Lamentations 3 (BOYCB)
1 Èmi ni ọkùnrin tí ó rí ìpọ́njúpẹ̀lú ọ̀pá ìbínú rẹ. 2 Ó ti lé mi jáde ó sì mú mi rìnnínú òkùnkùn ju ti ìmọ́lẹ̀. 3 Nítòótọ́, ó ti yí ọwọ́ rẹ̀ padà sí misíwájú àti síwájú sí i ní gbogbo ọjọ́. 4 Ó jẹ́ kí àwọ̀ mi àti ẹran-ara mi gbóó sì tún ṣẹ́ egungun mi. 5 Ó ti fi mí sí ìgbèkùn, ó sì ti yí mi kápẹ̀lú ìkorò àti làálàá. 6 Ó mú mi gbé nínú òkùnkùn,bí ti àwọn tó ti kú fún ìgbà pípẹ́. 7 Ó ti tì mí mọ́ ilé, nítorí náà n kò le è sálọ;ó ti fi ẹ̀wọ̀n mú mi mọ́lẹ̀. 8 Pàápàá nígbà tí mo ké fún ìrànlọ́wọ́,ó kọ àdúrà mi. 9 Ó fi ògiri òkúta dí ọ̀nà mi;ó sì mú ọ̀nà mi wọ́. 10 Bí i beari tí ó dùbúlẹ̀,bí i kìnnìún tí ó sá pamọ́. 11 Ó wọ́ mi kúrò ní ọ̀nà, ó tẹ̀ mí mọ́lẹ̀ó fi mi sílẹ̀ láìsí ìrànlọ́wọ́. 12 Ó fa ọfà rẹ̀ yọó sì fi mí ṣe ohun ìtafàsí. 13 Ó fa ọkàn mí yapẹ̀lú ọfà nínú àkọ̀ rẹ̀. 14 Mo di ẹni yẹ̀yẹ́ láàrín àwọn ènìyàn mi;wọn yẹ̀yẹ́ mi pẹ̀lú orin ní gbogbo ọjọ́. 15 Ó ti kún mi pẹ̀lú ewé kíkoròàti ìdààmú bí omi. 16 Ó ti fi òkúta kán eyín mi;ó ti tẹ̀ mí mọ́lẹ̀ nínú eruku. 17 Mo ti jìnnà sí àlàáfíà;mo ti gbàgbé ohun tí àṣeyege ń ṣe. 18 Nítorí náà mo wí pé, “Ògo mi ti lọàti ìrètí mi nínú OLÚWA.” 19 Mo ṣe ìrántí ìpọ́njú àti ìdààmú mi,ìkorò àti ìbànújẹ́. 20 Mo ṣèrántí wọn,ọkàn mi sì gbọgbẹ́ nínú mi. 21 Síbẹ̀, èyí ni mo ní ní ọkànàti nítorí náà ní mo nírètí. 22 Nítorí ìfẹ́ OLÚWA tí ó lágbára ni àwa kò fi ṣègbé,nítorí ti àánú rẹ kì í kùnà. 23 Wọ́n jẹ́ ọ̀tún ní àárọ̀;títóbi ni òdodo rẹ̀. 24 Mo wí fún ara mi, ìpín mi ni OLÚWA;nítorí náà èmi yóò dúró dè ọ́. 25 Dídára ni OLÚWA fún àwọn tí ó ní ìrètí nínú rẹ̀,sí àwọn tí ó ń wá a. 26 Ó dára kí a ní sùúrùfún ìgbàlà OLÚWA. 27 Ó dára fún ènìyàn láti gbé àjàgànígbà tí ó wà ní èwe. 28 Jẹ́ kí ó jókòó ní ìdákẹ́ jẹ́ẹ́,nítorí OLÚWA ti fi fún un. 29 Jẹ́ kí ó bo ojú rẹ̀ sínú eruku—ìrètí sì lè wà. 30 Jẹ́ kí ó fi ẹ̀rẹ̀kẹ́ fún àwọn tí yóò gbá a,sì jẹ́ kí ó wà ní ìdójútì. 31 Ènìyàn kò di ìtanùlọ́dọ̀ Olúwa títí láé. 32 Lóòtítọ́ ó mú ìbànújẹ́ wá, yóò fi àánú hàn,nítorí títóbi ni ìfẹ́ rẹ̀. 33 Nítorí kò mọ̀ ọ́n mọ̀ mú ìpọ́njú wátàbí ìrora wá fún ọmọ ènìyàn. 