Job 22 (BOYCB)
1 Ìgbà náà ni Elifasi, ará Temani, dáhùn wí pé, 2 “Ènìyàn lè è ṣe rere fún Ọlọ́run?Bí ọlọ́gbọ́n ti í ṣe rere fún ara rẹ̀? 3 Ohun ayọ̀ ha ni fún Olódùmarè pé olódodo ni ìwọ?Tàbí èrè kí ni fún un ti ìwọ mú ọ̀nà rẹ̀ pé? 4 “Yóò ha bá ọ wí bí, nítorí ìbẹ̀rùỌlọ́run rẹ? Yóò ha bá ọ lọ sínú ìdájọ́ bí? 5 Ìwà búburú rẹ kò ha tóbi,àti ẹ̀ṣẹ̀ rẹ láìníye? 6 Nítòótọ́ ìwọ béèrè fún ààbò ni ọwọ́ arákùnrin rẹ láìnídìí,ìwọ sì tú oníhòhò ní aṣọ wọn. 7 Ìwọ kò fi omi fún aláàárẹ̀ mu,ìwọ sì háwọ́ oúnjẹ fún ẹni tí ebi ń pa. 8 Bí ó ṣe ti alágbára nì, òun ni ó ní ilẹ̀,ọlọ́lá sì tẹ̀dó sínú rẹ̀. 9 Ìwọ ti rán àwọn opó padà lọ ní ọwọ́ òfo,apá àwọn ọmọ aláìní baba ti di ṣiṣẹ́. 10 Nítorí náà ni ìdẹ̀kùn ṣe yí ọ káàkiri,àti ìbẹ̀rù òjijì ń yọ ọ́ lẹ́nu. 11 Èéṣe tí òkùnkùn fi pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ tí ìwọ kò fi lè ríran.Èéṣe tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ omi sì bò ọ́ mọ́lẹ̀. 12 “Ọlọ́run kò ha jẹ́ ẹni gíga ọ̀run?Sá wo orí àwọn ìràwọ̀ bí wọ́n ti ga tó! 13 Ìwọ sì wí pé, Ọlọ́run ti ṣe mọ̀?Òun ha lè ṣe ìdájọ́ láti inú òkùnkùn wá bí? 14 Ǹjẹ́ àwọsánmọ̀ tí ó nípọn jẹ ìbora fún un,tí kò fi lè ríran; ó sì ń rìn nínú àyíká ọ̀run. 15 Ǹjẹ́ ìwọ fẹ́ rin ipa ọ̀nà ìgbàanì tí àwọnènìyàn búburú tí rìn? 16 A ké wọn lulẹ̀ kúrò nínú ayé láìpé ọjọ́ wọn,ìpìlẹ̀ wọn ti da bí odò ṣíṣàn. 17 Àwọn ẹni tí ó wí fún Ọlọ́run pé, ‘Lọ kúrò lọ́dọ̀ wa!Kí ni Olódùmarè yóò ṣe fún wọn?’ 18 Síbẹ̀ ó fi ohun rere kún ilé wọn!Ṣùgbọ́n ìmọ̀ ènìyàn búburú jìnnà sí mi! 19 Àwọn olódodo rí ìparun wọn, wọ́n sì yọ̀,àwọn aláìlẹ́ṣẹ̀ sì fi wọ́n rẹ́rìn-ín ẹlẹ́yà pé, 20 ‘Lóòtítọ́ àwọn ọ̀tá wa ni a ké kúrò,iná yóò sì jó oró wọn run.’ 21 “Fa ara rẹ súnmọ́ Ọlọ́run, ìwọ ó sì rí àlàáfíà;nípa èyí ni rere yóò wá bá ọ. 22 Èmi bẹ̀ ọ́, gba òfin láti ẹnu rẹ̀ wá,kí o sì to ọ̀rọ̀ rẹ̀ sí àyà rẹ. 23 Bí ìwọ bá yípadà sọ́dọ̀ Olódùmarè, a sì gbé ọ ró.Bí ìwọ bá sì mú ẹ̀ṣẹ̀ jìnnà réré kúrò nínú àgọ́ rẹ, 24 tí ìwọ bá tẹ́ wúrà dáradára sílẹ̀,lórí erùpẹ̀ àti wúrà Ofiri lábẹ́ òkúta odò, 25 nígbà náà ní Olódùmarè yóò jẹ́ wúrà rẹ,àní yóò sì jẹ́ fàdákà fún ọ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀. 26 Lóòtítọ́ nígbà náà ní ìwọ ó ní inú dídùn nínú Olódùmarè,ìwọ ó sì gbé ojú rẹ sókè sọ́dọ̀ Ọlọ́run. 27 Bí ìwọ bá gbàdúrà rẹ sọ́dọ̀ rẹ̀, yóò sì gbọ́ tìrẹ,ìwọ ó sì san ẹ̀jẹ́ rẹ. 28 Ìwọ ó sì gbìmọ̀ ohun kan pẹ̀lú, yóò sì fi ìdí múlẹ̀ fún ọ;ìmọ́lẹ̀ yóò sì mọ́ sípa ọ̀nà rẹ. 29 Nígbà tí ipa ọ̀nà rẹ bá lọ sísàlẹ̀,nígbà náà ni ìwọ o wí pé, ‘Ìgbésókè ń bẹ!’Ọlọ́run yóò sì gba onírẹ̀lẹ̀ là! 30 Yóò gba ẹni tí kì í ṣe aláìjẹ̀bi là,a ó sì gbà á nípa mímọ́ ọwọ́ rẹ̀.”
