Job 38 (BOYCB)
1 Nígbà náà ní OLÚWA dá Jobu lóhùn láti inú ìjì àjàyíká wá, ó sì wí pé, 2 “Ta ni èyí tí ń fi ọ̀rọ̀ àìlóyeláti fi ṣókùnkùn bo ìmọ̀ mi? 3 Di ẹ̀gbẹ́ ara rẹ ní àmùrè bí ọkùnrin nísinsin yìí,nítorí pé èmi yóò béèrè lọ́wọ́ rẹkí o sì dá mi lóhùn. 4 “Níbo ni ìwọ wà nígbà tí mo fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀?Wí bí ìwọ bá mòye. 5 Ta ni ó fi ìwọ̀n rẹ lélẹ̀, dájú bí ìwọ bá mọ̀ ọ́n?Tàbí ta ni ó ta okùn wíwọ̀n sórí rẹ? 6 Lórí ibo ni a gbé kan ìpìlẹ̀ rẹ̀ mọ́,tàbí ta ni ó fi òkúta igun rẹ̀ lélẹ̀, 7 nígbà náà àwọn ìràwọ̀ òwúrọ̀ jùmọ̀ kọrin pọ̀,tí gbogbo àwọn ọmọ Ọlọ́run hó ìhó ayọ̀? 8 “Tàbí ta ni ó fi ìlẹ̀kùn sé omi òkun mọ́,nígbà tí ó ya padà bí ẹni pé ó ti inú jáde wá. 9 Nígbà tí mo fi àwọsánmọ̀ ṣe aṣọ rẹ̀,tí mo sì fi òkùnkùn biribiri ṣe ọ̀já ìgbà inú rẹ̀. 10 Nígbà tí mo ti pàṣẹ ìpinnu mi fún un,tí mo sì ṣe bèbè àti ìlẹ̀kùn. 11 Tí mo sì wí pé níhìn-ín ni ìwọ ó dé, kí o má sì rékọjá,níhìn-ín sì ni ìgbéraga rẹ yóò gbé dúró mọ? 12 “Ìwọ pàṣẹ fún òwúrọ̀ láti ìgbà ọjọ́ rẹ̀ wá,ìwọ sì mú ìlà-oòrùn mọ ipò rẹ̀, 13 í ó lè di òpin ilẹ̀ ayé mú,ki a lè gbọ́n àwọn ènìyàn búburú kúrò nínú rẹ̀? 14 Kí ó yí padà bí amọ̀ fún èdìdì amọ̀,kí gbogbo rẹ̀ kí ó sì fi ara rẹ̀ hàn bí ẹni pé nínú aṣọ ìgúnwà. 15 A sì fa ìmọ́lẹ̀ wọn sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ ènìyàn búburú,apá gíga ni a sì ṣẹ́. 16 “Ìwọ ha wọ inú ìsun òkun lọ rí bí?Ìwọ sì rìn lórí ìsàlẹ̀ ibú ńlá? 17 A ha ṣílẹ̀kùn ikú sílẹ̀ fún ọ rí bí,ìwọ sì rí ìlẹ̀kùn òjìji òkú? 18 Ìwọ mòye ìbú ayé bí?Sọ bí ìwọ bá mọ gbogbo èyí. 19 “Ọ̀nà wo ni ìmọ́lẹ̀ ń gbé?Bí ó ṣe ti òkùnkùn, níbo ni ipò rẹ̀, 20 tí ìwọ í fi mú un lọ sí ibi àlá rẹ̀,tí ìwọ ó sì le mọ ipa ọ̀nà lọ sínú ilé rẹ̀? 