Isaiah 2 (BOYCB)

1 Èyí ni ohun tí Isaiah ọmọ Amosi rí nípa Juda àti Jerusalẹmu. 2 Ní ìgbẹ̀yìn ọjọ́òkè tẹmpili OLÚWA ni a ó fi ìdí rẹ̀ kalẹ̀gẹ́gẹ́ bí olú nínú àwọn òkè,a ó sì gbé e ga ju àwọn òkè kéékèèké lọ,gbogbo orílẹ̀-èdè yóò sì máa sàn sínú un rẹ̀. 3 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni yóò wá, wọn yóò sì wí pé,“Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á gòkè ńlá OLÚWA,àti sí ilé Ọlọ́run Jakọbu.Òun yóò kọ́ wa ní ọ̀nà rẹ̀,kí àwa kí ó lè rìn ní ọ̀nà rẹ̀.”Òfin yóò jáde láti Sioni wá,àti ọ̀rọ̀ OLÚWA láti Jerusalẹmu. 4 Òun ó ṣe ìdájọ́ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè,yóò sì parí aáwọ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn.Wọn yóò fi idà wọn rọ ọkọ́ ìtulẹ̀,wọn yóò sì fi ọ̀kọ̀ wọn rọ dòjé.Orílẹ̀-èdè kì yóò sì gbé idà sí orílẹ̀-èdè mọ́,bẹ́ẹ̀ ní wọn kì yóò kọ́ ogun jíjà mọ́. 5 Wá, ẹ̀yìn ará ilé e Jakọbu,ẹ jẹ́ kí a rìn nínú ìmọ́lẹ̀ OLÚWA. 6 Ìwọ ti kọ àwọn ènìyàn rẹ sílẹ̀,ìwọ ilé Jakọbu.Wọ́n kún fún ìgbàgbọ́ tí kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀ tí ó ti ìlà-oòrùn wá,wọ́n ń wo iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí àwọn Filistini,wọ́n ń pa ọwọ́ pọ̀ pẹ̀lú àwọn abọ̀rìṣà. 7 Ilẹ̀ wọn kún fún fàdákà àti wúrà,ìṣúra wọn kò sì ní òpin.Ilẹ̀ ẹ wọn kún fún ẹṣin,kẹ̀kẹ́ ogun wọn kò sì lópin. 8 Ilẹ̀ ẹ wọn kún fún ère,wọ́n sì ń foríbalẹ̀ fún iṣẹ́ ọwọ́ ara wọn,èyí tí ìka ọwọ́ àwọn tìkára wọn ti ṣe. 9 Nítorí náà ni a ó ṣe rẹ ènìyàn sílẹ̀ìran ọmọ ènìyàn ni yóò sì di onírẹ̀lẹ̀,má ṣe dáríjì wọ́n. 10 Wọ inú àpáta lọ,fi ara pamọ́ nínú erùpẹ̀kúrò nínú ìpayà OLÚWA,àti ògo ọláńlá rẹ̀! 11 Ojú agbéraga ènìyàn ni a ó rẹ̀ sílẹ̀a ó sì tẹrí ìgbéraga ènìyàn ba, OLÚWA nìkan ṣoṣo ni a ó gbéga ní ọjọ́ náà. 12 OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ní ọjọ́ kan ní ìpamọ́fún gbogbo agbéraga àti ọlọ́kàn gíganítorí gbogbo àwọn tí a gbéga (ni a ó rẹ̀ sílẹ̀), 13 nítorí gbogbo igi kedari Lebanoni, tó ga tó rìpóàti gbogbo óákù Baṣani, 14 nítorí gbogbo òkè gíga ńlá ńláàti àwọn òkè kéékèèké, 15 fún ilé ìṣọ́ gíga gígaàti àwọn odi ìdáàbòbò, 16 fún gbogbo ọkọ̀ àwọn oníṣòwòàwọn ọkọ̀ tí a ṣe lọ́ṣọ̀ọ́. 17 Ìgbéraga ènìyàn ni a ó tẹ̀ lórí baa ó sì rẹ ìgbéraga ènìyàn sílẹ̀, OLÚWA nìkan ṣoṣo ni a ó gbéga ní ọjọ́ náà, 18 gbogbo ère òrìṣà yóò pòórá. 19 Àwọn ènìyàn yóò sálọ sínú ihò àpátaàti sínú ihò ilẹ̀kúrò lọ́wọ́ ìpayà OLÚWAàti ògo ọláńlá rẹ̀,nígbà tí ó bá dìde láti mi ayé tìtì. 20 Ní ọjọ́ náà ni àwọn ènìyàn yóò máa sọàwọn ère fàdákà àti ère wúràtí wọ́n ti yá fún bíbọsí èkúté àti àwọn àdán. 21 Wọn yóò sálọ sínú ihò ìsàlẹ̀ àpátaàti sínú ihò pàlàpálá àpátakúrò lọ́wọ́ ìpayà OLÚWAàti ògo ọláńlá rẹ̀,nígbà tí ó bá dìde láti mi ayé tìtì. 22 Dẹ́kun à ń gba ènìyàn gbọ́,èémí ẹni tó wà ní ihò imú rẹ̀.Nítorí nínú kín ni a lè kà á sí?

