Job 30 (BOYCB)
1 “Ṣùgbọ́n nísinsin yìí,àwọn tí mo gbà ní àbúrò ń fi mí ṣe ẹlẹ́yàbaba ẹni tí èmi kẹ́gànláti tò pẹ̀lú àwọn ajá nínú agbo ẹran mi. 2 Kí ni ìwúlò agbára ọwọ́ wọn sí mi,níwọ̀n ìgbà tí agbára wọn ti fi wọ́n sílẹ̀? 3 Wọ́n rù nítorí àìní àti ìyànwọ́n ń rìn káàkiri ní ilẹ̀ gbígbẹní ibi ìkọ̀sílẹ̀ ní òru. 4 Àwọn ẹni tí ń já ewé iyọ̀ ní ẹ̀bá igbó;gbogbo igikígi ni oúnjẹ jíjẹ wọn. 5 A lé wọn kúrò láàrín ènìyàn,àwọn ènìyàn sì pariwo lé wọn lórí bí ẹní pariwo lé olè lórí. 6 A mú wọn gbe inú pàlàpálá òkúta àfonífojì,nínú ihò ilẹ̀ àti ti òkúta. 7 Wọ́n ń dún ní àárín igbówọ́n kó ara wọn jọ pọ̀ ní abẹ́ ẹ̀gún neteli. 8 Àwọn ọmọ ẹni tí òye kò yé,àní àwọn ọmọ lásán, a sì lé wọn jáde kúrò ní orí ilẹ̀. 9 “Ǹjẹ́ nísinsin yìí, àwọn ọmọ wọn ń fi mí ṣe ẹlẹ́yà nínú orin;àní èmi di ẹni ìṣọ̀rọ̀ sí láàrín wọn. 10 Wọ́n kórìíra mi; wọ́n sá kúrò jìnnà sí mi,wọn kò sì bìkítà láti tutọ́ sí mi lójú. 11 Nítorí Ọlọ́run ti tú okùn ìyè mi, ó sì pọ́n mi lójú;àwọn pẹ̀lú sì dẹ ìdẹ̀kùn níwájú mi. 12 Àwọn ènìyàn lásán dìde ní apá ọ̀tún mi;wọ́n tì ẹsẹ̀ mi kúrò,wọ́n sì la ipa ọ̀nà ìparun sílẹ̀ dè mí. 13 Wọ́n da ipa ọ̀nà mi rú;wọ́n sì sọ ìparun mi di púpọ̀,àwọn tí kò ní olùrànlọ́wọ́. 14 Wọ́n ya sí mi bí i omi tí ó ya gbuuru;ní ariwo ńlá ni wọ́n rọ́ wá. 15 Ẹ̀rù ńlá bà mí;wọ́n lépa ọkàn mi bí ẹ̀fúùfù,àlàáfíà mi sì kọjá lọ bí àwọ̀ sánmọ̀. 16 “Àti nísinsin yìí, ayé mi n yòrò lọ díẹ̀díẹ̀;ọjọ́ ìpọ́njú mi dì mímú. 17 Òru gún mi nínú egungun mi,èyí tí ó bù mí jẹ kò sì sinmi. 18 Nípa agbára ńlá rẹ̀ Ọlọ́run wà bí aṣọ ìbora fún mi,ó sì lẹ̀ mọ́ mi ní ara yíká bí aṣọ ìlekè mi. 19 Ọlọ́run ti mú mi lọ sínú ẹrẹ̀,èmi sì dàbí eruku àti eérú. 20 “Èmi ké pè ọ́ ìwọ Ọlọ́run, ṣùgbọ́n ìwọ kò dá mi lóhùn;èmi dìde dúró ìwọ sì wò mí lásán. 21 Ìwọ padà di ẹni ìkà sí mi;ọwọ́ agbára rẹ ni ìwọ fi dè mí ní ọ̀nà. 22 Ìwọ gbé mi sókè sí inú ẹ̀fúùfù, ìwọ mú mi fò lọ,bẹ́ẹ̀ ni ìwọ sì sọ mí di asán pátápátá. 23 Èmi sá à mọ̀ pé ìwọ yóò mú mi lọ sínú ikú,sí ilé ìpéjọ tí a yàn fún gbogbo alààyè. 24 “Bí ó ti wù kí ó rí, ẹnìkan kí yóò ha nawọ́ rẹ̀ nígbà ìṣubú rẹ̀,tàbí kì yóò ké nínú ìparun rẹ̀. 25 Èmi kò ha sọkún bí fún ẹni tí ó wà nínú ìṣòro?Ọkàn mi kò ha bàjẹ́ fún tálákà bí? 26 Nígbà tí mo fojú ṣọ́nà fún àlàáfíà, ibi sì dé;nígbà tí mo dúró de ìmọ́lẹ̀, òkùnkùn sì dé. 27 Ikùn mí n ru kò sì sinmi,ọjọ́ ìpọ́njú ti dé bá mi. 28 Èmí ń rìn kiri nínú ọ̀fọ̀, ṣùgbọ́n kì í ṣe nínú oòrùn;èmi dìde dúró ní àwùjọ mo sì kígbe fún ìrànlọ́wọ́. 29 Èmi ti di arákùnrin ìkookò,èmi di ẹgbẹ́ àwọn ògòǹgò. 30 Àwọ̀ mi di dúdú ní ara mi;egungun mi sì jórun fún ooru. 31 Ohun èlò orin mi pẹ̀lú sì di ti ọ̀fọ̀,àti ìpè orin mi sì di ohùn àwọn tí ń sọkún.
