Hebrews 4 (BOYCB)
1 Nítorí náà, gẹ́gẹ́ bí Ọlọ́run ti ṣe ìlérí àtiwọ inú ìsinmi rẹ̀ fún wa, ẹ jẹ́ kí á bẹ̀rù, kí ẹnikẹ́ni nínú yín má ba à dàbí ẹni pé ó tí kùnà rẹ̀. 2 Nítorí tí àwa gbọ́ ìwàásù ìyìnrere, gẹ́gẹ́ bí a ti wàásù rẹ̀ fún àwọn náà pẹ̀lú, ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ tí wọ́n gbọ́ kò ṣe wọ́n ní àǹfààní, nítorí tí kò dàpọ̀ mọ́ ìgbàgbọ́ nínú àwọn tí ó gbọ́ ọ. 3 Nítorí pé àwa tí ó ti gbàgbọ́ wọ inú ìsinmi gẹ́gẹ́ bí ó tí wí,“Bí mo tí búra nínú ìbínú mi,‘Wọn kì yóò wọ inú ìsinmi mi.’ ”Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a tí parí iṣẹ́ wọ̀nyí láti ìpìlẹ̀ ayé. 4 Nítorí ó ti sọ níbìkan ní ti ọjọ́ keje báyìí pé, “Ọlọ́run sì sinmi ní ọjọ́ keje kúrò nínú iṣẹ́ rẹ̀ gbogbo.” 5 Àti níhìn-ín yìí pẹ̀lú ó wí pé, “Wọn kì yóò wọ inú ìsinmi mi.” 6 Nítorí náà bí ó tí jẹ́ pé, ó ku kí àwọn kan wọ inú rẹ̀, àti àwọn tí a ti wàásù ìyìnrere náà fún ní ìṣáájú kò wọ inú rẹ̀ nítorí àìgbọ́ràn. 7 Àti pé, ó yan ọjọ́ kan, ó wí nínú ìwé Dafidi pé, “Lónìí,” lẹ́yìn ìgbà pípẹ́ bẹ́ẹ̀; bí a tí wí níṣàájú,“Lónìí bí ẹ̀yin bá gbọ́ ohùn rẹ̀,ẹ má ṣe sé ọkàn yín le.” 8 Nítorí, ìbá ṣe pé Joṣua tí fún wọn ní ìsinmi, òun kì bá tí sọ̀rọ̀ nípa ọjọ́ ìsinmi mìíràn lẹ́yìn náà, 9 nítorí náà ìsinmi kan kù fún àwọn ènìyàn Ọlọ́run. 10 Nítorí pé ẹni tí ó ba bọ́ sínú ìsinmi rẹ̀, òun pẹ̀lú sinmi kúrò nínú iṣẹ́ tirẹ̀, gẹ́gẹ́ bí Ọlọ́run ti sinmi kúrò nínú iṣẹ́ tirẹ̀. 11 Nítorí náà, ẹ jẹ́ kí á múra gírí láti wọ inú ìsinmi náà, kí ẹnikẹ́ni má ba à ṣubú nípa irú àìgbàgbọ́ kan náà. 12 Nítorí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run yè, ó sì ní agbára, ó sì mu ju idàkídà olójú méjì lọ, ó sì ń gún ni, àní títí dé pínpín ọkàn àti ẹ̀mí ní yà, àti ní oríkèé àti ọ̀rá inú egungun, òun sì ni olùmọ̀ èrò inú àti ète ọkàn. 13 Kò sí ẹ̀dá kan tí kò farahàn níwájú rẹ̀, ṣùgbọ́n ohun gbogbo ni ó wà níhòhò tí a sì ṣípáyà fún ojú rẹ̀, níwájú ẹni tí àwa yóò jíyìn. 14 Ǹjẹ́ bí a ti ní olórí àlùfáà ńlá kan, tí ó ti la àwọn ọ̀run kọjá lọ, Jesu Ọmọ Ọlọ́run, ẹ jẹ́ kí a di ìjẹ́wọ́ wa mú ṣinṣin. 15 Nítorí a kò ní olórí àlùfáà tí kò lè ṣàì ba ni kẹ́dùn nínú àìlera wa, ẹni tí a ti dánwò lọ́nà gbogbo gẹ́gẹ́ bí àwa, ṣùgbọ́n òun kò dẹ́ṣẹ̀. 16 Nítorí náà, ẹ jẹ́ kí a wá si ibi ìtẹ́ oore-ọ̀fẹ́ pẹ̀lú ìgboyà, kí a lè rí àánú gbà, kí a sì rí oore-ọ̀fẹ́ láti máa ran ni lọ́wọ́ ní àkókò tí ó wọ̀.
