Zephaniah 2 (BOYCB)
1 Ẹ kó ara yín jọ pọ̀, àní ẹ kó ra yín jọ pọ̀orílẹ̀-èdè tí kò ní ìtìjú, 2 kí a tó pa àṣẹ náà, kí ọjọ́ náà tó kọjá bí ìyàngbò ọkà,kí gbígbóná ìbínú OLÚWA tó dé bá a yín,kí ọjọ́ ìbínú OLÚWA kí ó tó dé bá a yín. 3 Ẹ wá OLÚWA, gbogbo ẹ̀yin onírẹ̀lẹ̀ ilẹ̀ náà,ẹ̀yin tí ń ṣe ohun tí ó bá pàṣẹ.Ẹ wá òdodo, ẹ wá ìrẹ̀lẹ̀ pẹ̀lú,bóyá á ó pa yín mọ́ ní ọjọ́ ìbínú OLÚWA. 4 Nítorí pé, a ó kọ Gasa sílẹ̀,Aṣkeloni yóò sì dahoro.Ní ọ̀sán gangan ni a ó lé Aṣdodu jáde,a ó sì fa Ekroni tu kúrò. 5 Ègbé ni fún ẹ̀yin tí ń gbé etí Òkun,ẹ̀yin ènìyàn ara Kereti;ọ̀rọ̀ OLÚWA dojúkọ ọ́, ìwọ Kenaani,ilẹ̀ àwọn ara Filistini.“Èmi yóò pa yín run,ẹnìkan kò sì ní ṣẹ́kù nínú yín.” 6 Ilẹ̀ náà ní etí Òkun, ni ibùgbé àwọn ará Kereti,ni yóò jẹ́ ibùjókòó fún àwọn olùṣọ́-àgùntàn àti agbo àgùntàn. 7 Agbègbè náà yóò sì jẹ́ ti ìyókù àwọn ilé Juda,níbẹ̀ ni wọn yóò sì ti rí koríko fún ẹran.Ní ilé Aṣkeloni ni wọn yóòdùbúlẹ̀ ni àṣálẹ́. OLÚWA Ọlọ́run wọn yóò bẹ̀ wọn wò,yóò sì yí ìgbèkùn wọn padà. 8 “Èmi ti gbọ́ ẹ̀gàn Moabu,àti ẹlẹ́yà àwọn Ammoni,àwọn tó kẹ́gàn àwọn ènìyàn mi,tí wọ́n sì ti gbé ara wọn ga sí agbègbè wọn. 9 Nítorí náà, bí Èmi tí wà,”ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogun,Ọlọ́run àwọn Israẹli wí,“nítòótọ́ Moabu yóò dàbí Sodomu,àti Ammoni yóò sì dàbí Gomorra,ibi tí ó kún fún yèrèpè,àti ìhó iyọ̀ àti ìdahoro títí láéláé.Ìyókù àwọn ènìyàn mi yóò kó wọn;àwọn tí ó sì yọ nínú ewu ní orílẹ̀-èdè mi ni yóò jogún ilẹ̀ wọn.” 10 Èyí ni ohun tí wọn yóò gbà padà nítorí ìgbéraga wọn,nítorí wọ́n kẹ́gàn, wọn sì ti fi àwọn ènìyàn OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ṣe ẹlẹ́yà. 11 OLÚWA yóò jẹ́ ìbẹ̀rù fún wọn;nígbà tí Òun bá pa gbogbo òrìṣà ilẹ̀ náà run.Orílẹ̀-èdè láti etí odò yóò máa sìn,olúkúlùkù láti ilẹ̀ rẹ̀ wá. 12 “Ẹ̀yin Etiopia pẹ̀lú,a ó fi idà mi pa yín.” 13 Òun yóò sì na ọwọ́ rẹ̀ sí apá àríwá,yóò sì pa Asiria run,yóò sì sọ Ninefe di ahoro,àti di gbígbẹ bí aginjù. 14 Agbo ẹran yóò sì dùbúlẹ̀ ni àárín rẹ̀,àti gbogbo ẹranko àwọn orílẹ̀-èdè.Òwìwí aginjù àti ti n kígbe ẹyẹ òwìwíyóò wọ bí ẹyẹ ni ọwọ̀n rẹ̀.Ohùn wọn yóò kọrin ni ojú fèrèsé,ìdahoro yóò wà nínú ìloro ẹnu-ọ̀nà,òun yóò sì ṣẹ́ ọ̀pá kedari sílẹ̀. 15 Èyí ni ìlú aláyọ̀ tí ó ń gbé láìléwu.Ó sì sọ fun ara rẹ̀ pé,“Èmi ni, kò sì sí ẹnìkan tí ó ń bẹ lẹ́yìn mi.”Irú ahoro wo ni òun ha ti jẹ́,ibùgbé fún àwọn ẹranko igbó!Gbogbo ẹni tí ó bá kọjá ọ̀dọ̀ rẹ̀yóò fi rẹ́rìn-ín ẹlẹ́yà,wọ́n yóò sì gbọn ẹsẹ̀ wọn.
