Psalms 105 (BOYCB)
1 Ẹ fi ọpẹ́ fún OLÚWA, ké pe orúkọ rẹ̀,jẹ́ kí a mọ ohun tí ó ṣe láàrín àwọn orílẹ̀-èdè. 2 Kọrin sí i, kọrin ìyìn sí i;sọ ti iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ gbogbo. 3 Ṣògo nínú orúkọ mímọ́ rẹ̀,jẹ́ kí ọkàn àwọn tí ń wá OLÚWA kí ó yọ̀. 4 Wá OLÚWA àti ipá rẹ̀;wa ojú rẹ̀ nígbà gbogbo. 5 Rántí àwọn ìyanu tí ó ti ṣe,ìyanu rẹ̀, àti ìdájọ́ tí ó sọ, 6 ẹ̀yin ìran Abrahamu ìránṣẹ́ rẹ̀,ẹ̀yin ọmọkùnrin Jakọbu, àyànfẹ́ rẹ̀. 7 Òun ni OLÚWA Ọlọ́run wa:ìdájọ́ rẹ̀ wà ní gbogbo ayé. 8 Ó rántí májẹ̀mú rẹ̀ láéláé,ọ̀rọ̀ tí ó pàṣẹ, fún ẹgbẹẹgbẹ̀rún ìran, 9 májẹ̀mú tí ó dá pẹ̀lú Abrahamu,ìbúra tí ó ṣe pẹ̀lú fún Isaaki. 10 Ó ṣe ìdánilójú u rẹ̀ fún Jakọbu gẹ́gẹ́ bí àṣẹ,sí Israẹli, gẹ́gẹ́ bi májẹ̀mú ayérayé: 11 “Fún ìwọ ni èmi ó fún ní ilẹ̀ Kenaanigẹ́gẹ́ bí ìpín tí ìwọ ó jogún.” 12 Nígbà tí wọn kéré níye,wọ́n kéré jọjọ, àti àwọn àjèjì níbẹ̀ 13 wọ́n rìn kiri láti orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè,láti ìjọba kan sí èkejì. 14 Kò gba ẹnikẹ́ni láààyè láti pọ́n wọn lójú;ó fi ọba bú nítorí tiwọn: 15 “Má ṣe fọwọ́ kan ẹni àmì òróró mi; má sì ṣe wòlíì mi níbi.” 16 Ó pe ìyàn sórí ilẹ̀ náàó sì pa gbogbo ìpèsè oúnjẹ wọn run; 17 Ó sì rán ọkùnrin kan síwájú wọnJosẹfu tí a tà gẹ́gẹ́ bí ẹrú. 18 Wọn fi ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ bọ ẹsẹ̀ rẹ̀a gbé ọrùn rẹ̀ sínú irin, 19 títí ọ̀rọ̀ tí ó sọtẹ́lẹ̀ fi ṣẹtítí ọ̀rọ̀ OLÚWA fi dá a láre. 20 Ọba ránṣẹ́ lọ tú u sílẹ̀àwọn aláṣẹ ènìyàn tú u sílẹ̀ 21 Ó fi jẹ olúwa lórí ilẹ̀ rẹ̀,aláṣẹ lórí ohun gbogbo tí ó ní, 22 gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ rẹ̀, kí ó máaṣe àkóso àwọn ọmọ-aládékí ó sì kọ́ àwọn àgbàgbà rẹ̀ ní ọgbọ́n. 23 Israẹli wá sí Ejibiti;Jakọbu sì ṣe àtìpó ní ilé Hamu. 24 OLÚWA, sì mú àwọn ọmọ rẹ̀ bí sí ió sì mú wọn lágbára jùàwọn ọ̀tá wọn lọ 25 Ó yí wọn lọ́kàn padà láti kórìíra àwọn ènìyànláti ṣe àrékérekè sí àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. 26 Ó rán Mose ìránṣẹ́ rẹ̀,àti Aaroni tí ó ti yàn. 27 Wọ́n ń ṣe iṣẹ́ ìyanu láàrín wọnó ṣe iṣẹ́ ìyanu ní Hamu. 28 Ó rán òkùnkùn, o sì mú ilẹ̀ ṣúwọn kò sì sọ̀rọ̀-òdì sí ọ̀rọ̀ rẹ̀. 