Nahum 3 (BOYCB)
1 Ègbé ni fún ìlú ẹ̀jẹ̀ nì,gbogbo rẹ̀ kún fún èké,ó kún fún olè,ìjẹ kò kúrò! 2 Ariwo pàṣán àti ariwokíkùn kẹ̀kẹ́ ogunàti jíjó ẹṣinàti gbígbọn kẹ̀kẹ́ ogun jìgìjìgì! 3 Ológun orí ẹṣin ń fi ìgbónáraju idà wọn mọ̀nàmọ́náọ̀kọ̀ rẹ̀ ti ń dán yanran sí òkè!Ọ̀pọ̀lọpọ̀ si ní àwọn ẹni tí a pa,àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ òkú;òkú kò sì ni òpin;àwọn ènìyàn sì ń kọsẹ̀ lára àwọn òkú. 4 Nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ panṣágààgbèrè tí ó rójú rere gbà,ìyá àjẹ́ tí ó ṣọ́ àwọn Orílẹ̀-èdè di ẹrúnípa àgbèrè rẹ̀àti àwọn ìdílé nípa ìṣe àjẹ́ rẹ̀. 5 “Èmi dojúkọ ọ́,” ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí.“Èmi ó si ká aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ rẹ ní ojú rẹ.Èmi yóò sì fi ìhòhò rẹ̀ han àwọn orílẹ̀-èdèàti ìtìjú rẹ̀ han àwọn ilẹ̀ ọba. 6 Èmi yóò da ẹ̀gbin tí ó ni ìríra sí ọ ní ara,èmi yóò sì sọ ọ́ di aláìmọ́,èmi yóò sì sọ ọ́ di ẹlẹ́yà. 7 Gbogbo àwọn tí ó ba sì wò ọ́ yóò sì káàánú fún ọ, wọn yóò sì wí pé,‘Ninefe ṣòfò, ta ni yóò kẹ́dùn rẹ?’Níbo ni èmi o ti wá olùtùnú fún ọ?” 8 Ǹjẹ́ ìwọ ha sàn ju Tebesi lọ,èyí tí ó wà ní ibi odò Naili,tí omi sì yí káàkiri?Odò náà sì jẹ́ ààbò rẹ̀,omi si jẹ́ odi rẹ̀. 9 Etiopia àti Ejibiti ni agbára rẹ, kò sí ní òpin;Puti àti Libia ni àwọn olùgbèjà rẹ̀. 10 Síbẹ̀síbẹ̀ a kó o ní ìgbèkùno sì lọ sí oko ẹrú.Àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ rẹ̀ ni a ó fọ́ mọ́lẹ̀ní orí ìta gbogbo ìgboro.Wọ́n sì di ìbò nítorí àwọn ọlọ́lá rẹ̀ ọkùnrin,gbogbo àwọn ọlọ́lá rẹ ni a sì fi ẹ̀wọ̀n dè. 11 Ìwọ pẹ̀lú yóò sì mu àmupara;a ó sì fi ọ́ pamọ́ìwọ pẹ̀lú yóò máa ṣe àfẹ́rí ààbò nítorí ti ọ̀tá náà. 12 Gbogbo ilé ìṣọ́ agbára rẹ yóò dàbí igi ọ̀pọ̀tọ́pẹ̀lú àkọ́pọ́n èso wọn;nígbà tí wọ́n bá ń gbọ̀n wọ́n,ọ̀pọ̀tọ́ yóò sì bọ́ sí ẹnu àwọn ọ̀jẹun. 13 Kíyèsi gbogbo àwọn jagunjagun!Obìnrin ni gbogbo wọn.Ojú ibodè rẹ ní a ó ṣí sílẹ̀ gbagada,fún àwọn ọ̀tá rẹ;iná yóò jó ọ̀pá ìdábùú ìlẹ̀kùn ibodè rẹ. 14 Pọn omi nítorí ìhámọ́,mú ilé ìṣọ́ rẹ lágbára sí iwọ inú amọ̀kí o sì tẹ erùpẹ̀,kí ó sì tún ibi tí a ti ń sun bíríkì-amọ̀ ṣe kí ó le. 15 Níbẹ̀ ni iná