Revelation 8 (BOYCB)

1 Nígbà tí ó sì ṣí èdìdì keje, ìdákẹ́rọ́rọ́ sì wà ní ọ̀run níwọ̀n ààbọ̀ wákàtí kan. 2 Mo sì rí àwọn angẹli méje tí wọn dúró níwájú Ọlọ́run; a sì fi ìpè méje fún wọn. 3 Angẹli mìíràn sì wá, ó sì dúró ti pẹpẹ, ó ní àwo tùràrí wúrà kan a sì fi tùràrí púpọ̀ fún un, láti máa fi kún àdúrà gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́ lórí pẹpẹ, pẹpẹ wúrà tí ń bẹ níwájú ìtẹ́. 4 Àti èéfín tùràrí náà pẹ̀lú àdúrà àwọn ènìyàn mímọ́ sì gòkè lọ síwájú Ọlọ́run láti ọwọ́ angẹli náà wá. 5 Angẹli náà sì mú àwo tùràrí náà, ó sì fi iná orí pẹpẹ kùn ún, ó sì dà á sórí ilẹ̀ ayé, a sì gbọ́ ohùn, àrá sì sán, mọ̀nàmọ́ná sì kọ, àti ilẹ̀-rírì. 6 Àwọn angẹli méje náà tí wọn ni ìpè méje sì múra láti fún wọn. 7 Èkínní sì fọn ìpè tirẹ̀, Yìnyín àti iná, tí o dàpọ̀ pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀, sì jáde, a sì dà wọ́n sórí ilẹ̀ ayé: ìdámẹ́ta ilẹ̀ ayé si jóná, ìdámẹ́ta àwọn igi sì jóná, àti gbogbo koríko tútù sì jóná. 8 Angẹli kejì si fún ìpè tirẹ̀, a sì sọ ohun kan, bí òkè ńlá tí ń jóná, sínú Òkun: ìdámẹ́ta Òkun si di ẹ̀jẹ̀; 9 àti ìdámẹ́ta àwọn ẹ̀dá tí ń bẹ nínú Òkun tí ó ni ẹ̀mí sì kú; àti ìdámẹ́ta àwọn ọkọ̀ si bàjẹ́. 10 Angẹli kẹta sì fún ìpè tirẹ̀, ìràwọ̀ ńlá kan tí ń jó bí fìtílà sì bọ́ láti ọ̀run wá, ó sì bọ́ sórí ìdámẹ́ta àwọn odò ṣíṣàn, àti sórí àwọn orísun omi. 11 A sì ń pe orúkọ ìràwọ̀ náà ní Iwọ, ìdámẹ́ta àwọn omi sì di iwọ, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn sì tí ipa àwọn omi náà kú, nítorí tí a sọ wọn di kíkorò. 12 Angẹli kẹrin sì fún ìpè tirẹ̀, a sì kọlu ìdámẹ́ta oòrùn, àti ìdámẹ́ta òṣùpá, àti ìdámẹ́ta àwọn ìràwọ̀, ki ìdámẹ́ta wọn lè ṣókùnkùn, kí ọjọ́ má ṣe mọ́lẹ̀ fún ìdámẹ́ta rẹ̀, àti òru bákan náà. 13 Mo sì wò, mo sì gbọ́ idì kan tí ń fò ni àárín ọ̀run, ó ń wí lóhùn rara pé, “Ègbé, ègbé, fún àwọn tí ń gbé orí ilẹ̀ ayé nítorí ohun ìpè ìyókù tí àwọn angẹli mẹ́ta tí ń bọ̀ wá yóò fún!”

