Revelation 5 (BOYCB)
1 Mo sì rí i ni ọwọ́ ọ̀tún ẹni tí ó jókòó lórí ìtẹ́ náà, ìwé kan ti a kọ nínú àti lẹ́yìn, ti a sì fi èdìdì méje dí. 2 Mó sì rí angẹli alágbára kan, ó ń fi ohùn rara kéde pé, “Ta ni ó yẹ láti ṣí ìwé náà, àti láti tu èdìdì rẹ̀?” 3 Kò sì ṣí ẹni kan ní ọ̀run, tàbí lórí ilẹ̀ ayé, tàbí nísàlẹ̀ ilẹ̀, tí ó le ṣí ìwé náà, tàbí ti o lè wo inú rẹ̀. 4 Èmi sì sọkún gidigidi, nítorí tí a kò ri ẹnìkan tí o yẹ láti sí i àti láti ka ìwé náà, tàbí láti wo inú rẹ̀. 5 Ọ̀kan nínú àwọn àgbà náà sì wí fún mi pé, “Má ṣe sọkún: kíyèsi i, kìnnìún ẹ̀yà Juda, Gbòǹgbò Dafidi, tí borí láti ṣí ìwé náà, àti láti tú èdìdì rẹ̀ méjèèje.” 6 Mo sì rí Ọ̀dọ́-Àgùntàn ni àárín ìtẹ́ náà, àti àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin náà, àti ni àárín àwọn àgbà náà, Ọ̀dọ́-àgùntàn kan dúró bí èyí tí a ti pa, ó ní ìwo méje àti ojú méje, tí o jẹ́ Ẹ̀mí méje tí Ọlọ́run, tí a rán jáde lọ sì orí ilẹ̀ ayé gbogbo. 7 Ó sì wá, o sì gbà á ìwé náà ni ọwọ́ ọ̀tún ẹni tí ó jókòó lórí ìtẹ́ náà. 8 Nígbà tí ó sì gba ìwé náà, àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin náà, àti àwọn àgbà mẹ́rìnlélógún náà wólẹ̀ níwájú Ọ̀dọ́-àgùntàn náà, olúkúlùkù wọn mú ohun èlò orin olókùn kan lọ́wọ́, àti ago wúrà tí ó kún fún tùràrí tí i ṣe àdúrà àwọn ènìyàn mímọ́. 9 Wọn sì ń kọ orin tuntun kan, wí pé:“Ìwọ ní o yẹ láti gba ìwé náà,àti láti ṣí èdìdì rẹ̀:nítorí tí a tí pa ọ,ìwọ sì tí fi ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ ṣe ìràpadà ènìyàn sí Ọlọ́run láti inú ẹ̀yà gbogbo,àti èdè gbogbo, àti inú ènìyàn gbogbo, àti orílẹ̀-èdè gbogbo wá. 10 Ìwọ sì tí ṣe wọ́n ni ọba àti àlùfáà sì Ọlọ́run wá:wọ́n sì ń jẹ ọba lórí ilẹ̀ ayé.” 11 Èmi sì wò, mo sì gbọ́ ohùn àwọn angẹli púpọ̀ yí ìtẹ́ náà ká, àti yí àwọn ẹ̀dá alààyè náà àti àwọn àgbà náà ká. Iye wọn sì jẹ́ ẹgbàárùn-ún ọ̀nà ẹgbàárùn-ún àti ẹgbẹẹgbẹ̀rún ọ̀nà ẹgbẹẹgbẹ̀rún. 12 Wọn ń wí lóhùn rara pé:“Yíyẹ ni Ọ̀dọ́-àgùntàn náà tí a tí pa,láti gba agbára,àti ọ̀rọ̀ àti ọgbọ́n, àti ipá, àti ọlá,àti ògo, àti ìbùkún.” 13 Gbogbo ẹ̀dá tí o sì ń bẹ ni ọ̀run, àti lórí ilẹ̀ ayé, àti nísàlẹ̀ ilẹ̀ àti irú àwọn tí ń bẹ nínú Òkun, àti gbogbo àwọn tí ń bẹ nínú wọn, ni mo gbọ́ tí ń wí pé,“Kí a fi ìbùkún àti ọlá, àti ògo, àti agbára,fún Ẹni tí ó jókòó lórí ìtẹ́ àti fún Ọ̀dọ́-àgùntànnáà láé àti láéláé.” 14 Àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin náà wí pé, “Àmín!” Àwọn àgbà mẹ́rìnlélógún náà wólẹ̀, wọn sì foríbalẹ̀ fún ẹni tí ń bẹ láààyè láé àti láéláé.
