Isaiah 26 (BOYCB)

1 Ní ọjọ́ náà ni a ó kọ orin yìí ní ilẹ̀ Juda.Àwa ní ìlú alágbára kan,Ọlọ́run fi ìgbàlà ṣeògiri àti ààbò rẹ̀. 2 Ṣí àwọn ìlẹ̀kùnkí àwọn olódodo orílẹ̀-èdè kí ó lè wọlé,orílẹ̀-èdè tí ó pa ìgbàgbọ́ mọ́. 3 Ìwọ yóò pa á mọ́ ní àlàáfíà pípéọkàn ẹni tí ó dúró ṣinṣin,nítorí ó gbẹ́kẹ̀lé ọ. 4 Gbẹ́kẹ̀lé OLÚWA títí láé,nítorí OLÚWA, OLÚWA ni àpáta ayérayé náà. 5 Ó sọ àwọn tí ó ń gbé ní òkè di onírẹ̀lẹ̀ó rẹ ìlú agbéraga náà nílẹ̀;ó sọ ọ́ di ilẹ̀ pẹrẹsẹó sì sọ ọ́ sílẹ̀ nínú erùpẹ̀. 6 Ẹsẹ̀ tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀ẹsẹ̀ aninilára n nì,ipasẹ̀ àwọn òtòṣì. 7 Ipa ọ̀nà àwọn olódodo tẹ́jú,ìwọ tó dúró ṣinṣin, ìwọ mú ọ̀nààwọn olódodo ṣe geere. 8 Bẹ́ẹ̀ ni, OLÚWA, rírìn ní ọ̀nà òfin rẹàwa dúró dè ọ́;orúkọ rẹ àti òkìkí rẹàwọn ni ohun tí ọkàn wa ń fẹ́. 9 Ọkàn mi ń pòùngbẹẹ̀ rẹ ní ọ̀gànjọ́ òru;ní òwúrọ̀ ni ẹ̀mí mi ń ṣàfẹ́rí rẹ.Nígbà tí ìdájọ́ rẹ bá sọ̀kalẹ̀ sórí ayéàwọn ènìyàn yóò kọ́ ìṣòdodo. 10 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a fi oore-ọ̀fẹ́ hàn sí àwọn ìkàwọn kò kọ́ láti sọ òdodo;kódà ní ilẹ̀ àwọn tí ó dúró ṣinṣin wọ́ntẹ̀síwájú láti máa ṣe ibiwọn kò sì ka ọláńlá OLÚWA sí. 11 OLÚWA, ti gbé ọwọ́ rẹ̀ sókèṣùgbọ́n àwọn kò rí i.Jẹ́ kí wọ́n rí ìtara rẹ fún àwọn ènìyàn rẹkí ojú kí ó tì wọ́n;jẹ́ kí iná tí a fi pamọ́ fún àwọnọ̀tá rẹ jó wọn run. 12 OLÚWA, ìwọ fi àlàáfíà lélẹ̀ fún wa;ohun gbogbo tí a ti ṣe yọrí ìwọ nió ṣe é fún wa. 13 OLÚWA Ọlọ́run wa, àwọn olúwa mìírànlẹ́yìn rẹ ti jẹ ọba lé wa lórí,ṣùgbọ́n orúkọ rẹ nìkan ni àwa fi ọ̀wọ̀ fún. 14 Wọ́n ti kú báyìí, wọn ò sí láààyè mọ́;gbogbo ẹ̀mí tí ó ti kọjá lọ wọ̀nyí kò le dìde mọ́.Ìwọ jẹ́ wọ́n ní ìyà o sì sọ wọ́n di asán,ìwọ pa gbogbo ìrántí wọn rẹ́ pátápátá. 15 Ìwọ ti mú orílẹ̀-èdè gbòòrò, OLÚWA;ìwọ ti mú orílẹ̀-èdè bí sí i.Ìwọ ti gba ògo fún ara rẹ;ìwọ ti sún gbogbo àwọn ààlà ilẹ̀ sẹ́yìn. 16 OLÚWA, wọ́n wá sọ́dọ̀ rẹ nínú ìpọ́njú wọn;nígbà tí ìbáwí rẹ wà lára wọn,wọ́n gbàdúrà kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́. 17 Gẹ́gẹ́ bí obìnrin tí ó lóyún tí ó sì fẹ́rẹ̀ bímọtí í rúnra tí ó sì ń sọkún nínú ìrora rẹ̀,bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni àwa rí níwájú rẹ OLÚWA. 18 Àwa wà nínú oyún, a wà nínú ìrora,ṣùgbọ́n, afẹ́fẹ́ ni a bí lọ́mọ.Àwa kò mú ìgbàlà wá sí ilẹ̀ ayé;àwa kọ́ ni a bí àwọn ènìyàn tí ó wà láyé. 19 Ṣùgbọ́n àwọn òkú yín yóò wà láààyèara wọn yóò dìde.Ìwọ tí o wà nínú erùpẹ̀,dìde nílẹ̀ kí o sì ké igbe ayọ̀.Ìrì rẹ dàbí ìrì òwúrọ̀,ayé yóò bí àwọn òkú rẹ̀ lọ́mọ. 20 Ẹ lọ, ẹ̀yin ènìyàn mi, ẹ wọ ìyẹ̀wù yín lọkí ẹ sì ti àwọn ìlẹ̀kùn lẹ́yìn yín,ẹ fi ara yín pamọ́ fún ìgbà díẹ̀títí tí ìbínú rẹ̀ yóò fi rékọjá. 21 Kíyèsi i, OLÚWA ń jáde bọ̀ láti ibùgbé rẹ̀láti jẹ àwọn ènìyàn ilẹ̀ ayé ní ìyà fún ẹ̀ṣẹ̀ wọn.Ayé yóò sì sọ àwọn ẹ̀jẹ̀ tí a ta sí orí rẹ̀;kì yóò sì fi àwọn tí a ti pa pamọ́ mọ́.

