Titus 1 (BOYCB)

1 Paulu, ìránṣẹ́ Ọlọ́run àti aposteli Jesu Kristi, gẹ́gẹ́ bí ìgbàgbọ́ àwọn àyànfẹ́ Ọlọ́run àti ìmọ̀ òtítọ́ irú èyí tí í máa darí ènìyàn sí ìgbé ayé ìwà-bí-Ọlọ́run— 2 ìgbàgbọ́ àti ìmọ̀ tí ó dúró lórí ìrètí iyè àìnípẹ̀kun, èyí tí Ọlọ́run tí kì í purọ́ ti ṣe ìlérí rẹ̀ ṣáájú kí ayé tó bẹ̀rẹ̀, 3 àti pé ní àkókò tirẹ̀, òun ti fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ hàn nínú ìwàásù tí a fi lé mi lọ́wọ́ nípa àṣẹ Ọlọ́run Olùgbàlà wa, 4 Sí Titu, ọmọ mi tòótọ́ nínú ìgbàgbọ́ wa kan náà: Oore-ọ̀fẹ́ àti àlàáfíà láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba àti Kristi Jesu Olùgbàlà wa. 5 Ìdí tí mo fi fi ọ́ sílẹ̀ ní Krete ni pé kí o lè ṣe àṣepé àwọn iṣẹ́ tó ṣẹ́kù. Mo sì ń rọ̀ ọ́ kí o yan àwọn alàgbà ní ìlú kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí mo ṣe darí rẹ̀. 6 Ẹni tí yóò jẹ́ alàgbà gbọdọ̀ jẹ́ aláìlábùkù, wọ́n gbọdọ̀ jẹ́ onìyàwó kan, ọmọ wọn náà gbọdọ̀ jẹ́ onígbàgbọ́ tí kò ní ẹ̀sùn ìwà ipá tàbí ẹ̀sùn àìgbọ́ràn kankan. 7 Alábojútó jẹ́ ẹni tí a gbé iṣẹ́ Ọlọ́run lé lọ́wọ́, nítorí náà, kò gbọdọ̀ ní àbùkù kankan tàbí agbéraga, oníjà, kò gbọdọ̀ jẹ́ ọ̀mùtí tàbí alágídí tàbí olójúkòkòrò. 8 Wọ́n ní láti jẹ́ olùfẹ́ àlejò ṣíṣe, olùfẹ́ ohun tí ó dára. Wọ́n ní láti jẹ́ ẹni tí ó kò ara rẹ̀ ní ìjánu, ẹni dúró ṣinṣin, ọlọ́kàn mímọ́, àti ẹni oníwàtítọ́. 9 Ó gbọdọ̀ di ẹ̀kọ́ nípa ìdúró ṣinṣin mú dáradára gẹ́gẹ́ bí ó ti kọ́ ọ, kí ó lè fi ẹ̀kọ́ tí ó yè kooro kọ́ àwọn ẹlòmíràn. Nípa èyí, yóò lè fi ìdí òtítọ́ múlẹ̀ fún àwọn alátakò. 10 Nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni ọlọ̀tẹ̀, asọ̀rọ̀ asán àti ẹlẹ́tàn pàápàá jùlọ láàrín àwọn onílà. 11 Ó gbọdọ̀ pa wọ́n lẹ́nu mọ́, nítorí wí pé wọ́n ń pa agbo Ọlọ́run run, nípasẹ̀ àwọn ẹ̀kọ́ tí kò jẹ́ èyí tí wọ́n ń kọ́ni. Èyí ni wọ́n ń ṣe fún ère àìṣòdodo. 12 Ọ̀kan nínú àwọn wòlíì wọn pàápàá sọ wí pé. “Òpùrọ́ ní àwọn ará Krete, wọ́n jẹ́ ẹranko búburú tí kò sé tù lójú, ọ̀lẹ, àti oníwọra”. 13 Òtítọ́ ni ẹ̀rí yìí. Nítorí náà, bá wọn wí gidigidi, kí wọn ba à lè yè koro nínú ìgbàgbọ́ 14 kí àwọn má ṣe fiyèsí ìtàn lásán ti àwọn Júù, àti òfin àwọn ènìyàn tí wọ́n yípadà kúrò nínú òtítọ́. 15 Sí ọlọ́kàn mímọ́, ohun gbogbo ló jẹ́ mímọ́, ṣùgbọ́n àwọn tó ti díbàjẹ́ tí wọ́n kò sí ka ohunkóhun sí mímọ́. Nítòótọ́, àti ọkàn àti ẹ̀rí ọkàn wọn ló ti díbàjẹ́. 16 Wọ́n ń fẹnu sọ wí pé àwọn mọ Ọlọ́run, ṣùgbọ́n wọ́n sẹ́ ẹ nípa ìṣe wọn. Wọ́n díbàjẹ́, wọn si jẹ aláìgbọ́ràn, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n kò wúlò lọ́nàkọnà ní ti iṣẹ́ rere gbogbo.

