Psalms 44 (BOYCB)
undefined Fún adarí orin. Ti àwọn ọmọ Kora. Maskili. 1 À ti fi etí wa gbọ́, Ọlọ́run;àwọn baba wa tí sọ fún waohun tí ìwọ ṣe ní ọjọ́ wọn,ní ọjọ́ pípẹ́ sẹ́yìn. 2 Ìwọ fi ọwọ́ rẹ lé orílẹ̀-èdè jáde,Ìwọ sì gbin àwọn baba wa;ìwọ run àwọn ènìyàn náàÌwọ sì mú àwọn baba wa gbilẹ̀. 3 Kì í ṣe nípa idà wọn ni wọ́n gba ilẹ̀ náà,bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe apá wọn ní ó gbà wọ́n bí kò ṣe;ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ àti, apá rẹ;àti ìmọ́lẹ̀ ojú rẹ̀, nítorí ìwọ fẹ́ wọn. 4 Ìwọ ni ọba àti Ọlọ́run mi,ẹni tí ó pàṣẹ ìṣẹ́gun fún Jakọbu. 5 Nípasẹ̀ rẹ ni àwa ó bi àwọn ọ̀tá wa ṣubú;nípasẹ̀ orúkọ rẹ ni àwa ó tẹ àwọn ọ̀tá tí ó dìde sí wa mọ́lẹ̀, 6 èmi kì yóò gbẹ́kẹ̀lé ọrun mi,idà mi kì yóò mú ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá wá, 7 ṣùgbọ́n ìwọ fún wa ní ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá wa,ìwọ sì ti dójúti àwọn tí ó kórìíra wa. 8 Nínú Ọlọ́run àwa ń ṣògo ní gbogbo ọjọ́,àwa ó sì yin orúkọ rẹ títí láé. Sela. 9 Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, ìwọ ti kọ̀ wá, ìwọ sì ti dójútì wá,Ìwọ kò sì bá àwọn ọmọ-ogun wa jáde mọ́. 10 Ìwọ ti bá wa jà,ìwọ sì ti ṣẹ́gun wa níwájú àwọn ọ̀tá wa,àwọn ọ̀tá wa ti gba ilẹ̀ wa,wọ́n sì fi ipá gba oko wa. 11 Ìwọ fi wá fún jíjẹ bí ẹran àgùntàn,Ìwọ sì ti tú wa ká sí àárín àwọn kèfèrí. 12 Ìwọ ta àwọn ènìyàn rẹ fún owó kékeré,Ìwọ kò sì jẹ èrè kankan lórí iye tí ìwọ tà wọ́n. 13 Ìwọ sọ wá di ẹni ẹ̀sín ní ọ̀dọ̀ àwọn aládùúgbò wa,ẹlẹ́yà àti ẹni àbùkù sí àwọn tí ó yí wa ká. 14 Ìwọ ti sọ wá di ẹni ìfisọ̀rọ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè;àwọn ènìyàn ń mi orí wọn sí wa. 15 Ìdójútì mi ń bẹ pẹ̀lú mi ní gbogbo ọjọ́,ìtìjú sì bojú mi mọ́lẹ̀, 16 nítorí ọ̀rọ̀ ẹ̀gàn àti ọ̀rọ̀ ẹ̀tànní ojú àwọn ọ̀tá àti olùgbẹ̀san. 17 Gbogbo àwọn nǹkan wọ̀nyí ń ṣẹlẹ̀ sí wa,síbẹ̀ àwa kò gbàgbé rẹbẹ́ẹ̀ ni a kò ṣèké sí májẹ̀mú rẹ̀. 18 Ọkàn wa kò padà sẹ́yìn;bẹ́ẹ̀ ni ẹsẹ̀ wa kò yẹ̀ kúrò ní ọ̀nà rẹ̀. 19 Ṣùgbọ́n wọ́n kọlù wá,ìwọ sì sọ wá di ẹran ọdẹ fún àwọn ẹranko búburú,tí wọn sì fi òkùnkùn biribiri bò wá mọ́lẹ̀. 20 Bí àwa bá ti gbàgbé orúkọ Ọlọ́run watàbí tí a na ọwọ́ wa sí ọlọ́run àjèjì. 21 Ǹjẹ́ Ọlọ́run kì yóò rí ìdí rẹ̀,níwọ̀n ìgbà tí ó mọ ohun ìkọ̀kọ̀ inú ọkàn? 22 Síbẹ̀, nítorí rẹ̀ àwa da àyà kọ ikú, ní ojoojúmọ́a ń kà wá sí bí àgùntàn fún pípa. 23 Jí, OLÚWA! Èéṣe tí ìwọ ń sùn?Dìde fúnra rẹ̀! Má ṣe kọ̀ wá sílẹ̀ láéláé. 24 Èéṣe tí ìwọ ń pa ojú rẹ mọ́tí ìwọ sì gbàgbé ìpọ́njú àti ìnira wa? 25 Nítorí a tẹrí ọkàn wa ba sínú eruku;ara wa sì dì mọ́ erùpẹ̀ ilẹ̀. 26 Dìde kí o sì ràn wá lọ́wọ́;rà wá padà nítorí ìfẹ́ rẹ tí ó dúró ṣinṣin.