In Other Versions

Isaiah 26 in the ANGEFD

Isaiah 26 in the ANTPNG2D

Isaiah 26 in the AS21

Isaiah 26 in the BAGH

Isaiah 26 in the BBPNG

Isaiah 26 in the BBT1E

Isaiah 26 in the BDS

Isaiah 26 in the BEV

Isaiah 26 in the BHAD

Isaiah 26 in the BIB

Isaiah 26 in the BLPT

Isaiah 26 in the BNT

Isaiah 26 in the BNTABOOT

Isaiah 26 in the BNTLV

Isaiah 26 in the BOATCB

Isaiah 26 in the BOATCB2

Isaiah 26 in the BOBCV

Isaiah 26 in the BOCNT

Isaiah 26 in the BOECS

Isaiah 26 in the BOGWICC

Isaiah 26 in the BOHCB

Isaiah 26 in the BOHCV

Isaiah 26 in the BOHLNT

Isaiah 26 in the BOHNTLTAL

Isaiah 26 in the BOICB

Isaiah 26 in the BOILNTAP

Isaiah 26 in the BOITCV

Isaiah 26 in the BOKCV

Isaiah 26 in the BOKCV2

Isaiah 26 in the BOKHWOG

Isaiah 26 in the BOKSSV

Isaiah 26 in the BOLCB

Isaiah 26 in the BOLCB2

Isaiah 26 in the BOMCV

Isaiah 26 in the BONAV

Isaiah 26 in the BONCB

Isaiah 26 in the BONLT

Isaiah 26 in the BONUT2

Isaiah 26 in the BOPLNT

Isaiah 26 in the BOSCB

Isaiah 26 in the BOSNC

Isaiah 26 in the BOTLNT

Isaiah 26 in the BOVCB

Isaiah 26 in the BPBB

Isaiah 26 in the BPH

Isaiah 26 in the BSB

Isaiah 26 in the CCB

Isaiah 26 in the CUV

Isaiah 26 in the CUVS

Isaiah 26 in the DBT

Isaiah 26 in the DGDNT

Isaiah 26 in the DHNT

Isaiah 26 in the DNT

Isaiah 26 in the ELBE

Isaiah 26 in the EMTV

Isaiah 26 in the ESV

Isaiah 26 in the FBV

Isaiah 26 in the FEB

Isaiah 26 in the GGMNT

Isaiah 26 in the GNT

Isaiah 26 in the HARY

Isaiah 26 in the HNT

Isaiah 26 in the IRVA

Isaiah 26 in the IRVB

Isaiah 26 in the IRVG

Isaiah 26 in the IRVH

Isaiah 26 in the IRVK

Isaiah 26 in the IRVM

Isaiah 26 in the IRVM2

Isaiah 26 in the IRVO

Isaiah 26 in the IRVP

Isaiah 26 in the IRVT

Isaiah 26 in the IRVT2

Isaiah 26 in the IRVU

Isaiah 26 in the ISVN

Isaiah 26 in the JSNT

Isaiah 26 in the KAPI

Isaiah 26 in the KBT1ETNIK

Isaiah 26 in the KBV

Isaiah 26 in the KJV