In Other Versions
Revelation 5 in the ANGEFD
Revelation 5 in the ANTPNG2D
Revelation 5 in the AS21
Revelation 5 in the BAGH
Revelation 5 in the BBPNG
Revelation 5 in the BBT1E
Revelation 5 in the BDS
Revelation 5 in the BEV
Revelation 5 in the BHAD
Revelation 5 in the BIB
Revelation 5 in the BLPT
Revelation 5 in the BNT
Revelation 5 in the BNTABOOT
Revelation 5 in the BNTLV
Revelation 5 in the BOATCB
Revelation 5 in the BOATCB2
Revelation 5 in the BOBCV
Revelation 5 in the BOCNT
Revelation 5 in the BOECS
Revelation 5 in the BOGWICC
Revelation 5 in the BOHCB
Revelation 5 in the BOHCV
Revelation 5 in the BOHLNT
Revelation 5 in the BOHNTLTAL
Revelation 5 in the BOICB
Revelation 5 in the BOILNTAP
Revelation 5 in the BOITCV
Revelation 5 in the BOKCV
Revelation 5 in the BOKCV2
Revelation 5 in the BOKHWOG
Revelation 5 in the BOKSSV
Revelation 5 in the BOLCB
Revelation 5 in the BOLCB2
Revelation 5 in the BOMCV
Revelation 5 in the BONAV
Revelation 5 in the BONCB
Revelation 5 in the BONLT
Revelation 5 in the BONUT2
Revelation 5 in the BOPLNT
Revelation 5 in the BOSCB
Revelation 5 in the BOSNC
Revelation 5 in the BOTLNT
Revelation 5 in the BOVCB
Revelation 5 in the BPBB
Revelation 5 in the BPH
Revelation 5 in the BSB
Revelation 5 in the CCB
Revelation 5 in the CUV
Revelation 5 in the CUVS
Revelation 5 in the DBT
Revelation 5 in the DGDNT
Revelation 5 in the DHNT
Revelation 5 in the DNT
Revelation 5 in the ELBE
Revelation 5 in the EMTV
Revelation 5 in the ESV
Revelation 5 in the FBV
Revelation 5 in the FEB
Revelation 5 in the GGMNT
Revelation 5 in the GNT
Revelation 5 in the HARY
Revelation 5 in the HNT
Revelation 5 in the IRVA
Revelation 5 in the IRVB
Revelation 5 in the IRVG
Revelation 5 in the IRVH
Revelation 5 in the IRVK
Revelation 5 in the IRVM
Revelation 5 in the IRVM2
Revelation 5 in the IRVO
Revelation 5 in the IRVP
Revelation 5 in the IRVT
Revelation 5 in the IRVT2
Revelation 5 in the IRVU
Revelation 5 in the ISVN
Revelation 5 in the JSNT
Revelation 5 in the KAPI
Revelation 5 in the KBT1ETNIK
Revelation 5 in the KBV
Revelation 5 in the KJV
Revelation 5 in the KNFD
Revelation 5 in the LBA
Revelation 5 in the LBLA
Revelation 5 in the LNT
Revelation 5 in the LSV
Revelation 5 in the MAAL
Revelation 5 in the MBV
Revelation 5 in the MBV2
Revelation 5 in the MHNT
Revelation 5 in the MKNFD
Revelation 5 in the MNG
Revelation 5 in the MNT
Revelation 5 in the MNT2
Revelation 5 in the MRS1T
Revelation 5 in the NAA
Revelation 5 in the NASB
Revelation 5 in the NBLA
Revelation 5 in the NBS
Revelation 5 in the NBVTP
Revelation 5 in the NET2
Revelation 5 in the NIV11
Revelation 5 in the NNT
Revelation 5 in the NNT2
Revelation 5 in the NNT3
Revelation 5 in the PDDPT
Revelation 5 in the PFNT
Revelation 5 in the RMNT
Revelation 5 in the SBIAS
Revelation 5 in the SBIBS
Revelation 5 in the SBIBS2
Revelation 5 in the SBICS
Revelation 5 in the SBIDS
Revelation 5 in the SBIGS
Revelation 5 in the SBIHS
Revelation 5 in the SBIIS
Revelation 5 in the SBIIS2
Revelation 5 in the SBIIS3
Revelation 5 in the SBIKS
Revelation 5 in the SBIKS2
Revelation 5 in the SBIMS
Revelation 5 in the SBIOS
Revelation 5 in the SBIPS
Revelation 5 in the SBISS
Revelation 5 in the SBITS
Revelation 5 in the SBITS2
Revelation 5 in the SBITS3
Revelation 5 in the SBITS4
Revelation 5 in the SBIUS
Revelation 5 in the SBIVS
Revelation 5 in the SBT
Revelation 5 in the SBT1E
Revelation 5 in the SCHL
Revelation 5 in the SNT
Revelation 5 in the SUSU
Revelation 5 in the SUSU2
Revelation 5 in the SYNO
Revelation 5 in the TBIAOTANT
Revelation 5 in the TBT1E
Revelation 5 in the TBT1E2
Revelation 5 in the TFTIP
Revelation 5 in the TFTU
Revelation 5 in the TGNTATF3T
Revelation 5 in the THAI
Revelation 5 in the TNFD
Revelation 5 in the TNT
Revelation 5 in the TNTIK
Revelation 5 in the TNTIL
Revelation 5 in the TNTIN
Revelation 5 in the TNTIP
Revelation 5 in the TNTIZ
Revelation 5 in the TOMA
Revelation 5 in the TTENT
Revelation 5 in the UBG
Revelation 5 in the UGV
Revelation 5 in the UGV2
Revelation 5 in the UGV3
Revelation 5 in the VBL
Revelation 5 in the VDCC
Revelation 5 in the YALU
Revelation 5 in the YAPE
Revelation 5 in the YBVTP
Revelation 5 in the ZBP