Revelation 4 (BOYCB)

1 Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí èmi wò, sì kíyèsi i, ìlẹ̀kùn kan ṣí sílẹ̀ ní ọ̀run, ohùn kìn-ín-ní tí mo gbọ́ bí ohùn ìpè tí ń bá mi sọ̀rọ̀, tí ó wí pé, “Gòkè wá níhìn-ín, èmi ó sì fi ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn èyí hàn ọ́.” 2 Lójúkan náà, mo sì wà nínú Ẹ̀mí, sì kíyèsi i, a tẹ́ ìtẹ́ kan ní ọ̀run, ẹnìkan sì jókòó lórí ìtẹ́ náà. 3 Ẹni tí ó sì jókòó náà dàbí òkúta jasperi àti kaneliani lójú. Ni àyíká ìtẹ́ náà ni òṣùmàrè kan wà tí ó dàbí òkúta emeradi lójú. 4 Yí ìtẹ́ náà ká sì ni ìtẹ́ mẹ́rìnlélógún mìíràn; àti lórí àwọn ìtẹ́ náà mo rí àwọn àgbà mẹ́rìnlélógún jókòó, tí a wọ̀ ni aṣọ àlà; adé wúrà sì wà ni orí wọn. 5 Àti láti ibi ìtẹ́ náà ni ìró mọ̀nàmọ́ná àti ohùn àti àrá ti jáde wá: níwájú ìtẹ́ náà ni fìtílà iná méje sì ń tàn, èyí tí ń ṣe Ẹ̀mí méje ti Ọlọ́run. 6 Àti láti ibi ìtẹ́ náà ni òkun bi dígí wà tí o dàbí kristali.Àti yí ìtẹ́ náà ká ní ẹ̀gbẹ́ kọ̀ọ̀kan ni ẹ̀dá alààyè mẹ́rin tí ó kún fún ojú níwájú àti lẹ́yìn wọn. 7 Ẹ̀dá kìn-ín-ní sì dàbí kìnnìún, ẹ̀dá kejì si dàbí ọmọ màlúù, ẹ̀dá kẹta sì ni ojú bi ti ènìyàn, ẹ̀dá kẹrin sì dàbí idì tí ń fò. 8 Àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin náà, tí olúkúlùkù wọn ni ìyẹ́ mẹ́fà, kún fún ojú yíká ara àti nínú; wọn kò sì sinmi lọ́sàn àti lóru, láti wí pé:“ ‘Mímọ́, mímọ́, mímọ́,Olúwa Ọlọ́run Olódùmarè,’tí ó ti wà, tí ó sì ń bẹ, tí ó sì ń bọ̀ wá!” 9 Nígbà tí àwọn ẹ̀dá alààyè náà bá sì fi ògo àti ọlá, àti ọpẹ́ fún ẹni tí o jókòó lórí ìtẹ́, tí o ń bẹ láààyè láé àti láéláé. 10 Àwọn àgbà mẹ́rìnlélógún náà yóò sì wólẹ̀ níwájú ẹni tí o jókòó lórí ìtẹ́, wọn yóò sì tẹríba fún ẹni tí ń bẹ láààyè láé àti láéláé, wọn yóò sì fi adé wọn lélẹ̀ níwájú ìtẹ́ náà, wí pé: 11 “Olúwa àti Ọlọ́run, ìwọ ni o yẹ,láti gba ògo àti ọlá àti agbára,nítorí pé ìwọ ni o dá ohun gbogbo,àti nítorí ìfẹ́ inú rẹ̀ niwọn fi wà tí a sì dá wọn.”

