Ecclesiastes 7 (BOYCB)
1 Orúkọ rere sàn ju ìpara olóòórùn dídùn lọ,ọjọ́ ikú sì dára ju ọjọ́ tí a bí ènìyàn lọ. 2 Ó dára láti lọ sí ilé ọ̀fọ̀ju ibi àsè,nítorí pé ikú jẹ́ àyànmọ́ gbogbo ènìyàn;kí alààyè ní èyí ní ọkàn. 3 Ìbànújẹ́ dára ju ẹ̀rín lọ,ó le è mú kí ojú rẹ̀ dàrú,ṣùgbọ́n yóò jẹ́ kí àyà rẹ le. 4 Ọkàn ọlọ́gbọ́n wà ní ilé ọ̀fọ̀,ṣùgbọ́n ọkàn òmùgọ̀ ní ilé àríyá. 5 Ó dára láti gba ìbáwí ọlọ́gbọ́n,ju fífetísílẹ̀ sí orin òmùgọ̀ lọ. 6 Gẹ́gẹ́ bí ẹ̀gún ti ń dún lábẹ́ ìkòkòni ẹ̀rín òmùgọ̀.Asán sì ni eléyìí pẹ̀lú. 7 Ìrẹ́jẹ a máa sọ ọlọ́gbọ́n di òmùgọ̀,àbẹ̀tẹ́lẹ̀ sì máa ń ba ìwà jẹ́ ni. 8 Òpin ọ̀rọ̀ dára ju ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ lọ,sùúrù sì dára ju ìgbéraga lọ. 9 Má ṣe yára bínú ní ọkàn rẹnítorí pé orí ẹsẹ̀ òmùgọ̀ ni ìbínú ń gbé. 10 Má ṣe sọ wí pé, “Kí ni ìdí tí àtijọ́ fi dára ju èyí?”Nítorí pé, kò mú ọgbọ́n wá láti béèrè irú ìbéèrè bẹ́ẹ̀. 11 Ọgbọ́n, gẹ́gẹ́ bí ogún ìní jẹ́ ohun tí ó dáraó sì ṣe àwọn tí ó rí oòrùn láǹfààní. 12 Ọgbọ́n jẹ́ ààbògẹ́gẹ́ bí owó ti jẹ́ ààbòṣùgbọ́n àǹfààní òye ni èyípé ọgbọ́n a máa tọ́jú ẹ̀mí ẹni tí ó bá ní. 13 Wo ohun tí Ọlọ́run ti ṣe:“Ta ni ó le è toohun tí ó ti ṣe ní wíwọ́?” 14 Nígbà tí àkókò bá dára, jẹ́ kí inú rẹ dùn,ṣùgbọ́n nígbà tí àkókò kò bá dára, rò ó:Ọlọ́run tí ó dá èkínnínáà ni ó dá èkejì.Nítorí náà, ènìyàn kò le è ṣàwáríohun kankan nípa ọjọ́ iwájú rẹ̀. 15 Nínú ayé àìní ìtumọ̀ yìí ni mo ti rí gbogbo èyíènìyàn olóòtítọ́, ọkùnrin olódodo ń parun nínú òtítọ́ rẹ̀ìkà ènìyàn sì ń gbé ìgbé ayé pípẹ́ nínú ìkà rẹ̀. 16 Má ṣe jẹ́ olódodo jùlọtàbí ọlọ́gbọ́n jùlọkí ló dé tí o fi fẹ́ pa ara rẹ run? 17 Ìwọ ma ṣe búburú jùlọ kí ìwọ má sì ṣe aṣiwèrè,èéṣe tí ìwọ yóò fi kú kí ọjọ́ rẹ tó pé 18 Ó dára láti mú ọ̀kankí o má sì ṣe fi èkejì sílẹ̀.Ọkùnrin tí ó bẹ̀rù Ọlọ́run yóò bọ́ lọ́wọ́ gbogbo àrékérekè. 19 Ọgbọ́n máa ń mú kí ọlọ́gbọ́n ènìyàn ní agbáraju alákòóso mẹ́wàá lọ ní ìlú. 20 Kò sí olódodo ènìyàn kan láyétí ó ṣe ohun tí ó tọ́ tí kò dẹ́ṣẹ̀ rárá. 21 Má ṣe kíyèsi gbogbo ọ̀rọ̀ tí ènìyàn ń sọbí bẹ́ẹ̀ kọ́, o le è gbọ́ pé ìránṣẹ́ rẹ ń ṣépè fún ọ. 22 Tí o sì mọ̀ nínú ọkàn rẹpé ọ̀pọ̀ ìgbà ni ìwọ fúnra rẹ̀ ti ṣépè fún àwọn ẹlòmíràn. 23 Gbogbo èyí ni mo ti dánwò nípa ọgbọ́n, tí mo sì wí pé,“Mo pinnu láti jẹ́ ọlọ́gbọ́n”;ṣùgbọ́n eléyìí ti jù mí lọ. 24 Ohun tí ó wù kí ọgbọ́n le è jẹ́,ó ti lọ jìnnà, ó sì jinlẹ̀ta ni ó le è ṣe àwárí rẹ̀? 25 Mo wá rò ó nínú ọkàn mi láti mọ̀,láti wá àti láti ṣàwárí ọgbọ́nàti ìdí ohun gbogbo, àti láti mọ ìwà àgọ́búburú àti ti ìsínwín tàbí òmùgọ̀. 