Acts 6 (BOYCB)
1 Ǹjẹ́ ní ọjọ́ wọ̀nyí, nígbà tí iye àwọn ọmọ-ẹ̀yìn ń pọ̀ sí i, ìkùnsínú wà ní àárín àwọn Helleni tí ṣe Júù àti àwọn Heberu tí ṣe Júù, nítorí tí a gbàgbé nípa ti àwọn opó wọn nínú ìpín fún ni ojoojúmọ́. 2 Àwọn méjìlá sì pe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn jọ sọ́dọ̀, wọn wí pé, “Kò yẹ kí àwa ó fi ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sílẹ̀, kí a sì máa ṣe ìránṣẹ́ tábìlì. 3 Nítorí náà, ará, ẹ wo ọkùnrin méje nínú yín, olórúkọ rere, tí ó kún fún Ẹ̀mí Mímọ́ àti fún ọgbọ́n, tí àwa lè yàn sí iṣẹ́ yìí. 4 Ṣùgbọ́n àwa yóò dúró ṣinṣin nínú àdúrà gbígbà, àti nínú iṣẹ́ ìránṣẹ́ ọ̀rọ̀ náà.” 5 Ọ̀rọ̀ náà sì tọ́ lójú gbogbo ìjọ; wọ́n sì yan Stefanu, ọkùnrin tí ó kún fún ìgbàgbọ́ àti fún Ẹ̀mí Mímọ́ àti Filipi, àti Prokoru, àti Nikanoru, àti Timoni, àti Parimena, àti Nikolasi aláwọ̀ṣe Júù ará Antioku. 6 Ẹni tí wọ́n mú dúró níwájú àwọn Aposteli; nígbà tí wọ́n sì gbàdúrà, wọ́n gbé ọwọ́ lé wọn. 7 Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sì gbilẹ̀, iye àwọn ọmọ-ẹ̀yìn sì pọ̀ sí i gidigidi ni Jerusalẹmu, ọ̀pọ̀ nínú ẹgbẹ́ àwọn àlùfáà sí fetí sí tí ìgbàgbọ́ náà. 8 Stefanu tí ó kún fún oore-ọ̀fẹ́ àti agbára, ó ṣe iṣẹ́ ìyanu, àti iṣẹ́ àmì ńlá láàrín àwọn ènìyàn. 9 Ṣùgbọ́n àwọn kan dìde nínú àwọn ti ń ṣe ara Sinagọgu, tí a ń pè ní Libataini. Àwọn Júù Kirene àti ti Alekisandiria àti ti Kilikia, àti ti Asia wá, wọ́n ń bá Stefanu jiyàn, 10 ṣùgbọ́n wọn kò sí lè ko ọgbọ́n àti Ẹ̀mí tí ó fi ń sọ̀rọ̀ lójú. 11 Nígbà náà ni wọ́n fún àwọn ọkùnrin kan ní àbẹ̀tẹ́lẹ̀, kí wọn ń wí pé, “Àwa gbọ́ tí Stefanu ń sọ ọ̀rọ̀-òdì sí Mose àti sí Ọlọ́run.” 12 Wọ́n sí ru àwọn ènìyàn sókè, àti àwọn alàgbà, àti àwọn olùkọ́ni ní òfin. Wọ́n dìde sí i, wọ́n gbá a mú, wọ́n sì mú un wá sí iwájú àjọ ìgbìmọ̀. 13 Wọ́n sí mú àwọn ẹlẹ́rìí èké wá, tiwọn wí pé, “Ọkùnrin yìí kò sinmi láti sọ ọ̀rọ̀-òdì sí ibi mímọ́ yìí, àti sí òfin. 14 Nítorí àwa gbọ́ o wí pé Jesu ti Nasareti yìí yóò fọ́ ibí yìí, yóò sì yí àṣà ti Mose fi fún wa padà.” 15 Gbogbo àwọn tí ó sì jókòó ni àjọ ìgbìmọ̀ tẹjúmọ́ Stefanu, wọ́n sì rí ojú rẹ̀ dàbí ojú angẹli.
