Nahum 1 (BOYCB)
1 Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ nípa Ninefe. Ìwé ìran Nahumu ará Elkoṣi. 2 Ọlọ́run ń jẹ owú, ó sì ń gbẹ̀san, OLÚWA ń gbẹ̀san, ó sì kún fún ìbínú. OLÚWA ń gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá rẹ̀.Ìbínú rẹ̀ kò sì yí padà lórí àwọn ọ̀tá rẹ̀. 3 OLÚWA lọ́ra láti bínú, ó sì tóbi ní agbára; OLÚWA kì yóò fi àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ sílẹ̀ láìjìyà.Ọ̀nà rẹ̀ wà nínú afẹ́fẹ́ àti nínú ìjì,ìkùùkuu sánmọ̀ sì ni eruku ẹsẹ̀ rẹ̀. 4 Ó bá òkun wí, ó sì mú kí ó gbẹ;Ó sìsọ gbogbo odò di gbígbẹ.Baṣani àti Karmeli sì rọ.Ìtànná Lebanoni sì rẹ̀ sílẹ̀. 5 Àwọn òkè ńlá wárìrì níwájú rẹ̀,àwọn òkè kéékèèké sì di yíyọ́,ilẹ̀ ayé sì jóná níwájú rẹ̀,àní ayé àti gbogbo àwọn tí ń gbé inú rẹ̀. 6 Ta ni ó lé dúró níwájú ìbínú rẹ̀?Ta ni ó lé faradà gbígbóná ìbínú rẹ̀?Ìbínú rẹ̀ tú jáde bí iná;àwọn àpáta sì fọ́ túútúú níwájú rẹ̀. 7 Rere ni OLÚWA,òun ni ààbò ní ọjọ́ ìpọ́njú.Òun sì tọ́jú àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé e, 8 ṣùgbọ́n pẹ̀lú ìkún omi ńlání òun yóò fi ṣe ìparun láti ibẹ̀ dé òpin;òkùnkùn yóò sì máa lépa àwọn ọ̀tá rẹ̀. 9 Kí ni ẹ̀yìn ń gbìmọ̀ lòdì sí OLÚWA?Òun yóò fi òpin sí i,ìpọ́njú kì yóò wáyé ní ìgbà kejì. 10 Wọn yóò sì lọ́lù papọ̀ bí ẹ̀gún òṣùṣúwọn yóò sì mu àmupara nínú ọtí wáìnì wọna ó sì run wọn gẹ́gẹ́ bi àgékù koríko gbígbẹ. 11 Láti ọ̀dọ̀ rẹ, ìwọ Ninefe, ni ẹnìkan ti jáde wátí ó ń gbèrò ibi sí OLÚWAti ó sì ń gbìmọ̀ búburú. 12 Báyìí ni OLÚWA wí:“Bí wọ́n tilẹ̀ ni ìfọwọ́sowọ́pọ̀, tí wọ́n sì pọ̀ níye,ṣùgbọ́n, báyìí ní a ó ké wọn lulẹ̀,nígbà tí òun ó bá kọjá.Bí mo tilẹ̀ ti pọ́n ọ lójú ìwọ Juda, èmi kì yóò pọ́n ọ lójúmọ́. 13 Nísinsin yìí ni èmi yóò já àjàgà wọn kúrò ní ọrùn rẹèmi yóò já ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ rẹ dànù.” 14 OLÚWA ti fi àṣẹ kan lélẹ̀ nítorí tìrẹ Ninefe:“Ìwọ kì yóò ni irú-ọmọ láti máa jẹ́ orúkọ rẹ mọ́,Èmi yóò pa ère fínfín àti ère dídà runtí ó wà nínú tẹmpili àwọn ọlọ́run rẹ.Èmi yóò wa ibojì rẹ,nítorí ẹ̀gbin ni ìwọ.” 15 Wò ó, lórí àwọn òkè,àwọn ẹsẹ̀ ẹni tí ó mú ìròyìn ayọ̀ wá,ẹni tí ó ń kéde àlàáfíà.Ìwọ Juda, pa àṣẹ rẹ tí ó ní ìrònú mọ́,kí ó sì san àwọn ẹ̀jẹ́ rẹ.Àwọn ènìyàn búburú kì yóò sì gbóguntì ọ́ mọ́;wọn yóò sì parun pátápátá.
