ṣe ríran,kí ẹ̀yin wọn di títẹ̀ títí láé. 24 Tú ìbínú rẹ jáde sí wọn;kí ìbínú gbígbóná rẹ bò wọ́n mọ́lẹ̀. 25 Kí ibùjókòó wọn di ahoro;kí ẹnikẹ́ni má ṣe gbé nínú wọn. 26 Nítorí wọ́n ń ṣe inúnibíni sí ẹni tí ìwọ ti lù,àti ìrora àwọn tí ó ti ṣèṣe. 27 Fi ẹ̀sùn kún ẹ̀sùn wọn;Má ṣe jẹ́ kí wọn pín nínú ìgbàlà rẹ. 28 Jẹ́ kí a yọ wọ́n kúrò nínú ìwé ìyèkí á má kà wọ́n pẹ̀lú àwọn olódodo. 29 Ṣùgbọ́n tálákà àti ẹni-ìkáàánú ni èmí,Ọlọ́run, jẹ́ kí ìgbàlà rẹ gbé mi lékè. 30 Èmi yóò fi orin gbé orúkọ Ọlọ́run gaèmi yóò fi ọpẹ́ gbé orúkọ rẹ̀ ga. 31 Eléyìí tẹ́ OLÚWA lọ́rùn ju ọ̀dá màlúù lọju akọ màlúù pẹ̀lú ìwo rẹ̀ àti bàtà rẹ̀. 32 Àwọn òtòṣì yóò rí, wọn yóò sì yọ̀:ẹ̀yin yóò wá Ọlọ́run, ọkàn yín yóò sì wà láààyè! 33 OLÚWA, gbọ́ ti aláìní,kì ó sì kọ àwọn ìgbèkùn sílẹ̀. 34 Kí ọ̀run àti ayé yìn ín,òkun àti àwọn tí ń gbé inú rẹ̀, 35 nítorí tí Ọlọ́run yóò gba Sioni làyóò sì tún àwọn ìlú Juda wọ̀nyí kọ́.Kí wọn ó lè máa gbé ibẹ̀, kí wọn ó lè máa ní ní ilẹ̀ ìní; 36 àwọn ọmọ ọmọ ọ̀dọ̀ ni yóò máa jogún rẹ̀,àwọn tí ó fẹ́ orúkọ rẹ ni yóò máa gbé inú rẹ̀.
In Other Versions
Psalms 69 in the ANGEFD
Psalms 69 in the ANTPNG2D
Psalms 69 in the AS21
Psalms 69 in the BAGH
Psalms 69 in the BBPNG
Psalms 69 in the BBT1E
Psalms 69 in the BDS
Psalms 69 in the BEV
Psalms 69 in the BHAD
Psalms 69 in the BIB
Psalms 69 in the BLPT
Psalms 69 in the BNT
Psalms 69 in the BNTABOOT
Psalms 69 in the BNTLV
Psalms 69 in the BOATCB
Psalms 69 in the BOATCB2
Psalms 69 in the BOBCV
Psalms 69 in the BOCNT
Psalms 69 in the BOECS
Psalms 69 in the BOGWICC
Psalms 69 in the BOHCB
Psalms 69 in the BOHCV
Psalms 69 in the BOHLNT
Psalms 69 in the BOHNTLTAL
Psalms 69 in the BOICB
Psalms 69 in the BOILNTAP
Psalms 69 in the BOITCV
Psalms 69 in the BOKCV
Psalms 69 in the BOKCV2
Psalms 69 in the BOKHWOG
Psalms 69 in the BOKSSV
Psalms 69 in the BOLCB
Psalms 69 in the BOLCB2
Psalms 69 in the BOMCV
Psalms 69 in the BONAV
Psalms 69 in the BONCB
Psalms 69 in the BONLT
Psalms 69 in the BONUT2
Psalms 69 in the BOPLNT
Psalms 69 in the BOSCB
Psalms 69 in the BOSNC
Psalms 69 in the BOTLNT
Psalms 69 in the BOVCB
Psalms 69 in the BPBB
Psalms 69 in the BPH
Psalms 69 in the BSB
Psalms 69 in the CCB
Psalms 69 in the CUV
Psalms 69 in the CUVS
Psalms 69 in the DBT
Psalms 69 in the DGDNT
Psalms 69 in the DHNT
Psalms 69 in the DNT
Psalms 69 in the ELBE
Psalms 69 in the EMTV
Psalms 69 in the ESV
Psalms 69 in the FBV
