Isaiah 38 (BOYCB)

1 Ní ọjọ́ náà ni Hesekiah ṣe àìsàn dé ojú ikú. Wòlíì Isaiah ọmọ Amosi sì lọ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀, ó sì wí pé, “Ohun tí OLÚWA wí nìyìí: Palẹ̀ ilé è rẹ mọ́, bí ó ti yẹ nítorí pé ìwọ yóò kú; ìwọ kì yóò dìde àìsàn yìí.” 2 Hesekiah yí ojú u rẹ̀ sí ara ògiri, ó sì gba àdúrà sí OLÚWA, 3 “Rántí, Ìwọ OLÚWA, bí mo ti rìn pẹ̀lú òtítọ́ níwájú rẹ, àti bí mo ti fi ọkàn dídúró ṣinṣin ṣe ohun tí ó dára ní ojú ù rẹ.” Bẹ́ẹ̀ ni Hesekiah sì sọkún kíkorò. 4 Lẹ́yìn náà ni ọ̀rọ̀ OLÚWA tọ Isaiah wá pé, 5 “Lọ kí o sì sọ fún Hesekiah pé, ‘Ohun tí OLÚWA wí nìyìí, Ọlọ́run Dafidi baba rẹ sọ pé, Èmi ti gbọ́ àdúrà rẹ mo sì ti rí omijé rẹ, Èmi yóò fi ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dógún kún ọjọ́ ayé rẹ. 6 Èmi yóò sì gba ìwọ àti ìlú yìí sílẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ọba Asiria. Èmi yóò sì dáàbò bo ìlú yìí. 7 “ ‘Èyí yìí ni àmì tí OLÚWA fún ọ láti fihàn wí pé OLÚWA yóò mú ìpinnu rẹ̀ ṣẹ. 8 Èmi yóò mú òjìji oòrùn kí ó padà sẹ́yìn ní ìṣísẹ̀ mẹ́wàá nínú èyí tí ó fi sọ̀kalẹ̀ ní ibi àtẹ̀gùn ti Ahasi.’ ” Bẹ́ẹ̀ ni oòrùn padà sẹ́yìn ní ìṣísẹ̀ mẹ́wàá sí ibi tí ó ti dé tẹ́lẹ̀. 9 Ìwé tí Hesekiah ọba Juda kọ lẹ́yìn àìsàn rẹ̀ nígbà tí ó ti gbádùn tán. 10 Èmi wí pé, “Ní àárín gbùngbùn ọjọ́ ayé mièmi ó ha kọjá lọ ní ibodè ikúkí a sì dùn mí ní àwọn ọdún mi tí ó ṣẹ́kù?” 11 Èmi wí pé, “Èmi kì yóò lè tún rí OLÚWA mọ́,àní OLÚWA, ní ilẹ̀ àwọn alààyè;èmi kì yóò lè síjú wo ọmọ ènìyàn mọ́,tàbí kí n wà pẹ̀lú àwọn tí ó sì ńgbe orílẹ̀ ayé báyìí. 