Job 6 (BOYCB)
1 Jobu sì dáhùn ó si wí pé, 2 “Háà! À bá lè wọ́n ìbìnújẹ́ mi nínú òsùwọ̀n,kí a sì le gbé ọ̀fọ̀ mi lé orí òsùwọ̀n ṣọ̀kan pọ̀! 3 Ǹjẹ́ nísinsin yìí, ìbá wúwo jú iyanrìn òkun lọ,nítorí náà ni ọ̀rọ̀ mi ṣe ń tàsé. 4 Nítorí pé ọfà Olódùmarè wọ̀ mi nínú,oró èyí tí ọkàn mi mú;ìpayà-ẹ̀rù Ọlọ́run dúró tì mí. 5 Ǹjẹ́ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó á máa dún nígbà tí ó bá ní koríko,tàbí ọ̀dá màlúù a máa dún lórí ìjẹ rẹ̀? 6 A ha lè jẹ ohun tí kò ní adùn ní àìní iyọ̀,tàbí adùn ha wà nínú funfun ẹyin? 7 Ohun ti ọ̀kan mi kọ̀ láti tọ́wò,òun ni ó dàbí oúnjẹ tí ó mú mi ṣàárẹ̀. 8 “Háà! èmi ìbá lè rí ìbéèrè mi gbà;àti pé, kí Ọlọ́run lè fi ohun tí èmi ṣàfẹ́rí fún mi. 9 Àní Ọlọ́run ìbá jẹ́ pa mí run,tí òun ìbá jẹ́ ṣíwọ́ rẹ̀ kì ó sì ké mi kúrò. 10 Nígbà náà ní èmi ìbá ní ìtùnú síbẹ̀,àní, èmi ìbá mú ọkàn mi le nínú ìbànújẹ́ mi ti kò dá ni sí:nítorí èmi kò fi ọ̀rọ̀ ẹni mímọ́ ni sin rí. 11 “Kí ní agbára mi tí èmi ó fi retí?Kí sì ní òpin mi tí èmi ó fi ní sùúrù? 12 Agbára mi ha ṣe agbára òkúta bí?Ẹran-ara mi í ṣe idẹ? 13 Ìrànlọ́wọ́ mi kò ha wà nínú mi:ọgbọ́n kò ha ti sálọ kúrò lọ́dọ̀ mi bí? 14 “Ẹni tí àyà rẹ̀ yọ́ dànù, ta ni a bá máa ṣàánú fún láti ọ̀dọ̀ ọ̀rẹ́ rẹ̀ wá,kí ó má ba à kọ ìbẹ̀rù Olódùmarè sílẹ̀? 15 Àwọn ará mi dàbí odò tí kò ṣe gbẹ́kẹ̀lébí ìṣàn omi odò, wọ́n sàn kọjá lọ. 16 Tí ó dúdú nítorí omi dídì,àti níbi tí yìnyín dídì gbé di yíyọ́. 17 Nígbàkígbà tí wọ́n bá gbóná wọn a sì yọ́ sàn lọ,nígbà tí oòrùn bá mú, wọn a sì gbẹ kúrò ni ipò wọn. 18 Àwọn oníṣòwò yà kúrò ní ọ̀nà wọn,wọ́n gòkè sí ibi asán, wọ́n sì run. 19 Ẹgbẹ́ oníṣòwò Tema ń wá omi,àwọn oníṣòwò Ṣeba ń dúró dè wọ́n ní ìrètí. 20 Wọ́n káàárẹ̀, nítorí tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ wọn lé e;wọ́n dé bẹ̀, wọ́n sì dààmú. 21 Ǹjẹ́ nísinsin yìí, ẹ̀yin dàbí wọn;ẹ̀yin rí ìrẹ̀sílẹ̀ mi àyà sì fò mí. 22 Èmi ó ha wí pé, ‘Ẹ mú ohun fún mi wá,tàbí pé ẹ fún mi ní ẹ̀bùn nínú ohun ìní yín? 23 Tàbí, ẹ gbà mí lọ́wọ́ ọ̀tá ni,tàbí, ẹ rà mí padà kúrò lọ́wọ́ alágbára nì’? 24 “Ẹ kọ́ mi, èmi ó sì pa ẹnu mi mọ́kí ẹ sì mú mi wòye níbi tí mo gbé ti ṣìnà. 25 Wò ó! Bí ọ̀rọ̀ òtítọ́ ti lágbára tóṣùgbọ́n kí ni àròyé ìbáwí yín jásí? 26 Ẹ̀yin ṣè bí ẹ tún ọ̀rọ̀ mi ṣeàti ohùn ẹnu tí ó dàbí afẹ́fẹ́ ṣe àárẹ̀. 27 Àní ẹ̀yin ṣe gẹ́gẹ́ bí aláìní baba,ẹ̀yin sì da iye lé ọ̀rẹ́ yín. 28 “Nítorí náà, kí èyí kí ó tó fún yín.Ẹ má wò mi! Nítorí pé ó hàn gbangba pé,ní ojú yín ni èmi kì yóò ṣèké. 29 Èmi ń bẹ̀ yín, ẹ padà, kí ó má sì ṣe jásí ẹ̀ṣẹ̀;àní, ẹ sì tún padà, àre mi ń bẹ nínú ọ̀rọ̀ yìí. 30 Àìṣedéédéé ha wà ní ahọ́n mi?Ǹjẹ́ ìtọ́wò ẹnu mi kò kúkú le mọ ohun ti ó burú jù?
