2 John 1 (BOYCB)
1 Alàgbà, Sì àyànfẹ́ obìnrin ọlọ́lá àti àwọn ọmọ rẹ̀, àwọn tí mo fẹ́ ní òtítọ́, kì í sì í ṣe èmi nìkan, ṣùgbọ́n gbogbo àwọn tí ó mọ òtítọ́ pẹ̀lú; 2 nítorí òtítọ́ tí ń gbé inú wa, yóò sì bá wa gbé títí: 3 Oore-ọ̀fẹ́, àánú, àti àlàáfíà, láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba, àti láti ọ̀dọ̀ Jesu Kristi, Ọmọ Baba, yóò wà pẹ̀lú wa nínú òtítọ́ àti nínú ìfẹ́. 4 Mo yọ̀ gidigidi pé mo rí nínú àwọn ọmọ rẹ tí ń rìn nínú òtítọ́, gẹ́gẹ́ bí Baba ti pa àṣẹ fún wa. 5 Ǹjẹ́ nísinsin yìí, mo bẹ̀ ọ́, obìnrin ọlọ́lá, kì í ṣe bí ẹni pé èmi ń kọ̀wé òfin tuntun kan sí ọ, bí kò ṣe èyí ti àwa tí ní ní àtètèkọ́ṣe, pé kí àwa fẹ́ràn ara wa. 6 Èyí sì ni ìfẹ́, pé, kí àwa máa rin nípa òfin rẹ̀, èyí ni òfin náà, àní bí ẹ ti gbọ́ ni àtètèkọ́ṣe, pé, kí ẹ̀yin rìn nínú rẹ̀. 7 Nítorí ẹlẹ́tàn púpọ̀ ti jáde wa sínú ayé, àwọn tí kò jẹ́wọ́ pé Jesu Kristi wá nínú ara. Èyí ni ẹlẹ́tàn àti aṣòdì sí Kristi. 8 Ẹ kíyèsára yín, kí ẹ má ba à sọ iṣẹ́ tí ẹ tí ṣe nù, ṣùgbọ́n kí ẹ̀yin lè rí èrè kíkún gbà. 9 Olúkúlùkù ẹni tí ó bá ń rú òfin tí kò si dúró nínú ẹ̀kọ́ Kristi, kò mọ Ọlọ́run. Ẹni tí ó bá dúró nínú ẹ̀kọ́, òun ni ó mọ Baba àti Ọmọ. 10 Bí ẹnikẹ́ni bá tọ̀ yín wá, tí kò sì mu ẹ̀kọ́ yìí wá, ẹ má ṣe gbà á sí ilé, kí ẹ má sì ṣe kí i kú ààbọ̀. 11 Nítorí ẹni tí ó bá kí kú ààbọ̀, ó ní ọwọ́ nínú iṣẹ́ búburú rẹ̀. 12 Bí mo tilẹ̀ ní ohun púpọ̀ láti ṣe alábápín pẹ̀lú yín, síbẹ̀ èmi kò fẹ́ lo ìwé ìkọ̀wé àti jẹ́lú ìkọ̀wé. Ṣùgbọ́n èmi ní ìrètí láti tọ̀ yín wá àti láti bá a yín sọ̀rọ̀ lójúkojú, kí ayọ̀ yín bá à le è kún. 13 Àwọn ọmọ arábìnrin rẹ àyànfẹ́ kí ọ.
