Habakkuk 1 (BOYCB)
1 Àsọtẹ́lẹ̀ tí wòlíì Habakuku rí. 2 OLÚWA, èmi yóò ti ké pẹ́ tó fún ìrànlọ́wọ́,ṣùgbọ́n ti ìwọ kò ni fetí sí mi?Tàbí kígbe sí ọ ní ti, “Ìwà ipá!”Ṣùgbọ́n tí ìwọ kò sì gbàlà? 3 Èéṣe tí ìwọ fi mú mi rí àìṣedéédéé?Èéṣe tí ìwọ sì fi ààyè gba ìwà ìkà?Ìparun àti ìwà ipá wà ní iwájú mi;ìjà ń bẹ, ìkọlù sì wà pẹ̀lú. 4 Nítorí náà, òfin di ohun àìkàsí,ìdájọ́ òdodo kò sì borí.Àwọn ẹni búburú yí àwọn olódodo ká,nítorí náà ni ìdájọ́ òdodo ṣe yí padà. 5 “Ẹ wo inú àwọn kèfèrí, ki ẹ sí wòye,kí háà kí ó sì ṣe yin gidigidi.Nítorí èmi ó ṣe ohun kan ní ọjọ́ yíntí ẹ̀yin kò jẹ́ gbàgbọ́,bí a tilẹ̀ sọ fún yin. 6 Nítorí pé, èmi yóò gbé àwọn ara Babeli dìde,àwọn aláìláàánú àti onínú-fùfù ènìyàntí ó rin gbogbo ilẹ̀ ayé jáláti fi agbára gbà àwọn ibùgbé tí kì í ṣe tiwọn. 7 Wọn jẹ́ ènìyàn ti a bẹ̀rù, tí a sì páyà,ìdájọ́ wọn, àti ọláńlá wọn,yóò máa ti inú wọn jáde. 8 Ẹṣin wọn yára ju ẹkùn lọ,wọ́n sì gbóná jú ìkookò àṣálẹ́ lọàwọn ẹlẹ́ṣin wọn yóò sí tan ara wọn ká;wọn yóò sì wá láti ọ̀nà jíjìn réré,wọn yóò sí fò bí ẹyẹ igún tí ń wá láti jẹrun, 9 gbogbo wọn sì wà fún ìwà ipáìwò ojú wọn yóò sì wá síwájú;wọn sì ko ìgbèkùn jọ bí iyanrìn. 10 Wọn ó si máa fi àwọn ọba ṣẹ̀sínwọn ó sì tún kẹ́gàn àwọn aládé.Wọn yóò sì fi gbogbo ìlú odi alágbára nì rẹ́rìn-ín;nítorí pé, wọn yóò ko erùpẹ̀ jọ, wọn yóò sì gbà á. 11 Nígbà náà ni inú rẹ̀ yóò yípadà,yóò sì rékọjá, yóò si ṣẹ̀ ní kíka agbára rẹ̀ yìí sí iṣẹ́ òrìṣà rẹ̀.” 12 OLÚWA, ǹjẹ́ láti ayérayé kọ ni ìwọ tí wà? OLÚWA Ọlọ́run mi. Ẹni mímọ́ mi, àwa kì yóò kú OLÚWA, ìwọ tí yàn wọn fún ìdájọ́;Ọlọ́run alágbára, ìwọ tí fi ẹsẹ̀ wọn múlẹ̀ fún ìbáwí. 13 Ojú rẹ mọ́ tónítóní láti wo ibi;ìwọ kò le gbà ìwà ìkànítorí kí ni ìwọ ṣe gba àwọn alárékérekè láààyè?Nítorí kí ni ìwọ ṣe dákẹ́ nígbà tí ẹni búburú ń paẹni tí i ṣe olódodo ju wọn lọ run? 14 Ìwọ sì tí sọ ènìyàn di bí ẹja inú Òkun,bí ohun tí ń rákò tí wọn ko ni alákòóso. 15 Àwọn ènìyàn búburú fi àwọ̀n wọn gbé wọn sókèó sì kó wọn jọ nínú àwọ̀n ńlá rẹ̀;nítorí náà, ó dunnú, ó sì yọ̀ pẹ̀lú. 16 Nítorí náà, ó rú ẹbọ sí àwọ̀n rẹ̀,ó sì ń sun tùràrí fún àwọ̀n ńlá rẹ̀nítorí pẹ̀lú àwọ̀n rẹ̀ ni ó fi ń gbé ní ìgbádùntí ó sì ń gbádùn pẹ̀lú oúnjẹ tí ó bá wù ú. 17 Ǹjẹ́ wọn yóò ha máa pa àwọ̀n wọn mọ́ ní òfìfo bí,tí wọn yóò sì pa orílẹ̀-èdè run láìsí àánú?
