Revelation 22 (BOYCB)
1 Ó sì fi odò omi ìyè kan hàn mi, tí ó mọ́ bí kirisitali, tí ń tí ibi ìtẹ́ Ọlọ́run àti tí Ọ̀dọ́-Àgùntàn jáde wá, 2 ní àárín ìgboro rẹ̀, àti níhà èkínní kejì odò náà, ni igi ìyè gbé wà, tí o máa ń so onírúurú èso méjìlá, a sì máa so èso rẹ̀ ni oṣooṣù ewé igi náà sí wà fún mímú àwọn orílẹ̀-èdè láradà. 3 Ègún kì yóò sì ṣí mọ: ìtẹ́ Ọlọ́run àti tí Ọ̀dọ́-àgùntàn ni yóò sì máa wà níbẹ̀; àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ yóò sì máa sìn ín. 4 Wọ́n ó si máa rí ojú rẹ̀; orúkọ rẹ̀ yóò si máa wà ni iwájú orí wọn. 5 Òru kì yóò sí mọ́; wọn kò sì ní wa ìmọ́lẹ̀ fìtílà, tàbí ìmọ́lẹ̀ oòrùn; nítorí pé Olúwa Ọlọ́run ni yóò tan ìmọ́lẹ̀ fún wọn: wọn ó sì máa jẹ ọba láé àti láéláé. 6 Ó sì wí fún mi pé, “Òdodo àti òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ wọ̀nyí: Olúwa Ọlọ́run ẹ̀mí àwọn wòlíì ni ó sì ran angẹli rẹ̀ láti fi ohun tí ó ní láti ṣẹlẹ̀ láìpẹ́ yìí hàn àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀.” 7 “Kíyèsi i, èmi ń bọ̀ kánkán! Ìbùkún ni fún ẹni tí ń pa ọ̀rọ̀ ìsọtẹ́lẹ̀ inú ìwé yìí mọ́!” 8 Èmi, Johanu, ni ẹni tí ó gbọ́ tí ó sì ri nǹkan wọ̀nyí. Nígbà tí mo sì gbọ́ tí mo sì rí, mo wólẹ̀ láti foríbalẹ̀ níwájú ẹsẹ̀ angẹli náà, tí o fi nǹkan wọ̀nyí hàn mi. 9 Nígbà náà ni ó wí fún mi pé, “Wó ò, má ṣe bẹ́ẹ̀, ìránṣẹ́ ẹlẹgbẹ́ rẹ ni èmi, àti ti àwọn arákùnrin rẹ̀ wòlíì, àti ti àwọn tí ń pa ọ̀rọ̀ inú ìwé yìí mọ́. Foríbalẹ̀ fún Ọlọ́run!” 10 Ó sì wí fún mi pé, “Má ṣe fi èdìdì di ọ̀rọ̀ ìsọtẹ́lẹ̀ tí inú ìwé yìí, nítorí ìgbà kù sí dẹ̀dẹ̀. 11 Ẹni tí ń ṣe aláìṣòótọ́, kí ó máa ṣe aláìṣòótọ́ nì só; àti ẹni tí ń ṣe ẹlẹ́gbin, kí ó máa ṣe ẹ̀gbin nì só; àti ẹni tí ń ṣe olódodo, kí ó máa ṣe òdodo nì só; àti ẹni tí ń ṣe mímọ́, kí ó máa ṣe mímọ́ nì só.” 12 “Kíyèsi i, èmi ń bọ̀ kánkán; èrè mí sì ń bẹ pẹ̀lú mi, láti sán fún olúkúlùkù gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀ yóò tí rí. 13 Èmi ni Alfa àti Omega, ẹni ìṣáájú àti ẹni ìkẹyìn, ìpilẹ̀ṣẹ̀ àti òpin. 14 “Ìbùkún ni fún àwọn ti ń fọ aṣọ wọn, kí wọ́n lè ni ẹ̀tọ́ láti wá sí ibi igi ìyè náà, àti kí wọ́n lè gbà àwọn ẹnu ibodè wọ inú ìlú náà. 15 Nítorí ni òde ni àwọn ajá gbé wà, àti àwọn oṣó, àti àwọn àgbèrè, àti àwọn apànìyàn, àti àwọn abọ̀rìṣà, àti olúkúlùkù ẹni tí ó fẹ́ràn èké tí ó sì ń hùwà èké. 16 “Èmi, Jesu, ni ó rán angẹli mi láti jẹ́rìí nǹkan wọ̀nyí fún yin ní tí àwọn ìjọ. Èmi ni gbòǹgbò àti irú-ọmọ Dafidi, àti ìràwọ̀ òwúrọ̀ tí ń tàn.” 17 Ẹ̀mí àti ìyàwó wí pé, “Máa bọ!” Àti ẹni tí ó ń gbọ́ kí ó wí pé, “Máa bọ̀!” Àti ẹni tí òǹgbẹ ń gbẹ kí ó wá, àti ẹni tí o bá sì fẹ́, kí ó gba omi ìyè náà lọ́fẹ̀ẹ́. 