In Other Versions
Acts 6 in the ANGEFD
Acts 6 in the ANTPNG2D
Acts 6 in the AS21
Acts 6 in the BAGH
Acts 6 in the BBPNG
Acts 6 in the BBT1E
Acts 6 in the BDS
Acts 6 in the BEV
Acts 6 in the BHAD
Acts 6 in the BIB
Acts 6 in the BLPT
Acts 6 in the BNT
Acts 6 in the BNTABOOT
Acts 6 in the BNTLV
Acts 6 in the BOATCB
Acts 6 in the BOATCB2
Acts 6 in the BOBCV
Acts 6 in the BOCNT
Acts 6 in the BOECS
Acts 6 in the BOGWICC
Acts 6 in the BOHCB
Acts 6 in the BOHCV
Acts 6 in the BOHLNT
Acts 6 in the BOHNTLTAL
Acts 6 in the BOICB
Acts 6 in the BOILNTAP
Acts 6 in the BOITCV
Acts 6 in the BOKCV
Acts 6 in the BOKCV2
Acts 6 in the BOKHWOG
Acts 6 in the BOKSSV
Acts 6 in the BOLCB
Acts 6 in the BOLCB2
Acts 6 in the BOMCV
Acts 6 in the BONAV
Acts 6 in the BONCB
Acts 6 in the BONLT
Acts 6 in the BONUT2
Acts 6 in the BOPLNT
Acts 6 in the BOSCB
Acts 6 in the BOSNC
Acts 6 in the BOTLNT
Acts 6 in the BOVCB
Acts 6 in the BPBB
Acts 6 in the BPH
Acts 6 in the BSB
Acts 6 in the CCB
Acts 6 in the CUV
Acts 6 in the CUVS
Acts 6 in the DBT
Acts 6 in the DGDNT
Acts 6 in the DHNT
Acts 6 in the DNT
Acts 6 in the ELBE
Acts 6 in the EMTV
Acts 6 in the ESV
Acts 6 in the FBV
Acts 6 in the FEB
Acts 6 in the GGMNT
Acts 6 in the GNT
Acts 6 in the HARY
Acts 6 in the HNT
Acts 6 in the IRVA
Acts 6 in the IRVB
Acts 6 in the IRVG
Acts 6 in the IRVH
Acts 6 in the IRVK
Acts 6 in the IRVM
Acts 6 in the IRVM2
Acts 6 in the IRVO
Acts 6 in the IRVP
Acts 6 in the IRVT
Acts 6 in the IRVT2
Acts 6 in the IRVU
Acts 6 in the ISVN
Acts 6 in the JSNT
Acts 6 in the KAPI
Acts 6 in the KBT1ETNIK
Acts 6 in the KBV
Acts 6 in the KJV
Acts 6 in the KNFD
Acts 6 in the LBA
Acts 6 in the LBLA
Acts 6 in the LNT
Acts 6 in the LSV
Acts 6 in the MAAL
Acts 6 in the MBV
Acts 6 in the MBV2
Acts 6 in the MHNT
Acts 6 in the MKNFD
Acts 6 in the MNG
Acts 6 in the MNT
Acts 6 in the MNT2
Acts 6 in the MRS1T
Acts 6 in the NAA
Acts 6 in the NASB
Acts 6 in the NBLA
Acts 6 in the NBS
Acts 6 in the NBVTP
Acts 6 in the NET2
Acts 6 in the NIV11
Acts 6 in the NNT
Acts 6 in the NNT2
Acts 6 in the NNT3
Acts 6 in the PDDPT
Acts 6 in the PFNT
Acts 6 in the RMNT
Acts 6 in the SBIAS
Acts 6 in the SBIBS
Acts 6 in the SBIBS2
Acts 6 in the SBICS
Acts 6 in the SBIDS
Acts 6 in the SBIGS
Acts 6 in the SBIHS
Acts 6 in the SBIIS
Acts 6 in the SBIIS2
Acts 6 in the SBIIS3
Acts 6 in the SBIKS
Acts 6 in the SBIKS2
Acts 6 in the SBIMS
Acts 6 in the SBIOS
Acts 6 in the SBIPS
Acts 6 in the SBISS
Acts 6 in the SBITS
Acts 6 in the SBITS2
Acts 6 in the SBITS3
Acts 6 in the SBITS4
Acts 6 in the SBIUS
Acts 6 in the SBIVS
Acts 6 in the SBT
Acts 6 in the SBT1E
Acts 6 in the SCHL
Acts 6 in the SNT
Acts 6 in the SUSU
Acts 6 in the SUSU2
Acts 6 in the SYNO
Acts 6 in the TBIAOTANT
Acts 6 in the TBT1E
Acts 6 in the TBT1E2
Acts 6 in the TFTIP
Acts 6 in the TFTU
Acts 6 in the TGNTATF3T
Acts 6 in the THAI
Acts 6 in the TNFD
Acts 6 in the TNT
Acts 6 in the TNTIK
Acts 6 in the TNTIL
Acts 6 in the TNTIN
Acts 6 in the TNTIP
Acts 6 in the TNTIZ
Acts 6 in the TOMA
Acts 6 in the TTENT
Acts 6 in the UBG
Acts 6 in the UGV
Acts 6 in the UGV2
Acts 6 in the UGV3
Acts 6 in the VBL
Acts 6 in the VDCC
Acts 6 in the YALU
Acts 6 in the YAPE
Acts 6 in the YBVTP
Acts 6 in the ZBP