In Other Versions
Job 30 in the ANGEFD
Job 30 in the ANTPNG2D
Job 30 in the AS21
Job 30 in the BAGH
Job 30 in the BBPNG
Job 30 in the BBT1E
Job 30 in the BDS
Job 30 in the BEV
Job 30 in the BHAD
Job 30 in the BIB
Job 30 in the BLPT
Job 30 in the BNT
Job 30 in the BNTABOOT
Job 30 in the BNTLV
Job 30 in the BOATCB
Job 30 in the BOATCB2
Job 30 in the BOBCV
Job 30 in the BOCNT
Job 30 in the BOECS
Job 30 in the BOGWICC
Job 30 in the BOHCB
Job 30 in the BOHCV
Job 30 in the BOHLNT
Job 30 in the BOHNTLTAL
Job 30 in the BOICB
Job 30 in the BOILNTAP
Job 30 in the BOITCV
Job 30 in the BOKCV
Job 30 in the BOKCV2
Job 30 in the BOKHWOG
Job 30 in the BOKSSV
Job 30 in the BOLCB
Job 30 in the BOLCB2
Job 30 in the BOMCV
Job 30 in the BONAV
Job 30 in the BONCB
Job 30 in the BONLT
Job 30 in the BONUT2
Job 30 in the BOPLNT
Job 30 in the BOSCB
Job 30 in the BOSNC
Job 30 in the BOTLNT
Job 30 in the BOVCB
Job 30 in the BPBB
Job 30 in the BPH
Job 30 in the BSB
Job 30 in the CCB
Job 30 in the CUV
Job 30 in the CUVS
Job 30 in the DBT
Job 30 in the DGDNT
Job 30 in the DHNT
Job 30 in the DNT
Job 30 in the ELBE
Job 30 in the EMTV
Job 30 in the ESV
Job 30 in the FBV
Job 30 in the FEB
Job 30 in the GGMNT
Job 30 in the GNT
Job 30 in the HARY
Job 30 in the HNT
Job 30 in the IRVA
Job 30 in the IRVB
Job 30 in the IRVG
Job 30 in the IRVH
Job 30 in the IRVK
Job 30 in the IRVM
Job 30 in the IRVM2
Job 30 in the IRVO
Job 30 in the IRVP
Job 30 in the IRVT
Job 30 in the IRVT2
Job 30 in the IRVU
Job 30 in the ISVN
Job 30 in the JSNT
Job 30 in the KAPI
Job 30 in the KBT1ETNIK
Job 30 in the KBV
Job 30 in the KJV
Job 30 in the KNFD
Job 30 in the LBA
Job 30 in the LBLA
Job 30 in the LNT
Job 30 in the LSV
Job 30 in the MAAL
Job 30 in the MBV
Job 30 in the MBV2
Job 30 in the MHNT
Job 30 in the MKNFD
Job 30 in the MNG
Job 30 in the MNT
Job 30 in the MNT2
Job 30 in the MRS1T
Job 30 in the NAA
Job 30 in the NASB
Job 30 in the NBLA
Job 30 in the NBS
Job 30 in the NBVTP
Job 30 in the NET2
Job 30 in the NIV11
Job 30 in the NNT
Job 30 in the NNT2
Job 30 in the NNT3
Job 30 in the PDDPT
Job 30 in the PFNT
Job 30 in the RMNT
Job 30 in the SBIAS
Job 30 in the SBIBS
Job 30 in the SBIBS2
Job 30 in the SBICS
Job 30 in the SBIDS
Job 30 in the SBIGS
Job 30 in the SBIHS
Job 30 in the SBIIS
Job 30 in the SBIIS2
Job 30 in the SBIIS3
Job 30 in the SBIKS
Job 30 in the SBIKS2
Job 30 in the SBIMS
Job 30 in the SBIOS
Job 30 in the SBIPS
Job 30 in the SBISS
Job 30 in the SBITS
Job 30 in the SBITS2
Job 30 in the SBITS3
Job 30 in the SBITS4
Job 30 in the SBIUS
Job 30 in the SBIVS
Job 30 in the SBT
Job 30 in the SBT1E
Job 30 in the SCHL
Job 30 in the SNT
Job 30 in the SUSU
Job 30 in the SUSU2
Job 30 in the SYNO
Job 30 in the TBIAOTANT
Job 30 in the TBT1E
Job 30 in the TBT1E2
Job 30 in the TFTIP
Job 30 in the TFTU
Job 30 in the TGNTATF3T
Job 30 in the THAI
Job 30 in the TNFD
Job 30 in the TNT
Job 30 in the TNTIK
Job 30 in the TNTIL
Job 30 in the TNTIN
Job 30 in the TNTIP
Job 30 in the TNTIZ
Job 30 in the TOMA
Job 30 in the TTENT
Job 30 in the UBG
Job 30 in the UGV
Job 30 in the UGV2
Job 30 in the UGV3
Job 30 in the VBL
Job 30 in the VDCC
Job 30 in the YALU
Job 30 in the YAPE
Job 30 in the YBVTP
Job 30 in the ZBP