18 Èmi kìlọ̀ fún olúkúlùkù ẹni tó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ ìsọtẹ́lẹ̀ inú ìwé yìí pé, bí ẹnikẹ́ni ba fi kún wọn, Ọlọ́run yóò fi kún àwọn ìyọnu tí a kọ sínú ìwé yìí fún un. 19 Bí ẹnikẹ́ni bá sì mú kúrò nínú ọ̀rọ̀ ìwé ìsọtẹ́lẹ̀ yìí, Ọlọ́run yóò sì mú ipa tirẹ̀ kúrò nínú ìwé ìyè, àti kúrò nínú ìlú mímọ́ náà, àti kúrò nínú àwọn ohun tí a kọ sínú ìwé yìí. 20 Ẹni tí ó jẹ́rìí nǹkan wọ̀nyí wí pé, “Nítòótọ́ èmi ń bọ̀ kánkán.”Àmín. Máa bọ̀, Jesu Olúwa! 21 Oore-ọ̀fẹ́ Jesu Olúwa kí ó wà pẹ̀lú gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́. Àmín.
In Other Versions
Revelation 22 in the ANGEFD
Revelation 22 in the ANTPNG2D
Revelation 22 in the AS21
Revelation 22 in the BAGH
Revelation 22 in the BBPNG
Revelation 22 in the BBT1E
Revelation 22 in the BDS
Revelation 22 in the BEV
Revelation 22 in the BHAD
Revelation 22 in the BIB
Revelation 22 in the BLPT
Revelation 22 in the BNT
Revelation 22 in the BNTABOOT
Revelation 22 in the BNTLV
Revelation 22 in the BOATCB
Revelation 22 in the BOATCB2
Revelation 22 in the BOBCV
Revelation 22 in the BOCNT
Revelation 22 in the BOECS
Revelation 22 in the BOGWICC
Revelation 22 in the BOHCB
Revelation 22 in the BOHCV
Revelation 22 in the BOHLNT
Revelation 22 in the BOHNTLTAL
Revelation 22 in the BOICB
Revelation 22 in the BOILNTAP
Revelation 22 in the BOITCV
Revelation 22 in the BOKCV
Revelation 22 in the BOKCV2
Revelation 22 in the BOKHWOG
Revelation 22 in the BOKSSV
Revelation 22 in the BOLCB
Revelation 22 in the BOLCB2
Revelation 22 in the BOMCV
Revelation 22 in the BONAV
Revelation 22 in the BONCB
Revelation 22 in the BONLT
Revelation 22 in the BONUT2
Revelation 22 in the BOPLNT
Revelation 22 in the BOSCB
Revelation 22 in the BOSNC
Revelation 22 in the BOTLNT
Revelation 22 in the BOVCB
Revelation 22 in the BPBB
Revelation 22 in the BPH
Revelation 22 in the BSB
Revelation 22 in the CCB
Revelation 22 in the CUV
Revelation 22 in the CUVS
Revelation 22 in the DBT
Revelation 22 in the DGDNT
Revelation 22 in the DHNT
Revelation 22 in the DNT
Revelation 22 in the ELBE
Revelation 22 in the EMTV
Revelation 22 in the ESV
Revelation 22 in the FBV
Revelation 22 in the FEB
Revelation 22 in the GGMNT
Revelation 22 in the GNT
Revelation 22 in the HARY
Revelation 22 in the HNT
Revelation 22 in the IRVA
Revelation 22 in the IRVB
Revelation 22 in the IRVG
Revelation 22 in the IRVH
Revelation 22 in the IRVK
Revelation 22 in the IRVM
