Isaiah 51 (BOYCB)

1 “Tẹ́tí sí mi, ẹ̀yin tí ó ń lépa òdodoàti ẹ̀yin tí ń wá OLÚWA.Wo àpáta, nínú èyí tí a ti gé yín jádeàti ihò òkúta níbi tí a ti gbẹ́ yín jáde; 2 ẹ wo Abrahamu baba yín,àti Sara, ẹni tó bí i yín.Nígbà tí mo pè é, òun nìkan ni,Èmi sì bùkún un, mo sì ṣọ́ ọ di ọ̀pọ̀lọpọ̀. 3 Dájúdájú, OLÚWA yóò tu Sioni nínúyóò sì bojú àánú wo gbogbo ahoro rẹ̀;Òun yóò sọ gbogbo aṣálẹ̀ rẹ̀ di Edeni,àti aṣálẹ̀ rẹ̀ yóò rí bí ọgbà OLÚWA.Ayọ̀ àti inú dídùn ni a ó rí nínú rẹ̀,ọpẹ́ àti ariwo orín kíkọ. 4 “Tẹ́tí sí mi, ẹ̀yin ènìyàn mi;gbọ́ tèmi, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè mi.Òfin yóò ti ọ̀dọ̀ mi jáde wá;ìdájọ́ mi yóò di ìmọ́lẹ̀ sí àwọn orílẹ̀-èdè. 5 Òdodo mi ń bọ̀ wá kíkankíkan,ìgbàlà mi ń bọ̀ lójú ọ̀nà,àti apá mi yóò sì mú ìdájọ́ wásí àwọn orílẹ̀-èdè.Àwọn erékùṣù yóò wò míwọn yóò sì dúró ní ìrètí fún apá mi. 6 Gbé ojú rẹ sókè sí àwọn ọ̀run,wo ilẹ̀ ní ìsàlẹ̀ ilẹ̀;àwọn ọ̀run yóò pòórá bí èéfín,ilẹ̀ yóò sì gbó bí ẹ̀wùàwọn olùgbé inú rẹ̀ yóò kú gẹ́gẹ́ bí àwọn eṣinṣin.Ṣùgbọ́n ìgbàlà mi yóò wà títí láé,òdodo mi kì yóò yẹ̀ láé. 7 “Ẹ gbọ́ mi, ẹ̀yin tí ó mọ ohun òtítọ́,ẹ̀yin ènìyàn tí ó ní òfin mi ní àyà yín.Ẹ má ṣe bẹ̀rù ẹ̀gàn àwọn ènìyàntàbí kí ẹ̀rù èébú wọn já a yín láyà. 8 Nítorí kòkòrò yóò mú wọn lá bí aṣọ,ìdin yóò sì mú wọn jẹ bí ẹ̀gbọ̀n òwú.Ṣùgbọ́n òdodo mi yóò wà títí ayérayé,àti ìgbàlà mi láti ìrandíran.” 9 Dìde, dìde! Kí o sì wọ ara rẹ ní agbáraìwọ apá OLÚWA;dìde gẹ́gẹ́ bí i ti ọjọ́ ìgbà n nì,àti gẹ́gẹ́ bí i ti ìran àtijọ́.Ìwọ kọ́ lo ké Rahabu sí wẹ́wẹ́tí o sì fa ẹ̀mí búburú ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ? 10 Ìwọ kọ́ ni ó gbẹ omi Òkun bíàti àwọn omi inú ọ̀gbun,tí o sì ṣe ọ̀nà nínú ìsàlẹ̀ Òkuntó bẹ́ẹ̀ tí àwọn ẹni ìràpadà yóò fi le là á kọjá? 11 Àwọn ẹni ìràpadà OLÚWA yóò padà wá.Wọn yóò wọ Sioni wá pẹ̀lú orin kíkọ;ayọ̀ ayérayé ni yóò sì bo orí wọn.Ayọ̀ àti inú dídùn yóò sì bà lé wọnìbànújẹ́ àti ìtìjú yóò sì sá kúrò. 12 “Èmi, àní Èmi, èmi ni