Isaiah 59 (BOYCB)

1 Lódodo ọwọ́ OLÚWA kò kúrú láti gbàlà,tàbí kí etí rẹ̀ wúwo láti gbọ́. 2 Ṣùgbọ́n ẹ̀ṣẹ̀ yín ló ti yà yín kúrò lọ́dọ̀ Ọlọ́run yín;ẹ̀ṣẹ̀ yín ti fi ojú u rẹ̀ pamọ́ fún un yíntó bẹ́ẹ̀ tí òun kò fi le gbọ́. 3 Nítorí ọwọ́ yín di aláìmọ́ fún ẹ̀jẹ̀,àti ìka ọwọ́ yín fún ẹ̀bi.Ètè yín ń pa irọ́ púpọ̀,ahọ́n yín sì ń sọ̀rọ̀ nǹkan ibi. 4 Kò sí ẹni tí ó béèrè fún ìdájọ́ òdodo;kò sí ẹni tí ó ro ẹjọ́ rẹ̀ pẹ̀lú òtítọ́.Wọ́n gbẹ́kẹ̀lé àwíjàre asán àti ọ̀rọ̀ irọ́;wọ́n lóyún ìkà, wọn sì bí wàhálà. 5 Wọn ń pa ẹ̀yin paramọ́lẹ̀wọn sì ń ta owú aláǹtakùn.Ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ ẹyin wọn yóò kú,àti nígbà tí a pa ọ̀kan, paramọ́lẹ̀ ni ó jáde. 6 Òwú wọn kò wúlò fún aṣọ rírán;wọn kò lè fi aṣọ tí wọ́n hun bo ara wọn.Iṣẹ́ wọn jẹ́ ti ibi, ìwà jàǹdùkú sì kún ọwọ́ wọn. 7 Ẹsẹ̀ wọn yára bọ́ sínú ẹ̀ṣẹ̀;wọ́n yára láti ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀.Èrò wọn sì jẹ́ èrò ibi;ìparun àti ìdahoro ni ó wà ní ṣíṣe àmì ọ̀nà wọn. 8 Ọ̀nà àlàáfíà èyí ni wọn kò mọ̀;kò sí òdodo ní ojú ọ̀nà wọnwọ́n ti sọ wọ́n dì ọ̀nà kọ́rọkọ̀rọ,kò sí ẹni tí ó tọ ọ̀nà yìí tí yóò rí àlàáfíà. 9 Nítorí èyí ni ẹ̀tọ́ fi jìnnà sí wa,àti tí òdodo kò fi tẹ̀ wá lọ́wọ́.A ń wá ìmọ́lẹ̀, ṣùgbọ́n gbogbo rẹ̀ jẹ́ òkùnkùn;ìmọ́lẹ̀, ṣùgbọ́n à ń rìn nínú òjìji. 10 Gẹ́gẹ́ bí afọ́jú à ń táràrà lọ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ògirití a ń wá ọ̀nà wa gẹ́gẹ́ bí ènìyàn tí kò ní ojú.Ní ọ̀sán gangan ni à ń kọsẹ̀ bí ẹni pé alẹ́ ni;láàrín alágbára àwa dàbí òkú. 11 Gbogbo wa là ń ké bí i beari;àwa pohùnréré ẹkún bí àdàbà.A ń wá ìdájọ́ òdodo ṣùgbọ́n kò sí; à ń wọ́nà fún ìtúsílẹ̀,ṣùgbọ́n ó jìnnà réré. 12 Nítorí àwọn àṣìṣe wa pọ̀ níwájú rẹ,àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa sì ń jẹ́rìí takò wá.