In Other Versions
Nahum 1 in the ANGEFD
Nahum 1 in the ANTPNG2D
Nahum 1 in the AS21
Nahum 1 in the BAGH
Nahum 1 in the BBPNG
Nahum 1 in the BBT1E
Nahum 1 in the BDS
Nahum 1 in the BEV
Nahum 1 in the BHAD
Nahum 1 in the BIB
Nahum 1 in the BLPT
Nahum 1 in the BNT
Nahum 1 in the BNTABOOT
Nahum 1 in the BNTLV
Nahum 1 in the BOATCB
Nahum 1 in the BOATCB2
Nahum 1 in the BOBCV
Nahum 1 in the BOCNT
Nahum 1 in the BOECS
Nahum 1 in the BOGWICC
Nahum 1 in the BOHCB
Nahum 1 in the BOHCV
Nahum 1 in the BOHLNT
Nahum 1 in the BOHNTLTAL
Nahum 1 in the BOICB
Nahum 1 in the BOILNTAP
Nahum 1 in the BOITCV
Nahum 1 in the BOKCV
Nahum 1 in the BOKCV2
Nahum 1 in the BOKHWOG
Nahum 1 in the BOKSSV
Nahum 1 in the BOLCB
Nahum 1 in the BOLCB2
Nahum 1 in the BOMCV
Nahum 1 in the BONAV
Nahum 1 in the BONCB
Nahum 1 in the BONLT
Nahum 1 in the BONUT2
Nahum 1 in the BOPLNT
Nahum 1 in the BOSCB
Nahum 1 in the BOSNC
Nahum 1 in the BOTLNT
Nahum 1 in the BOVCB
Nahum 1 in the BPBB
Nahum 1 in the BPH
Nahum 1 in the BSB
Nahum 1 in the CCB
Nahum 1 in the CUV
Nahum 1 in the CUVS
Nahum 1 in the DBT
Nahum 1 in the DGDNT
Nahum 1 in the DHNT
Nahum 1 in the DNT
Nahum 1 in the ELBE
Nahum 1 in the EMTV
Nahum 1 in the ESV
Nahum 1 in the FBV
Nahum 1 in the FEB
Nahum 1 in the GGMNT
Nahum 1 in the GNT
Nahum 1 in the HARY
Nahum 1 in the HNT
Nahum 1 in the IRVA
Nahum 1 in the IRVB
Nahum 1 in the IRVG
Nahum 1 in the IRVH
Nahum 1 in the IRVK
Nahum 1 in the IRVM
Nahum 1 in the IRVM2
Nahum 1 in the IRVO
Nahum 1 in the IRVP
Nahum 1 in the IRVT
Nahum 1 in the IRVT2
Nahum 1 in the IRVU
Nahum 1 in the ISVN
Nahum 1 in the JSNT
Nahum 1 in the KAPI
Nahum 1 in the KBT1ETNIK
Nahum 1 in the KBV
Nahum 1 in the KJV
Nahum 1 in the KNFD
Nahum 1 in the LBA
Nahum 1 in the LBLA
Nahum 1 in the LNT
Nahum 1 in the LSV
Nahum 1 in the MAAL
Nahum 1 in the MBV
Nahum 1 in the MBV2
Nahum 1 in the MHNT
Nahum 1 in the MKNFD
Nahum 1 in the MNG
Nahum 1 in the MNT
Nahum 1 in the MNT2
Nahum 1 in the MRS1T
Nahum 1 in the NAA
Nahum 1 in the NASB
Nahum 1 in the NBLA
Nahum 1 in the NBS
Nahum 1 in the NBVTP
Nahum 1 in the NET2
Nahum 1 in the NIV11
Nahum 1 in the NNT
Nahum 1 in the NNT2
Nahum 1 in the NNT3
Nahum 1 in the PDDPT
Nahum 1 in the PFNT
Nahum 1 in the RMNT
Nahum 1 in the SBIAS
Nahum 1 in the SBIBS
Nahum 1 in the SBIBS2
Nahum 1 in the SBICS
Nahum 1 in the SBIDS
Nahum 1 in the SBIGS
Nahum 1 in the SBIHS
Nahum 1 in the SBIIS
Nahum 1 in the SBIIS2
Nahum 1 in the SBIIS3
Nahum 1 in the SBIKS
Nahum 1 in the SBIKS2
Nahum 1 in the SBIMS
Nahum 1 in the SBIOS
Nahum 1 in the SBIPS
Nahum 1 in the SBISS
Nahum 1 in the SBITS
Nahum 1 in the SBITS2
Nahum 1 in the SBITS3
Nahum 1 in the SBITS4
Nahum 1 in the SBIUS
Nahum 1 in the SBIVS
Nahum 1 in the SBT
Nahum 1 in the SBT1E
Nahum 1 in the SCHL
Nahum 1 in the SNT
Nahum 1 in the SUSU
Nahum 1 in the SUSU2
Nahum 1 in the SYNO
Nahum 1 in the TBIAOTANT
Nahum 1 in the TBT1E
Nahum 1 in the TBT1E2
Nahum 1 in the TFTIP
Nahum 1 in the TFTU
Nahum 1 in the TGNTATF3T
Nahum 1 in the THAI
Nahum 1 in the TNFD
Nahum 1 in the TNT
Nahum 1 in the TNTIK
Nahum 1 in the TNTIL
Nahum 1 in the TNTIN
Nahum 1 in the TNTIP
Nahum 1 in the TNTIZ
Nahum 1 in the TOMA
Nahum 1 in the TTENT
Nahum 1 in the UBG
Nahum 1 in the UGV
Nahum 1 in the UGV2
Nahum 1 in the UGV3
Nahum 1 in the VBL
Nahum 1 in the VDCC
Nahum 1 in the YALU
Nahum 1 in the YAPE
Nahum 1 in the YBVTP
Nahum 1 in the ZBP