29 Ó sọ omi wọn di ẹ̀jẹ̀,ó pa ẹja wọn. 30 Ilẹ̀ mú ọ̀pọ̀lọ́ jáde wá,èyí tí ó lọ sí ìyẹ̀wù àwọn ọba wọn. 31 Ó sọ̀rọ̀, onírúurú eṣinṣin sì dìde,ó sì hu kantíkantí ní ilẹ̀ wọn 32 Ó sọ òjò di yìnyín,àti ọ̀wọ́-iná ní ilẹ̀ wọn; 33 Ó lu àjàrà wọn àti igi ọ̀pọ̀tọ́ wọnó sì dá igi orílẹ̀-èdè wọn. 34 Ó sọ̀rọ̀, eṣú sì dé,àti kòkòrò ní àìníye, 35 wọn sì jẹ gbogbo ewé ilẹ̀ wọn,wọ́n sì jẹ èso ilẹ̀ wọn run. 36 Nígbà náà, ó kọlu gbogbo àwọn ilẹ̀ wọn,ààyò gbogbo ipá wọn. 37 Ó mú Israẹli jádeti òun ti fàdákà àti wúrà,nínú ẹ̀yà rẹ̀ kò sí aláìlera kan. 38 Inú Ejibiti dùn nígbà tí wọn ń lọ,nítorí ẹ̀rù àwọn Israẹli ń bá wọ́n. 39 Ó ta àwọsánmọ̀ fún ìbòrí,àti iná láti fún wọn ní ìmọ́lẹ̀ lálẹ́. 40 Wọn béèrè, ó sì mú ẹyẹ àparò wá,ó sì fi oúnjẹ ọ̀run tẹ́ wọn lọ́rùn. 41 Ó sì la àpáta, ó sì mú omi jáde;gẹ́gẹ́ bí odò tí ń sàn níbi gbígbẹ. 42 Nítorí ó rántí ìlérí mímọ́ rẹ̀àti Abrahamu ìránṣẹ́ rẹ̀. 43 Ó sì fi ayọ̀ mú àwọn ènìyàn rẹ̀ jádepẹ̀lú ayọ̀ ní ó yan àyànfẹ́ rẹ̀ 44 Ó fún wọn ní ilẹ̀ ìní náà,wọ́n sì jogún iṣẹ́ àwọn ènìyàn náà, 45 kí wọn kí ó lè máa pa àṣẹ rẹ̀ mọ́kí wọn kí ó lè kíyèsi òfin rẹ̀. Ẹ fi ìyìn fún OLÚWA.
In Other Versions
Psalms 105 in the ANGEFD
Psalms 105 in the ANTPNG2D
Psalms 105 in the AS21
Psalms 105 in the BAGH
Psalms 105 in the BBPNG
Psalms 105 in the BBT1E
Psalms 105 in the BDS
Psalms 105 in the BEV
Psalms 105 in the BHAD
Psalms 105 in the BIB
Psalms 105 in the BLPT
Psalms 105 in the BNT
Psalms 105 in the BNTABOOT
Psalms 105 in the BNTLV
Psalms 105 in the BOATCB
Psalms 105 in the BOATCB2
Psalms 105 in the BOBCV
Psalms 105 in the BOCNT
Psalms 105 in the BOECS
Psalms 105 in the BOGWICC
Psalms 105 in the BOHCB
Psalms 105 in the BOHCV
Psalms 105 in the BOHLNT
Psalms 105 in the BOHNTLTAL
Psalms 105 in the BOICB
Psalms 105 in the BOILNTAP
Psalms 105 in the BOITCV
Psalms 105 in the BOKCV
Psalms 105 in the BOKCV2
Psalms 105 in the BOKHWOG
Psalms 105 in the BOKSSV
Psalms 105 in the BOLCB
Psalms 105 in the BOLCB2
Psalms 105 in the BOMCV
Psalms 105 in the BONAV
Psalms 105 in the BONCB
Psalms 105 in the BONLT
Psalms 105 in the BONUT2
Psalms 105 in the BOPLNT
Psalms 105 in the BOSCB
Psalms 105 in the BOSNC
Psalms 105 in the BOTLNT
Psalms 105 in the BOVCB
Psalms 105 in the BPBB
Psalms 105 in the BPH
Psalms 105 in the BSB
Psalms 105 in the CCB
Psalms 105 in the CUV
Psalms 105 in the CUVS
Psalms 105 in the DBT
Psalms 105 in the DGDNT
Psalms 105 in the DHNT
Psalms 105 in the DNT
Psalms 105 in the ELBE
Psalms 105 in the EMTV
Psalms 105 in the ESV
Psalms 105 in the FBV
Psalms 105 in the FEB
Psalms 105 in the GGMNT
Psalms 105 in the GNT
Psalms 105 in the HARY
Psalms 105 in the HNT