Àwọn àìṣedéédéé wa sì wà pẹ̀lú wa,àwa pẹ̀lú sì mọ àìṣedéédéé wa, 13 ọ̀tẹ̀ àti àrékérekè wa sí OLÚWA,kíkọ ẹ̀yìn wa sí Ọlọ́run,dídá yánpọnyánrin àti ìnilára sílẹ̀,pípààrọ̀ tí ọkàn wa ti gbèrò síta. 14 Nítorí èyí ni a ṣe lé ìdájọ́ òdodo sẹ́yìn,àti ti òdodo dúró lókèèrè;òtítọ́ ti ṣubú ní òpópó ọ̀nà,òdodo kò sì le è wọlé. 15 A kò rí òtítọ́ mọ́,àti ẹni tí ó bá sá fun ibi tì di ìjẹ. OLÚWA wò ó ọkàn rẹ̀ sì bàjẹ́pé kò sí ìdájọ́ òdodo. 16 Òun rí i pé kò sí ẹnìkan,àyà fò ó pé kò sí ẹnìkan láti ṣèrànwọ́;nítorí apá òun tìkára rẹ̀ ló ṣiṣẹ́ ìgbàlà fún ara rẹ̀,àti òdodo òun tìkára rẹ̀ ló gbé e ró. 17 Ó gbé òdodo wọ̀ gẹ́gẹ́ bí ìgbàyà rẹ̀,àti àṣíborí ìgbàlà ní orí rẹ̀;ó gbé ẹ̀wù ẹ̀san wọ̀ó sì yí ara rẹ̀ ní ìtara bí ẹ̀wù. 18 Gẹ́gẹ́ bí ohun tí wọ́n ti ṣe,bẹ́ẹ̀ ni yóò san ánìbínú fún àwọn ọ̀tá rẹ̀àti ẹ̀san fún àwọn ọ̀tá rẹ̀;òun yóò san án fún àwọn erékùṣù ẹ̀tọ́ wọn. 19 Láti ìwọ̀-oòrùn, àwọn ènìyàn yóò bẹ̀rù orúkọ OLÚWA,àti láti ìlà-oòrùn, wọn yóò bọ̀wọ̀ fún ògo rẹ̀.Nítorí òun yóò wá gẹ́gẹ́ bí i rírú omièyí tí èémí OLÚWA ń tì lọ. 20 “Olùdáǹdè yóò wá sí Sioni,sí àwọn tí ó wà ní Jakọbu tí óronúpìwàdà ẹ̀ṣẹ̀ wọn,” ni OLÚWA wí. 21 “Àti fún èmi, májẹ̀mú mi pẹ̀lú wọn nìyìí,” ni OLÚWA wí, “Ẹ̀mí mi, tí ó wà nínú yín, àti ọ̀rọ̀ mi tí mo ti fi sí ẹnu yín, kì yóò kúrò lẹ́nu yín, tàbí lẹ́nu àwọn ọmọ yín, tàbí láti ẹnu àwọn ìrandíran wọn láti àkókò yìí lọ àti títí láéláé,” ni OLÚWA wí.

