Hebrews 1 (BOYCB)
1 Ní ìgbà àtijọ́, Ọlọ́run bá àwọn baba ńlá wa sọ̀rọ̀ láti ẹnu àwọn wòlíì ní ọ̀pọ̀ ìgbà àti ní onírúurú ọ̀nà, 2 ṣùgbọ́n ní ìgbà ìkẹyìn yìí Ọlọ́run ń bá wa sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ Ọmọ rẹ̀ Jesu Kristi, ẹni tí ó fi ṣe ajogún ohun gbogbo, nípasẹ̀ ẹni tí ó dá gbogbo ayé yìí àti ohun gbogbo tí ń bẹ nínú rẹ̀. 3 Ọmọ tí í ṣe ìtànṣán ògo Ọlọ́run àti àwòrán òun tìkára rẹ̀, tí ó sì ń fi ọ̀rọ̀ agbára rẹ̀ mú ohun gbogbo dúró. Lẹ́yìn tí ó ti ṣe ìwẹ̀nù ẹ̀ṣẹ̀ wa tan, ó wá jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún Ọláńlá ní òkè. 4 Nítorí náà, ó sì ti fi bẹ́ẹ̀ di ẹni tí ó ga ní ipò ju angẹli lọ, bí ó ti jogún orúkọ èyí tí ó tayọ̀ tiwọn. 5 Nítorí kò sí ọ̀kan nínú àwọn angẹli tí Ọlọ́run fi ìgbà kan sọ fún pé:“Ìwọ ni ọmọ mi;lónìí ni mo bí ọ”?Àti pẹ̀lú pé,“Èmi yóò jẹ́ baba fún un,Òun yóò sì jẹ́ ọmọ mi”? 6 Àti pẹ̀lú, nígbà tí Ọlọ́run rán àkọ́bí rẹ̀ wá si ayé wa yìí. Ó pàṣẹ pé,“Ẹ jẹ́ kí gbogbo àwọn angẹli Ọlọ́run foríbalẹ̀ fún un.” 7 Àti nípa ti àwọn angẹli, ó wí pé,“Ẹni tí ó dá àwọn angẹli rẹ̀ ní ẹ̀mí,àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ ní ọwọ́ iná.” 8 Ṣùgbọ́n ó sọ nípa tí Ọmọ rẹ̀ pé,“Ìtẹ́ rẹ, Ọlọ́run, láé àti láéláé ni,ọ̀pá aládé òdodo ni ọ̀pá ìjọba rẹ. 9 Ìwọ fẹ́ òdodo, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kórìíra iṣẹ́ búburú;nítorí èyí ni Ọlọ́run, àní Ọlọ́run rẹ ṣe fi àmì òróró ayọ̀ yàn ọtí ó gbé ọ ju àwọn ẹgbẹ́ rẹ lọ.” 10 Ó tún sọ pé,“Ní àtètèkọ́ṣe, ìwọ Olúwa, ìwọ fi ìdí ayé sọlẹ̀,àwọn ọ̀run sì jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ ara rẹ. 11 Wọn yóò ṣègbé, ṣùgbọ́n ìwọ yóò wà síbẹ̀gbogbo wọn ni yóò di àkísà bí ẹ̀wù. 12 Ní kíká ni ìwọ yóò ká wọn bí aṣọ,bí ìpààrọ̀ aṣọ ni a ó sì pààrọ̀ wọn.Ṣùgbọ́n ìwọ fúnra rẹ̀ kì yóò yípadààti pé ọdún rẹ kì yóò ní òpin.” 13 Èwo nínú àwọn angẹli ní a gbọ́ pé Ọlọ́run fi ìgbà kan wí fún pé,“Jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mitítí èmi yóò fi sọ àwọn ọ̀tá rẹdi àpótí ìtìsẹ̀ rẹ”? 14 Kì í ha á ṣe ẹ̀mí tí ń jíṣẹ́ ni àwọn angẹli í ṣe bí; tí a rán lọ síta láti máa ṣiṣẹ́ fún àwọn tí yóò jogún ìgbàlà?