21 Ìwọ mọ èyí, nítorí nígbà náà ni a bí ọ?Iye ọjọ́ rẹ sì pọ̀. 22 “Ìwọ ha wọ inú ìṣúra ìdì òjò lọ rí bí,ìwọ sì rí ilé ìṣúra yìnyín rí, 23 tí mo ti fi pamọ́ de ìgbà ìyọnu,dé ọjọ́ ogun àti ìjà? 24 Ọ̀nà wo ni ó lọ sí ibi tí ìmọ́lẹ̀ fi ń la,tí afẹ́fẹ́ ìlà-oòrùn ń tàn káàkiri lórí ilẹ̀ ayé? 25 Ta ni ó la ipadò fún ẹ̀kún omi,àti ọ̀nà fún mọ̀nàmọ́ná àrá, 26 láti mú u rọ̀jò sórí ayé níbi tí ènìyàn kò sí,ní aginjù níbi tí ènìyàn kò sí; 27 láti mú ilẹ̀ tútù, ijù àti aláìroláti mú àṣẹ̀ṣẹ̀yọ ewéko rú jáde? 28 Òjò ha ní baba bí?Tàbí ta ni o bí ìkún ìṣe ìrì? 29 Láti inú ta ni ìdì omi ti jáde wá?Ta ni ó bí ìrì dídì ọ̀run? 30 Nígbà tí omi di líle bí òkúta,nígbà tí ojú ibú ńlá sì dìpọ̀. 31 “Ìwọ ha le fi ọ̀já de àwọn ìràwọ̀ Pleiadesi dáradára?Tàbí ìwọ le tún di ìràwọ̀ Orioni? 32 Ìwọ le mú àwọn àmì méjìlá ìràwọ̀ Masaroti jáde wá nígbà àkókò wọn?Tàbí ìwọ le ṣe amọ̀nà Beari pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀? 33 Ǹjẹ́ ìwọ mọ ìlànà ọ̀run?Ìwọ le fi ìjọba Ọlọ́run lélẹ̀ lórí ayé? 34 “Ìwọ le gbé ohùn rẹ sókè dé àwọsánmọ̀kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ omi kí ó lè bò ọ́? 35 Ìwọ le rán mọ̀nàmọ́ná kí wọn kí ó le lọ,ní ọ̀nà wọn kí wọn kí ó sì wí fún wọn pé, ‘Àwa nìyí’? 36 Ta ni ó fi ọgbọ́n pamọ́ sí odò ikùntàbí tí ó fi òye sínú àyà? 37 Ta ni ó fi ọgbọ́n ka iye àwọsánmọ̀?Ta ni ó sì mú ìgò ọ̀run dà jáde, 38 nígbà tí erùpẹ̀ di líle,àti ògúlùtu dìpọ̀? 39 “Ìwọ ha dẹ ọdẹ fún abo kìnnìún bí?Ìwọ ó sì tẹ ebi ẹgbọrọ kìnnìún lọ́rùn, 40 nígbà tí wọ́n bá mọ́lẹ̀ nínú ihòtí wọ́n sì ba ní ibùba de ohun ọdẹ? 41 Ta ni ó ń pèsè ohun jíjẹ fún ẹyẹ ìwò,nígbà tí àwọn ọmọ rẹ ń ké pe Ọlọ́run,tí wọ́n sì máa ń fò kiri nítorí àìní ohun jíjẹ?