34 Láti tẹ mọ́lẹ̀ lábẹ́ ẹsẹ̀gbogbo àwọn ẹlẹ́wọ̀n ní ilẹ̀ náà. 35 Láti ṣẹ́ ọmọ ènìyàn fún ẹ̀tọ́ rẹ̀níwájú Ọ̀gá-ògo jùlọ, 36 láti yí ìdájọ́ ènìyàn padà,ǹjẹ́ Olúwa kò rí ohun bẹ́ẹ̀. 37 Ta ni yóò sọ̀rọ̀ tí yóò rí bẹ́ẹ̀tí Olúwa kò bá fi àṣẹ sí i. 38 Ǹjẹ́ kì í ṣe láti ẹnu Ọ̀gá-ògo jùlọni rere àti búburú tí ń wá? 39 Kí ló dé tí ẹ̀dá alààyè ṣe ń kùnnígbà tí ó bá ń jìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀? 40 Ẹ jẹ́ kí a yẹ ọ̀nà wa, kí a sì dán an wò,kí a sì tọ OLÚWA lọ. 41 Ẹ jẹ́ kí a gbé ọkàn àti ọwọ́ wa sókèsí Ọlọ́run ní ọ̀run, kí a wí pé, 42 “Àwa ti ṣẹ̀ a sì ti ṣọ̀tẹ̀ìwọ kò sì fi ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá. 43 “Ìwọ fi ìbínú bo ara rẹ ìwọ sì ń lépa wa;ìwọ ń parun láìsí àánú. 44 Ìwọ ti fi àwọsánmọ̀ bo ara rẹpé kí àdúrà wa má ba à dé ọ̀dọ̀ rẹ. 45 Ó ti sọ wá di èérí àti ààtànláàrín orílẹ̀-èdè gbogbo. 46 “Gbogbo àwọn ọ̀tá wa ti la ẹnu wọngbòòrò sí wa. 47 Àwa ti jìyà àti ìparun,nínú ìbẹ̀rù àti ewu.” 48 Omijé ń sàn ní ojú mi bí odònítorí a pa àwọn ènìyàn mi run. 49 Ojú mi kò dá fún omijé,láì sinmi, 50 títí ìgbà tí OLÚWA yóò síjú wolẹ̀láti òkè ọ̀run tí yóò sì rí i. 51 Ohun tí mo rí mú ìbẹ̀rù wá ọkàn minítorí gbogbo àwọn obìnrin ìlú mi. 52 Àwọn tí ó jẹ́ ọ̀tá mi láìnídìídẹ mí bí ẹyẹ. 53 Wọ́n gbìyànjú láti mú òpin dé bá ayé mi nínú ihòwọ́n sì ju òkúta lù mí. 54 Orí mi kún fún omi,mo sì rò pé ìgbẹ̀yìn dé. 55 Mo pe orúkọ rẹ, OLÚWA,láti ọ̀gbun ìsàlẹ̀ ihò. 56 Ìwọ gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi, “Má ṣe di etí rẹsí igbe ẹ̀bẹ̀ mi fún ìtura.” 57 O wá tòsí nígbà tí mo ké pè ọ́,o sì wí pé, “Má ṣe bẹ̀rù.” 58 OLÚWA, ìwọ gba ẹjọ́ mi rò,o ra ẹ̀mí mi padà. 59 O ti rí i, OLÚWA, búburú tí a ṣe sí mi.Gba ẹjọ́ mi ró! 60 Ìwọ ti rí ọ̀gbun ẹ̀san wọn,gbogbo ìmọ̀ wọn sí mi. 61 OLÚWA ìwọ ti gbọ́ ẹ̀gàn wọnàti ìmọ̀ búburú wọn sí mi, 62 ohun tí àwọn ọ̀tá mi ń sọsí mi ní gbogbo ọjọ́. 63 Wò wọ́n! Ní jíjòkòó tàbí ní dídìde,wọ́n ń ṣẹlẹ́yà mi nínú orin wọn. 64 OLÚWA san wọ́n lẹ́san ohun tí ó tọ́ sí wọnfún ohun tí ọwọ́ wọn ti ṣe. 65 Fi ìbòjú bò wọ́n ní ọkàn,kí o sì fi wọ́n ré. 66 Ni wọ́n lára kí o sì pa wọ́n run pẹ̀lú ìbínú,lábẹ́ ọ̀run OLÚWA.
