Hosea 2 (BOYCB)
1 “Sọ fún àwọn arákùnrin rẹ, ‘Ènìyàn mi,’ kí o sì wí fún àwọn arábìnrin rẹ ‘Àyànfẹ́ mi.’ 2 “Ẹ bá ìyá yín wí, ẹ bá a wí,nítorí pé kì í ṣe ìyàwó mi,Èmi náà kì í sì í ṣe ọkọ rẹ̀.Jẹ́ kí ó yọ àgbèrè rẹ̀ kúrò lójú rẹ̀àti àìṣòótọ́ kúrò ní àyà rẹ̀. 3 Àìṣe bẹ́ẹ̀ èmi yóò tú u sí ìhòhò,Èmi yóò sì gbé e kalẹ̀ bí ọjọ́ tí a bí i.Èmi yóò ṣe ọ́ bí i aṣálẹ̀ ilẹ̀,Èmi yóò sì sọ ọ́ di ìyàngbẹ ilẹ̀Èmi yóò sì fi òǹgbẹ gbẹ ẹ́. 4 Èmi kò ní fi àánú mi hàn sí àwọn ọmọ rẹ̀nítorí ọmọ àgbèrè ni wọ́n jẹ́. 5 Nítorí ìyá wọn ti hùwà àgbèrè,ó sì lóyún wọn nínú ìtìjú.Ó wí pé, ‘Èmi ó tún tọ́ àwọn àyànfẹ́ mi lẹ́yìn,tó ń fún mi ní oúnjẹ àti omi,ní irun àgùntàn mi àti ọ̀gbọ̀ mi,òróró mi àti ohun mímu mi.’ 6 Nítorí náà, èmi ó fi ẹ̀gún dì í lọ́nà,Èmi ó mọ odi yí i ká kí ó má ba à rọ́nà lọ. 7 Yóò sáré lé àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ ṣùgbọ́n kò ní bá wọn;yóò wá wọn ṣùgbọ́n kò ní rí wọn.Nígbà náà ni yóò sọ pé,‘Èmi ó padà sí ọ̀dọ̀ ọkọ mi àkọ́kọ́nítorí pé ó dára fún mi nígbà náà ju ìsinsin yìí lọ.’ 8 Nítorí pé kò tí ì mọ̀ pé èmi niàti ẹni tó fún un ní ọkà,ọtí wáìnì tuntun àti òróróẹni tí ó fún un ní fàdákà àti wúrà lọ́pọ̀lọ́pọ̀, èyí tí wọ́n lò fún Baali. 9 “Nítorí náà, èmi yóò mú ọkà mi kúrò nígbà tó bá pọ́n,èmi yóò sì mú wáìnì mi kúrò ní àsìkò rẹ̀.Èmi yóò sì gba irun àgùntàn àti ọ̀gbọ̀ mi padàti mo ti fi fún un láti bo ìhòhò rẹ̀. 10 Èmi yóò sì fi ìwà ìtìjú rẹ̀ hànlójú àwọn olólùfẹ́ rẹ̀kò sí ẹni tí yóò gbà á sílẹ̀ lọ́wọ́ mi, 11 Èmi yóò mú gbogbo ayọ̀ rẹ̀ wá sí òpin:àjọ̀dún ọdọọdún rẹ̀, oṣù tuntun rẹ̀,ọjọ́ ìsinmi, àti gbogbo àwọn àjọ̀dún tí a yàn. 12 Èmi yóò pa àjàrà àti igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀ run,èyí tí ó pè ní èrè rẹ̀ láti ọ̀dọ̀ àwọn olólùfẹ́ rẹ̀,Èmi yóò sọ wọ́n di igbó,àwọn ẹranko búburú yóò sì jẹ́ wọn run. 13 Èmi yóò bẹ̀ ọjọ́ Baalimu wò ní ara rẹ̀nínú èyí tó ń fi tùràrí jóná fún Baali;tí ó fi òrùka etí àti ohun ọ̀ṣọ́ rẹ̀, ṣe ara rẹ̀ lọ́ṣọ̀ọ́,tó sì tẹ̀lé àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ lọ.Ṣùgbọ́n èmi ni òun gbàgbé,”ni OLÚWA wí. 14 “Nítorí náà, èmi yóò tàn án,Èmi ó sì mú u lọ sí ilẹ̀ aṣálẹ̀,Èmi ó fi pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ bá a sọ̀rọ̀ 15 Níbẹ̀ ni èmi yóò ti dá ọgbà àjàrà rẹ̀ padà fún un,Èmi yóò fi àfonífojì Akori ṣe ìlẹ̀kùn ìrètí fún un.Yóò sì kọrin níbẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìgbà èwe rẹ̀gẹ́gẹ́ bí ìgbà tó kúrò ní Ejibiti. 