Revelation 22 in the IRVM2
Revelation 22 in the IRVO
Revelation 22 in the IRVP
Revelation 22 in the IRVT
Revelation 22 in the IRVT2
Revelation 22 in the IRVU
Revelation 22 in the ISVN
Revelation 22 in the JSNT
Revelation 22 in the KAPI
Revelation 22 in the KBT1ETNIK
Revelation 22 in the KBV
Revelation 22 in the KJV
Revelation 22 in the KNFD
Revelation 22 in the LBA
Revelation 22 in the LBLA
Revelation 22 in the LNT
Revelation 22 in the LSV
Revelation 22 in the MAAL
Revelation 22 in the MBV
Revelation 22 in the MBV2
Revelation 22 in the MHNT
Revelation 22 in the MKNFD
Revelation 22 in the MNG
Revelation 22 in the MNT
Revelation 22 in the MNT2
Revelation 22 in the MRS1T
Revelation 22 in the NAA
Revelation 22 in the NASB
Revelation 22 in the NBLA
Revelation 22 in the NBS
Revelation 22 in the NBVTP
Revelation 22 in the NET2
Revelation 22 in the NIV11
Revelation 22 in the NNT
Revelation 22 in the NNT2
Revelation 22 in the NNT3
Revelation 22 in the PDDPT
Revelation 22 in the PFNT
Revelation 22 in the RMNT
Revelation 22 in the SBIAS
Revelation 22 in the SBIBS
Revelation 22 in the SBIBS2
Revelation 22 in the SBICS
Revelation 22 in the SBIDS
Revelation 22 in the SBIGS
Revelation 22 in the SBIHS
Revelation 22 in the SBIIS
Revelation 22 in the SBIIS2
Revelation 22 in the SBIIS3
Revelation 22 in the SBIKS
Revelation 22 in the SBIKS2
Revelation 22 in the SBIMS
Revelation 22 in the SBIOS
Revelation 22 in the SBIPS
Revelation 22 in the SBISS
Revelation 22 in the SBITS
Revelation 22 in the SBITS2
Revelation 22 in the SBITS3
Revelation 22 in the SBITS4
Revelation 22 in the SBIUS
Revelation 22 in the SBIVS
Revelation 22 in the SBT
Revelation 22 in the SBT1E
Revelation 22 in the SCHL
Revelation 22 in the SNT
Revelation 22 in the SUSU
Revelation 22 in the SUSU2
Revelation 22 in the SYNO
Revelation 22 in the TBIAOTANT
Revelation 22 in the TBT1E
Revelation 22 in the TBT1E2
Revelation 22 in the TFTIP
Revelation 22 in the TFTU
Revelation 22 in the TGNTATF3T
Revelation 22 in the THAI
Revelation 22 in the TNFD
Revelation 22 in the TNT
Revelation 22 in the TNTIK
Revelation 22 in the TNTIL
Revelation 22 in the TNTIN
Revelation 22 in the TNTIP
Revelation 22 in the TNTIZ
Revelation 22 in the TOMA
Revelation 22 in the TTENT
Revelation 22 in the UBG
Revelation 22 in the UGV
Revelation 22 in the UGV2
Revelation 22 in the UGV3
Revelation 22 in the VBL
Revelation 22 in the VDCC
Revelation 22 in the YALU
Revelation 22 in the YAPE
Revelation 22 in the YBVTP
Revelation 22 in the ZBP