Isaiah 24 (BOYCB)

1 Kíyèsi i, OLÚWA yóò sọ ohungbogbo dòfo ní ilẹ̀ ayéyóò sì pa á runòun yóò pa ojú u rẹ̀ rẹ́yóò sì fọ́n àwọn olùgbé ibẹ̀ káàkiri— 2 bákan náà ni yóò sì rífún àlùfáà àti àwọn ènìyàn,fún ọ̀gá àti ọmọ ọ̀dọ̀,fún ìyá-ilé àti ọmọbìnrin,fún olùtà àti olùrà,fún ayáni àti atọrọfún ayánilówó àti onígbèsè. 3 Ilé ayé ni a ó sọ di ahoro pátápátáa ó sì jẹ gbogbo rẹ̀ run. OLÚWA ni ó ti sọ ọ̀rọ̀ yìí. 4 Ilẹ̀ ayé ti gbẹ ó sì sá,ayé ń ṣòjòjò, àárẹ̀ mú un,àwọn ẹni gíga ilẹ̀ ayé wà nínú ìpọ́njú 5 àwọn ènìyàn ayé ti bà á jẹ́;wọ́n ti pa àwọn òfin runwọ́n ṣe lòdì sí àwọn ìlànàwọ́n sì ti ba májẹ̀mú ayérayé jẹ́. 6 Nítorí náà, ègún kan ti jẹ ayé run;àwọn ènìyàn rẹ̀ ní láti ru ẹ̀bi wọn.Nítorí náà, àwọn olùgbé ayé ti gbiná dànù,àwọn ẹ̀tàhóró ló sì kù. 7 Wáìnì tuntun ti gbẹ, àjàrà sì ti rọ,gbogbo àwọn aláríyá sì kérora. 8 Àríyá ti ṣaworo ti dákẹ́ariwo àwọn tí ń ṣàjọyọ̀ ti dáwọ́ dúróayọ̀ dùùrù ti dákẹ́ jẹ́ẹ́. 9 Kò ṣe é ṣe fún wọn láti máa mu wáìnì pẹ̀lú orin kíkọ mọ́ọtí líle ti di ìkorò fún àwọn ọ̀mu. 10 Ìlú tí a run ti dahoro,ẹnu-ọ̀nà àbáwọlé kọ̀ọ̀kan ni a dí pa. 11 Ní òpópónà ni wọ́n ti ń kígbe fún wáìnìgbogbo ayọ̀ ọ wọn ti di ìbànújẹ́,gbogbo àríyá ni a lé kúrò lórí ilẹ̀ ayé. 12 Ìlú ni a ti fi sílẹ̀ ní ahoro,ìlẹ̀kùn rẹ̀ ni a sì tì pa bámú bámú. 13 Bẹ́ẹ̀ ni yóò sì rí ní orí ilẹ̀ ayéàti láàrín àwọn orílẹ̀-èdè pẹ̀lú,gẹ́gẹ́ bí ìgbà tí a lu igi olifi,tàbí gẹ́gẹ́ bí i pàǹtí tí ó ṣẹ́kù lẹ́yìntí a kórè èso tán. 14 Wọ́n gbé ohùn wọn sókè, wọ́n sì hó fún ayọ̀;láti ìwọ̀-oòrùn ni wọn yóò ti polongoọláńlá OLÚWA. 15 Nítorí náà ní ìlà-oòrùn ẹ fi ògo fún OLÚWA;gbé orúkọ OLÚWA ga, àníỌlọ́run Israẹli,ní àwọn erékùṣù ti inú Òkun. 16 Láti òpin ayé wá ni a ti gbọ́ orin;“Ògo ni fún olódodo n nì.”Ṣùgbọ́n mo wí pé, “Mo ṣègbé, mo ṣègbé! “Ègbé ni fún mi!Alárékérekè dalẹ̀!Pẹ̀lú ìhàlẹ̀ ni àgàbàgebè fi dalẹ̀!” 17 Ìpayà, isà òkú, àti ìdẹ̀kùn ń dúró dè ọ́,ìwọ ènìyàn ilẹ̀ ayé. 18 Ẹnikẹ́ni tí ó bá sá nítorí ariwo ìpayàyóò ṣubú sínú ihò,ẹnikẹ́ni tí ó bá sì yọ́ jáde nínú ihòni ìdẹ̀kùn yóò gbámú. Ibodè ọ̀run ti wà ní ṣíṣí sílẹ̀,ìpìlẹ̀ ayé mì tìtì. 19 Ilẹ̀ ayé ti fọ́ilẹ̀ ayé ti fọ́ dànù,a ti mi ilẹ̀ ayé rìrìrìrì. 20 Ilẹ̀ ayé yí gbiri bí ọ̀mùtí,ó bì síwá sẹ́yìn bí ahéré nínú afẹ́fẹ́;ẹ̀bi ìṣọ̀tẹ̀ rẹ̀ ń pa á lẹ́rùtó bẹ́ẹ̀ tí ó fi ṣubú láìní lè dìde mọ́. 21 Ní ọjọ́ náà ni OLÚWA yóò jẹ ẹ́ ní yàgbogbo agbára tí ó wà lókè lọ́runàti àwọn ọba tí ó wà lórí ilẹ̀ ayé. 22 A ó sì kó wọn jọ pọ̀,gẹ́gẹ́ bí ará túbú jọ sínú ihò,a ó tì wọ́n mọ́ inú túbú,a ó sì bẹ̀ wọ́n wò lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọjọ́. 23 A ó rẹ òṣùpá sílẹ̀, ojú yóò sì ti oòrùn;nítorí OLÚWA àwọn ọmọ-ogun yóò jẹ ọbaní orí òkè Sioni àti ní Jerusalẹmu,àti níwájú àwọn àgbàgbà rẹ ní ògo.