In Other Versions
Psalms 44 in the ANGEFD
Psalms 44 in the ANTPNG2D
Psalms 44 in the AS21
Psalms 44 in the BAGH
Psalms 44 in the BBPNG
Psalms 44 in the BBT1E
Psalms 44 in the BDS
Psalms 44 in the BEV
Psalms 44 in the BHAD
Psalms 44 in the BIB
Psalms 44 in the BLPT
Psalms 44 in the BNT
Psalms 44 in the BNTABOOT
Psalms 44 in the BNTLV
Psalms 44 in the BOATCB
Psalms 44 in the BOATCB2
Psalms 44 in the BOBCV
Psalms 44 in the BOCNT
Psalms 44 in the BOECS
Psalms 44 in the BOGWICC
Psalms 44 in the BOHCB
Psalms 44 in the BOHCV
Psalms 44 in the BOHLNT
Psalms 44 in the BOHNTLTAL
Psalms 44 in the BOICB
Psalms 44 in the BOILNTAP
Psalms 44 in the BOITCV
Psalms 44 in the BOKCV
Psalms 44 in the BOKCV2
Psalms 44 in the BOKHWOG
Psalms 44 in the BOKSSV
Psalms 44 in the BOLCB
Psalms 44 in the BOLCB2
Psalms 44 in the BOMCV
Psalms 44 in the BONAV
Psalms 44 in the BONCB
Psalms 44 in the BONLT
Psalms 44 in the BONUT2
Psalms 44 in the BOPLNT
Psalms 44 in the BOSCB
Psalms 44 in the BOSNC
Psalms 44 in the BOTLNT
Psalms 44 in the BOVCB
Psalms 44 in the BPBB
Psalms 44 in the BPH
Psalms 44 in the BSB
Psalms 44 in the CCB
Psalms 44 in the CUV
Psalms 44 in the CUVS
Psalms 44 in the DBT
Psalms 44 in the DGDNT
Psalms 44 in the DHNT
Psalms 44 in the DNT
Psalms 44 in the ELBE
Psalms 44 in the EMTV
Psalms 44 in the ESV
Psalms 44 in the FBV
Psalms 44 in the FEB
Psalms 44 in the GGMNT
Psalms 44 in the GNT
Psalms 44 in the HARY
Psalms 44 in the HNT
Psalms 44 in the IRVA
Psalms 44 in the IRVB
Psalms 44 in the IRVG
Psalms 44 in the IRVH
Psalms 44 in the IRVK
Psalms 44 in the IRVM
Psalms 44 in the IRVM2
Psalms 44 in the IRVO
Psalms 44 in the IRVP
Psalms 44 in the IRVT
Psalms 44 in the IRVT2
Psalms 44 in the IRVU
Psalms 44 in the ISVN
Psalms 44 in the JSNT
Psalms 44 in the KAPI
Psalms 44 in the KBT1ETNIK
Psalms 44 in the KBV
Psalms 44 in the KJV
Psalms 44 in the KNFD
Psalms 44 in the LBA
Psalms 44 in the LBLA
Psalms 44 in the LNT
Psalms 44 in the LSV
Psalms 44 in the MAAL
Psalms 44 in the MBV
Psalms 44 in the MBV2
Psalms 44 in the MHNT
Psalms 44 in the MKNFD
Psalms 44 in the MNG
Psalms 44 in the MNT
Psalms 44 in the MNT2
Psalms 44 in the MRS1T
Psalms 44 in the NAA
Psalms 44 in the NASB
Psalms 44 in the NBLA
Psalms 44 in the NBS
Psalms 44 in the NBVTP
Psalms 44 in the NET2
Psalms 44 in the NIV11
Psalms 44 in the NNT
Psalms 44 in the NNT2
Psalms 44 in the NNT3
Psalms 44 in the PDDPT
Psalms 44 in the PFNT
Psalms 44 in the RMNT
Psalms 44 in the SBIAS
Psalms 44 in the SBIBS
Psalms 44 in the SBIBS2
Psalms 44 in the SBICS
Psalms 44 in the SBIDS
Psalms 44 in the SBIGS
Psalms 44 in the SBIHS
Psalms 44 in the SBIIS
Psalms 44 in the SBIIS2
Psalms 44 in the SBIIS3
Psalms 44 in the SBIKS
Psalms 44 in the SBIKS2
Psalms 44 in the SBIMS
Psalms 44 in the SBIOS
Psalms 44 in the SBIPS
Psalms 44 in the SBISS
Psalms 44 in the SBITS
Psalms 44 in the SBITS2
Psalms 44 in the SBITS3
Psalms 44 in the SBITS4
Psalms 44 in the SBIUS
Psalms 44 in the SBIVS
Psalms 44 in the SBT
Psalms 44 in the SBT1E
Psalms 44 in the SCHL
Psalms 44 in the SNT
Psalms 44 in the SUSU
Psalms 44 in the SUSU2
Psalms 44 in the SYNO
Psalms 44 in the TBIAOTANT
Psalms 44 in the TBT1E
Psalms 44 in the TBT1E2
Psalms 44 in the TFTIP
Psalms 44 in the TFTU
Psalms 44 in the TGNTATF3T
Psalms 44 in the THAI
Psalms 44 in the TNFD
Psalms 44 in the TNT
Psalms 44 in the TNTIK
Psalms 44 in the TNTIL
Psalms 44 in the TNTIN
Psalms 44 in the TNTIP
Psalms 44 in the TNTIZ
Psalms 44 in the TOMA
Psalms 44 in the TTENT
Psalms 44 in the UBG
Psalms 44 in the UGV
Psalms 44 in the UGV2
Psalms 44 in the UGV3
Psalms 44 in the VBL
Psalms 44 in the VDCC
Psalms 44 in the YALU
Psalms 44 in the YAPE
Psalms 44 in the YBVTP
Psalms 44 in the ZBP