12 Gẹ́gẹ́ bí àgọ́ olùṣọ́-àgùntàn,ilé mi ni a ti wó lulẹ̀ tí a sì gbà kúrò lọ́wọ́ mi.Gẹ́gẹ́ bí ahunṣọ mo ti ká ayé mi nílẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni òun sì ti ké mi kúrò lára àṣà;ọ̀sán àti òru ni ìwọ ṣe òpin mi. 13 Èmi fi sùúrù dúró títí di àfẹ̀mọ́júmọ́,ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí kìnnìún ó ti fọ́ gbogbo egungun mi;ọ̀sán àti òru ni ìwọ fi ṣe òpin mi. 14 Èmi dún gẹ́gẹ́ bí àkọ̀ tàbí alápáǹdẹ̀dẹ̀,èmi káàánú gẹ́gẹ́ bí aṣọ̀fọ̀ àdàbà.Ojú mi rẹ̀wẹ̀sì gẹ́gẹ́ bí mo ti ń wo àwọn ọ̀run.Ìdààmú bá mi, Ìwọ OLÚWA, wá fún ìrànlọ́wọ́ mi!” 15 Ṣùgbọ́n kí ni èmi lè sọ?Òun ti bá mi sọ̀rọ̀ àti pé òuntìkára rẹ̀ ló ti ṣe èyí.Èmi yóò máa rìn ní ìrẹ̀lẹ̀ ní gbogbo ọjọ́ minítorí ìpọ́njú ẹ̀mí mi yìí. 16 OLÚWA, nípa nǹkan báwọ̀nyí ni àwọn ènìyàn ń gbé;àti pé ẹ̀mí mi rí iyè nínú wọn pẹ̀lú.Ìwọ dá ìlera mi padàkí o sì jẹ́ kí n wà láààyè. 17 Nítòótọ́ fún àlàáfíà ara mi ni,ní ti pé mo ní ìkorò ńlá.Nínú ìfẹ́ rẹ ìwọ pa mí mọ́,kúrò nínú ọ̀gbun ìparun;ìwọ sì ti fi gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi sí ẹ̀yìn rẹ. 18 Nítorí pé isà òkú kò le è yìn ọ́,ipò òkú kò le è kọ orin ìyìn rẹ;àwọn tí ó sọ̀kalẹ̀ sínú ọ̀gbunkò lè ní ìrètí fún òtítọ́ rẹ. 19 Alààyè, àwọn alààyè wọ́n ń yìn ọ́,gẹ́gẹ́ bí èmi ti ń ṣe lónìí;àwọn baba sọ fún àwọn ọmọ wọn nípa òtítọ́ rẹ. 20 OLÚWA yóò gbà mí làbẹ́ẹ̀ ni àwa yóò sì kọrin pẹ̀lú ohun èlò olókùnní gbogbo ọjọ́ ayé wanínú tẹmpili ti OLÚWA. 21 Isaiah ti sọ pé, “Pèsè ìṣù ọ̀pọ̀tọ́ (ohun gbígbóná tí a dì mọ́ ojú egbò) kí o sì fi sí ojú oówo náà, òun yóò sì gbádùn.” 22 Hesekiah sì béèrè pé, “Kí ni yóò jẹ́ àmì pé èmi yóò gòkè lọ sí tẹmpili OLÚWA?”

