Hosea 7 (BOYCB)
1 nígbà tí èmi ìbá mú Israẹli láradá.Ẹ̀ṣẹ̀ Efraimu ń farahànìwà búburú Samaria sì ń hàn síta.Wọ́n ń ṣe ẹ̀tàn,àwọn olè ń fọ́ ilé;àwọn ọlọ́ṣà ń jalè ní òpópónà; 2 ṣùgbọ́n wọn kò mọ̀ pémo rántí gbogbo ìwà búburú wọn.Ẹ̀ṣẹ̀ wọn gbé wọn mì pátápátá;wọ́n wà níwájú mi nígbà gbogbo. 3 “Wọ́n ń mú inú ọba dùn pẹ̀lú ìwà búburú wọn,àti inú ọmọ-aládé dùn pẹ̀lú irọ́ wọn. 4 Alágbèrè ni gbogbo wọnwọ́n gbóná bí ààrò àkàràtí a dáwọ́ kíkoná dúró,lẹ́yìn ìgbà tí o ti pò ìyẹ̀fun tán, títí ìgbà tí yóò wú. 5 Ní ọjọ́ àjọ̀dún ọba wawáìnì mú ara ọmọ-aládé gbónáó sì darapọ̀ mọ́ àwọn oníyẹ̀yẹ́. 6 Ọkàn wọn ń gbóná bí i ààròwọ́n sì tọ̀ ọ́ lọ pẹ̀lú rìkíṣí,ìbínú wọn pa lọ́lọ́ ní gbogbo òruó sì bú jáde bí ọ̀wọ́-iná ní òwúrọ̀. 7 Gbogbo wọn gbóná bí ààròwọ́n pa gbogbo olórí wọn run,gbogbo ọba wọn si ṣubúkò sì ṣí ẹnìkan nínú wọn tí ó ké pè mí. 8 “Efraimu ti darapọ̀ mọ́ àwọn ènìyàn náà;Efraimu jẹ́ àkàrà tí a kò yípadà. 9 Àwọn àlejò ti jẹ agbára rẹ̀ runṣùgbọ́n kò sì mọ̀.Ewú ti wà ní orí rẹ̀ káàkiribẹ́ẹ̀ ni kò kíyèsi i. 10 Ìgbéraga Israẹli ń jẹ́rìí sí iṣùgbọ́n pẹ̀lú gbogbo èyíkò padà sí ọ̀dọ̀ OLÚWAỌlọ́run, tàbí kí ó wá a. 11 “Efraimu dàbí àdàbàtó rọrùn láti tànjẹ àti aláìgbọ́ntó wá ń pé Ejibiti nísinsin yìító sì tún ń padà lọ si Asiria. 12 Nígbà tí wọ́n bá lọ, èmi ó ta àwọ̀n mi sórí wọn,Èmi ó fà wọ́n lulẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹyẹ ojú ọ̀run.Nígbà tí mo bá gbọ́ pé wọ́n rìn pọ̀,Èmi ó nà wọ́n fún iṣẹ́ búburú ọwọ́ wọn. 13 Ègbé ní fún wọn,nítorí pé wọ́n ti yà kúrò lọ́dọ̀ mi!Ìparun wà lórí wọn,nítorí pé wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi!Èmi fẹ́ láti rà wọ́n padà.Ṣùgbọ́n wọ́n ń parọ́ mọ́ mi. 14 Wọn kò kégbe pè mí láti ọkàn wọn,ṣùgbọ́n wọ́n ń pohùnréré ẹkún lórí ibùsùn wọn.Wọ́n kó ara wọn jọ, nítorí ọkà àti wáìnìṣùgbọ́n wọ́n yípadà kúrò ní ọ̀dọ̀ mi. 15 Mo kọ́ wọn, mo sì fún wọn ní agbára,síbẹ̀ wọ́n tún ń dìtẹ̀ mọ́ mi. 16 Wọn kò padà sí ọ̀dọ̀ Ọ̀gá-ògo;wọ́n dàbí ọfà tí ó ti bàjẹ́.Àwọn aṣíwájú wọn yóò ti ipa idà ṣubúnítorí ìrunú ahọ́n wọn.Torí èyí, wọn ó fi wọ́n ṣeẹlẹ́yà ní ilẹ̀ Ejibiti.
