Joel 1 (BOYCB)
1 Ọ̀rọ̀ OLÚWA tí ó tọ Joẹli ọmọ Petueli wá. 2 Ẹ gbọ́ èyí ẹ̀yin àgbàgbà;ẹ fi etí sílẹ̀ gbogbo ẹ̀yin ènìyàn ará ilẹ̀ náà.Ǹjẹ́ irú èyí ha wà ní ọjọ́ yín,tàbí ní ọjọ́ àwọn baba yín? 3 Ẹ sọ ọ́ fún àwọn ọmọ yín,ki àwọn ọmọ yín sọ fún àwọn ọmọ wọn,ki àwọn ọmọ wọn sọ fún àwọn ìran mìíràn. 4 Èyí tí eṣú tí agénijẹ jẹ kùní ọ̀wọ́ eṣú ńlá ńlá ti jẹ,èyí tí ọ̀wọ́ eṣú ńlá ńlá jẹ kùní eṣú kéékèèké jẹ,èyí tí eṣú kéékèèké jẹ kùni eṣú apanirun mìíràn jẹ. 5 Ẹ jí gbogbo ẹ̀yin ọ̀mùtí kí ẹ sì sọkúnẹ hu gbogbo ẹ̀yin ọ̀mu-wáìnì;ẹ hu nítorí wáìnì tuntunnítorí a gbà á kúrò lẹ́nu yín. 6 Nítorí orílẹ̀-èdè kan ti ṣígun sí ilẹ̀ mìírànó ní agbára púpọ̀, kò sì ní òǹkà;ó ní eyín kìnnìúnó sì ní èrìgì abo kìnnìún. 7 Ó ti pa àjàrà mi run,ó sì ti ya ẹ̀ka igi ọ̀pọ̀tọ́ mi kúrò,ó ti bò èèpo rẹ̀ jálẹ̀, ó sì sọ ọ́ nù;àwọn ẹ̀ka rẹ̀ ni a sì sọ di funfun. 8 Ẹ pohùnréré ẹkún bí wúńdíátí a fi aṣọ ọ̀fọ̀ dí ni àmùrè, nítorí ọkọ ìgbà èwe rẹ̀. 9 A ké ọrẹ jíjẹ́ àti ọrẹ mímukúrò ní ilé OLÚWA.Àwọn àlùfáà ń ṣọ̀fọ̀,àwọn ìránṣẹ́ OLÚWA. 10 Oko di ìgboro, ilẹ̀ ń ṣọ̀fọ̀,nítorí a fi ọkà ṣòfò:ọtí wáìnì tuntun gbẹ, òróró ń bùṣe. 11 Kí ojú kí ó tì yín, ẹ̀yin àgbẹ̀;ẹ pohùnréré ẹkún ẹ̀yin olùtọ́jú àjàrà,nítorí alikama àti nítorí ọkà barle;nítorí ìkórè oko ṣègbé. 12 Àjàrà gbẹ, igi ọ̀pọ̀tọ́ sì rọ̀ dànù;igi pomegiranate, igi ọ̀pẹ pẹ̀lú,àti igi apiili, gbogbo igi igbó ni o rọ.Nítorí náà ayọ̀ ọmọ ènìyàn gbẹ kúrò lọ́dọ̀ wọn. 13 Ẹ di ara yín ni àmùrè,sí pohùnréré ẹkún ẹ̀yin àlùfáà:ẹ pohùnréré ẹkún, ẹ̀yin ìránṣẹ́ pẹpẹ:ẹ wá, fi gbogbo òru dùbúlẹ̀ nínú aṣọ ọ̀fọ̀,ẹ̀yin ìránṣẹ́ Ọlọ́run mi, nítorí tí a dá ọrẹ-jíjẹ àti ọrẹmímu dúró ní ilé Ọlọ́run yín. 14 Ẹ yà àwẹ̀ kan sí mímọ́,ẹ pe àjọ kan tí o ní ìrònú,ẹ pe àwọn àgbàgbà,àti gbogbo àwọn ará ilẹ̀ náàjọ sí ilé OLÚWA Ọlọ́run yín,kí ẹ sí ké pe OLÚWA. 15 A! Fún ọjọ́ náà,nítorí ọjọ́ OLÚWA kù sí dẹ̀dẹ̀,yóò de bí ìparun láti ọwọ́ Olódùmarè. 16 A kò ha ké oúnjẹ kúrò níwájúojú wá yìí,ayọ̀ àti inú dídùn kúrò nínú iléỌlọ́run wá? 17 Irúgbìn bàjẹ́ nínú ebè wọn,a sọ àká di ahoro, a wó àká palẹ̀;nítorí tí a mú ọkà rọ. 18 Àwọn ẹranko tí ń kérora tó!Àwọn agbo ẹran dààmú,nítorí tí wọ́n kò ni pápá oko;nítòótọ́, àwọn agbo àgùntàn jìyà. 19 OLÚWA, sí ọ ni èmi o ké pè,nítorí iná tí run pápá oko tútù aginjù,ọwọ́ iná sí ti jó gbogbo igi igbó. 20 Àwọn ẹranko igbó gbé ojú sókè sí ọ pẹ̀lú,nítorí tí àwọn ìṣàn omi gbẹ,iná sí ti jó àwọn pápá oko aginjù run.