ẹni tí ó tù ọ́ nínú.Ta ni ọ́ tí o fi ń bẹ̀rù ènìyàn ẹlẹ́ran ara,àti ọmọ ènìyàn, tí ó jẹ́ koríko lásán, 13 tí ìwọ sì gbàgbé OLÚWA ẹlẹ́dàá rẹ,ẹni tí ó ta àwọn ọ̀runtí ó sì fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀,tí ẹ sì ń gbé nínú ìpayà lójoojúmọ́nítorí ìbínú àwọn aninilára,tí wọ́n sì gbẹ́kẹ̀lé ìpanirun?Nítorí ibo ni ìbínú àwọn aninilára gbé wà? 14 Àwọn ẹlẹ́wọ̀n tí ń ṣojo la ó dá sílẹ̀ ní àìpẹ́ jọjọwọn kò ní kú sínú túbú wọn,bẹ́ẹ̀ ni wọn kò ní ṣe aláìní àkàrà. 15 Nítorí Èmi ni OLÚWA Ọlọ́run rẹ,tí ó ń ru Òkun sókè tó bẹ́ẹ̀ tíìgbì rẹ̀ fi ń pariwo OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ̀. 16 Mo ti fi ọ̀rọ̀ mi sí ẹnu rẹmo sì ti fi òjìji ọwọ́ mi bò ọ́,Èmi tí mo tẹ́ àwọn ọ̀run sí ààyè rẹ̀,ẹni tí ó fi ìpìlẹ̀ ilẹ̀ ayé lélẹ̀,àti ẹni tí ó sọ fún Sioni pé,‘Ẹ̀yin ni ènìyàn mi.’ ” 17 Jí, jí!Gbéra nílẹ̀ ìwọ Jerusalẹmu,ìwọ tí o ti mu láti ọwọ́ OLÚWAago ìbínú rẹ̀,ìwọ tí o ti fà á mu dé gẹ̀dẹ̀gẹ́dẹ̀tí ó n mú kí ènìyàn ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n. 18 Nínú gbogbo ọmọ tí ó bíkò sí ọ̀kankan tí ó lè tọ́ ọ ṣọ́nànínú gbogbo ọmọ tí ó tọ́kò sí èyí tí ó le fà á lọ́wọ́. 19 Àjálù ìlọ́po ìlọ́po yìí ti dé bá ọ—ta ni yóò tù ọ́ nínú?Ìparun àti ìdahoro, ìyàn àti idàta ni yó pẹ̀tù sí ọ lọ́kàn? 20 Àwọn ọmọkùnrin rẹ ti dákú;wọ́n sùn sí oríta gbogbo òpópónà,gẹ́gẹ́ bí etu tí a dé mọ́nú àwọ̀n.Ìbínú OLÚWA ti kún inú wọn fọ́fọ́àti ìbáwí Ọlọ́run yín. 21 Nítorí náà ẹ gbọ́ èyí, ẹ̀yin tí a ti ṣẹ́ níṣẹ̀ẹ́,tí ọtí ń pa, ṣùgbọ́n kì í ṣe fún wáìnì. 22 Ohun tí OLÚWA Olódùmarè yín wí nìyìí,Ọlọ́run rẹ, ẹni tí ó ń pa ènìyàn rẹ̀ mọ́,“Kíyèsi i, mo ti mú un kúrò ní ọwọ́ rẹago tí ó mú ọ ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n;láti inú ago náà, ẹ̀kún ìbínú mi,ni ìwọ kì yóò mu mọ́. 23 Èmi yóò fi lé àwọn apọ́nilójú rẹ lọ́wọ́,àwọn tí ó wí fún ọ pé,‘Dọ̀bálẹ̀, tó bẹ́ẹ̀ tí a ó fi máa rìn lórí rẹ.’Ìwọ náà ṣe ẹ̀yìn rẹ gẹ́gẹ́ bí ilẹ̀gẹ́gẹ́ bí òpópónà láti máa rìn lórí i rẹ̀.”