In Other Versions
Habakkuk 1 in the ANGEFD
Habakkuk 1 in the ANTPNG2D
Habakkuk 1 in the AS21
Habakkuk 1 in the BAGH
Habakkuk 1 in the BBPNG
Habakkuk 1 in the BBT1E
Habakkuk 1 in the BDS
Habakkuk 1 in the BEV
Habakkuk 1 in the BHAD
Habakkuk 1 in the BIB
Habakkuk 1 in the BLPT
Habakkuk 1 in the BNT
Habakkuk 1 in the BNTABOOT
Habakkuk 1 in the BNTLV
Habakkuk 1 in the BOATCB
Habakkuk 1 in the BOATCB2
Habakkuk 1 in the BOBCV
Habakkuk 1 in the BOCNT
Habakkuk 1 in the BOECS
Habakkuk 1 in the BOGWICC
Habakkuk 1 in the BOHCB
Habakkuk 1 in the BOHCV
Habakkuk 1 in the BOHLNT
Habakkuk 1 in the BOHNTLTAL
Habakkuk 1 in the BOICB
Habakkuk 1 in the BOILNTAP
Habakkuk 1 in the BOITCV
Habakkuk 1 in the BOKCV
Habakkuk 1 in the BOKCV2
Habakkuk 1 in the BOKHWOG
Habakkuk 1 in the BOKSSV
Habakkuk 1 in the BOLCB
Habakkuk 1 in the BOLCB2
Habakkuk 1 in the BOMCV
Habakkuk 1 in the BONAV
Habakkuk 1 in the BONCB
Habakkuk 1 in the BONLT
Habakkuk 1 in the BONUT2
Habakkuk 1 in the BOPLNT
Habakkuk 1 in the BOSCB
Habakkuk 1 in the BOSNC
Habakkuk 1 in the BOTLNT
Habakkuk 1 in the BOVCB
Habakkuk 1 in the BPBB
Habakkuk 1 in the BPH
Habakkuk 1 in the BSB
Habakkuk 1 in the CCB
Habakkuk 1 in the CUV
Habakkuk 1 in the CUVS
Habakkuk 1 in the DBT
Habakkuk 1 in the DGDNT
Habakkuk 1 in the DHNT
Habakkuk 1 in the DNT
Habakkuk 1 in the ELBE
Habakkuk 1 in the EMTV
Habakkuk 1 in the ESV
Habakkuk 1 in the FBV
Habakkuk 1 in the FEB
Habakkuk 1 in the GGMNT
Habakkuk 1 in the GNT
Habakkuk 1 in the HARY
Habakkuk 1 in the HNT
Habakkuk 1 in the IRVA
Habakkuk 1 in the IRVB
Habakkuk 1 in the IRVG
Habakkuk 1 in the IRVH
Habakkuk 1 in the IRVK
Habakkuk 1 in the IRVM
Habakkuk 1 in the IRVM2
Habakkuk 1 in the IRVO
Habakkuk 1 in the IRVP
Habakkuk 1 in the IRVT
Habakkuk 1 in the IRVT2
Habakkuk 1 in the IRVU
Habakkuk 1 in the ISVN
Habakkuk 1 in the JSNT
Habakkuk 1 in the KAPI
Habakkuk 1 in the KBT1ETNIK
Habakkuk 1 in the KBV
Habakkuk 1 in the KJV
Habakkuk 1 in the KNFD
Habakkuk 1 in the LBA
Habakkuk 1 in the LBLA
Habakkuk 1 in the LNT
Habakkuk 1 in the LSV
Habakkuk 1 in the MAAL
Habakkuk 1 in the MBV
Habakkuk 1 in the MBV2
Habakkuk 1 in the MHNT
Habakkuk 1 in the MKNFD
Habakkuk 1 in the MNG
Habakkuk 1 in the MNT
Habakkuk 1 in the MNT2
Habakkuk 1 in the MRS1T
Habakkuk 1 in the NAA
Habakkuk 1 in the NASB
Habakkuk 1 in the NBLA
Habakkuk 1 in the NBS
Habakkuk 1 in the NBVTP
Habakkuk 1 in the NET2
Habakkuk 1 in the NIV11
Habakkuk 1 in the NNT
Habakkuk 1 in the NNT2
Habakkuk 1 in the NNT3
Habakkuk 1 in the PDDPT
Habakkuk 1 in the PFNT
Habakkuk 1 in the RMNT
Habakkuk 1 in the SBIAS
Habakkuk 1 in the SBIBS
Habakkuk 1 in the SBIBS2
Habakkuk 1 in the SBICS
Habakkuk 1 in the SBIDS
Habakkuk 1 in the SBIGS
Habakkuk 1 in the SBIHS
Habakkuk 1 in the SBIIS
Habakkuk 1 in the SBIIS2
Habakkuk 1 in the SBIIS3
Habakkuk 1 in the SBIKS
Habakkuk 1 in the SBIKS2
Habakkuk 1 in the SBIMS
Habakkuk 1 in the SBIOS
Habakkuk 1 in the SBIPS
Habakkuk 1 in the SBISS
Habakkuk 1 in the SBITS
Habakkuk 1 in the SBITS2
Habakkuk 1 in the SBITS3
Habakkuk 1 in the SBITS4
Habakkuk 1 in the SBIUS
Habakkuk 1 in the SBIVS
Habakkuk 1 in the SBT
Habakkuk 1 in the SBT1E
Habakkuk 1 in the SCHL
Habakkuk 1 in the SNT
Habakkuk 1 in the SUSU
Habakkuk 1 in the SUSU2
Habakkuk 1 in the SYNO
Habakkuk 1 in the TBIAOTANT
Habakkuk 1 in the TBT1E
Habakkuk 1 in the TBT1E2
Habakkuk 1 in the TFTIP
Habakkuk 1 in the TFTU
Habakkuk 1 in the TGNTATF3T
Habakkuk 1 in the THAI
Habakkuk 1 in the TNFD
Habakkuk 1 in the TNT
Habakkuk 1 in the TNTIK
Habakkuk 1 in the TNTIL
Habakkuk 1 in the TNTIN
Habakkuk 1 in the TNTIP
Habakkuk 1 in the TNTIZ
Habakkuk 1 in the TOMA
Habakkuk 1 in the TTENT
Habakkuk 1 in the UBG
Habakkuk 1 in the UGV
Habakkuk 1 in the UGV2
Habakkuk 1 in the UGV3
Habakkuk 1 in the VBL
Habakkuk 1 in the VDCC
Habakkuk 1 in the YALU
Habakkuk 1 in the YAPE
Habakkuk 1 in the YBVTP
Habakkuk 1 in the ZBP