In Other Versions
Zephaniah 2 in the ANGEFD
Zephaniah 2 in the ANTPNG2D
Zephaniah 2 in the AS21
Zephaniah 2 in the BAGH
Zephaniah 2 in the BBPNG
Zephaniah 2 in the BBT1E
Zephaniah 2 in the BDS
Zephaniah 2 in the BEV
Zephaniah 2 in the BHAD
Zephaniah 2 in the BIB
Zephaniah 2 in the BLPT
Zephaniah 2 in the BNT
Zephaniah 2 in the BNTABOOT
Zephaniah 2 in the BNTLV
Zephaniah 2 in the BOATCB
Zephaniah 2 in the BOATCB2
Zephaniah 2 in the BOBCV
Zephaniah 2 in the BOCNT
Zephaniah 2 in the BOECS
Zephaniah 2 in the BOGWICC
Zephaniah 2 in the BOHCB
Zephaniah 2 in the BOHCV
Zephaniah 2 in the BOHLNT
Zephaniah 2 in the BOHNTLTAL
Zephaniah 2 in the BOICB
Zephaniah 2 in the BOILNTAP
Zephaniah 2 in the BOITCV
Zephaniah 2 in the BOKCV
Zephaniah 2 in the BOKCV2
Zephaniah 2 in the BOKHWOG
Zephaniah 2 in the BOKSSV
Zephaniah 2 in the BOLCB
Zephaniah 2 in the BOLCB2
Zephaniah 2 in the BOMCV
Zephaniah 2 in the BONAV
Zephaniah 2 in the BONCB
Zephaniah 2 in the BONLT
Zephaniah 2 in the BONUT2
Zephaniah 2 in the BOPLNT
Zephaniah 2 in the BOSCB
Zephaniah 2 in the BOSNC
Zephaniah 2 in the BOTLNT
Zephaniah 2 in the BOVCB
Zephaniah 2 in the BPBB
Zephaniah 2 in the BPH
Zephaniah 2 in the BSB
Zephaniah 2 in the CCB
Zephaniah 2 in the CUV
Zephaniah 2 in the CUVS
Zephaniah 2 in the DBT
Zephaniah 2 in the DGDNT
Zephaniah 2 in the DHNT
Zephaniah 2 in the DNT
Zephaniah 2 in the ELBE
Zephaniah 2 in the EMTV
Zephaniah 2 in the ESV
Zephaniah 2 in the FBV
Zephaniah 2 in the FEB
Zephaniah 2 in the GGMNT
Zephaniah 2 in the GNT
Zephaniah 2 in the HARY
Zephaniah 2 in the HNT
Zephaniah 2 in the IRVA
Zephaniah 2 in the IRVB
Zephaniah 2 in the IRVG
Zephaniah 2 in the IRVH
Zephaniah 2 in the IRVK
Zephaniah 2 in the IRVM
Zephaniah 2 in the IRVM2
Zephaniah 2 in the IRVO
Zephaniah 2 in the IRVP
Zephaniah 2 in the IRVT
Zephaniah 2 in the IRVT2
Zephaniah 2 in the IRVU
Zephaniah 2 in the ISVN
Zephaniah 2 in the JSNT
Zephaniah 2 in the KAPI
Zephaniah 2 in the KBT1ETNIK
Zephaniah 2 in the KBV
Zephaniah 2 in the KJV