In Other Versions

Isaiah 51 in the ANGEFD

Isaiah 51 in the ANTPNG2D

Isaiah 51 in the AS21

Isaiah 51 in the BAGH

Isaiah 51 in the BBPNG

Isaiah 51 in the BBT1E

Isaiah 51 in the BDS

Isaiah 51 in the BEV

Isaiah 51 in the BHAD

Isaiah 51 in the BIB

Isaiah 51 in the BLPT

Isaiah 51 in the BNT

Isaiah 51 in the BNTABOOT

Isaiah 51 in the BNTLV

Isaiah 51 in the BOATCB

Isaiah 51 in the BOATCB2

Isaiah 51 in the BOBCV

Isaiah 51 in the BOCNT

Isaiah 51 in the BOECS

Isaiah 51 in the BOGWICC

Isaiah 51 in the BOHCB

Isaiah 51 in the BOHCV

Isaiah 51 in the BOHLNT

Isaiah 51 in the BOHNTLTAL

Isaiah 51 in the BOICB

Isaiah 51 in the BOILNTAP

Isaiah 51 in the BOITCV

Isaiah 51 in the BOKCV

Isaiah 51 in the BOKCV2

Isaiah 51 in the BOKHWOG

Isaiah 51 in the BOKSSV

Isaiah 51 in the BOLCB

Isaiah 51 in the BOLCB2

Isaiah 51 in the BOMCV

Isaiah 51 in the BONAV

Isaiah 51 in the BONCB

Isaiah 51 in the BONLT

Isaiah 51 in the BONUT2

Isaiah 51 in the BOPLNT

Isaiah 51 in the BOSCB

Isaiah 51 in the BOSNC

Isaiah 51 in the BOTLNT

Isaiah 51 in the BOVCB

Isaiah 51 in the BPBB

Isaiah 51 in the BPH

Isaiah 51 in the BSB

Isaiah 51 in the CCB

Isaiah 51 in the CUV

Isaiah 51 in the CUVS

Isaiah 51 in the DBT

Isaiah 51 in the DGDNT

Isaiah 51 in the DHNT

Isaiah 51 in the DNT

Isaiah 51 in the ELBE

Isaiah 51 in the EMTV

Isaiah 51 in the ESV

Isaiah 51 in the FBV

Isaiah 51 in the FEB

Isaiah 51 in the GGMNT

Isaiah 51 in the GNT

Isaiah 51 in the HARY

Isaiah 51 in the HNT

Isaiah 51 in the IRVA

Isaiah 51 in the IRVB

Isaiah 51 in the IRVG

Isaiah 51 in the IRVH

Isaiah 51 in the IRVK

Isaiah 51 in the IRVM

Isaiah 51 in the IRVM2

Isaiah 51 in the IRVO

Isaiah 51 in the IRVP

Isaiah 51 in the IRVT

Isaiah 51 in the IRVT2

Isaiah 51 in the IRVU

Isaiah 51 in the ISVN

Isaiah 51 in the JSNT

Isaiah 51 in the KAPI

Isaiah 51 in the KBT1ETNIK

Isaiah 51 in the KBV

Isaiah 51 in the KJV

Isaiah 51 in the KNFD

Isaiah 51 in the LBA

Isaiah 51 in the LBLA

Isaiah 51 in the LNT

Isaiah 51 in the LSV

Isaiah 51 in the MAAL

Isaiah 51 in the MBV

Isaiah 51 in the MBV2

Isaiah 51 in the MHNT

Isaiah 51 in the MKNFD

Isaiah 51 in the MNG

Isaiah 51 in the MNT

Isaiah 51 in the MNT2

Isaiah 51 in the MRS1T

Isaiah 51 in the NAA

Isaiah 51 in the NASB

Isaiah 51 in the NBLA

Isaiah 51 in the NBS

Isaiah 51 in the NBVTP

Isaiah 51 in the NET2

Isaiah 51 in the NIV11

Isaiah 51 in the NNT

Isaiah 51 in the NNT2

Isaiah 51 in the NNT3

Isaiah 51 in the PDDPT

Isaiah 51 in the PFNT

Isaiah 51 in the RMNT

Isaiah 51 in the SBIAS

Isaiah 51 in the SBIBS

Isaiah 51 in the SBIBS2

Isaiah 51 in the SBICS

Isaiah 51 in the SBIDS

Isaiah 51 in the SBIGS

Isaiah 51 in the SBIHS

Isaiah 51 in the SBIIS

Isaiah 51 in the SBIIS2

Isaiah 51 in the SBIIS3

Isaiah 51 in the SBIKS

Isaiah 51 in the SBIKS2

Isaiah 51 in the SBIMS

Isaiah 51 in the SBIOS

Isaiah 51 in the SBIPS

Isaiah 51 in the SBISS

Isaiah 51 in the SBITS

Isaiah 51 in the SBITS2

Isaiah 51 in the SBITS3

Isaiah 51 in the SBITS4

Isaiah 51 in the SBIUS

Isaiah 51 in the SBIVS

Isaiah 51 in the SBT

Isaiah 51 in the SBT1E

Isaiah 51 in the SCHL

Isaiah 51 in the SNT

Isaiah 51 in the SUSU

Isaiah 51 in the SUSU2

Isaiah 51 in the SYNO

Isaiah 51 in the TBIAOTANT

Isaiah 51 in the TBT1E

Isaiah 51 in the TBT1E2

Isaiah 51 in the TFTIP

Isaiah 51 in the TFTU

Isaiah 51 in the TGNTATF3T

Isaiah 51 in the THAI

Isaiah 51 in the TNFD

Isaiah 51 in the TNT

Isaiah 51 in the TNTIK

Isaiah 51 in the TNTIL

Isaiah 51 in the TNTIN

Isaiah 51 in the TNTIP

Isaiah 51 in the TNTIZ

Isaiah 51 in the TOMA

Isaiah 51 in the TTENT

Isaiah 51 in the UBG

Isaiah 51 in the UGV

Isaiah 51 in the UGV2

Isaiah 51 in the UGV3

Isaiah 51 in the VBL

Isaiah 51 in the VDCC

Isaiah 51 in the YALU

Isaiah 51 in the YAPE

Isaiah 51 in the YBVTP

Isaiah 51 in the ZBP