In Other Versions

Isaiah 24 in the ANGEFD

Isaiah 24 in the ANTPNG2D

Isaiah 24 in the AS21

Isaiah 24 in the BAGH

Isaiah 24 in the BBPNG

Isaiah 24 in the BBT1E

Isaiah 24 in the BDS

Isaiah 24 in the BEV

Isaiah 24 in the BHAD

Isaiah 24 in the BIB

Isaiah 24 in the BLPT

Isaiah 24 in the BNT

Isaiah 24 in the BNTABOOT

Isaiah 24 in the BNTLV

Isaiah 24 in the BOATCB

Isaiah 24 in the BOATCB2

Isaiah 24 in the BOBCV

Isaiah 24 in the BOCNT

Isaiah 24 in the BOECS

Isaiah 24 in the BOGWICC

Isaiah 24 in the BOHCB

Isaiah 24 in the BOHCV

Isaiah 24 in the BOHLNT

Isaiah 24 in the BOHNTLTAL

Isaiah 24 in the BOICB

Isaiah 24 in the BOILNTAP

Isaiah 24 in the BOITCV

Isaiah 24 in the BOKCV

Isaiah 24 in the BOKCV2

Isaiah 24 in the BOKHWOG

Isaiah 24 in the BOKSSV

Isaiah 24 in the BOLCB

Isaiah 24 in the BOLCB2

Isaiah 24 in the BOMCV

Isaiah 24 in the BONAV

Isaiah 24 in the BONCB

Isaiah 24 in the BONLT

Isaiah 24 in the BONUT2

Isaiah 24 in the BOPLNT

Isaiah 24 in the BOSCB

Isaiah 24 in the BOSNC

Isaiah 24 in the BOTLNT

Isaiah 24 in the BOVCB

Isaiah 24 in the BPBB

Isaiah 24 in the BPH

Isaiah 24 in the BSB

Isaiah 24 in the CCB

Isaiah 24 in the CUV

Isaiah 24 in the CUVS

Isaiah 24 in the DBT

Isaiah 24 in the DGDNT

Isaiah 24 in the DHNT

Isaiah 24 in the DNT

Isaiah 24 in the ELBE

Isaiah 24 in the EMTV

Isaiah 24 in the ESV

Isaiah 24 in the FBV

Isaiah 24 in the FEB

Isaiah 24 in the GGMNT

Isaiah 24 in the GNT

Isaiah 24 in the HARY

Isaiah 24 in the HNT

Isaiah 24 in the IRVA

Isaiah 24 in the IRVB

Isaiah 24 in the IRVG

Isaiah 24 in the IRVH

Isaiah 24 in the IRVK

Isaiah 24 in the IRVM

Isaiah 24 in the IRVM2

Isaiah 24 in the IRVO

Isaiah 24 in the IRVP

Isaiah 24 in the IRVT

Isaiah 24 in the IRVT2

Isaiah 24 in the IRVU

Isaiah 24 in the ISVN

Isaiah 24 in the JSNT

Isaiah 24 in the KAPI

Isaiah 24 in the KBT1ETNIK

Isaiah 24 in the KBV

Isaiah 24 in the KJV

