1 John 4 (BOYCB)
1 Olùfẹ́, ẹ má ṣe gba gbogbo ẹ̀mí gbọ́, ṣùgbọ́n ẹ dán àwọn ẹ̀mí wò bí wọn ba ń ṣe tí Ọlọ́run, nítorí àwọn wòlíì èké púpọ̀ tí jáde lọ sínú ayé. 2 Èyí ni ẹ ó fi mọ Ẹ̀mí Ọlọ́run. Gbogbo ẹ̀mí tí ó ba jẹ́wọ́ pé, Jesu Kristi wá nínú ara, ti Ọlọ́run ni. 3 Gbogbo ẹ̀mí tí kò si jẹ́wọ́ pé Jesu Kristi wà nínú ara, kì í ṣe tí Ọlọ́run, èyí sì ni ẹ̀mí aṣòdì sí Kristi náà, tí ẹ̀yin ti gbọ́ pé ó ń bọ̀, àti nísinsin yìí ó sì tí de sínú ayé. 4 Ẹ̀yin ọmọ mi, ti Ọlọ́run ni yín, ẹ̀yin sì tí ṣẹ́gun wọn, nítorí ẹni tí ń bẹ nínú yin tóbi jú ẹni tí ń bẹ nínú ayé lọ. 5 Tí ayé ni wọ́n, nítorí náà ni wọn ṣe ń sọ̀rọ̀ bí ẹni ti ayé, ayé sì ń gbọ́ tí wọn. 6 Ti Ọlọ́run ni àwa: ẹni tí ó bá mọ Ọlọ́run, ó ń gbọ́ tiwa; ẹni tí kì í ṣe ti Ọlọ́run kò ni gbọ́ ti wa. Nípa èyí ni àwa mọ ẹ̀mí òtítọ́, àti ẹ̀mí èké. 7 Olùfẹ́, ẹ jẹ́ kí a fẹ́ràn ara wa, nítorí ìfẹ́ ti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá; àti gbogbo ẹni tí ó bá ní ìfẹ́, a bí i nípa ti Ọlọ́run, ó sì mọ Ọlọ́run. 8 Ẹni tí kò bá ní ìfẹ́ kò mọ Ọlọ́run: nítorí pé ìfẹ́ ni Ọlọ́run. 9 Nípa èyí ni a gbé fi ìfẹ́ Ọlọ́run hàn nínú wa, nítorí tí Ọlọ́run rán ọmọ bíbí rẹ̀ nìkan ṣoṣo sì ayé, kí àwa lè yè nípasẹ̀ rẹ̀. 10 Nínú èyí ni ìfẹ́ wà, kì í ṣe pé àwa fẹ́ Ọlọ́run, ṣùgbọ́n òun fẹ́ wá, ó sì rán Ọmọ rẹ̀ láti jẹ́ ètùtù fún ẹ̀ṣẹ̀ wa. 11 Olùfẹ́, bí Ọlọ́run bá fẹ́ wa báyìí, ó yẹ kí a fẹ́ràn ara wa pẹ̀lú. 12 Ẹnikẹ́ni kò ri Ọlọ́run nígbà kan rí. Bí àwa bá fẹ́ràn ara wa, Ọlọ́run ń gbé inú wa, a sì mú ìfẹ́ rẹ̀ pé nínú wa. 13 Nípa èyí ni àwa mọ̀ pé àwa ń gbé inú rẹ̀, àti Òun nínú wa, nítorí tí ó ti fi Ẹ̀mí rẹ̀ fún wa. 14 Àwa tí rí, a sì jẹ́rìí pé Baba rán Ọmọ rẹ̀ láti jẹ́ Olùgbàlà fún aráyé. 15 Ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ́wọ́ pé Jesu Ọmọ Ọlọ́run ni, Ọlọ́run ń gbé inú rẹ̀, àti òun nínú Ọlọ́run. 16 Báyìí ni àwa mọ̀, tí a sì gba ìfẹ́ tí Ọlọ́run ní sí wa gbọ́.Ìfẹ́ ni Ọlọ́run; ẹni tí ó bá sì ń gbé inú ìfẹ́, ó ń gbé inú Ọlọ́run, àti Ọlọ́run nínú rẹ̀. 17 Nínú èyí ni a mú ìfẹ́ tí ó wà nínú wa pé, kí àwa bà á lè ni ìgboyà ní ọjọ́ ìdájọ́: nítorí pé bí òun tí rí, bẹ́ẹ̀ ni àwa sì rí ni ayé yìí. 18 Ìbẹ̀rù kò sí nínú ìfẹ́; ṣùgbọ́n ìfẹ́ tí ó pé ń lé ìbẹ̀rù jáde; nítorí tí ìbẹ̀rù ni ìyà nínú. Ẹni tí ó bẹ̀rù kò pé nínú ìfẹ́. 19 Àwa fẹ́ràn rẹ̀ nítorí òun ni ó kọ́ fẹ́ràn wa. 20 Bí ẹnikẹ́ni bá wí pé, “Èmi fẹ́ràn Ọlọ́run,” tí ó sì kórìíra arákùnrin rẹ̀, èké ni: nítorí ẹni tí kò fẹ́ràn arákùnrin rẹ̀ tí ó rí, báwo ni yóò tí ṣe lè fẹ́ràn Ọlọ́run tí òun kò rí? 21 Òfin yìí ni àwa sì rí gbà láti ọwọ́ rẹ̀ wá, pé ẹni tí ó bá fẹ́ràn Ọlọ́run kí ó fẹ́ràn arákùnrin rẹ̀ pẹ̀lú.