In Other Versions

Revelation 8 in the ANGEFD

Revelation 8 in the ANTPNG2D

Revelation 8 in the AS21

Revelation 8 in the BAGH

Revelation 8 in the BBPNG

Revelation 8 in the BBT1E

Revelation 8 in the BDS

Revelation 8 in the BEV

Revelation 8 in the BHAD

Revelation 8 in the BIB

Revelation 8 in the BLPT

Revelation 8 in the BNT

Revelation 8 in the BNTABOOT

Revelation 8 in the BNTLV

Revelation 8 in the BOATCB

Revelation 8 in the BOATCB2

Revelation 8 in the BOBCV

Revelation 8 in the BOCNT

Revelation 8 in the BOECS

Revelation 8 in the BOGWICC

Revelation 8 in the BOHCB

Revelation 8 in the BOHCV

Revelation 8 in the BOHLNT

Revelation 8 in the BOHNTLTAL

Revelation 8 in the BOICB

Revelation 8 in the BOILNTAP

Revelation 8 in the BOITCV

Revelation 8 in the BOKCV

Revelation 8 in the BOKCV2

Revelation 8 in the BOKHWOG

Revelation 8 in the BOKSSV

Revelation 8 in the BOLCB

Revelation 8 in the BOLCB2

Revelation 8 in the BOMCV

Revelation 8 in the BONAV

Revelation 8 in the BONCB

Revelation 8 in the BONLT

Revelation 8 in the BONUT2

Revelation 8 in the BOPLNT

Revelation 8 in the BOSCB

Revelation 8 in the BOSNC

Revelation 8 in the BOTLNT

Revelation 8 in the BOVCB

Revelation 8 in the BPBB

Revelation 8 in the BPH

Revelation 8 in the BSB

Revelation 8 in the CCB

Revelation 8 in the CUV

Revelation 8 in the CUVS

Revelation 8 in the DBT

Revelation 8 in the DGDNT

Revelation 8 in the DHNT

Revelation 8 in the DNT

Revelation 8 in the ELBE

Revelation 8 in the EMTV

Revelation 8 in the ESV

Revelation 8 in the FBV

Revelation 8 in the FEB

Revelation 8 in the GGMNT

Revelation 8 in the GNT

Revelation 8 in the HARY

Revelation 8 in the HNT

Revelation 8 in the IRVA

Revelation 8 in the IRVB

Revelation 8 in the IRVG

Revelation 8 in the IRVH

Revelation 8 in the IRVK

Revelation 8 in the IRVM

Revelation 8 in the IRVM2

Revelation 8 in the IRVO

Revelation 8 in the IRVP

Revelation 8 in the IRVT

Revelation 8 in the IRVT2

Revelation 8 in the IRVU

Revelation 8 in the ISVN

Revelation 8 in the JSNT

Revelation 8 in the KAPI

Revelation 8 in the KBT1ETNIK

Revelation 8 in the KBV

Revelation 8 in the KJV

Revelation 8 in the KNFD

Revelation 8 in the LBA

Revelation 8 in the LBLA

Revelation 8 in the LNT

Revelation 8 in the LSV

Revelation 8 in the MAAL

Revelation 8 in the MBV

Revelation 8 in the MBV2

Revelation 8 in the MHNT

Revelation 8 in the MKNFD

Revelation 8 in the MNG

Revelation 8 in the MNT

Revelation 8 in the MNT2

Revelation 8 in the MRS1T

Revelation 8 in the NAA

Revelation 8 in the NASB

Revelation 8 in the NBLA

Revelation 8 in the NBS

Revelation 8 in the NBVTP

Revelation 8 in the NET2

Revelation 8 in the NIV11

Revelation 8 in the NNT

Revelation 8 in the NNT2

Revelation 8 in the NNT3

Revelation 8 in the PDDPT

Revelation 8 in the PFNT

Revelation 8 in the RMNT

Revelation 8 in the SBIAS

Revelation 8 in the SBIBS

Revelation 8 in the SBIBS2

Revelation 8 in the SBICS

Revelation 8 in the SBIDS

Revelation 8 in the SBIGS

Revelation 8 in the SBIHS

Revelation 8 in the SBIIS

Revelation 8 in the SBIIS2

Revelation 8 in the SBIIS3

Revelation 8 in the SBIKS

Revelation 8 in the SBIKS2

Revelation 8 in the SBIMS

Revelation 8 in the SBIOS

Revelation 8 in the SBIPS

Revelation 8 in the SBISS

Revelation 8 in the SBITS

Revelation 8 in the SBITS2

Revelation 8 in the SBITS3

Revelation 8 in the SBITS4

Revelation 8 in the SBIUS

Revelation 8 in the SBIVS

Revelation 8 in the SBT

Revelation 8 in the SBT1E

Revelation 8 in the SCHL

Revelation 8 in the SNT

Revelation 8 in the SUSU

Revelation 8 in the SUSU2

Revelation 8 in the SYNO

Revelation 8 in the TBIAOTANT

Revelation 8 in the TBT1E

Revelation 8 in the TBT1E2

Revelation 8 in the TFTIP

Revelation 8 in the TFTU

Revelation 8 in the TGNTATF3T

Revelation 8 in the THAI

Revelation 8 in the TNFD

Revelation 8 in the TNT

Revelation 8 in the TNTIK

Revelation 8 in the TNTIL

Revelation 8 in the TNTIN

Revelation 8 in the TNTIP

Revelation 8 in the TNTIZ

Revelation 8 in the TOMA

Revelation 8 in the TTENT

Revelation 8 in the UBG

Revelation 8 in the UGV

Revelation 8 in the UGV2

Revelation 8 in the UGV3

Revelation 8 in the VBL

Revelation 8 in the VDCC

Revelation 8 in the YALU

Revelation 8 in the YAPE

Revelation 8 in the YBVTP

Revelation 8 in the ZBP