In Other Versions
Hebrews 1 in the ANGEFD
Hebrews 1 in the ANTPNG2D
Hebrews 1 in the AS21
Hebrews 1 in the BAGH
Hebrews 1 in the BBPNG
Hebrews 1 in the BBT1E
Hebrews 1 in the BDS
Hebrews 1 in the BEV
Hebrews 1 in the BHAD
Hebrews 1 in the BIB
Hebrews 1 in the BLPT
Hebrews 1 in the BNT
Hebrews 1 in the BNTABOOT
Hebrews 1 in the BNTLV
Hebrews 1 in the BOATCB
Hebrews 1 in the BOATCB2
Hebrews 1 in the BOBCV
Hebrews 1 in the BOCNT
Hebrews 1 in the BOECS
Hebrews 1 in the BOGWICC
Hebrews 1 in the BOHCB
Hebrews 1 in the BOHCV
Hebrews 1 in the BOHLNT
Hebrews 1 in the BOHNTLTAL
Hebrews 1 in the BOICB
Hebrews 1 in the BOILNTAP
Hebrews 1 in the BOITCV
Hebrews 1 in the BOKCV
Hebrews 1 in the BOKCV2
Hebrews 1 in the BOKHWOG
Hebrews 1 in the BOKSSV
Hebrews 1 in the BOLCB
Hebrews 1 in the BOLCB2
Hebrews 1 in the BOMCV
Hebrews 1 in the BONAV
Hebrews 1 in the BONCB
Hebrews 1 in the BONLT
Hebrews 1 in the BONUT2
Hebrews 1 in the BOPLNT
Hebrews 1 in the BOSCB
Hebrews 1 in the BOSNC
Hebrews 1 in the BOTLNT
Hebrews 1 in the BOVCB
Hebrews 1 in the BPBB
Hebrews 1 in the BPH
Hebrews 1 in the BSB
Hebrews 1 in the CCB
Hebrews 1 in the CUV
Hebrews 1 in the CUVS
Hebrews 1 in the DBT
Hebrews 1 in the DGDNT
Hebrews 1 in the DHNT
Hebrews 1 in the DNT
Hebrews 1 in the ELBE
Hebrews 1 in the EMTV
Hebrews 1 in the ESV
Hebrews 1 in the FBV
Hebrews 1 in the FEB
Hebrews 1 in the GGMNT
Hebrews 1 in the GNT
Hebrews 1 in the HARY
Hebrews 1 in the HNT
Hebrews 1 in the IRVA
Hebrews 1 in the IRVB
Hebrews 1 in the IRVG
Hebrews 1 in the IRVH
Hebrews 1 in the IRVK
Hebrews 1 in the IRVM
Hebrews 1 in the IRVM2
Hebrews 1 in the IRVO
Hebrews 1 in the IRVP
Hebrews 1 in the IRVT
Hebrews 1 in the IRVT2
Hebrews 1 in the IRVU
Hebrews 1 in the ISVN
Hebrews 1 in the JSNT
Hebrews 1 in the KAPI
Hebrews 1 in the KBT1ETNIK
Hebrews 1 in the KBV
Hebrews 1 in the KJV
Hebrews 1 in the KNFD
Hebrews 1 in the LBA
Hebrews 1 in the LBLA
Hebrews 1 in the LNT
Hebrews 1 in the LSV
Hebrews 1 in the MAAL
Hebrews 1 in the MBV
Hebrews 1 in the MBV2
Hebrews 1 in the MHNT
Hebrews 1 in the MKNFD
Hebrews 1 in the MNG
Hebrews 1 in the MNT
Hebrews 1 in the MNT2
Hebrews 1 in the MRS1T
Hebrews 1 in the NAA
Hebrews 1 in the NASB
Hebrews 1 in the NBLA
Hebrews 1 in the NBS
Hebrews 1 in the NBVTP
Hebrews 1 in the NET2
Hebrews 1 in the NIV11
Hebrews 1 in the NNT
Hebrews 1 in the NNT2
Hebrews 1 in the NNT3
Hebrews 1 in the PDDPT
Hebrews 1 in the PFNT
Hebrews 1 in the RMNT
Hebrews 1 in the SBIAS
Hebrews 1 in the SBIBS
Hebrews 1 in the SBIBS2
Hebrews 1 in the SBICS
Hebrews 1 in the SBIDS
Hebrews 1 in the SBIGS
Hebrews 1 in the SBIHS
Hebrews 1 in the SBIIS
Hebrews 1 in the SBIIS2
Hebrews 1 in the SBIIS3
Hebrews 1 in the SBIKS
Hebrews 1 in the SBIKS2
Hebrews 1 in the SBIMS
Hebrews 1 in the SBIOS
Hebrews 1 in the SBIPS
Hebrews 1 in the SBISS
Hebrews 1 in the SBITS
Hebrews 1 in the SBITS2
Hebrews 1 in the SBITS3
Hebrews 1 in the SBITS4
Hebrews 1 in the SBIUS
Hebrews 1 in the SBIVS
Hebrews 1 in the SBT
Hebrews 1 in the SBT1E
Hebrews 1 in the SCHL
Hebrews 1 in the SNT
Hebrews 1 in the SUSU
Hebrews 1 in the SUSU2
Hebrews 1 in the SYNO
Hebrews 1 in the TBIAOTANT
Hebrews 1 in the TBT1E
Hebrews 1 in the TBT1E2
Hebrews 1 in the TFTIP
Hebrews 1 in the TFTU
Hebrews 1 in the TGNTATF3T
Hebrews 1 in the THAI
Hebrews 1 in the TNFD
Hebrews 1 in the TNT
Hebrews 1 in the TNTIK
Hebrews 1 in the TNTIL
Hebrews 1 in the TNTIN
Hebrews 1 in the TNTIP
Hebrews 1 in the TNTIZ
Hebrews 1 in the TOMA
Hebrews 1 in the TTENT
Hebrews 1 in the UBG
Hebrews 1 in the UGV
Hebrews 1 in the UGV2
Hebrews 1 in the UGV3
Hebrews 1 in the VBL
Hebrews 1 in the VDCC
Hebrews 1 in the YALU
Hebrews 1 in the YAPE
Hebrews 1 in the YBVTP
Hebrews 1 in the ZBP