yóò ti jó ọ́ run;idà yóò sì ké ọ kúrò,yóò sì jẹ ọ́ bí i kòkòrò,yóò sì sọ ara rẹ̀ di púpọ̀ bí i tata,àní, di púpọ̀ bí eṣú! 16 Ìwọ ti sọ àwọn oníṣòwò rẹ di púpọ̀títí wọn yóò fi pọ̀ ju ìràwọ̀ ojú ọ̀run lọ,ṣùgbọ́n bi eṣú ni wọn yóò sọ ilẹ̀ náà di ahoro, wọn yóò sì fò lọ. 17 Àwọn aládé rẹ̀ dàbí eṣú,àwọn ọ̀gágun rẹ dàbí ẹlẹ́ǹgà ńlá,èyí tí ń dó sínú ọgbà ni ọjọ́ òtútù,ṣùgbọ́n nígbà tí oòrùn jáde, wọ́n sálọ,ẹnìkan kò sì mọ ibi tí wọ́n gbé wà. 18 Ìwọ ọba Asiria,àwọn olùṣọ́-àgùntàn rẹ̀ ń tòògbé;àwọn ọlọ́lá rẹ dùbúlẹ̀ láti sinmi.Àwọn ènìyàn rẹ fọ́nká lórí àwọn òkè ńlá,tí ẹnikẹ́ni kò sì kó wọn jọ. 19 Kò sì sí ohun tí ó lè wo ọgbẹ́ ẹ̀ rẹ sàn;ọgbẹ́ rẹ kún fún ìrora,Gbogbo ẹni tí ó bá sì gbọ́ ìròyìn rẹyóò pàtẹ́wọ́ lé ọ lórí,nítorí ta ni kò ní pín nínúìwà búburú rẹ ti kò ti lópin.
In Other Versions
Nahum 3 in the ANGEFD
Nahum 3 in the ANTPNG2D
Nahum 3 in the AS21
Nahum 3 in the BAGH
Nahum 3 in the BBPNG
Nahum 3 in the BBT1E
Nahum 3 in the BDS
Nahum 3 in the BEV
Nahum 3 in the BHAD
Nahum 3 in the BIB
Nahum 3 in the BLPT
Nahum 3 in the BNT
Nahum 3 in the BNTABOOT
Nahum 3 in the BNTLV
Nahum 3 in the BOATCB
Nahum 3 in the BOATCB2
Nahum 3 in the BOBCV
Nahum 3 in the BOCNT
Nahum 3 in the BOECS
Nahum 3 in the BOGWICC
Nahum 3 in the BOHCB
Nahum 3 in the BOHCV
Nahum 3 in the BOHLNT
Nahum 3 in the BOHNTLTAL
Nahum 3 in the BOICB
Nahum 3 in the BOILNTAP
Nahum 3 in the BOITCV
Nahum 3 in the BOKCV
Nahum 3 in the BOKCV2
Nahum 3 in the BOKHWOG
Nahum 3 in the BOKSSV
Nahum 3 in the BOLCB
Nahum 3 in the BOLCB2
Nahum 3 in the BOMCV
Nahum 3 in the BONAV
Nahum 3 in the BONCB
Nahum 3 in the BONLT
Nahum 3 in the BONUT2
Nahum 3 in the BOPLNT
Nahum 3 in the BOSCB
Nahum 3 in the BOSNC
Nahum 3 in the BOTLNT
Nahum 3 in the BOVCB
Nahum 3 in the BPBB
Nahum 3 in the BPH
Nahum 3 in the BSB
Nahum 3 in the CCB
Nahum 3 in the CUV
Nahum 3 in the CUVS
Nahum 3 in the DBT
Nahum 3 in the DGDNT
Nahum 3 in the DHNT
Nahum 3 in the DNT
Nahum 3 in the ELBE
Nahum 3 in the EMTV
Nahum 3 in the ESV
Nahum 3 in the FBV
Nahum 3 in the FEB
Nahum 3 in the GGMNT
Nahum 3 in the GNT
Nahum 3 in the HARY