In Other Versions

Isaiah 59 in the ANGEFD

Isaiah 59 in the ANTPNG2D

Isaiah 59 in the AS21

Isaiah 59 in the BAGH

Isaiah 59 in the BBPNG

Isaiah 59 in the BBT1E

Isaiah 59 in the BDS

Isaiah 59 in the BEV

Isaiah 59 in the BHAD

Isaiah 59 in the BIB

Isaiah 59 in the BLPT

Isaiah 59 in the BNT

Isaiah 59 in the BNTABOOT

Isaiah 59 in the BNTLV

Isaiah 59 in the BOATCB

Isaiah 59 in the BOATCB2

Isaiah 59 in the BOBCV

Isaiah 59 in the BOCNT

Isaiah 59 in the BOECS

Isaiah 59 in the BOGWICC

Isaiah 59 in the BOHCB

Isaiah 59 in the BOHCV

Isaiah 59 in the BOHLNT

Isaiah 59 in the BOHNTLTAL

Isaiah 59 in the BOICB

Isaiah 59 in the BOILNTAP

Isaiah 59 in the BOITCV

Isaiah 59 in the BOKCV

Isaiah 59 in the BOKCV2

Isaiah 59 in the BOKHWOG

Isaiah 59 in the BOKSSV

Isaiah 59 in the BOLCB

Isaiah 59 in the BOLCB2

Isaiah 59 in the BOMCV

Isaiah 59 in the BONAV

Isaiah 59 in the BONCB

Isaiah 59 in the BONLT

Isaiah 59 in the BONUT2

Isaiah 59 in the BOPLNT

Isaiah 59 in the BOSCB

Isaiah 59 in the BOSNC

Isaiah 59 in the BOTLNT

Isaiah 59 in the BOVCB

Isaiah 59 in the BPBB

Isaiah 59 in the BPH

Isaiah 59 in the BSB

Isaiah 59 in the CCB

Isaiah 59 in the CUV

Isaiah 59 in the CUVS

Isaiah 59 in the DBT

Isaiah 59 in the DGDNT

Isaiah 59 in the DHNT

Isaiah 59 in the DNT

Isaiah 59 in the ELBE

Isaiah 59 in the EMTV

Isaiah 59 in the ESV

Isaiah 59 in the FBV

Isaiah 59 in the FEB

Isaiah 59 in the GGMNT

Isaiah 59 in the GNT

Isaiah 59 in the HARY

Isaiah 59 in the HNT

Isaiah 59 in the IRVA

Isaiah 59 in the IRVB

Isaiah 59 in the IRVG

Isaiah 59 in the IRVH

Isaiah 59 in the IRVK

Isaiah 59 in the IRVM

Isaiah 59 in the IRVM2

Isaiah 59 in the IRVO

Isaiah 59 in the IRVP

Isaiah 59 in the IRVT

Isaiah 59 in the IRVT2

Isaiah 59 in the IRVU

Isaiah 59 in the ISVN

Isaiah 59 in the JSNT

Isaiah 59 in the KAPI

Isaiah 59 in the KBT1ETNIK

Isaiah 59 in the KBV

Isaiah 59 in the KJV

Isaiah 59 in the KNFD

Isaiah 59 in the LBA

Isaiah 59 in the LBLA

Isaiah 59 in the LNT

Isaiah 59 in the LSV

Isaiah 59 in the MAAL

Isaiah 59 in the MBV

Isaiah 59 in the MBV2

Isaiah 59 in the MHNT

Isaiah 59 in the MKNFD

Isaiah 59 in the MNG

Isaiah 59 in the MNT

Isaiah 59 in the MNT2

Isaiah 59 in the MRS1T

Isaiah 59 in the NAA

Isaiah 59 in the NASB

Isaiah 59 in the NBLA

Isaiah 59 in the NBS

Isaiah 59 in the NBVTP

Isaiah 59 in the NET2

Isaiah 59 in the NIV11

Isaiah 59 in the NNT

Isaiah 59 in the NNT2

Isaiah 59 in the NNT3

Isaiah 59 in the PDDPT

Isaiah 59 in the PFNT

Isaiah 59 in the RMNT

Isaiah 59 in the SBIAS

Isaiah 59 in the SBIBS

Isaiah 59 in the SBIBS2

Isaiah 59 in the SBICS

Isaiah 59 in the SBIDS

Isaiah 59 in the SBIGS

Isaiah 59 in the SBIHS

Isaiah 59 in the SBIIS

Isaiah 59 in the SBIIS2

Isaiah 59 in the SBIIS3

Isaiah 59 in the SBIKS

Isaiah 59 in the SBIKS2

Isaiah 59 in the SBIMS

Isaiah 59 in the SBIOS

Isaiah 59 in the SBIPS

Isaiah 59 in the SBISS

Isaiah 59 in the SBITS

Isaiah 59 in the SBITS2

Isaiah 59 in the SBITS3

Isaiah 59 in the SBITS4

Isaiah 59 in the SBIUS

Isaiah 59 in the SBIVS

Isaiah 59 in the SBT

Isaiah 59 in the SBT1E

Isaiah 59 in the SCHL

Isaiah 59 in the SNT

Isaiah 59 in the SUSU

Isaiah 59 in the SUSU2

Isaiah 59 in the SYNO

Isaiah 59 in the TBIAOTANT

Isaiah 59 in the TBT1E

Isaiah 59 in the TBT1E2

Isaiah 59 in the TFTIP

Isaiah 59 in the TFTU

Isaiah 59 in the TGNTATF3T

Isaiah 59 in the THAI

Isaiah 59 in the TNFD

Isaiah 59 in the TNT

Isaiah 59 in the TNTIK

Isaiah 59 in the TNTIL

Isaiah 59 in the TNTIN

Isaiah 59 in the TNTIP

Isaiah 59 in the TNTIZ

Isaiah 59 in the TOMA

Isaiah 59 in the TTENT

Isaiah 59 in the UBG

Isaiah 59 in the UGV

Isaiah 59 in the UGV2

Isaiah 59 in the UGV3

Isaiah 59 in the VBL

Isaiah 59 in the VDCC

Isaiah 59 in the YALU

Isaiah 59 in the YAPE

Isaiah 59 in the YBVTP

Isaiah 59 in the ZBP