In Other Versions

Revelation 4 in the ANGEFD

Revelation 4 in the ANTPNG2D

Revelation 4 in the AS21

Revelation 4 in the BAGH

Revelation 4 in the BBPNG

Revelation 4 in the BBT1E

Revelation 4 in the BDS

Revelation 4 in the BEV

Revelation 4 in the BHAD

Revelation 4 in the BIB

Revelation 4 in the BLPT

Revelation 4 in the BNT

Revelation 4 in the BNTABOOT

Revelation 4 in the BNTLV

Revelation 4 in the BOATCB

Revelation 4 in the BOATCB2

Revelation 4 in the BOBCV

Revelation 4 in the BOCNT

Revelation 4 in the BOECS

Revelation 4 in the BOGWICC

Revelation 4 in the BOHCB

Revelation 4 in the BOHCV

Revelation 4 in the BOHLNT

Revelation 4 in the BOHNTLTAL

Revelation 4 in the BOICB

Revelation 4 in the BOILNTAP

Revelation 4 in the BOITCV

Revelation 4 in the BOKCV

Revelation 4 in the BOKCV2

Revelation 4 in the BOKHWOG

Revelation 4 in the BOKSSV

Revelation 4 in the BOLCB

Revelation 4 in the BOLCB2

Revelation 4 in the BOMCV

Revelation 4 in the BONAV

Revelation 4 in the BONCB

Revelation 4 in the BONLT

Revelation 4 in the BONUT2

Revelation 4 in the BOPLNT

Revelation 4 in the BOSCB

Revelation 4 in the BOSNC

Revelation 4 in the BOTLNT

Revelation 4 in the BOVCB

Revelation 4 in the BPBB

Revelation 4 in the BPH

Revelation 4 in the BSB

Revelation 4 in the CCB

Revelation 4 in the CUV

Revelation 4 in the CUVS

Revelation 4 in the DBT

Revelation 4 in the DGDNT

Revelation 4 in the DHNT

Revelation 4 in the DNT

Revelation 4 in the ELBE

Revelation 4 in the EMTV

Revelation 4 in the ESV

Revelation 4 in the FBV

Revelation 4 in the FEB

Revelation 4 in the GGMNT

Revelation 4 in the GNT

Revelation 4 in the HARY

Revelation 4 in the HNT

Revelation 4 in the IRVA

Revelation 4 in the IRVB

Revelation 4 in the IRVG

Revelation 4 in the IRVH

Revelation 4 in the IRVK

Revelation 4 in the IRVM

Revelation 4 in the IRVM2

Revelation 4 in the IRVO

Revelation 4 in the IRVP

Revelation 4 in the IRVT

Revelation 4 in the IRVT2

Revelation 4 in the IRVU

Revelation 4 in the ISVN

Revelation 4 in the JSNT

Revelation 4 in the KAPI

Revelation 4 in the KBT1ETNIK

Revelation 4 in the KBV

Revelation 4 in the KJV

Revelation 4 in the KNFD

Revelation 4 in the LBA

Revelation 4 in the LBLA

Revelation 4 in the LNT

Revelation 4 in the LSV

Revelation 4 in the MAAL

Revelation 4 in the MBV

Revelation 4 in the MBV2

Revelation 4 in the MHNT

Revelation 4 in the MKNFD

Revelation 4 in the MNG

Revelation 4 in the MNT

Revelation 4 in the MNT2

Revelation 4 in the MRS1T

Revelation 4 in the NAA

Revelation 4 in the NASB

Revelation 4 in the NBLA

Revelation 4 in the NBS

Revelation 4 in the NBVTP

Revelation 4 in the NET2

Revelation 4 in the NIV11

Revelation 4 in the NNT

Revelation 4 in the NNT2

Revelation 4 in the NNT3

Revelation 4 in the PDDPT

Revelation 4 in the PFNT

Revelation 4 in the RMNT

Revelation 4 in the SBIAS

Revelation 4 in the SBIBS

Revelation 4 in the SBIBS2

Revelation 4 in the SBICS

Revelation 4 in the SBIDS

Revelation 4 in the SBIGS

Revelation 4 in the SBIHS

Revelation 4 in the SBIIS

Revelation 4 in the SBIIS2

Revelation 4 in the SBIIS3

Revelation 4 in the SBIKS

Revelation 4 in the SBIKS2

Revelation 4 in the SBIMS

Revelation 4 in the SBIOS

Revelation 4 in the SBIPS

Revelation 4 in the SBISS

Revelation 4 in the SBITS

Revelation 4 in the SBITS2

Revelation 4 in the SBITS3

Revelation 4 in the SBITS4

Revelation 4 in the SBIUS

Revelation 4 in the SBIVS

Revelation 4 in the SBT

Revelation 4 in the SBT1E

Revelation 4 in the SCHL

Revelation 4 in the SNT

Revelation 4 in the SUSU

Revelation 4 in the SUSU2

Revelation 4 in the SYNO

Revelation 4 in the TBIAOTANT

Revelation 4 in the TBT1E

Revelation 4 in the TBT1E2

Revelation 4 in the TFTIP

Revelation 4 in the TFTU

Revelation 4 in the TGNTATF3T

Revelation 4 in the THAI

Revelation 4 in the TNFD

Revelation 4 in the TNT

Revelation 4 in the TNTIK

Revelation 4 in the TNTIL

Revelation 4 in the TNTIN

Revelation 4 in the TNTIP

Revelation 4 in the TNTIZ

Revelation 4 in the TOMA

Revelation 4 in the TTENT

Revelation 4 in the UBG

Revelation 4 in the UGV

Revelation 4 in the UGV2

Revelation 4 in the UGV3

Revelation 4 in the VBL

Revelation 4 in the VDCC

Revelation 4 in the YALU

Revelation 4 in the YAPE

Revelation 4 in the YBVTP

Revelation 4 in the ZBP