Zephaniah 2 in the KNFD
Zephaniah 2 in the LBA
Zephaniah 2 in the LBLA
Zephaniah 2 in the LNT
Zephaniah 2 in the LSV
Zephaniah 2 in the MAAL
Zephaniah 2 in the MBV
Zephaniah 2 in the MBV2
Zephaniah 2 in the MHNT
Zephaniah 2 in the MKNFD
Zephaniah 2 in the MNG
Zephaniah 2 in the MNT
Zephaniah 2 in the MNT2
Zephaniah 2 in the MRS1T
Zephaniah 2 in the NAA
Zephaniah 2 in the NASB
Zephaniah 2 in the NBLA
Zephaniah 2 in the NBS
Zephaniah 2 in the NBVTP
Zephaniah 2 in the NET2
Zephaniah 2 in the NIV11
Zephaniah 2 in the NNT
Zephaniah 2 in the NNT2
Zephaniah 2 in the NNT3
Zephaniah 2 in the PDDPT
Zephaniah 2 in the PFNT
Zephaniah 2 in the RMNT
Zephaniah 2 in the SBIAS
Zephaniah 2 in the SBIBS
Zephaniah 2 in the SBIBS2
Zephaniah 2 in the SBICS
Zephaniah 2 in the SBIDS
Zephaniah 2 in the SBIGS
Zephaniah 2 in the SBIHS
Zephaniah 2 in the SBIIS
Zephaniah 2 in the SBIIS2
Zephaniah 2 in the SBIIS3
Zephaniah 2 in the SBIKS
Zephaniah 2 in the SBIKS2
Zephaniah 2 in the SBIMS
Zephaniah 2 in the SBIOS
Zephaniah 2 in the SBIPS
Zephaniah 2 in the SBISS
Zephaniah 2 in the SBITS
Zephaniah 2 in the SBITS2
Zephaniah 2 in the SBITS3
Zephaniah 2 in the SBITS4
Zephaniah 2 in the SBIUS
Zephaniah 2 in the SBIVS
Zephaniah 2 in the SBT
Zephaniah 2 in the SBT1E
Zephaniah 2 in the SCHL
Zephaniah 2 in the SNT
Zephaniah 2 in the SUSU
Zephaniah 2 in the SUSU2
Zephaniah 2 in the SYNO
Zephaniah 2 in the TBIAOTANT
Zephaniah 2 in the TBT1E
Zephaniah 2 in the TBT1E2
Zephaniah 2 in the TFTIP
Zephaniah 2 in the TFTU
Zephaniah 2 in the TGNTATF3T
Zephaniah 2 in the THAI
Zephaniah 2 in the TNFD
Zephaniah 2 in the TNT
Zephaniah 2 in the TNTIK
Zephaniah 2 in the TNTIL
Zephaniah 2 in the TNTIN
Zephaniah 2 in the TNTIP
Zephaniah 2 in the TNTIZ
Zephaniah 2 in the TOMA
Zephaniah 2 in the TTENT
Zephaniah 2 in the UBG
Zephaniah 2 in the UGV
Zephaniah 2 in the UGV2
Zephaniah 2 in the UGV3
Zephaniah 2 in the VBL
Zephaniah 2 in the VDCC
Zephaniah 2 in the YALU
Zephaniah 2 in the YAPE
Zephaniah 2 in the YBVTP
Zephaniah 2 in the ZBP