1 Thessalonians 1 (BOYCB)
1 Paulu, Sila àti Timotiu, A kọ ọ́ sí ìjọ tí ó wà ní ìlú Tẹsalonika, àwọn ẹni tí ó jẹ́ ti Ọlọ́run Baba àti ti Olúwa Jesu Kristi: Kí ìbùkún àti àlàáfíà láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba àti Jesu Kristi kí ó jẹ́ tiyín. 2 Gbogbo ìgbà ni a máa ń fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run nítorí yín, a sì ń gbàdúrà fún un yín nígbà gbogbo pẹ̀lú. 3 A ń rántí yin ni àìsimi nígbà gbogbo níwájú Ọlọ́run àti Baba nípa iṣẹ́ ìgbàgbọ́ yín, iṣẹ́ ìfẹ́ yín àti ìdúró ṣinṣin ìrètí yín nínú Jesu Kristi Olúwa wa. 4 Àwa mọ̀ dájúdájú, ẹ̀yin olùfẹ́ wa, wí pé Ọlọ́run ti yàn yín fẹ́ fún ara rẹ̀. 5 Nítorí pé, nígbà tí a mú ìyìnrere tọ̀ yín wà, kò rí bí ọ̀rọ̀ lásán tí kò ní ìtumọ̀ sí i yín, bí kò ṣe pẹ̀lú agbára, pẹ̀lú Ẹ̀mí Mímọ́, pẹ̀lú ìdánilójú tó jinlẹ̀. Bí ẹ̀yin ti mọ irú ènìyàn tí àwa jẹ́ láàrín yín nítorí yín. 6 Tó bẹ́ẹ̀ tí ẹ̀yin pàápàá di aláwòkọ́ṣe wa àti ti Olúwa, ìdí ni pé, ẹ gba ẹ̀rí náà láti ọwọ́ Ẹ̀mí Mímọ́ pẹ̀lú ayọ̀ bí o tilẹ̀ jẹ́ pé, ó mú wàhálà àti ìbànújẹ́ wá fún yín. 7 Tó bẹ́ẹ̀ tí ẹ̀yin pàápàá fi di àpẹẹrẹ fún gbogbo àwọn onígbàgbọ́ tó wà ní agbègbè Makedonia àti Akaia. 8 Ọ̀rọ̀ Olúwa ti gbilẹ̀ níbi gbogbo láti ọ̀dọ̀ yín láti agbègbè Makedonia àti Akaia lọ, ìgbàgbọ́ yín nínú Ọlọ́run tàn káàkiri. Nítorí náà, a kò ni láti ṣẹ̀ṣẹ̀ ń sọ fún wọn nípa rẹ̀. 9 Ṣe ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí i ròyìn fún wa bí ẹ ti gbà wá lálejò. Wọ́n ròyìn fún wa pẹ̀lú pé, ẹ ti yípadà kúrò nínú ìbọ̀rìṣà àti wí pé Ọlọ́run alààyè àti òtítọ́ nìkan ṣoṣo ni ẹ ń sìn, 10 àti láti fi ojú ṣọ́nà fún ìpadàbọ̀ Ọmọ rẹ̀ láti ọ̀run wá, ẹni tí ó jí dìde kúrò nínú òkú, Jesu, ẹni tí ó gbà wá lọ́wọ́ ìbínú tí ń bọ̀.
In Other Versions
1 Thessalonians 1 in the ANGEFD
1 Thessalonians 1 in the ANTPNG2D
1 Thessalonians 1 in the BBPNG
1 Thessalonians 1 in the BBT1E
1 Thessalonians 1 in the BNTABOOT
1 Thessalonians 1 in the BNTLV
1 Thessalonians 1 in the BOATCB
1 Thessalonians 1 in the BOATCB2
1 Thessalonians 1 in the BOBCV
1 Thessalonians 1 in the BOCNT
1 Thessalonians 1 in the BOECS
1 Thessalonians 1 in the BOGWICC
1 Thessalonians 1 in the BOHCB
1 Thessalonians 1 in the BOHCV
1 Thessalonians 1 in the BOHLNT
1 Thessalonians 1 in the BOHNTLTAL
1 Thessalonians 1 in the BOICB
1 Thessalonians 1 in the BOILNTAP
1 Thessalonians 1 in the BOITCV
1 Thessalonians 1 in the BOKCV
1 Thessalonians 1 in the BOKCV2
1 Thessalonians 1 in the BOKHWOG
1 Thessalonians 1 in the BOKSSV
1 Thessalonians 1 in the BOLCB
1 Thessalonians 1 in the BOLCB2
1 Thessalonians 1 in the BOMCV
1 Thessalonians 1 in the BONAV
1 Thessalonians 1 in the BONCB
1 Thessalonians 1 in the BONLT
1 Thessalonians 1 in the BONUT2
1 Thessalonians 1 in the BOPLNT
1 Thessalonians 1 in the BOSCB
1 Thessalonians 1 in the BOSNC
1 Thessalonians 1 in the BOTLNT
1 Thessalonians 1 in the BOVCB
1 Thessalonians 1 in the DGDNT
1 Thessalonians 1 in the GGMNT
1 Thessalonians 1 in the IRVM2
1 Thessalonians 1 in the IRVT2
1 Thessalonians 1 in the KBT1ETNIK
1 Thessalonians 1 in the MKNFD
1 Thessalonians 1 in the MRS1T
1 Thessalonians 1 in the NBVTP
1 Thessalonians 1 in the NIV11
1 Thessalonians 1 in the PDDPT
1 Thessalonians 1 in the SBIAS
1 Thessalonians 1 in the SBIBS
1 Thessalonians 1 in the SBIBS2
1 Thessalonians 1 in the SBICS
1 Thessalonians 1 in the SBIDS
1 Thessalonians 1 in the SBIGS
1 Thessalonians 1 in the SBIHS
1 Thessalonians 1 in the SBIIS
1 Thessalonians 1 in the SBIIS2
1 Thessalonians 1 in the SBIIS3
1 Thessalonians 1 in the SBIKS
1 Thessalonians 1 in the SBIKS2
1 Thessalonians 1 in the SBIMS
1 Thessalonians 1 in the SBIOS
1 Thessalonians 1 in the SBIPS
1 Thessalonians 1 in the SBISS
1 Thessalonians 1 in the SBITS
1 Thessalonians 1 in the SBITS2
1 Thessalonians 1 in the SBITS3
1 Thessalonians 1 in the SBITS4
1 Thessalonians 1 in the SBIUS
1 Thessalonians 1 in the SBIVS
1 Thessalonians 1 in the SBT1E
1 Thessalonians 1 in the SUSU2
1 Thessalonians 1 in the TBIAOTANT
1 Thessalonians 1 in the TBT1E
1 Thessalonians 1 in the TBT1E2
1 Thessalonians 1 in the TFTIP
1 Thessalonians 1 in the TGNTATF3T
1 Thessalonians 1 in the TNTIK
1 Thessalonians 1 in the TNTIL
1 Thessalonians 1 in the TNTIN
1 Thessalonians 1 in the TNTIP
1 Thessalonians 1 in the TNTIZ
1 Thessalonians 1 in the TTENT