26 Mo rí ohun tí ó korò ju ikú lọobìnrin tí ó jẹ́ ẹ̀bìtì,tí ọkàn rẹ̀ jẹ́ tàkútétí ọwọ́ rẹ̀ sì jẹ́ ẹ̀wọ̀n,ọkùnrin tí ó bá tẹ́ Ọlọ́run lọ́rùn yóò le è yọ sílẹ̀ṣùgbọ́n ẹni dẹ́ṣẹ̀ kò le è bọ́ nínú tàkúté rẹ̀. 27 Oniwaasu wí pé, “Wò ó, eléyìí ni ohun tí mo ti ṣàwárí:“Mímú ohun kan pọ̀ mọ́ òmíràn láti ṣàwárí ìdí ohun gbogbo. 28 Nígbà tí mo sì ń wá a kiriṣùgbọ́n tí n kò rí imo rí ọkùnrin tí ó dúró dáradára kan láàrín ẹgbẹ̀rún (1,000),ṣùgbọ́n n kò rí obìnrin,kankan kí ó dúró láàrín gbogbo wọn. 29 Eléyìí nìkan ni mo tí ì rí:Ọlọ́run dá ìran ènìyàn dáradára,ṣùgbọ́n ènìyàn ti lọ láti ṣàwárí ohun púpọ̀.”
In Other Versions
Ecclesiastes 7 in the ANGEFD
Ecclesiastes 7 in the ANTPNG2D
Ecclesiastes 7 in the AS21
Ecclesiastes 7 in the BAGH
Ecclesiastes 7 in the BBPNG
Ecclesiastes 7 in the BBT1E
Ecclesiastes 7 in the BDS
Ecclesiastes 7 in the BEV
Ecclesiastes 7 in the BHAD
Ecclesiastes 7 in the BIB
Ecclesiastes 7 in the BLPT
Ecclesiastes 7 in the BNT
Ecclesiastes 7 in the BNTABOOT
Ecclesiastes 7 in the BNTLV
Ecclesiastes 7 in the BOATCB
Ecclesiastes 7 in the BOATCB2
Ecclesiastes 7 in the BOBCV
Ecclesiastes 7 in the BOCNT
Ecclesiastes 7 in the BOECS
Ecclesiastes 7 in the BOGWICC
Ecclesiastes 7 in the BOHCB
Ecclesiastes 7 in the BOHCV
Ecclesiastes 7 in the BOHLNT
Ecclesiastes 7 in the BOHNTLTAL
Ecclesiastes 7 in the BOICB
Ecclesiastes 7 in the BOILNTAP
Ecclesiastes 7 in the BOITCV
Ecclesiastes 7 in the BOKCV
Ecclesiastes 7 in the BOKCV2
Ecclesiastes 7 in the BOKHWOG
Ecclesiastes 7 in the BOKSSV
Ecclesiastes 7 in the BOLCB
Ecclesiastes 7 in the BOLCB2
Ecclesiastes 7 in the BOMCV
Ecclesiastes 7 in the BONAV
Ecclesiastes 7 in the BONCB
Ecclesiastes 7 in the BONLT
Ecclesiastes 7 in the BONUT2
Ecclesiastes 7 in the BOPLNT
Ecclesiastes 7 in the BOSCB
Ecclesiastes 7 in the BOSNC
Ecclesiastes 7 in the BOTLNT
Ecclesiastes 7 in the BOVCB
Ecclesiastes 7 in the BPBB
Ecclesiastes 7 in the BPH
Ecclesiastes 7 in the BSB
Ecclesiastes 7 in the CCB
Ecclesiastes 7 in the CUV
Ecclesiastes 7 in the CUVS
Ecclesiastes 7 in the DBT
Ecclesiastes 7 in the DGDNT
Ecclesiastes 7 in the DHNT
Ecclesiastes 7 in the DNT
Ecclesiastes 7 in the ELBE
Ecclesiastes 7 in the EMTV
Ecclesiastes 7 in the ESV
Ecclesiastes 7 in the FBV
Ecclesiastes 7 in the FEB
Ecclesiastes 7 in the GGMNT
Ecclesiastes 7 in the GNT
Ecclesiastes 7 in the HARY
Ecclesiastes 7 in the HNT
Ecclesiastes 7 in the IRVA
Ecclesiastes 7 in the IRVB
Ecclesiastes 7 in the IRVG
Ecclesiastes 7 in the IRVH
Ecclesiastes 7 in the IRVK
Ecclesiastes 7 in the IRVM
Ecclesiastes 7 in the IRVM2
Ecclesiastes 7 in the IRVO
Ecclesiastes 7 in the IRVP
