Jeremiah 20 (BOYCB)
1 Ní ìgbà tí àlùfáà Paṣuri ọmọkùnrin Immeri olórí àwọn ìjòyè tẹmpili OLÚWA gbọ́ tí Jeremiah ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ nǹkan wọ̀nyí. 2 Ó mú kí wọ́n lù wòlíì Jeremiah, kí wọ́n sì fi sínú túbú tí ó wà ní òkè ẹnu-ọ̀nà ti Benjamini ní tẹmpili OLÚWA. 3 Ní ọjọ́ kejì tí Paṣuri tú u sílẹ̀ nínú túbú, Jeremiah sì sọ fún un wí pé, “Orúkọ OLÚWA fun ọ kì í ṣe Paṣuri bí kò ṣe ìpayà. 4 Nítorí èyí ni ohun tí OLÚWA sọ. Èmi yóò mú ọ di ẹ̀rùjẹ̀jẹ̀ sí ara rẹ àti sí gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ rẹ. Ní ojú ara rẹ, ìwọ yóò sì rí tí wọ́n ṣubú nípa idà ọ̀tá wọn. Èmi yóò fi gbogbo àwọn ọ̀tá Juda lé ọba Babeli lọ́wọ́, òun yóò sì kó wọn lọ sí Babeli tàbí kí ó pa wọ́n. 5 Èmi yóò jọ̀wọ́ gbogbo ọrọ̀ inú ìlú yìí fún ọ̀tá wọn. Gbogbo ìní wọ́n gbogbo ọlá ọba Juda. Wọn yóò sì ru ìkógun lọ sí Babeli. 6 Àti ìwọ Paṣuri, gbogbo ènìyàn inú ilé rẹ yóò sì lọ ṣe àtìpó ní Babeli. Níbẹ̀ ni ìwọ yóò sì kú sí, tí wọn yóò sì sin ọ́ síbẹ̀, ìwọ àti gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ rẹ tí ìwọ ti sọ àsọtẹ́lẹ̀ irọ́ fún.” 7 OLÚWA, o tàn mí jẹ́,o sì ṣẹ́gun.Mo di ẹni ẹ̀gàn ní gbogbo ọjọ́,gbogbo ènìyàn fi mí ṣẹlẹ́yà. 8 Nígbàkígbà tí mo bá sọ̀rọ̀, èmi sì kígbe sítaèmi á sọ nípa ipá àti ìparun.Nítorí náà, ọ̀rọ̀ OLÚWA ti mú àbùkùàti ẹ̀gàn bá mi ni gbogbo ìgbà. 9 Ṣùgbọ́n bí mo bá sọ pé, “Èmi kì yóò dárúkọ rẹtàbí sọ nípa orúkọ rẹ̀ mọ́,ọ̀rọ̀ rẹ̀ ń bẹ bi iná tí ń jó nínú minínú egungun mi,agara dá mi ní inú minítòótọ́ èmi kò lè ṣe é. 10 Mo gbọ́ sísọ ọ̀rọ̀ kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́,ìbẹ̀rù ni ibi gbogbo.Fi í sùn! Jẹ́ kí a fi sùn!Gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ mi ń dúrókí èmi ṣubú, wọ́n sì ń sọ pé,bóyá yóò jẹ́ di títàn,nígbà náà ni àwa yóò borí rẹ̀,àwa yóò sì gba ẹ̀san wa lára rẹ̀.” 11 Ṣùgbọ́n OLÚWA ń bẹ pẹ̀lú mi gẹ́gẹ́ bí akọni ẹlẹ́rù.Nítorí náà, àwọn tí ó ń lépa mi yóò kọsẹ̀,wọn kì yóò sì borí.Wọn yóò kùnà, wọn yóò sì gba ìtìjú púpọ̀.Àbùkù wọn kì yóò sì di ohun ìgbàgbé. 12 OLÚWA àwọn ọmọ-ogun, ìwọ tí ó ń dán olódodo wòtí o sì ń ṣe àyẹ̀wò ọkàn àti ẹ̀mí fínní fínní,jẹ́ kí èmi kí ó rí ìgbẹ̀san rẹ lórí wọn,nítorí ìwọ ni mo gbé ara mi lé. 13 Kọrin sí OLÚWA!Fi ìyìn fún OLÚWA!Ó gba ẹ̀mí àwọn aláìnílọ́wọ́ àwọn ẹni búburú. 