In Other Versions
Joel 1 in the ANGEFD
Joel 1 in the ANTPNG2D
Joel 1 in the AS21
Joel 1 in the BAGH
Joel 1 in the BBPNG
Joel 1 in the BBT1E
Joel 1 in the BDS
Joel 1 in the BEV
Joel 1 in the BHAD
Joel 1 in the BIB
Joel 1 in the BLPT
Joel 1 in the BNT
Joel 1 in the BNTABOOT
Joel 1 in the BNTLV
Joel 1 in the BOATCB
Joel 1 in the BOATCB2
Joel 1 in the BOBCV
Joel 1 in the BOCNT
Joel 1 in the BOECS
Joel 1 in the BOGWICC
Joel 1 in the BOHCB
Joel 1 in the BOHCV
Joel 1 in the BOHLNT
Joel 1 in the BOHNTLTAL
Joel 1 in the BOICB
Joel 1 in the BOILNTAP
Joel 1 in the BOITCV
Joel 1 in the BOKCV
Joel 1 in the BOKCV2
Joel 1 in the BOKHWOG
Joel 1 in the BOKSSV
Joel 1 in the BOLCB
Joel 1 in the BOLCB2
Joel 1 in the BOMCV
Joel 1 in the BONAV
Joel 1 in the BONCB
Joel 1 in the BONLT
Joel 1 in the BONUT2
Joel 1 in the BOPLNT
Joel 1 in the BOSCB
Joel 1 in the BOSNC
Joel 1 in the BOTLNT
Joel 1 in the BOVCB
Joel 1 in the BPBB
Joel 1 in the BPH
Joel 1 in the BSB
Joel 1 in the CCB
Joel 1 in the CUV
Joel 1 in the CUVS
Joel 1 in the DBT
Joel 1 in the DGDNT
Joel 1 in the DHNT
Joel 1 in the DNT
Joel 1 in the ELBE
Joel 1 in the EMTV
Joel 1 in the ESV
Joel 1 in the FBV
Joel 1 in the FEB
Joel 1 in the GGMNT
Joel 1 in the GNT
Joel 1 in the HARY
Joel 1 in the HNT
Joel 1 in the IRVA
Joel 1 in the IRVB
Joel 1 in the IRVG
Joel 1 in the IRVH
Joel 1 in the IRVK
Joel 1 in the IRVM
Joel 1 in the IRVM2
Joel 1 in the IRVO
Joel 1 in the IRVP
Joel 1 in the IRVT
Joel 1 in the IRVT2
Joel 1 in the IRVU
Joel 1 in the ISVN
Joel 1 in the JSNT
Joel 1 in the KAPI
Joel 1 in the KBT1ETNIK
Joel 1 in the KBV
Joel 1 in the KJV
Joel 1 in the KNFD
Joel 1 in the LBA
Joel 1 in the LBLA
Joel 1 in the LNT
Joel 1 in the LSV
Joel 1 in the MAAL
Joel 1 in the MBV
Joel 1 in the MBV2
Joel 1 in the MHNT
Joel 1 in the MKNFD
Joel 1 in the MNG
Joel 1 in the MNT
Joel 1 in the MNT2
Joel 1 in the MRS1T
Joel 1 in the NAA
Joel 1 in the NASB
Joel 1 in the NBLA
Joel 1 in the NBS
Joel 1 in the NBVTP
Joel 1 in the NET2
Joel 1 in the NIV11
Joel 1 in the NNT
Joel 1 in the NNT2
Joel 1 in the NNT3
Joel 1 in the PDDPT
Joel 1 in the PFNT
Joel 1 in the RMNT
Joel 1 in the SBIAS
Joel 1 in the SBIBS
Joel 1 in the SBIBS2
Joel 1 in the SBICS
Joel 1 in the SBIDS
Joel 1 in the SBIGS
Joel 1 in the SBIHS
Joel 1 in the SBIIS
Joel 1 in the SBIIS2
Joel 1 in the SBIIS3
Joel 1 in the SBIKS
Joel 1 in the SBIKS2
Joel 1 in the SBIMS
Joel 1 in the SBIOS
Joel 1 in the SBIPS
Joel 1 in the SBISS
Joel 1 in the SBITS
Joel 1 in the SBITS2
Joel 1 in the SBITS3
Joel 1 in the SBITS4
Joel 1 in the SBIUS
Joel 1 in the SBIVS
Joel 1 in the SBT
Joel 1 in the SBT1E
Joel 1 in the SCHL
Joel 1 in the SNT
Joel 1 in the SUSU
Joel 1 in the SUSU2
Joel 1 in the SYNO
Joel 1 in the TBIAOTANT
Joel 1 in the TBT1E
Joel 1 in the TBT1E2
Joel 1 in the TFTIP
Joel 1 in the TFTU
Joel 1 in the TGNTATF3T
Joel 1 in the THAI
Joel 1 in the TNFD
Joel 1 in the TNT
Joel 1 in the TNTIK
Joel 1 in the TNTIL
Joel 1 in the TNTIN
Joel 1 in the TNTIP
Joel 1 in the TNTIZ
Joel 1 in the TOMA
Joel 1 in the TTENT
Joel 1 in the UBG
Joel 1 in the UGV
Joel 1 in the UGV2
Joel 1 in the UGV3
Joel 1 in the VBL
Joel 1 in the VDCC
Joel 1 in the YALU
Joel 1 in the YAPE
Joel 1 in the YBVTP
Joel 1 in the ZBP