Nahum 3 in the HNT
Nahum 3 in the IRVA
Nahum 3 in the IRVB
Nahum 3 in the IRVG
Nahum 3 in the IRVH
Nahum 3 in the IRVK
Nahum 3 in the IRVM
Nahum 3 in the IRVM2
Nahum 3 in the IRVO
Nahum 3 in the IRVP
Nahum 3 in the IRVT
Nahum 3 in the IRVT2
Nahum 3 in the IRVU
Nahum 3 in the ISVN
Nahum 3 in the JSNT
Nahum 3 in the KAPI
Nahum 3 in the KBT1ETNIK
Nahum 3 in the KBV
Nahum 3 in the KJV
Nahum 3 in the KNFD
Nahum 3 in the LBA
Nahum 3 in the LBLA
Nahum 3 in the LNT
Nahum 3 in the LSV
Nahum 3 in the MAAL
Nahum 3 in the MBV
Nahum 3 in the MBV2
Nahum 3 in the MHNT
Nahum 3 in the MKNFD
Nahum 3 in the MNG
Nahum 3 in the MNT
Nahum 3 in the MNT2
Nahum 3 in the MRS1T
Nahum 3 in the NAA
Nahum 3 in the NASB
Nahum 3 in the NBLA
Nahum 3 in the NBS
Nahum 3 in the NBVTP
Nahum 3 in the NET2
Nahum 3 in the NIV11
Nahum 3 in the NNT
Nahum 3 in the NNT2
Nahum 3 in the NNT3
Nahum 3 in the PDDPT
Nahum 3 in the PFNT
Nahum 3 in the RMNT
Nahum 3 in the SBIAS
Nahum 3 in the SBIBS
Nahum 3 in the SBIBS2
Nahum 3 in the SBICS
Nahum 3 in the SBIDS
Nahum 3 in the SBIGS
Nahum 3 in the SBIHS
Nahum 3 in the SBIIS
Nahum 3 in the SBIIS2
Nahum 3 in the SBIIS3
Nahum 3 in the SBIKS
Nahum 3 in the SBIKS2
Nahum 3 in the SBIMS
Nahum 3 in the SBIOS
Nahum 3 in the SBIPS
Nahum 3 in the SBISS
Nahum 3 in the SBITS
Nahum 3 in the SBITS2
Nahum 3 in the SBITS3
Nahum 3 in the SBITS4
Nahum 3 in the SBIUS
Nahum 3 in the SBIVS
Nahum 3 in the SBT
Nahum 3 in the SBT1E
Nahum 3 in the SCHL
Nahum 3 in the SNT
Nahum 3 in the SUSU
Nahum 3 in the SUSU2
Nahum 3 in the SYNO
Nahum 3 in the TBIAOTANT
Nahum 3 in the TBT1E
Nahum 3 in the TBT1E2
Nahum 3 in the TFTIP
Nahum 3 in the TFTU
Nahum 3 in the TGNTATF3T
Nahum 3 in the THAI
Nahum 3 in the TNFD
Nahum 3 in the TNT
Nahum 3 in the TNTIK
Nahum 3 in the TNTIL
Nahum 3 in the TNTIN
Nahum 3 in the TNTIP
Nahum 3 in the TNTIZ
Nahum 3 in the TOMA
Nahum 3 in the TTENT
Nahum 3 in the UBG
Nahum 3 in the UGV
Nahum 3 in the UGV2
Nahum 3 in the UGV3
Nahum 3 in the VBL
Nahum 3 in the VDCC
Nahum 3 in the YALU
Nahum 3 in the YAPE
Nahum 3 in the YBVTP
Nahum 3 in the ZBP