In Other Versions
Hosea 7 in the ANGEFD
Hosea 7 in the ANTPNG2D
Hosea 7 in the AS21
Hosea 7 in the BAGH
Hosea 7 in the BBPNG
Hosea 7 in the BBT1E
Hosea 7 in the BDS
Hosea 7 in the BEV
Hosea 7 in the BHAD
Hosea 7 in the BIB
Hosea 7 in the BLPT
Hosea 7 in the BNT
Hosea 7 in the BNTABOOT
Hosea 7 in the BNTLV
Hosea 7 in the BOATCB
Hosea 7 in the BOATCB2
Hosea 7 in the BOBCV
Hosea 7 in the BOCNT
Hosea 7 in the BOECS
Hosea 7 in the BOGWICC
Hosea 7 in the BOHCB
Hosea 7 in the BOHCV
Hosea 7 in the BOHLNT
Hosea 7 in the BOHNTLTAL
Hosea 7 in the BOICB
Hosea 7 in the BOILNTAP
Hosea 7 in the BOITCV
Hosea 7 in the BOKCV
Hosea 7 in the BOKCV2
Hosea 7 in the BOKHWOG
Hosea 7 in the BOKSSV
Hosea 7 in the BOLCB
Hosea 7 in the BOLCB2
Hosea 7 in the BOMCV
Hosea 7 in the BONAV
Hosea 7 in the BONCB
Hosea 7 in the BONLT
Hosea 7 in the BONUT2
Hosea 7 in the BOPLNT
Hosea 7 in the BOSCB
Hosea 7 in the BOSNC
Hosea 7 in the BOTLNT
Hosea 7 in the BOVCB
Hosea 7 in the BPBB
Hosea 7 in the BPH
Hosea 7 in the BSB
Hosea 7 in the CCB
Hosea 7 in the CUV
Hosea 7 in the CUVS
Hosea 7 in the DBT
Hosea 7 in the DGDNT
Hosea 7 in the DHNT
Hosea 7 in the DNT
Hosea 7 in the ELBE
Hosea 7 in the EMTV
Hosea 7 in the ESV
Hosea 7 in the FBV
Hosea 7 in the FEB
Hosea 7 in the GGMNT
Hosea 7 in the GNT
Hosea 7 in the HARY
Hosea 7 in the HNT
Hosea 7 in the IRVA
Hosea 7 in the IRVB
Hosea 7 in the IRVG
Hosea 7 in the IRVH
Hosea 7 in the IRVK
Hosea 7 in the IRVM
Hosea 7 in the IRVM2
Hosea 7 in the IRVO
Hosea 7 in the IRVP
Hosea 7 in the IRVT
Hosea 7 in the IRVT2
Hosea 7 in the IRVU
Hosea 7 in the ISVN
Hosea 7 in the JSNT
Hosea 7 in the KAPI
Hosea 7 in the KBT1ETNIK
Hosea 7 in the KBV
Hosea 7 in the KJV
Hosea 7 in the KNFD
Hosea 7 in the LBA
Hosea 7 in the LBLA
Hosea 7 in the LNT
Hosea 7 in the LSV
Hosea 7 in the MAAL
Hosea 7 in the MBV
Hosea 7 in the MBV2
Hosea 7 in the MHNT
Hosea 7 in the MKNFD
Hosea 7 in the MNG
Hosea 7 in the MNT
Hosea 7 in the MNT2
Hosea 7 in the MRS1T
Hosea 7 in the NAA
Hosea 7 in the NASB
Hosea 7 in the NBLA
Hosea 7 in the NBS
Hosea 7 in the NBVTP
Hosea 7 in the NET2
Hosea 7 in the NIV11
Hosea 7 in the NNT
Hosea 7 in the NNT2
Hosea 7 in the NNT3
Hosea 7 in the PDDPT
Hosea 7 in the PFNT
Hosea 7 in the RMNT
Hosea 7 in the SBIAS
Hosea 7 in the SBIBS
Hosea 7 in the SBIBS2
Hosea 7 in the SBICS
Hosea 7 in the SBIDS
Hosea 7 in the SBIGS
Hosea 7 in the SBIHS
Hosea 7 in the SBIIS
Hosea 7 in the SBIIS2
Hosea 7 in the SBIIS3
Hosea 7 in the SBIKS
Hosea 7 in the SBIKS2
Hosea 7 in the SBIMS
Hosea 7 in the SBIOS
Hosea 7 in the SBIPS
Hosea 7 in the SBISS
Hosea 7 in the SBITS
Hosea 7 in the SBITS2
Hosea 7 in the SBITS3
Hosea 7 in the SBITS4
Hosea 7 in the SBIUS
Hosea 7 in the SBIVS
Hosea 7 in the SBT
Hosea 7 in the SBT1E
Hosea 7 in the SCHL
Hosea 7 in the SNT
Hosea 7 in the SUSU
Hosea 7 in the SUSU2
Hosea 7 in the SYNO
Hosea 7 in the TBIAOTANT
Hosea 7 in the TBT1E
Hosea 7 in the TBT1E2
Hosea 7 in the TFTIP
Hosea 7 in the TFTU
Hosea 7 in the TGNTATF3T
Hosea 7 in the THAI
Hosea 7 in the TNFD
Hosea 7 in the TNT
Hosea 7 in the TNTIK
Hosea 7 in the TNTIL
Hosea 7 in the TNTIN
Hosea 7 in the TNTIP
Hosea 7 in the TNTIZ
Hosea 7 in the TOMA
Hosea 7 in the TTENT
Hosea 7 in the UBG
Hosea 7 in the UGV
Hosea 7 in the UGV2
Hosea 7 in the UGV3
Hosea 7 in the VBL
Hosea 7 in the VDCC
Hosea 7 in the YALU
Hosea 7 in the YAPE
Hosea 7 in the YBVTP
Hosea 7 in the ZBP