In Other Versions

Titus 1 in the ANGEFD

Titus 1 in the ANTPNG2D

Titus 1 in the AS21

Titus 1 in the BAGH

Titus 1 in the BBPNG

Titus 1 in the BBT1E

Titus 1 in the BDS

Titus 1 in the BEV

Titus 1 in the BHAD

Titus 1 in the BIB

Titus 1 in the BLPT

Titus 1 in the BNT

Titus 1 in the BNTABOOT

Titus 1 in the BNTLV

Titus 1 in the BOATCB

Titus 1 in the BOATCB2

Titus 1 in the BOBCV

Titus 1 in the BOCNT

Titus 1 in the BOECS

Titus 1 in the BOGWICC

Titus 1 in the BOHCB

Titus 1 in the BOHCV

Titus 1 in the BOHLNT

Titus 1 in the BOHNTLTAL

Titus 1 in the BOICB

Titus 1 in the BOILNTAP

Titus 1 in the BOITCV

Titus 1 in the BOKCV

Titus 1 in the BOKCV2

Titus 1 in the BOKHWOG

Titus 1 in the BOKSSV

Titus 1 in the BOLCB

Titus 1 in the BOLCB2

Titus 1 in the BOMCV

Titus 1 in the BONAV

Titus 1 in the BONCB

Titus 1 in the BONLT

Titus 1 in the BONUT2

Titus 1 in the BOPLNT

Titus 1 in the BOSCB

Titus 1 in the BOSNC

Titus 1 in the BOTLNT

Titus 1 in the BOVCB

Titus 1 in the BPBB

Titus 1 in the BPH

Titus 1 in the BSB

Titus 1 in the CCB

Titus 1 in the CUV

Titus 1 in the CUVS

Titus 1 in the DBT

Titus 1 in the DGDNT

Titus 1 in the DHNT

Titus 1 in the DNT

Titus 1 in the ELBE

Titus 1 in the EMTV

Titus 1 in the ESV

Titus 1 in the FBV

Titus 1 in the FEB

Titus 1 in the GGMNT

Titus 1 in the GNT

Titus 1 in the HARY

Titus 1 in the HNT

Titus 1 in the IRVA

Titus 1 in the IRVB

Titus 1 in the IRVG

Titus 1 in the IRVH

Titus 1 in the IRVK

Titus 1 in the IRVM

Titus 1 in the IRVM2

Titus 1 in the IRVO

Titus 1 in the IRVP

Titus 1 in the IRVT

Titus 1 in the IRVT2

Titus 1 in the IRVU

Titus 1 in the ISVN

Titus 1 in the JSNT

Titus 1 in the KAPI

Titus 1 in the KBT1ETNIK

Titus 1 in the KBV

Titus 1 in the KJV

Titus 1 in the KNFD

Titus 1 in the LBA

Titus 1 in the LBLA

Titus 1 in the LNT

Titus 1 in the LSV

Titus 1 in the MAAL

Titus 1 in the MBV

Titus 1 in the MBV2

Titus 1 in the MHNT

Titus 1 in the MKNFD

Titus 1 in the MNG

Titus 1 in the MNT

Titus 1 in the MNT2

Titus 1 in the MRS1T

Titus 1 in the NAA

Titus 1 in the NASB

Titus 1 in the NBLA

Titus 1 in the NBS

Titus 1 in the NBVTP

Titus 1 in the NET2

Titus 1 in the NIV11

Titus 1 in the NNT

Titus 1 in the NNT2

Titus 1 in the NNT3

Titus 1 in the PDDPT

Titus 1 in the PFNT

Titus 1 in the RMNT

Titus 1 in the SBIAS

Titus 1 in the SBIBS

Titus 1 in the SBIBS2

Titus 1 in the SBICS

Titus 1 in the SBIDS

Titus 1 in the SBIGS

Titus 1 in the SBIHS

Titus 1 in the SBIIS

Titus 1 in the SBIIS2

Titus 1 in the SBIIS3

Titus 1 in the SBIKS

Titus 1 in the SBIKS2

Titus 1 in the SBIMS

Titus 1 in the SBIOS

Titus 1 in the SBIPS

Titus 1 in the SBISS

Titus 1 in the SBITS

Titus 1 in the SBITS2

Titus 1 in the SBITS3

Titus 1 in the SBITS4

Titus 1 in the SBIUS

Titus 1 in the SBIVS

Titus 1 in the SBT

Titus 1 in the SBT1E

Titus 1 in the SCHL

Titus 1 in the SNT

Titus 1 in the SUSU

Titus 1 in the SUSU2

Titus 1 in the SYNO

Titus 1 in the TBIAOTANT

Titus 1 in the TBT1E

Titus 1 in the TBT1E2

Titus 1 in the TFTIP

Titus 1 in the TFTU

Titus 1 in the TGNTATF3T

Titus 1 in the THAI

Titus 1 in the TNFD

Titus 1 in the TNT

Titus 1 in the TNTIK

Titus 1 in the TNTIL

Titus 1 in the TNTIN

Titus 1 in the TNTIP

Titus 1 in the TNTIZ

Titus 1 in the TOMA

Titus 1 in the TTENT

Titus 1 in the UBG

Titus 1 in the UGV

Titus 1 in the UGV2

Titus 1 in the UGV3

Titus 1 in the VBL

Titus 1 in the VDCC

Titus 1 in the YALU

Titus 1 in the YAPE

Titus 1 in the YBVTP

Titus 1 in the ZBP