In Other Versions

Isaiah 2 in the ANGEFD

Isaiah 2 in the ANTPNG2D

Isaiah 2 in the AS21

Isaiah 2 in the BAGH

Isaiah 2 in the BBPNG

Isaiah 2 in the BBT1E

Isaiah 2 in the BDS

Isaiah 2 in the BEV

Isaiah 2 in the BHAD

Isaiah 2 in the BIB

Isaiah 2 in the BLPT

Isaiah 2 in the BNT

Isaiah 2 in the BNTABOOT

Isaiah 2 in the BNTLV

Isaiah 2 in the BOATCB

Isaiah 2 in the BOATCB2

Isaiah 2 in the BOBCV

Isaiah 2 in the BOCNT

Isaiah 2 in the BOECS

Isaiah 2 in the BOGWICC

Isaiah 2 in the BOHCB

Isaiah 2 in the BOHCV

Isaiah 2 in the BOHLNT

Isaiah 2 in the BOHNTLTAL

Isaiah 2 in the BOICB

Isaiah 2 in the BOILNTAP

Isaiah 2 in the BOITCV

Isaiah 2 in the BOKCV

Isaiah 2 in the BOKCV2

Isaiah 2 in the BOKHWOG

Isaiah 2 in the BOKSSV

Isaiah 2 in the BOLCB

Isaiah 2 in the BOLCB2

Isaiah 2 in the BOMCV

Isaiah 2 in the BONAV

Isaiah 2 in the BONCB

Isaiah 2 in the BONLT

Isaiah 2 in the BONUT2

Isaiah 2 in the BOPLNT

Isaiah 2 in the BOSCB

Isaiah 2 in the BOSNC

Isaiah 2 in the BOTLNT

Isaiah 2 in the BOVCB

Isaiah 2 in the BPBB

Isaiah 2 in the BPH

Isaiah 2 in the BSB

Isaiah 2 in the CCB

Isaiah 2 in the CUV

Isaiah 2 in the CUVS

Isaiah 2 in the DBT

Isaiah 2 in the DGDNT

Isaiah 2 in the DHNT

Isaiah 2 in the DNT

Isaiah 2 in the ELBE

Isaiah 2 in the EMTV

Isaiah 2 in the ESV

Isaiah 2 in the FBV

Isaiah 2 in the FEB

Isaiah 2 in the GGMNT

Isaiah 2 in the GNT

Isaiah 2 in the HARY

Isaiah 2 in the HNT

Isaiah 2 in the IRVA

Isaiah 2 in the IRVB

Isaiah 2 in the IRVG

Isaiah 2 in the IRVH

Isaiah 2 in the IRVK

Isaiah 2 in the IRVM

Isaiah 2 in the IRVM2

Isaiah 2 in the IRVO

Isaiah 2 in the IRVP

Isaiah 2 in the IRVT

Isaiah 2 in the IRVT2

Isaiah 2 in the IRVU

Isaiah 2 in the ISVN

Isaiah 2 in the JSNT

Isaiah 2 in the KAPI

Isaiah 2 in the KBT1ETNIK

Isaiah 2 in the KBV

Isaiah 2 in the KJV

Isaiah 2 in the KNFD

Isaiah 2 in the LBA

Isaiah 2 in the LBLA

Isaiah 2 in the LNT

Isaiah 2 in the LSV

Isaiah 2 in the MAAL

Isaiah 2 in the MBV

Isaiah 2 in the MBV2

Isaiah 2 in the MHNT

Isaiah 2 in the MKNFD

Isaiah 2 in the MNG

Isaiah 2 in the MNT

Isaiah 2 in the MNT2

Isaiah 2 in the MRS1T

Isaiah 2 in the NAA

Isaiah 2 in the NASB

Isaiah 2 in the NBLA

Isaiah 2 in the NBS

Isaiah 2 in the NBVTP

Isaiah 2 in the NET2

Isaiah 2 in the NIV11

Isaiah 2 in the NNT

Isaiah 2 in the NNT2

Isaiah 2 in the NNT3

Isaiah 2 in the PDDPT

Isaiah 2 in the PFNT

Isaiah 2 in the RMNT

Isaiah 2 in the SBIAS

Isaiah 2 in the SBIBS

Isaiah 2 in the SBIBS2

Isaiah 2 in the SBICS

Isaiah 2 in the SBIDS

Isaiah 2 in the SBIGS

Isaiah 2 in the SBIHS

Isaiah 2 in the SBIIS

Isaiah 2 in the SBIIS2

Isaiah 2 in the SBIIS3

Isaiah 2 in the SBIKS

Isaiah 2 in the SBIKS2

Isaiah 2 in the SBIMS

Isaiah 2 in the SBIOS

Isaiah 2 in the SBIPS

Isaiah 2 in the SBISS

Isaiah 2 in the SBITS

Isaiah 2 in the SBITS2

Isaiah 2 in the SBITS3

Isaiah 2 in the SBITS4

Isaiah 2 in the SBIUS

Isaiah 2 in the SBIVS

Isaiah 2 in the SBT

Isaiah 2 in the SBT1E

Isaiah 2 in the SCHL

Isaiah 2 in the SNT

Isaiah 2 in the SUSU

Isaiah 2 in the SUSU2

Isaiah 2 in the SYNO

Isaiah 2 in the TBIAOTANT

Isaiah 2 in the TBT1E

Isaiah 2 in the TBT1E2

Isaiah 2 in the TFTIP

Isaiah 2 in the TFTU

Isaiah 2 in the TGNTATF3T

Isaiah 2 in the THAI

Isaiah 2 in the TNFD

Isaiah 2 in the TNT

Isaiah 2 in the TNTIK

Isaiah 2 in the TNTIL

Isaiah 2 in the TNTIN

Isaiah 2 in the TNTIP

Isaiah 2 in the TNTIZ

Isaiah 2 in the TOMA

Isaiah 2 in the TTENT

Isaiah 2 in the UBG

Isaiah 2 in the UGV

Isaiah 2 in the UGV2

Isaiah 2 in the UGV3

Isaiah 2 in the VBL

Isaiah 2 in the VDCC

Isaiah 2 in the YALU

Isaiah 2 in the YAPE

Isaiah 2 in the YBVTP

Isaiah 2 in the ZBP