Ecclesiastes 7 in the IRVT
Ecclesiastes 7 in the IRVT2
Ecclesiastes 7 in the IRVU
Ecclesiastes 7 in the ISVN
Ecclesiastes 7 in the JSNT
Ecclesiastes 7 in the KAPI
Ecclesiastes 7 in the KBT1ETNIK
Ecclesiastes 7 in the KBV
Ecclesiastes 7 in the KJV
Ecclesiastes 7 in the KNFD
Ecclesiastes 7 in the LBA
Ecclesiastes 7 in the LBLA
Ecclesiastes 7 in the LNT
Ecclesiastes 7 in the LSV
Ecclesiastes 7 in the MAAL
Ecclesiastes 7 in the MBV
Ecclesiastes 7 in the MBV2
Ecclesiastes 7 in the MHNT
Ecclesiastes 7 in the MKNFD
Ecclesiastes 7 in the MNG
Ecclesiastes 7 in the MNT
Ecclesiastes 7 in the MNT2
Ecclesiastes 7 in the MRS1T
Ecclesiastes 7 in the NAA
Ecclesiastes 7 in the NASB
Ecclesiastes 7 in the NBLA
Ecclesiastes 7 in the NBS
Ecclesiastes 7 in the NBVTP
Ecclesiastes 7 in the NET2
Ecclesiastes 7 in the NIV11
Ecclesiastes 7 in the NNT
Ecclesiastes 7 in the NNT2
Ecclesiastes 7 in the NNT3
Ecclesiastes 7 in the PDDPT
Ecclesiastes 7 in the PFNT
Ecclesiastes 7 in the RMNT
Ecclesiastes 7 in the SBIAS
Ecclesiastes 7 in the SBIBS
Ecclesiastes 7 in the SBIBS2
Ecclesiastes 7 in the SBICS
Ecclesiastes 7 in the SBIDS
Ecclesiastes 7 in the SBIGS
Ecclesiastes 7 in the SBIHS
Ecclesiastes 7 in the SBIIS
Ecclesiastes 7 in the SBIIS2
Ecclesiastes 7 in the SBIIS3
Ecclesiastes 7 in the SBIKS
Ecclesiastes 7 in the SBIKS2
Ecclesiastes 7 in the SBIMS
Ecclesiastes 7 in the SBIOS
Ecclesiastes 7 in the SBIPS
Ecclesiastes 7 in the SBISS
Ecclesiastes 7 in the SBITS
Ecclesiastes 7 in the SBITS2
Ecclesiastes 7 in the SBITS3
Ecclesiastes 7 in the SBITS4
Ecclesiastes 7 in the SBIUS
Ecclesiastes 7 in the SBIVS
Ecclesiastes 7 in the SBT
Ecclesiastes 7 in the SBT1E
Ecclesiastes 7 in the SCHL
Ecclesiastes 7 in the SNT
Ecclesiastes 7 in the SUSU
Ecclesiastes 7 in the SUSU2
Ecclesiastes 7 in the SYNO
Ecclesiastes 7 in the TBIAOTANT
Ecclesiastes 7 in the TBT1E
Ecclesiastes 7 in the TBT1E2
Ecclesiastes 7 in the TFTIP
Ecclesiastes 7 in the TFTU
Ecclesiastes 7 in the TGNTATF3T
Ecclesiastes 7 in the THAI
Ecclesiastes 7 in the TNFD
Ecclesiastes 7 in the TNT
Ecclesiastes 7 in the TNTIK
Ecclesiastes 7 in the TNTIL
Ecclesiastes 7 in the TNTIN
Ecclesiastes 7 in the TNTIP
Ecclesiastes 7 in the TNTIZ
Ecclesiastes 7 in the TOMA
Ecclesiastes 7 in the TTENT
Ecclesiastes 7 in the UBG
Ecclesiastes 7 in the UGV
Ecclesiastes 7 in the UGV2
Ecclesiastes 7 in the UGV3
Ecclesiastes 7 in the VBL
Ecclesiastes 7 in the VDCC
Ecclesiastes 7 in the YALU
Ecclesiastes 7 in the YAPE
Ecclesiastes 7 in the YBVTP
Ecclesiastes 7 in the ZBP