Psalms 105 in the IRVA
Psalms 105 in the IRVB
Psalms 105 in the IRVG
Psalms 105 in the IRVH
Psalms 105 in the IRVK
Psalms 105 in the IRVM
Psalms 105 in the IRVM2
Psalms 105 in the IRVO
Psalms 105 in the IRVP
Psalms 105 in the IRVT
Psalms 105 in the IRVT2
Psalms 105 in the IRVU
Psalms 105 in the ISVN
Psalms 105 in the JSNT
Psalms 105 in the KAPI
Psalms 105 in the KBT1ETNIK
Psalms 105 in the KBV
Psalms 105 in the KJV
Psalms 105 in the KNFD
Psalms 105 in the LBA
Psalms 105 in the LBLA
Psalms 105 in the LNT
Psalms 105 in the LSV
Psalms 105 in the MAAL
Psalms 105 in the MBV
Psalms 105 in the MBV2
Psalms 105 in the MHNT
Psalms 105 in the MKNFD
Psalms 105 in the MNG
Psalms 105 in the MNT
Psalms 105 in the MNT2
Psalms 105 in the MRS1T
Psalms 105 in the NAA
Psalms 105 in the NASB
Psalms 105 in the NBLA
Psalms 105 in the NBS
Psalms 105 in the NBVTP
Psalms 105 in the NET2
Psalms 105 in the NIV11
Psalms 105 in the NNT
Psalms 105 in the NNT2
Psalms 105 in the NNT3
Psalms 105 in the PDDPT
Psalms 105 in the PFNT
Psalms 105 in the RMNT
Psalms 105 in the SBIAS
Psalms 105 in the SBIBS
Psalms 105 in the SBIBS2
Psalms 105 in the SBICS
Psalms 105 in the SBIDS
Psalms 105 in the SBIGS
Psalms 105 in the SBIHS
Psalms 105 in the SBIIS
Psalms 105 in the SBIIS2
Psalms 105 in the SBIIS3
Psalms 105 in the SBIKS
Psalms 105 in the SBIKS2
Psalms 105 in the SBIMS
Psalms 105 in the SBIOS
Psalms 105 in the SBIPS
Psalms 105 in the SBISS
Psalms 105 in the SBITS
Psalms 105 in the SBITS2
Psalms 105 in the SBITS3
Psalms 105 in the SBITS4
Psalms 105 in the SBIUS
Psalms 105 in the SBIVS
Psalms 105 in the SBT
Psalms 105 in the SBT1E
Psalms 105 in the SCHL
Psalms 105 in the SNT
Psalms 105 in the SUSU
Psalms 105 in the SUSU2
Psalms 105 in the SYNO
Psalms 105 in the TBIAOTANT
Psalms 105 in the TBT1E
Psalms 105 in the TBT1E2
Psalms 105 in the TFTIP
Psalms 105 in the TFTU
Psalms 105 in the TGNTATF3T
Psalms 105 in the THAI
Psalms 105 in the TNFD
Psalms 105 in the TNT
Psalms 105 in the TNTIK
Psalms 105 in the TNTIL
Psalms 105 in the TNTIN
Psalms 105 in the TNTIP
Psalms 105 in the TNTIZ
Psalms 105 in the TOMA
Psalms 105 in the TTENT
Psalms 105 in the UBG
Psalms 105 in the UGV
Psalms 105 in the UGV2
Psalms 105 in the UGV3
Psalms 105 in the VBL
Psalms 105 in the VDCC
Psalms 105 in the YALU
Psalms 105 in the YAPE
Psalms 105 in the YBVTP
Psalms 105 in the ZBP