In Other Versions
Lamentations 3 in the ANGEFD
Lamentations 3 in the ANTPNG2D
Lamentations 3 in the AS21
Lamentations 3 in the BAGH
Lamentations 3 in the BBPNG
Lamentations 3 in the BBT1E
Lamentations 3 in the BDS
Lamentations 3 in the BEV
Lamentations 3 in the BHAD
Lamentations 3 in the BIB
Lamentations 3 in the BLPT
Lamentations 3 in the BNT
Lamentations 3 in the BNTABOOT
Lamentations 3 in the BNTLV
Lamentations 3 in the BOATCB
Lamentations 3 in the BOATCB2
Lamentations 3 in the BOBCV
Lamentations 3 in the BOCNT
Lamentations 3 in the BOECS
Lamentations 3 in the BOGWICC
Lamentations 3 in the BOHCB
Lamentations 3 in the BOHCV
Lamentations 3 in the BOHLNT
Lamentations 3 in the BOHNTLTAL
Lamentations 3 in the BOICB
Lamentations 3 in the BOILNTAP
Lamentations 3 in the BOITCV
Lamentations 3 in the BOKCV
Lamentations 3 in the BOKCV2
Lamentations 3 in the BOKHWOG
Lamentations 3 in the BOKSSV
Lamentations 3 in the BOLCB
Lamentations 3 in the BOLCB2
Lamentations 3 in the BOMCV
Lamentations 3 in the BONAV
Lamentations 3 in the BONCB
Lamentations 3 in the BONLT
Lamentations 3 in the BONUT2
Lamentations 3 in the BOPLNT
Lamentations 3 in the BOSCB
Lamentations 3 in the BOSNC
Lamentations 3 in the BOTLNT
Lamentations 3 in the BOVCB
Lamentations 3 in the BPBB
Lamentations 3 in the BPH
Lamentations 3 in the BSB
Lamentations 3 in the CCB
Lamentations 3 in the CUV
Lamentations 3 in the CUVS
Lamentations 3 in the DBT
Lamentations 3 in the DGDNT
Lamentations 3 in the DHNT
Lamentations 3 in the DNT
Lamentations 3 in the ELBE
Lamentations 3 in the EMTV
Lamentations 3 in the ESV
Lamentations 3 in the FBV
Lamentations 3 in the FEB
Lamentations 3 in the GGMNT
Lamentations 3 in the GNT
Lamentations 3 in the HARY
Lamentations 3 in the HNT
Lamentations 3 in the IRVA
Lamentations 3 in the IRVB
Lamentations 3 in the IRVG
Lamentations 3 in the IRVH
Lamentations 3 in the IRVK
Lamentations 3 in the IRVM
Lamentations 3 in the IRVM2
Lamentations 3 in the IRVO
Lamentations 3 in the IRVP
Lamentations 3 in the IRVT
Lamentations 3 in the IRVT2
Lamentations 3 in the IRVU
Lamentations 3 in the ISVN
Lamentations 3 in the JSNT
Lamentations 3 in the KAPI
Lamentations 3 in the KBT1ETNIK
Lamentations 3 in the KBV
Lamentations 3 in the KJV
Lamentations 3 in the KNFD
Lamentations 3 in the LBA
Lamentations 3 in the LBLA
Lamentations 3 in the LNT
Lamentations 3 in the LSV
Lamentations 3 in the MAAL
Lamentations 3 in the MBV
Lamentations 3 in the MBV2
Lamentations 3 in the MHNT
Lamentations 3 in the MKNFD
Lamentations 3 in the MNG
Lamentations 3 in the MNT
Lamentations 3 in the MNT2
Lamentations 3 in the MRS1T
Lamentations 3 in the NAA
Lamentations 3 in the NASB
Lamentations 3 in the NBLA
Lamentations 3 in the NBS
Lamentations 3 in the NBVTP
Lamentations 3 in the NET2
Lamentations 3 in the NIV11
Lamentations 3 in the NNT
Lamentations 3 in the NNT2
Lamentations 3 in the NNT3
Lamentations 3 in the PDDPT
Lamentations 3 in the PFNT
Lamentations 3 in the RMNT
Lamentations 3 in the SBIAS
Lamentations 3 in the SBIBS
Lamentations 3 in the SBIBS2
Lamentations 3 in the SBICS
Lamentations 3 in the SBIDS
Lamentations 3 in the SBIGS
Lamentations 3 in the SBIHS
Lamentations 3 in the SBIIS
Lamentations 3 in the SBIIS2
Lamentations 3 in the SBIIS3
Lamentations 3 in the SBIKS
Lamentations 3 in the SBIKS2
Lamentations 3 in the SBIMS
Lamentations 3 in the SBIOS
Lamentations 3 in the SBIPS
Lamentations 3 in the SBISS
Lamentations 3 in the SBITS
Lamentations 3 in the SBITS2
Lamentations 3 in the SBITS3
Lamentations 3 in the SBITS4
Lamentations 3 in the SBIUS
Lamentations 3 in the SBIVS
Lamentations 3 in the SBT
Lamentations 3 in the SBT1E
Lamentations 3 in the SCHL
Lamentations 3 in the SNT
Lamentations 3 in the SUSU
Lamentations 3 in the SUSU2
Lamentations 3 in the SYNO
Lamentations 3 in the TBIAOTANT
Lamentations 3 in the TBT1E
Lamentations 3 in the TBT1E2
Lamentations 3 in the TFTIP
Lamentations 3 in the TFTU
Lamentations 3 in the TGNTATF3T
Lamentations 3 in the THAI
Lamentations 3 in the TNFD
Lamentations 3 in the TNT
Lamentations 3 in the TNTIK
Lamentations 3 in the TNTIL
Lamentations 3 in the TNTIN
Lamentations 3 in the TNTIP
Lamentations 3 in the TNTIZ
Lamentations 3 in the TOMA
Lamentations 3 in the TTENT
Lamentations 3 in the UBG
Lamentations 3 in the UGV
Lamentations 3 in the UGV2
Lamentations 3 in the UGV3
Lamentations 3 in the VBL
Lamentations 3 in the VDCC
Lamentations 3 in the YALU
Lamentations 3 in the YAPE
Lamentations 3 in the YBVTP
Lamentations 3 in the ZBP