In Other Versions
Job 38 in the ANGEFD
Job 38 in the ANTPNG2D
Job 38 in the AS21
Job 38 in the BAGH
Job 38 in the BBPNG
Job 38 in the BBT1E
Job 38 in the BDS
Job 38 in the BEV
Job 38 in the BHAD
Job 38 in the BIB
Job 38 in the BLPT
Job 38 in the BNT
Job 38 in the BNTABOOT
Job 38 in the BNTLV
Job 38 in the BOATCB
Job 38 in the BOATCB2
Job 38 in the BOBCV
Job 38 in the BOCNT
Job 38 in the BOECS
Job 38 in the BOGWICC
Job 38 in the BOHCB
Job 38 in the BOHCV
Job 38 in the BOHLNT
Job 38 in the BOHNTLTAL
Job 38 in the BOICB
Job 38 in the BOILNTAP
Job 38 in the BOITCV
Job 38 in the BOKCV
Job 38 in the BOKCV2
Job 38 in the BOKHWOG
Job 38 in the BOKSSV
Job 38 in the BOLCB
Job 38 in the BOLCB2
Job 38 in the BOMCV
Job 38 in the BONAV
Job 38 in the BONCB
Job 38 in the BONLT
Job 38 in the BONUT2
Job 38 in the BOPLNT
Job 38 in the BOSCB
Job 38 in the BOSNC
Job 38 in the BOTLNT
Job 38 in the BOVCB
Job 38 in the BPBB
Job 38 in the BPH
Job 38 in the BSB
Job 38 in the CCB
Job 38 in the CUV
Job 38 in the CUVS
Job 38 in the DBT
Job 38 in the DGDNT
Job 38 in the DHNT
Job 38 in the DNT
Job 38 in the ELBE
Job 38 in the EMTV
Job 38 in the ESV
Job 38 in the FBV
Job 38 in the FEB
Job 38 in the GGMNT
Job 38 in the GNT
Job 38 in the HARY
Job 38 in the HNT
Job 38 in the IRVA
Job 38 in the IRVB
Job 38 in the IRVG
Job 38 in the IRVH
Job 38 in the IRVK
Job 38 in the IRVM
Job 38 in the IRVM2
Job 38 in the IRVO
Job 38 in the IRVP
Job 38 in the IRVT
Job 38 in the IRVT2
Job 38 in the IRVU
Job 38 in the ISVN
Job 38 in the JSNT
Job 38 in the KAPI
Job 38 in the KBT1ETNIK
Job 38 in the KBV
Job 38 in the KJV
Job 38 in the KNFD
Job 38 in the LBA
Job 38 in the LBLA
Job 38 in the LNT
Job 38 in the LSV
Job 38 in the MAAL
Job 38 in the MBV
Job 38 in the MBV2
Job 38 in the MHNT
Job 38 in the MKNFD
Job 38 in the MNG
Job 38 in the MNT
Job 38 in the MNT2
Job 38 in the MRS1T
Job 38 in the NAA
Job 38 in the NASB
Job 38 in the NBLA
Job 38 in the NBS
Job 38 in the NBVTP
Job 38 in the NET2
Job 38 in the NIV11
Job 38 in the NNT
Job 38 in the NNT2
Job 38 in the NNT3
Job 38 in the PDDPT
Job 38 in the PFNT
Job 38 in the RMNT
Job 38 in the SBIAS
Job 38 in the SBIBS
Job 38 in the SBIBS2
Job 38 in the SBICS
Job 38 in the SBIDS
Job 38 in the SBIGS
Job 38 in the SBIHS
Job 38 in the SBIIS
Job 38 in the SBIIS2
Job 38 in the SBIIS3
Job 38 in the SBIKS
Job 38 in the SBIKS2
Job 38 in the SBIMS
Job 38 in the SBIOS
Job 38 in the SBIPS
Job 38 in the SBISS
Job 38 in the SBITS
Job 38 in the SBITS2
Job 38 in the SBITS3
Job 38 in the SBITS4
Job 38 in the SBIUS
Job 38 in the SBIVS
Job 38 in the SBT
Job 38 in the SBT1E
Job 38 in the SCHL
Job 38 in the SNT
Job 38 in the SUSU
Job 38 in the SUSU2
Job 38 in the SYNO
Job 38 in the TBIAOTANT
Job 38 in the TBT1E
Job 38 in the TBT1E2
Job 38 in the TFTIP
Job 38 in the TFTU
Job 38 in the TGNTATF3T
Job 38 in the THAI
Job 38 in the TNFD
Job 38 in the TNT
Job 38 in the TNTIK
Job 38 in the TNTIL
Job 38 in the TNTIN
Job 38 in the TNTIP
Job 38 in the TNTIZ
Job 38 in the TOMA
Job 38 in the TTENT
Job 38 in the UBG
Job 38 in the UGV
Job 38 in the UGV2
Job 38 in the UGV3
Job 38 in the VBL
Job 38 in the VDCC
Job 38 in the YALU
Job 38 in the YAPE
Job 38 in the YBVTP
Job 38 in the ZBP