Isaiah 24 in the KNFD

Isaiah 24 in the LBA

Isaiah 24 in the LBLA

Isaiah 24 in the LNT

Isaiah 24 in the LSV

Isaiah 24 in the MAAL

Isaiah 24 in the MBV

Isaiah 24 in the MBV2

Isaiah 24 in the MHNT

Isaiah 24 in the MKNFD

Isaiah 24 in the MNG

Isaiah 24 in the MNT

Isaiah 24 in the MNT2

Isaiah 24 in the MRS1T

Isaiah 24 in the NAA

Isaiah 24 in the NASB

Isaiah 24 in the NBLA

Isaiah 24 in the NBS

Isaiah 24 in the NBVTP

Isaiah 24 in the NET2

Isaiah 24 in the NIV11

Isaiah 24 in the NNT

Isaiah 24 in the NNT2

Isaiah 24 in the NNT3

Isaiah 24 in the PDDPT

Isaiah 24 in the PFNT

Isaiah 24 in the RMNT

Isaiah 24 in the SBIAS

Isaiah 24 in the SBIBS

Isaiah 24 in the SBIBS2

Isaiah 24 in the SBICS

Isaiah 24 in the SBIDS

Isaiah 24 in the SBIGS

Isaiah 24 in the SBIHS

Isaiah 24 in the SBIIS

Isaiah 24 in the SBIIS2

Isaiah 24 in the SBIIS3

Isaiah 24 in the SBIKS

Isaiah 24 in the SBIKS2

Isaiah 24 in the SBIMS

Isaiah 24 in the SBIOS

Isaiah 24 in the SBIPS

Isaiah 24 in the SBISS

Isaiah 24 in the SBITS

Isaiah 24 in the SBITS2

Isaiah 24 in the SBITS3

Isaiah 24 in the SBITS4

Isaiah 24 in the SBIUS

Isaiah 24 in the SBIVS

Isaiah 24 in the SBT

Isaiah 24 in the SBT1E

Isaiah 24 in the SCHL

Isaiah 24 in the SNT

Isaiah 24 in the SUSU

Isaiah 24 in the SUSU2

Isaiah 24 in the SYNO

Isaiah 24 in the TBIAOTANT

Isaiah 24 in the TBT1E

Isaiah 24 in the TBT1E2

Isaiah 24 in the TFTIP

Isaiah 24 in the TFTU

Isaiah 24 in the TGNTATF3T

Isaiah 24 in the THAI

Isaiah 24 in the TNFD

Isaiah 24 in the TNT

Isaiah 24 in the TNTIK

Isaiah 24 in the TNTIL

Isaiah 24 in the TNTIN

Isaiah 24 in the TNTIP

Isaiah 24 in the TNTIZ

Isaiah 24 in the TOMA

Isaiah 24 in the TTENT

Isaiah 24 in the UBG

Isaiah 24 in the UGV

Isaiah 24 in the UGV2

Isaiah 24 in the UGV3

Isaiah 24 in the VBL

Isaiah 24 in the VDCC

Isaiah 24 in the YALU

Isaiah 24 in the YAPE

Isaiah 24 in the YBVTP

Isaiah 24 in the ZBP