In Other Versions
1 John 4 in the ANGEFD
1 John 4 in the ANTPNG2D
1 John 4 in the AS21
1 John 4 in the BAGH
1 John 4 in the BBPNG
1 John 4 in the BBT1E
1 John 4 in the BDS
1 John 4 in the BEV
1 John 4 in the BHAD
1 John 4 in the BIB
1 John 4 in the BLPT
1 John 4 in the BNT
1 John 4 in the BNTABOOT
1 John 4 in the BNTLV
1 John 4 in the BOATCB
1 John 4 in the BOATCB2
1 John 4 in the BOBCV
1 John 4 in the BOCNT
1 John 4 in the BOECS
1 John 4 in the BOGWICC
1 John 4 in the BOHCB
1 John 4 in the BOHCV
1 John 4 in the BOHLNT
1 John 4 in the BOHNTLTAL
1 John 4 in the BOICB
1 John 4 in the BOILNTAP
1 John 4 in the BOITCV
1 John 4 in the BOKCV
1 John 4 in the BOKCV2
1 John 4 in the BOKHWOG
1 John 4 in the BOKSSV
1 John 4 in the BOLCB
1 John 4 in the BOLCB2
1 John 4 in the BOMCV
1 John 4 in the BONAV
1 John 4 in the BONCB
1 John 4 in the BONLT
1 John 4 in the BONUT2
1 John 4 in the BOPLNT
1 John 4 in the BOSCB
1 John 4 in the BOSNC
1 John 4 in the BOTLNT
1 John 4 in the BOVCB
1 John 4 in the BPBB
1 John 4 in the BPH
1 John 4 in the BSB
1 John 4 in the CCB
1 John 4 in the CUV
1 John 4 in the CUVS
1 John 4 in the DBT
1 John 4 in the DGDNT
1 John 4 in the DHNT
1 John 4 in the DNT
1 John 4 in the ELBE
1 John 4 in the EMTV
1 John 4 in the ESV
1 John 4 in the FBV
1 John 4 in the FEB
1 John 4 in the GGMNT
1 John 4 in the GNT
1 John 4 in the HARY
1 John 4 in the HNT
1 John 4 in the IRVA
1 John 4 in the IRVB
1 John 4 in the IRVG
1 John 4 in the IRVH
1 John 4 in the IRVK
1 John 4 in the IRVM
1 John 4 in the IRVM2
1 John 4 in the IRVO
1 John 4 in the IRVP
1 John 4 in the IRVT
1 John 4 in the IRVT2
1 John 4 in the IRVU
1 John 4 in the ISVN
1 John 4 in the JSNT
1 John 4 in the KAPI
1 John 4 in the KBT1ETNIK
1 John 4 in the KBV
1 John 4 in the KJV
1 John 4 in the KNFD
1 John 4 in the LBA
1 John 4 in the LBLA
1 John 4 in the LNT
1 John 4 in the LSV
1 John 4 in the MAAL
1 John 4 in the MBV
1 John 4 in the MBV2
1 John 4 in the MHNT
1 John 4 in the MKNFD
1 John 4 in the MNG
1 John 4 in the MNT
1 John 4 in the MNT2
1 John 4 in the MRS1T
1 John 4 in the NAA
1 John 4 in the NASB
1 John 4 in the NBLA
1 John 4 in the NBS
1 John 4 in the NBVTP
1 John 4 in the NET2
1 John 4 in the NIV11
1 John 4 in the NNT
1 John 4 in the NNT2
1 John 4 in the NNT3
1 John 4 in the PDDPT
1 John 4 in the PFNT
1 John 4 in the RMNT
1 John 4 in the SBIAS
1 John 4 in the SBIBS
1 John 4 in the SBIBS2
1 John 4 in the SBICS
1 John 4 in the SBIDS
1 John 4 in the SBIGS
1 John 4 in the SBIHS
1 John 4 in the SBIIS
1 John 4 in the SBIIS2
1 John 4 in the SBIIS3
1 John 4 in the SBIKS
1 John 4 in the SBIKS2
1 John 4 in the SBIMS
1 John 4 in the SBIOS
1 John 4 in the SBIPS
1 John 4 in the SBISS
1 John 4 in the SBITS
1 John 4 in the SBITS2
1 John 4 in the SBITS3
1 John 4 in the SBITS4
1 John 4 in the SBIUS
1 John 4 in the SBIVS
1 John 4 in the SBT
1 John 4 in the SBT1E
1 John 4 in the SCHL
1 John 4 in the SNT
1 John 4 in the SUSU
1 John 4 in the SUSU2
1 John 4 in the SYNO
1 John 4 in the TBIAOTANT
1 John 4 in the TBT1E
1 John 4 in the TBT1E2
1 John 4 in the TFTIP
1 John 4 in the TFTU
1 John 4 in the TGNTATF3T
1 John 4 in the THAI
1 John 4 in the TNFD
1 John 4 in the TNT
1 John 4 in the TNTIK
1 John 4 in the TNTIL
1 John 4 in the TNTIN
1 John 4 in the TNTIP
1 John 4 in the TNTIZ
1 John 4 in the TOMA
1 John 4 in the TTENT
1 John 4 in the UBG
1 John 4 in the UGV
1 John 4 in the UGV2
1 John 4 in the UGV3
1 John 4 in the VBL
1 John 4 in the VDCC
1 John 4 in the YALU
1 John 4 in the YAPE
1 John 4 in the YBVTP
1 John 4 in the ZBP