In Other Versions
Job 6 in the ANGEFD
Job 6 in the ANTPNG2D
Job 6 in the AS21
Job 6 in the BAGH
Job 6 in the BBPNG
Job 6 in the BBT1E
Job 6 in the BDS
Job 6 in the BEV
Job 6 in the BHAD
Job 6 in the BIB
Job 6 in the BLPT
Job 6 in the BNT
Job 6 in the BNTABOOT
Job 6 in the BNTLV
Job 6 in the BOATCB
Job 6 in the BOATCB2
Job 6 in the BOBCV
Job 6 in the BOCNT
Job 6 in the BOECS
Job 6 in the BOGWICC
Job 6 in the BOHCB
Job 6 in the BOHCV
Job 6 in the BOHLNT
Job 6 in the BOHNTLTAL
Job 6 in the BOICB
Job 6 in the BOILNTAP
Job 6 in the BOITCV
Job 6 in the BOKCV
Job 6 in the BOKCV2
Job 6 in the BOKHWOG
Job 6 in the BOKSSV
Job 6 in the BOLCB
Job 6 in the BOLCB2
Job 6 in the BOMCV
Job 6 in the BONAV
Job 6 in the BONCB
Job 6 in the BONLT
Job 6 in the BONUT2
Job 6 in the BOPLNT
Job 6 in the BOSCB
Job 6 in the BOSNC
Job 6 in the BOTLNT
Job 6 in the BOVCB
Job 6 in the BPBB
Job 6 in the BPH
Job 6 in the BSB
Job 6 in the CCB
Job 6 in the CUV
Job 6 in the CUVS
Job 6 in the DBT
Job 6 in the DGDNT
Job 6 in the DHNT
Job 6 in the DNT
Job 6 in the ELBE
Job 6 in the EMTV
Job 6 in the ESV
Job 6 in the FBV
Job 6 in the FEB
Job 6 in the GGMNT
Job 6 in the GNT
Job 6 in the HARY
Job 6 in the HNT
Job 6 in the IRVA
Job 6 in the IRVB
Job 6 in the IRVG
Job 6 in the IRVH
Job 6 in the IRVK
Job 6 in the IRVM
Job 6 in the IRVM2
Job 6 in the IRVO
Job 6 in the IRVP
Job 6 in the IRVT
Job 6 in the IRVT2
Job 6 in the IRVU
Job 6 in the ISVN
Job 6 in the JSNT
Job 6 in the KAPI
Job 6 in the KBT1ETNIK
Job 6 in the KBV
Job 6 in the KJV
Job 6 in the KNFD
Job 6 in the LBA
Job 6 in the LBLA
Job 6 in the LNT
Job 6 in the LSV
Job 6 in the MAAL
Job 6 in the MBV
Job 6 in the MBV2
Job 6 in the MHNT
Job 6 in the MKNFD
Job 6 in the MNG
Job 6 in the MNT
Job 6 in the MNT2
Job 6 in the MRS1T
Job 6 in the NAA
Job 6 in the NASB
Job 6 in the NBLA
Job 6 in the NBS
Job 6 in the NBVTP
Job 6 in the NET2
Job 6 in the NIV11
Job 6 in the NNT
Job 6 in the NNT2
Job 6 in the NNT3
Job 6 in the PDDPT
Job 6 in the PFNT
Job 6 in the RMNT
Job 6 in the SBIAS
Job 6 in the SBIBS
Job 6 in the SBIBS2
Job 6 in the SBICS
Job 6 in the SBIDS
Job 6 in the SBIGS
Job 6 in the SBIHS
Job 6 in the SBIIS
Job 6 in the SBIIS2
Job 6 in the SBIIS3
Job 6 in the SBIKS
Job 6 in the SBIKS2
Job 6 in the SBIMS
Job 6 in the SBIOS
Job 6 in the SBIPS
Job 6 in the SBISS
Job 6 in the SBITS
Job 6 in the SBITS2
Job 6 in the SBITS3
Job 6 in the SBITS4
Job 6 in the SBIUS
Job 6 in the SBIVS
Job 6 in the SBT
Job 6 in the SBT1E
Job 6 in the SCHL
Job 6 in the SNT
Job 6 in the SUSU
Job 6 in the SUSU2
Job 6 in the SYNO
Job 6 in the TBIAOTANT
Job 6 in the TBT1E
Job 6 in the TBT1E2
Job 6 in the TFTIP
Job 6 in the TFTU
Job 6 in the TGNTATF3T
Job 6 in the THAI
Job 6 in the TNFD
Job 6 in the TNT
Job 6 in the TNTIK
Job 6 in the TNTIL
Job 6 in the TNTIN
Job 6 in the TNTIP
Job 6 in the TNTIZ
Job 6 in the TOMA
Job 6 in the TTENT
Job 6 in the UBG
Job 6 in the UGV
Job 6 in the UGV2
Job 6 in the UGV3
Job 6 in the VBL
Job 6 in the VDCC
Job 6 in the YALU
Job 6 in the YAPE
Job 6 in the YBVTP
Job 6 in the ZBP