14 Ègbé ni fún ọjọ́ tí a bí mi!Kí ọjọ́ tí ìyá mi bí mi má ṣe di ti ìbùkún. 15 Ègbé ni fún ọkùnrin tí ó mú ìròyìn wá fún baba mi,tí ó mú kí ó yọ̀, tí ó sì sọ wí pé,“A bí ọmọ kan fún ọ—ọmọkùnrin!” 16 Kí ọkùnrin náà dàbí ìlútí OLÚWA gbàkóso lọ́wọ́ rẹ̀ láìkáàánúKí o sì gbọ́ ariwo ọ̀fọ̀ ní àárọ̀,ariwo ogun ní ọ̀sán. 17 Nítorí kò pa mí nínú,kí ìyá mi sì dàbí títóbi ibojì mi,kí ikùn rẹ̀ sì di títí láé. 18 Èéṣe tí mo jáde nínú ikùn,láti rí wàhálà àti ọ̀fọ̀àti láti parí ayé mi nínú ìtìjú?
In Other Versions
Jeremiah 20 in the ANGEFD
Jeremiah 20 in the ANTPNG2D
Jeremiah 20 in the AS21
Jeremiah 20 in the BAGH
Jeremiah 20 in the BBPNG
Jeremiah 20 in the BBT1E
Jeremiah 20 in the BDS
Jeremiah 20 in the BEV
Jeremiah 20 in the BHAD
Jeremiah 20 in the BIB
Jeremiah 20 in the BLPT
Jeremiah 20 in the BNT
Jeremiah 20 in the BNTABOOT
Jeremiah 20 in the BNTLV
Jeremiah 20 in the BOATCB
Jeremiah 20 in the BOATCB2
Jeremiah 20 in the BOBCV
Jeremiah 20 in the BOCNT
Jeremiah 20 in the BOECS
Jeremiah 20 in the BOGWICC
Jeremiah 20 in the BOHCB
Jeremiah 20 in the BOHCV
Jeremiah 20 in the BOHLNT
Jeremiah 20 in the BOHNTLTAL
Jeremiah 20 in the BOICB
Jeremiah 20 in the BOILNTAP
Jeremiah 20 in the BOITCV
Jeremiah 20 in the BOKCV
Jeremiah 20 in the BOKCV2
Jeremiah 20 in the BOKHWOG
Jeremiah 20 in the BOKSSV
Jeremiah 20 in the BOLCB
Jeremiah 20 in the BOLCB2
Jeremiah 20 in the BOMCV
Jeremiah 20 in the BONAV
Jeremiah 20 in the BONCB
Jeremiah 20 in the BONLT
Jeremiah 20 in the BONUT2
Jeremiah 20 in the BOPLNT
Jeremiah 20 in the BOSCB
Jeremiah 20 in the BOSNC
Jeremiah 20 in the BOTLNT
Jeremiah 20 in the BOVCB
Jeremiah 20 in the BPBB
Jeremiah 20 in the BPH
Jeremiah 20 in the BSB
Jeremiah 20 in the CCB
Jeremiah 20 in the CUV
Jeremiah 20 in the CUVS
Jeremiah 20 in the DBT
Jeremiah 20 in the DGDNT
Jeremiah 20 in the DHNT
Jeremiah 20 in the DNT
Jeremiah 20 in the ELBE
Jeremiah 20 in the EMTV
Jeremiah 20 in the ESV
Jeremiah 20 in the FBV
Jeremiah 20 in the FEB
Jeremiah 20 in the GGMNT
Jeremiah 20 in the GNT
Jeremiah 20 in the HARY
Jeremiah 20 in the HNT
Jeremiah 20 in the IRVA
Jeremiah 20 in the IRVB
Jeremiah 20 in the IRVG
Jeremiah 20 in the IRVH
Jeremiah 20 in the IRVK
Jeremiah 20 in the IRVM
Jeremiah 20 in the IRVM2
Jeremiah 20 in the IRVO