In Other Versions

Isaiah 38 in the ANGEFD

Isaiah 38 in the ANTPNG2D

Isaiah 38 in the AS21

Isaiah 38 in the BAGH

Isaiah 38 in the BBPNG

Isaiah 38 in the BBT1E

Isaiah 38 in the BDS

Isaiah 38 in the BEV

Isaiah 38 in the BHAD

Isaiah 38 in the BIB

Isaiah 38 in the BLPT

Isaiah 38 in the BNT

Isaiah 38 in the BNTABOOT

Isaiah 38 in the BNTLV

Isaiah 38 in the BOATCB

Isaiah 38 in the BOATCB2

Isaiah 38 in the BOBCV

Isaiah 38 in the BOCNT

Isaiah 38 in the BOECS

Isaiah 38 in the BOGWICC

Isaiah 38 in the BOHCB

Isaiah 38 in the BOHCV

Isaiah 38 in the BOHLNT

Isaiah 38 in the BOHNTLTAL

Isaiah 38 in the BOICB

Isaiah 38 in the BOILNTAP

Isaiah 38 in the BOITCV

Isaiah 38 in the BOKCV

Isaiah 38 in the BOKCV2

Isaiah 38 in the BOKHWOG

Isaiah 38 in the BOKSSV

Isaiah 38 in the BOLCB

Isaiah 38 in the BOLCB2

Isaiah 38 in the BOMCV

Isaiah 38 in the BONAV

Isaiah 38 in the BONCB

Isaiah 38 in the BONLT

Isaiah 38 in the BONUT2

Isaiah 38 in the BOPLNT

Isaiah 38 in the BOSCB

Isaiah 38 in the BOSNC

Isaiah 38 in the BOTLNT

Isaiah 38 in the BOVCB

Isaiah 38 in the BPBB

Isaiah 38 in the BPH

Isaiah 38 in the BSB

Isaiah 38 in the CCB

Isaiah 38 in the CUV

Isaiah 38 in the CUVS

Isaiah 38 in the DBT

Isaiah 38 in the DGDNT

Isaiah 38 in the DHNT

Isaiah 38 in the DNT

Isaiah 38 in the ELBE

Isaiah 38 in the EMTV

Isaiah 38 in the ESV

Isaiah 38 in the FBV

Isaiah 38 in the FEB

Isaiah 38 in the GGMNT

Isaiah 38 in the GNT

Isaiah 38 in the HARY

Isaiah 38 in the HNT

Isaiah 38 in the IRVA

Isaiah 38 in the IRVB

Isaiah 38 in the IRVG

Isaiah 38 in the IRVH

Isaiah 38 in the IRVK

Isaiah 38 in the IRVM

Isaiah 38 in the IRVM2

Isaiah 38 in the IRVO

Isaiah 38 in the IRVP

Isaiah 38 in the IRVT

Isaiah 38 in the IRVT2

Isaiah 38 in the IRVU

Isaiah 38 in the ISVN

Isaiah 38 in the JSNT

Isaiah 38 in the KAPI

Isaiah 38 in the KBT1ETNIK

Isaiah 38 in the KBV

Isaiah 38 in the KJV

Isaiah 38 in the KNFD

Isaiah 38 in the LBA

Isaiah 38 in the LBLA

Isaiah 38 in the LNT

Isaiah 38 in the LSV

Isaiah 38 in the MAAL

Isaiah 38 in the MBV

Isaiah 38 in the MBV2

Isaiah 38 in the MHNT

Isaiah 38 in the MKNFD

Isaiah 38 in the MNG

Isaiah 38 in the MNT

Isaiah 38 in the MNT2

Isaiah 38 in the MRS1T

Isaiah 38 in the NAA

Isaiah 38 in the NASB

Isaiah 38 in the NBLA

Isaiah 38 in the NBS

Isaiah 38 in the NBVTP

Isaiah 38 in the NET2

Isaiah 38 in the NIV11

Isaiah 38 in the NNT

Isaiah 38 in the NNT2

Isaiah 38 in the NNT3

Isaiah 38 in the PDDPT

Isaiah 38 in the PFNT

Isaiah 38 in the RMNT

Isaiah 38 in the SBIAS

Isaiah 38 in the SBIBS

Isaiah 38 in the SBIBS2

Isaiah 38 in the SBICS

Isaiah 38 in the SBIDS

Isaiah 38 in the SBIGS

Isaiah 38 in the SBIHS

Isaiah 38 in the SBIIS

Isaiah 38 in the SBIIS2

Isaiah 38 in the SBIIS3

Isaiah 38 in the SBIKS

Isaiah 38 in the SBIKS2

Isaiah 38 in the SBIMS

Isaiah 38 in the SBIOS

Isaiah 38 in the SBIPS

Isaiah 38 in the SBISS

Isaiah 38 in the SBITS

Isaiah 38 in the SBITS2

Isaiah 38 in the SBITS3

Isaiah 38 in the SBITS4

Isaiah 38 in the SBIUS

Isaiah 38 in the SBIVS

Isaiah 38 in the SBT

Isaiah 38 in the SBT1E

Isaiah 38 in the SCHL

Isaiah 38 in the SNT

Isaiah 38 in the SUSU

Isaiah 38 in the SUSU2

Isaiah 38 in the SYNO

Isaiah 38 in the TBIAOTANT

Isaiah 38 in the TBT1E

Isaiah 38 in the TBT1E2

Isaiah 38 in the TFTIP

Isaiah 38 in the TFTU

Isaiah 38 in the TGNTATF3T

Isaiah 38 in the THAI

Isaiah 38 in the TNFD

Isaiah 38 in the TNT

Isaiah 38 in the TNTIK

Isaiah 38 in the TNTIL

Isaiah 38 in the TNTIN

Isaiah 38 in the TNTIP

Isaiah 38 in the TNTIZ

Isaiah 38 in the TOMA

Isaiah 38 in the TTENT

Isaiah 38 in the UBG

Isaiah 38 in the UGV

Isaiah 38 in the UGV2

Isaiah 38 in the UGV3

Isaiah 38 in the VBL

Isaiah 38 in the VDCC

Isaiah 38 in the YALU

Isaiah 38 in the YAPE

Isaiah 38 in the YBVTP

Isaiah 38 in the ZBP