16 “Yóò sì ṣe ní ọjọ́ náà,ìwọ yóò pè mí ní ‘ọkọ mi’;ìwọ kò sì ní pè mí ní ‘olúwa à mi mọ́,’ni OLÚWA wí. 17 Èmi yóò mú orúkọ, àwọn òrìṣà Baali kúrò lẹ́nu rẹ̀;ìwọ kò sì ní rí orúkọ òrìṣà Baali pè mọ́. 18 Ní ọjọ́ náà, èmi yóò ṣe májẹ̀múfún wọn àti àwọn ẹranko igbó àti ẹyẹ ojú ọ̀run àtiàwọn ẹ̀dá tí ń rìn lórí ilẹ̀.Kí wọn má bà á bẹ̀rù ara wọn mọ́.Ọfà, idà àti ogun jíjà ni èmi ó parun ní ilẹ̀ náàkí gbogbo ènìyàn bá a lè wà ní àìléwu. 19 Èmi yóò fẹ́ ọ fún ara mi títí láé;Èmi ó fẹ́ ọ ní ìwà òdodo àti òtítọ́,ní ìfẹ́ àti àánú. 20 Èmi yóò fẹ́ ọ fún ara mi ní òtítọ́ìwọ yóò sì mọ OLÚWA. 21 “Èmi yóò sì dáhùn ní ọjọ́ náà,”ni OLÚWA wí;“Èmi yóò dá àwọn ọ̀run lóhùnàwọn ọ̀run yóò sì dá ilẹ̀ lóhùn; 22 ilẹ̀ náà yóò sì dá ọkà,wáìnì tuntun àti òróró lóhùnGbogbo wọn ó sì dá Jesreeli lóhùn. 23 Èmi ó sì gbìn ín fún ara mi lórí ilẹ̀ náà,Èmi yóò ṣàánú fún ẹni tí kò tì í ri ‘Àánú gbà.’Èmi yóò sọ fún àwọn tí ‘Kì í ṣe ènìyàn mi pé,’‘Ẹ̀yin ni ènìyàn mi’; àwọn náà yóò sì wí pé, ‘Ìwọ ni Ọlọ́run mi.’ ”
In Other Versions
Hosea 2 in the ANGEFD
Hosea 2 in the ANTPNG2D
Hosea 2 in the AS21
Hosea 2 in the BAGH
Hosea 2 in the BBPNG
Hosea 2 in the BBT1E
Hosea 2 in the BDS
Hosea 2 in the BEV
Hosea 2 in the BHAD
Hosea 2 in the BIB
Hosea 2 in the BLPT
Hosea 2 in the BNT
Hosea 2 in the BNTABOOT
Hosea 2 in the BNTLV
Hosea 2 in the BOATCB
Hosea 2 in the BOATCB2
Hosea 2 in the BOBCV
Hosea 2 in the BOCNT
Hosea 2 in the BOECS
Hosea 2 in the BOGWICC
Hosea 2 in the BOHCB
Hosea 2 in the BOHCV
Hosea 2 in the BOHLNT
Hosea 2 in the BOHNTLTAL
Hosea 2 in the BOICB
Hosea 2 in the BOILNTAP
Hosea 2 in the BOITCV
Hosea 2 in the BOKCV
Hosea 2 in the BOKCV2
Hosea 2 in the BOKHWOG
Hosea 2 in the BOKSSV
Hosea 2 in the BOLCB
Hosea 2 in the BOLCB2
Hosea 2 in the BOMCV
Hosea 2 in the BONAV
Hosea 2 in the BONCB
Hosea 2 in the BONLT
Hosea 2 in the BONUT2
Hosea 2 in the BOPLNT
Hosea 2 in the BOSCB
Hosea 2 in the BOSNC
Hosea 2 in the BOTLNT
Hosea 2 in the BOVCB
Hosea 2 in the BPBB
Hosea 2 in the BPH
Hosea 2 in the BSB
Hosea 2 in the CCB
Hosea 2 in the CUV
Hosea 2 in the CUVS
Hosea 2 in the DBT
Hosea 2 in the DGDNT
Hosea 2 in the DHNT