Isaiah 26 in the KNFD

Isaiah 26 in the LBA

Isaiah 26 in the LBLA

Isaiah 26 in the LNT

Isaiah 26 in the LSV

Isaiah 26 in the MAAL

Isaiah 26 in the MBV

Isaiah 26 in the MBV2

Isaiah 26 in the MHNT

Isaiah 26 in the MKNFD

Isaiah 26 in the MNG

Isaiah 26 in the MNT

Isaiah 26 in the MNT2

Isaiah 26 in the MRS1T

Isaiah 26 in the NAA

Isaiah 26 in the NASB

Isaiah 26 in the NBLA

Isaiah 26 in the NBS

Isaiah 26 in the NBVTP

Isaiah 26 in the NET2

Isaiah 26 in the NIV11

Isaiah 26 in the NNT

Isaiah 26 in the NNT2

Isaiah 26 in the NNT3

Isaiah 26 in the PDDPT

Isaiah 26 in the PFNT

Isaiah 26 in the RMNT

Isaiah 26 in the SBIAS

Isaiah 26 in the SBIBS

Isaiah 26 in the SBIBS2

Isaiah 26 in the SBICS

Isaiah 26 in the SBIDS

Isaiah 26 in the SBIGS

Isaiah 26 in the SBIHS

Isaiah 26 in the SBIIS

Isaiah 26 in the SBIIS2

Isaiah 26 in the SBIIS3

Isaiah 26 in the SBIKS

Isaiah 26 in the SBIKS2

Isaiah 26 in the SBIMS

Isaiah 26 in the SBIOS

Isaiah 26 in the SBIPS

Isaiah 26 in the SBISS

Isaiah 26 in the SBITS

Isaiah 26 in the SBITS2

Isaiah 26 in the SBITS3

Isaiah 26 in the SBITS4

Isaiah 26 in the SBIUS

Isaiah 26 in the SBIVS

Isaiah 26 in the SBT

Isaiah 26 in the SBT1E

Isaiah 26 in the SCHL

Isaiah 26 in the SNT

Isaiah 26 in the SUSU

Isaiah 26 in the SUSU2

Isaiah 26 in the SYNO

Isaiah 26 in the TBIAOTANT

Isaiah 26 in the TBT1E

Isaiah 26 in the TBT1E2

Isaiah 26 in the TFTIP

Isaiah 26 in the TFTU

Isaiah 26 in the TGNTATF3T

Isaiah 26 in the THAI

Isaiah 26 in the TNFD

Isaiah 26 in the TNT

Isaiah 26 in the TNTIK

Isaiah 26 in the TNTIL

Isaiah 26 in the TNTIN

Isaiah 26 in the TNTIP

Isaiah 26 in the TNTIZ

Isaiah 26 in the TOMA

Isaiah 26 in the TTENT

Isaiah 26 in the UBG

Isaiah 26 in the UGV

Isaiah 26 in the UGV2

Isaiah 26 in the UGV3

Isaiah 26 in the VBL

Isaiah 26 in the VDCC

Isaiah 26 in the YALU

Isaiah 26 in the YAPE

Isaiah 26 in the YBVTP

Isaiah 26 in the ZBP