In Other Versions
Hebrews 4 in the ANGEFD
Hebrews 4 in the ANTPNG2D
Hebrews 4 in the AS21
Hebrews 4 in the BAGH
Hebrews 4 in the BBPNG
Hebrews 4 in the BBT1E
Hebrews 4 in the BDS
Hebrews 4 in the BEV
Hebrews 4 in the BHAD
Hebrews 4 in the BIB
Hebrews 4 in the BLPT
Hebrews 4 in the BNT
Hebrews 4 in the BNTABOOT
Hebrews 4 in the BNTLV
Hebrews 4 in the BOATCB
Hebrews 4 in the BOATCB2
Hebrews 4 in the BOBCV
Hebrews 4 in the BOCNT
Hebrews 4 in the BOECS
Hebrews 4 in the BOGWICC
Hebrews 4 in the BOHCB
Hebrews 4 in the BOHCV
Hebrews 4 in the BOHLNT
Hebrews 4 in the BOHNTLTAL
Hebrews 4 in the BOICB
Hebrews 4 in the BOILNTAP
Hebrews 4 in the BOITCV
Hebrews 4 in the BOKCV
Hebrews 4 in the BOKCV2
Hebrews 4 in the BOKHWOG
Hebrews 4 in the BOKSSV
Hebrews 4 in the BOLCB
Hebrews 4 in the BOLCB2
Hebrews 4 in the BOMCV
Hebrews 4 in the BONAV
Hebrews 4 in the BONCB
Hebrews 4 in the BONLT
Hebrews 4 in the BONUT2
Hebrews 4 in the BOPLNT
Hebrews 4 in the BOSCB
Hebrews 4 in the BOSNC
Hebrews 4 in the BOTLNT
Hebrews 4 in the BOVCB
Hebrews 4 in the BPBB
Hebrews 4 in the BPH
Hebrews 4 in the BSB
Hebrews 4 in the CCB
Hebrews 4 in the CUV
Hebrews 4 in the CUVS
Hebrews 4 in the DBT
Hebrews 4 in the DGDNT
Hebrews 4 in the DHNT
Hebrews 4 in the DNT
Hebrews 4 in the ELBE
Hebrews 4 in the EMTV
Hebrews 4 in the ESV
Hebrews 4 in the FBV
Hebrews 4 in the FEB
Hebrews 4 in the GGMNT
Hebrews 4 in the GNT
Hebrews 4 in the HARY
Hebrews 4 in the HNT
Hebrews 4 in the IRVA
Hebrews 4 in the IRVB
Hebrews 4 in the IRVG
Hebrews 4 in the IRVH
Hebrews 4 in the IRVK
Hebrews 4 in the IRVM
Hebrews 4 in the IRVM2
Hebrews 4 in the IRVO
Hebrews 4 in the IRVP
Hebrews 4 in the IRVT
Hebrews 4 in the IRVT2
Hebrews 4 in the IRVU
Hebrews 4 in the ISVN
Hebrews 4 in the JSNT
Hebrews 4 in the KAPI
Hebrews 4 in the KBT1ETNIK
Hebrews 4 in the KBV
Hebrews 4 in the KJV
Hebrews 4 in the KNFD
Hebrews 4 in the LBA
Hebrews 4 in the LBLA
Hebrews 4 in the LNT
Hebrews 4 in the LSV
Hebrews 4 in the MAAL
Hebrews 4 in the MBV
Hebrews 4 in the MBV2
Hebrews 4 in the MHNT
Hebrews 4 in the MKNFD
Hebrews 4 in the MNG
Hebrews 4 in the MNT
Hebrews 4 in the MNT2
Hebrews 4 in the MRS1T
Hebrews 4 in the NAA
Hebrews 4 in the NASB
Hebrews 4 in the NBLA
Hebrews 4 in the NBS
Hebrews 4 in the NBVTP
Hebrews 4 in the NET2
Hebrews 4 in the NIV11
Hebrews 4 in the NNT
Hebrews 4 in the NNT2
Hebrews 4 in the NNT3
Hebrews 4 in the PDDPT
Hebrews 4 in the PFNT
Hebrews 4 in the RMNT
Hebrews 4 in the SBIAS
Hebrews 4 in the SBIBS
Hebrews 4 in the SBIBS2
Hebrews 4 in the SBICS
Hebrews 4 in the SBIDS
Hebrews 4 in the SBIGS
Hebrews 4 in the SBIHS
Hebrews 4 in the SBIIS
Hebrews 4 in the SBIIS2
Hebrews 4 in the SBIIS3
Hebrews 4 in the SBIKS
Hebrews 4 in the SBIKS2
Hebrews 4 in the SBIMS
Hebrews 4 in the SBIOS
Hebrews 4 in the SBIPS
Hebrews 4 in the SBISS
Hebrews 4 in the SBITS
Hebrews 4 in the SBITS2
Hebrews 4 in the SBITS3
Hebrews 4 in the SBITS4
Hebrews 4 in the SBIUS
Hebrews 4 in the SBIVS
Hebrews 4 in the SBT
Hebrews 4 in the SBT1E
Hebrews 4 in the SCHL
Hebrews 4 in the SNT
Hebrews 4 in the SUSU
Hebrews 4 in the SUSU2
Hebrews 4 in the SYNO
Hebrews 4 in the TBIAOTANT
Hebrews 4 in the TBT1E
Hebrews 4 in the TBT1E2
Hebrews 4 in the TFTIP
Hebrews 4 in the TFTU
Hebrews 4 in the TGNTATF3T
Hebrews 4 in the THAI
Hebrews 4 in the TNFD
Hebrews 4 in the TNT
Hebrews 4 in the TNTIK
Hebrews 4 in the TNTIL
Hebrews 4 in the TNTIN
Hebrews 4 in the TNTIP
Hebrews 4 in the TNTIZ
Hebrews 4 in the TOMA
Hebrews 4 in the TTENT
Hebrews 4 in the UBG
Hebrews 4 in the UGV
Hebrews 4 in the UGV2
Hebrews 4 in the UGV3
Hebrews 4 in the VBL
Hebrews 4 in the VDCC
Hebrews 4 in the YALU
Hebrews 4 in the YAPE
Hebrews 4 in the YBVTP
Hebrews 4 in the ZBP