In Other Versions
2 John 1 in the ANGEFD
2 John 1 in the ANTPNG2D
2 John 1 in the AS21
2 John 1 in the BAGH
2 John 1 in the BBPNG
2 John 1 in the BBT1E
2 John 1 in the BDS
2 John 1 in the BEV
2 John 1 in the BHAD
2 John 1 in the BIB
2 John 1 in the BLPT
2 John 1 in the BNT
2 John 1 in the BNTABOOT
2 John 1 in the BNTLV
2 John 1 in the BOATCB
2 John 1 in the BOATCB2
2 John 1 in the BOBCV
2 John 1 in the BOCNT
2 John 1 in the BOECS
2 John 1 in the BOGWICC
2 John 1 in the BOHCB
2 John 1 in the BOHCV
2 John 1 in the BOHLNT
2 John 1 in the BOHNTLTAL
2 John 1 in the BOICB
2 John 1 in the BOILNTAP
2 John 1 in the BOITCV
2 John 1 in the BOKCV
2 John 1 in the BOKCV2
2 John 1 in the BOKHWOG
2 John 1 in the BOKSSV
2 John 1 in the BOLCB
2 John 1 in the BOLCB2
2 John 1 in the BOMCV
2 John 1 in the BONAV
2 John 1 in the BONCB
2 John 1 in the BONLT
2 John 1 in the BONUT2
2 John 1 in the BOPLNT
2 John 1 in the BOSCB
2 John 1 in the BOSNC
2 John 1 in the BOTLNT
2 John 1 in the BOVCB
2 John 1 in the BPBB
2 John 1 in the BPH
2 John 1 in the BSB
2 John 1 in the CCB
2 John 1 in the CUV
2 John 1 in the CUVS
2 John 1 in the DBT
2 John 1 in the DGDNT
2 John 1 in the DHNT
2 John 1 in the DNT
2 John 1 in the ELBE
2 John 1 in the EMTV
2 John 1 in the ESV
2 John 1 in the FBV
2 John 1 in the FEB
2 John 1 in the GGMNT
2 John 1 in the GNT
2 John 1 in the HARY
2 John 1 in the HNT
2 John 1 in the IRVA
2 John 1 in the IRVB
2 John 1 in the IRVG
2 John 1 in the IRVH
2 John 1 in the IRVK
2 John 1 in the IRVM
2 John 1 in the IRVM2
2 John 1 in the IRVO
2 John 1 in the IRVP
2 John 1 in the IRVT
2 John 1 in the IRVT2
2 John 1 in the IRVU
2 John 1 in the ISVN
2 John 1 in the JSNT
2 John 1 in the KAPI
2 John 1 in the KBT1ETNIK
2 John 1 in the KBV
2 John 1 in the KJV
2 John 1 in the KNFD
2 John 1 in the LBA
2 John 1 in the LBLA
2 John 1 in the LNT
2 John 1 in the LSV
2 John 1 in the MAAL
2 John 1 in the MBV
2 John 1 in the MBV2
2 John 1 in the MHNT
2 John 1 in the MKNFD
2 John 1 in the MNG
2 John 1 in the MNT
2 John 1 in the MNT2
2 John 1 in the MRS1T
2 John 1 in the NAA
2 John 1 in the NASB
2 John 1 in the NBLA
2 John 1 in the NBS
2 John 1 in the NBVTP
2 John 1 in the NET2
2 John 1 in the NIV11
2 John 1 in the NNT
2 John 1 in the NNT2
2 John 1 in the NNT3
2 John 1 in the PDDPT
2 John 1 in the PFNT
2 John 1 in the RMNT
2 John 1 in the SBIAS
2 John 1 in the SBIBS
2 John 1 in the SBIBS2
2 John 1 in the SBICS
2 John 1 in the SBIDS
2 John 1 in the SBIGS
2 John 1 in the SBIHS
2 John 1 in the SBIIS
2 John 1 in the SBIIS2
2 John 1 in the SBIIS3
2 John 1 in the SBIKS
2 John 1 in the SBIKS2
2 John 1 in the SBIMS
2 John 1 in the SBIOS
2 John 1 in the SBIPS
2 John 1 in the SBISS
2 John 1 in the SBITS
2 John 1 in the SBITS2
2 John 1 in the SBITS3
2 John 1 in the SBITS4
2 John 1 in the SBIUS
2 John 1 in the SBIVS
2 John 1 in the SBT
2 John 1 in the SBT1E
2 John 1 in the SCHL
2 John 1 in the SNT
2 John 1 in the SUSU
2 John 1 in the SUSU2
2 John 1 in the SYNO
2 John 1 in the TBIAOTANT
2 John 1 in the TBT1E
2 John 1 in the TBT1E2
2 John 1 in the TFTIP
2 John 1 in the TFTU
2 John 1 in the TGNTATF3T
2 John 1 in the THAI
2 John 1 in the TNFD
2 John 1 in the TNT
2 John 1 in the TNTIK
2 John 1 in the TNTIL
2 John 1 in the TNTIN
2 John 1 in the TNTIP
2 John 1 in the TNTIZ
2 John 1 in the TOMA
2 John 1 in the TTENT
2 John 1 in the UBG
2 John 1 in the UGV
2 John 1 in the UGV2
2 John 1 in the UGV3
2 John 1 in the VBL
2 John 1 in the VDCC
2 John 1 in the YALU
2 John 1 in the YAPE
2 John 1 in the YBVTP
2 John 1 in the ZBP