In Other Versions
Job 22 in the ANGEFD
Job 22 in the ANTPNG2D
Job 22 in the AS21
Job 22 in the BAGH
Job 22 in the BBPNG
Job 22 in the BBT1E
Job 22 in the BDS
Job 22 in the BEV
Job 22 in the BHAD
Job 22 in the BIB
Job 22 in the BLPT
Job 22 in the BNT
Job 22 in the BNTABOOT
Job 22 in the BNTLV
Job 22 in the BOATCB
Job 22 in the BOATCB2
Job 22 in the BOBCV
Job 22 in the BOCNT
Job 22 in the BOECS
Job 22 in the BOGWICC
Job 22 in the BOHCB
Job 22 in the BOHCV
Job 22 in the BOHLNT
Job 22 in the BOHNTLTAL
Job 22 in the BOICB
Job 22 in the BOILNTAP
Job 22 in the BOITCV
Job 22 in the BOKCV
Job 22 in the BOKCV2
Job 22 in the BOKHWOG
Job 22 in the BOKSSV
Job 22 in the BOLCB
Job 22 in the BOLCB2
Job 22 in the BOMCV
Job 22 in the BONAV
Job 22 in the BONCB
Job 22 in the BONLT
Job 22 in the BONUT2
Job 22 in the BOPLNT
Job 22 in the BOSCB
Job 22 in the BOSNC
Job 22 in the BOTLNT
Job 22 in the BOVCB
Job 22 in the BPBB
Job 22 in the BPH
Job 22 in the BSB
Job 22 in the CCB
Job 22 in the CUV
Job 22 in the CUVS
Job 22 in the DBT
Job 22 in the DGDNT
Job 22 in the DHNT
Job 22 in the DNT
Job 22 in the ELBE
Job 22 in the EMTV
Job 22 in the ESV
Job 22 in the FBV
Job 22 in the FEB
Job 22 in the GGMNT
Job 22 in the GNT
Job 22 in the HARY
Job 22 in the HNT
Job 22 in the IRVA
Job 22 in the IRVB
Job 22 in the IRVG
Job 22 in the IRVH
Job 22 in the IRVK
Job 22 in the IRVM
Job 22 in the IRVM2
Job 22 in the IRVO
Job 22 in the IRVP
Job 22 in the IRVT
Job 22 in the IRVT2
Job 22 in the IRVU
Job 22 in the ISVN
Job 22 in the JSNT
Job 22 in the KAPI
Job 22 in the KBT1ETNIK
Job 22 in the KBV
Job 22 in the KJV
Job 22 in the KNFD
Job 22 in the LBA
Job 22 in the LBLA
Job 22 in the LNT
Job 22 in the LSV
Job 22 in the MAAL
Job 22 in the MBV
Job 22 in the MBV2
Job 22 in the MHNT
Job 22 in the MKNFD
Job 22 in the MNG
Job 22 in the MNT
Job 22 in the MNT2
Job 22 in the MRS1T
Job 22 in the NAA
Job 22 in the NASB
Job 22 in the NBLA
Job 22 in the NBS
Job 22 in the NBVTP
Job 22 in the NET2
Job 22 in the NIV11
Job 22 in the NNT
Job 22 in the NNT2
Job 22 in the NNT3
Job 22 in the PDDPT
Job 22 in the PFNT
Job 22 in the RMNT
Job 22 in the SBIAS
Job 22 in the SBIBS
Job 22 in the SBIBS2
Job 22 in the SBICS
Job 22 in the SBIDS
Job 22 in the SBIGS
Job 22 in the SBIHS
Job 22 in the SBIIS
Job 22 in the SBIIS2
Job 22 in the SBIIS3
Job 22 in the SBIKS
Job 22 in the SBIKS2
Job 22 in the SBIMS
Job 22 in the SBIOS
Job 22 in the SBIPS
Job 22 in the SBISS
Job 22 in the SBITS
Job 22 in the SBITS2
Job 22 in the SBITS3
Job 22 in the SBITS4
Job 22 in the SBIUS
Job 22 in the SBIVS
Job 22 in the SBT
Job 22 in the SBT1E
Job 22 in the SCHL
Job 22 in the SNT
Job 22 in the SUSU
Job 22 in the SUSU2
Job 22 in the SYNO
Job 22 in the TBIAOTANT
Job 22 in the TBT1E
Job 22 in the TBT1E2
Job 22 in the TFTIP
Job 22 in the TFTU
Job 22 in the TGNTATF3T
Job 22 in the THAI
Job 22 in the TNFD
Job 22 in the TNT
Job 22 in the TNTIK
Job 22 in the TNTIL
Job 22 in the TNTIN
Job 22 in the TNTIP
Job 22 in the TNTIZ
Job 22 in the TOMA
Job 22 in the TTENT
Job 22 in the UBG
Job 22 in the UGV
Job 22 in the UGV2
Job 22 in the UGV3
Job 22 in the VBL
Job 22 in the VDCC
Job 22 in the YALU
Job 22 in the YAPE
Job 22 in the YBVTP
Job 22 in the ZBP