Hosea 2 in the DNT
Hosea 2 in the ELBE
Hosea 2 in the EMTV
Hosea 2 in the ESV
Hosea 2 in the FBV
Hosea 2 in the FEB
Hosea 2 in the GGMNT
Hosea 2 in the GNT
Hosea 2 in the HARY
Hosea 2 in the HNT
Hosea 2 in the IRVA
Hosea 2 in the IRVB
Hosea 2 in the IRVG
Hosea 2 in the IRVH
Hosea 2 in the IRVK
Hosea 2 in the IRVM
Hosea 2 in the IRVM2
Hosea 2 in the IRVO
Hosea 2 in the IRVP
Hosea 2 in the IRVT
Hosea 2 in the IRVT2
Hosea 2 in the IRVU
Hosea 2 in the ISVN
Hosea 2 in the JSNT
Hosea 2 in the KAPI
Hosea 2 in the KBT1ETNIK
Hosea 2 in the KBV
Hosea 2 in the KJV
Hosea 2 in the KNFD
Hosea 2 in the LBA
Hosea 2 in the LBLA
Hosea 2 in the LNT
Hosea 2 in the LSV
Hosea 2 in the MAAL
Hosea 2 in the MBV
Hosea 2 in the MBV2
Hosea 2 in the MHNT
Hosea 2 in the MKNFD
Hosea 2 in the MNG
Hosea 2 in the MNT
Hosea 2 in the MNT2
Hosea 2 in the MRS1T
Hosea 2 in the NAA
Hosea 2 in the NASB
Hosea 2 in the NBLA
Hosea 2 in the NBS
Hosea 2 in the NBVTP
Hosea 2 in the NET2
Hosea 2 in the NIV11
Hosea 2 in the NNT
Hosea 2 in the NNT2
Hosea 2 in the NNT3
Hosea 2 in the PDDPT
Hosea 2 in the PFNT
Hosea 2 in the RMNT
Hosea 2 in the SBIAS
Hosea 2 in the SBIBS
Hosea 2 in the SBIBS2
Hosea 2 in the SBICS
Hosea 2 in the SBIDS
Hosea 2 in the SBIGS
Hosea 2 in the SBIHS
Hosea 2 in the SBIIS
Hosea 2 in the SBIIS2
Hosea 2 in the SBIIS3
Hosea 2 in the SBIKS
Hosea 2 in the SBIKS2
Hosea 2 in the SBIMS
Hosea 2 in the SBIOS
Hosea 2 in the SBIPS
Hosea 2 in the SBISS
Hosea 2 in the SBITS
Hosea 2 in the SBITS2
Hosea 2 in the SBITS3
Hosea 2 in the SBITS4
Hosea 2 in the SBIUS
Hosea 2 in the SBIVS
Hosea 2 in the SBT
Hosea 2 in the SBT1E
Hosea 2 in the SCHL
Hosea 2 in the SNT
Hosea 2 in the SUSU
Hosea 2 in the SUSU2
Hosea 2 in the SYNO
Hosea 2 in the TBIAOTANT
Hosea 2 in the TBT1E
Hosea 2 in the TBT1E2
Hosea 2 in the TFTIP
Hosea 2 in the TFTU
Hosea 2 in the TGNTATF3T
Hosea 2 in the THAI
Hosea 2 in the TNFD
Hosea 2 in the TNT
Hosea 2 in the TNTIK
Hosea 2 in the TNTIL
Hosea 2 in the TNTIN
Hosea 2 in the TNTIP
Hosea 2 in the TNTIZ
Hosea 2 in the TOMA
Hosea 2 in the TTENT
Hosea 2 in the UBG
Hosea 2 in the UGV
Hosea 2 in the UGV2
Hosea 2 in the UGV3
Hosea 2 in the VBL
Hosea 2 in the VDCC
Hosea 2 in the YALU
Hosea 2 in the YAPE
Hosea 2 in the YBVTP
Hosea 2 in the ZBP