Psalms 69 in the FEB
Psalms 69 in the GGMNT
Psalms 69 in the GNT
Psalms 69 in the HARY
Psalms 69 in the HNT
Psalms 69 in the IRVA
Psalms 69 in the IRVB
Psalms 69 in the IRVG
Psalms 69 in the IRVH
Psalms 69 in the IRVK
Psalms 69 in the IRVM
Psalms 69 in the IRVM2
Psalms 69 in the IRVO
Psalms 69 in the IRVP
Psalms 69 in the IRVT
Psalms 69 in the IRVT2
Psalms 69 in the IRVU
Psalms 69 in the ISVN
Psalms 69 in the JSNT
Psalms 69 in the KAPI
Psalms 69 in the KBT1ETNIK
Psalms 69 in the KBV
Psalms 69 in the KJV
Psalms 69 in the KNFD
Psalms 69 in the LBA
Psalms 69 in the LBLA
Psalms 69 in the LNT
Psalms 69 in the LSV
Psalms 69 in the MAAL
Psalms 69 in the MBV
Psalms 69 in the MBV2
Psalms 69 in the MHNT
Psalms 69 in the MKNFD
Psalms 69 in the MNG
Psalms 69 in the MNT
Psalms 69 in the MNT2
Psalms 69 in the MRS1T
Psalms 69 in the NAA
Psalms 69 in the NASB
Psalms 69 in the NBLA
Psalms 69 in the NBS
Psalms 69 in the NBVTP
Psalms 69 in the NET2
Psalms 69 in the NIV11
Psalms 69 in the NNT
Psalms 69 in the NNT2
Psalms 69 in the NNT3
Psalms 69 in the PDDPT
Psalms 69 in the PFNT
Psalms 69 in the RMNT
Psalms 69 in the SBIAS
Psalms 69 in the SBIBS
Psalms 69 in the SBIBS2
Psalms 69 in the SBICS
Psalms 69 in the SBIDS
Psalms 69 in the SBIGS
Psalms 69 in the SBIHS
Psalms 69 in the SBIIS
Psalms 69 in the SBIIS2
Psalms 69 in the SBIIS3
Psalms 69 in the SBIKS
Psalms 69 in the SBIKS2
Psalms 69 in the SBIMS
Psalms 69 in the SBIOS
Psalms 69 in the SBIPS
Psalms 69 in the SBISS
Psalms 69 in the SBITS
Psalms 69 in the SBITS2
Psalms 69 in the SBITS3
Psalms 69 in the SBITS4
Psalms 69 in the SBIUS
Psalms 69 in the SBIVS
Psalms 69 in the SBT
Psalms 69 in the SBT1E
Psalms 69 in the SCHL
Psalms 69 in the SNT
Psalms 69 in the SUSU
Psalms 69 in the SUSU2
Psalms 69 in the SYNO
Psalms 69 in the TBIAOTANT
Psalms 69 in the TBT1E
Psalms 69 in the TBT1E2
Psalms 69 in the TFTIP
Psalms 69 in the TFTU
Psalms 69 in the TGNTATF3T
Psalms 69 in the THAI
Psalms 69 in the TNFD
Psalms 69 in the TNT
Psalms 69 in the TNTIK
Psalms 69 in the TNTIL
Psalms 69 in the TNTIN
Psalms 69 in the TNTIP
Psalms 69 in the TNTIZ
Psalms 69 in the TOMA
Psalms 69 in the TTENT
Psalms 69 in the UBG
Psalms 69 in the UGV
Psalms 69 in the UGV2
Psalms 69 in the UGV3
Psalms 69 in the VBL
Psalms 69 in the VDCC
Psalms 69 in the YALU
Psalms 69 in the YAPE
Psalms 69 in the YBVTP
Psalms 69 in the ZBP