Jeremiah 20 in the IRVP
Jeremiah 20 in the IRVT
Jeremiah 20 in the IRVT2
Jeremiah 20 in the IRVU
Jeremiah 20 in the ISVN
Jeremiah 20 in the JSNT
Jeremiah 20 in the KAPI
Jeremiah 20 in the KBT1ETNIK
Jeremiah 20 in the KBV
Jeremiah 20 in the KJV
Jeremiah 20 in the KNFD
Jeremiah 20 in the LBA
Jeremiah 20 in the LBLA
Jeremiah 20 in the LNT
Jeremiah 20 in the LSV
Jeremiah 20 in the MAAL
Jeremiah 20 in the MBV
Jeremiah 20 in the MBV2
Jeremiah 20 in the MHNT
Jeremiah 20 in the MKNFD
Jeremiah 20 in the MNG
Jeremiah 20 in the MNT
Jeremiah 20 in the MNT2
Jeremiah 20 in the MRS1T
Jeremiah 20 in the NAA
Jeremiah 20 in the NASB
Jeremiah 20 in the NBLA
Jeremiah 20 in the NBS
Jeremiah 20 in the NBVTP
Jeremiah 20 in the NET2
Jeremiah 20 in the NIV11
Jeremiah 20 in the NNT
Jeremiah 20 in the NNT2
Jeremiah 20 in the NNT3
Jeremiah 20 in the PDDPT
Jeremiah 20 in the PFNT
Jeremiah 20 in the RMNT
Jeremiah 20 in the SBIAS
Jeremiah 20 in the SBIBS
Jeremiah 20 in the SBIBS2
Jeremiah 20 in the SBICS
Jeremiah 20 in the SBIDS
Jeremiah 20 in the SBIGS
Jeremiah 20 in the SBIHS
Jeremiah 20 in the SBIIS
Jeremiah 20 in the SBIIS2
Jeremiah 20 in the SBIIS3
Jeremiah 20 in the SBIKS
Jeremiah 20 in the SBIKS2
Jeremiah 20 in the SBIMS
Jeremiah 20 in the SBIOS
Jeremiah 20 in the SBIPS
Jeremiah 20 in the SBISS
Jeremiah 20 in the SBITS
Jeremiah 20 in the SBITS2
Jeremiah 20 in the SBITS3
Jeremiah 20 in the SBITS4
Jeremiah 20 in the SBIUS
Jeremiah 20 in the SBIVS
Jeremiah 20 in the SBT
Jeremiah 20 in the SBT1E
Jeremiah 20 in the SCHL
Jeremiah 20 in the SNT
Jeremiah 20 in the SUSU
Jeremiah 20 in the SUSU2
Jeremiah 20 in the SYNO
Jeremiah 20 in the TBIAOTANT
Jeremiah 20 in the TBT1E
Jeremiah 20 in the TBT1E2
Jeremiah 20 in the TFTIP
Jeremiah 20 in the TFTU
Jeremiah 20 in the TGNTATF3T
Jeremiah 20 in the THAI
Jeremiah 20 in the TNFD
Jeremiah 20 in the TNT
Jeremiah 20 in the TNTIK
Jeremiah 20 in the TNTIL
Jeremiah 20 in the TNTIN
Jeremiah 20 in the TNTIP
Jeremiah 20 in the TNTIZ
Jeremiah 20 in the TOMA
Jeremiah 20 in the TTENT
Jeremiah 20 in the UBG
Jeremiah 20 in the UGV
Jeremiah 20 in the UGV2
Jeremiah 20 in the UGV3
Jeremiah 20 in the VBL
Jeremiah 20 in the VDCC
Jeremiah 20 in the YALU
Jeremiah 20 in the YAPE
Jeremiah 20 in the YBVTP
Jeremiah 20 in the ZBP