Zephaniah 3 (BOYCB)
1 Ègbé ni fún ìlú aninilára,ọlọ̀tẹ̀ àti aláìmọ́. 2 Òun kò gbọ́rọ̀ sí ẹnikẹ́ni,òun kò gba ìtọ́ni,òun kò gbẹ́kẹ̀lé OLÚWA,bẹ́ẹ̀ ni òun kò súnmọ́ ọ̀dọ̀ Ọlọ́run rẹ̀. 3 Àwọn olórí rẹ̀ jẹ́ kìnnìún tí ń ké ramúramù,àwọn onídàájọ́ rẹ̀, ìkookò àṣálẹ́ ni wọn,wọn kò sì fi nǹkan kan kalẹ̀ fún òwúrọ̀. 4 Àwọn wòlíì rẹ̀ gbéraga,wọ́n sì jẹ́ alárékérekè ènìyàn.Àwọn àlùfáà rẹ̀ ti ba ibi mímọ́ jẹ́,wọ́n sì rú òfin. 5 OLÚWA ni àárín rẹ̀ jẹ́ olódodo;kì yóò ṣe ohun tí kò tọ̀nà.Àràárọ̀ ni ó máa ń mú ìdájọ́ rẹ̀ wá sí ìmọ́lẹ̀,kì í sì kùnà ní gbogbo ọjọ́ tuntun,síbẹ̀ àwọn aláìṣòótọ́ kò mọ ìtìjú. 6 “Èmi ti ké àwọn orílẹ̀-èdè kúrò,ilé gíga wọn sì ti bàjẹ́.Mo ti fi ìgboro wọn sílẹ̀ ní òfotó bẹ́ẹ̀ tí ẹnìkankan kò kọjá níbẹ̀.Ìlú wọn parun tó bẹ́ẹ̀ tí kò síẹnìkan tí yóò ṣẹ́kù,kò sì ní sí ẹnìkan rárá. 7 Èmi wí fún ìlú náà wí pé,‘Nítòótọ́, ìwọ yóò bẹ̀rù mi,ìwọ yóò sì gba ìtọ́ni!’Bẹ́ẹ̀ ni, a kì yóò ké ibùgbé rẹ̀ kúròbí ó ti wù kí ń jẹ wọ́n ní yà tó.Ṣùgbọ́n síbẹ̀ wọ́n sì tún ní ìtaraláti ṣe ìbàjẹ́. 8 Nítorí náà ẹ dúró dè mí,” ni OLÚWA wí,“títí di ọjọ́ náà tí èmi yóò fi jẹ́rìí sí yin.Nítorí ìpinnu mi ni láti kó orílẹ̀-èdè jọkí èmi kí ó lè kó ilẹ̀ ọba jọàti láti da ìbínú mi jáde sórí wọn,àní gbogbo ìbínú gbígbóná mi.Nítorí gbogbo ayéni a ó fi iná owú mi jẹ run. 9 “Nígbà náà ni èmi yóò yí èdè àwọn ènìyàn padà sí èdè mímọ́,nítorí kí gbogbo wọn bá a lè máa pe orúkọ OLÚWA,láti fi ọkàn kan sìn ín. 10 Láti òkè odò Etiopia,àwọn olùjọsìn mi, àwọn ènìyàn mi tí ó ti fọ́nká,yóò mú ọrẹ wá fún mi. 11 Ní ọjọ́ náà ni a kì yóò sì dójútìnítorí gbogbo iṣẹ́ ibi ni tí ó ti ṣẹ̀ sí mi,nígbà náà ni èmi yóò mukúrò nínú ìlú yìí, àwọn tí ń yọ̀ nínú ìgbéraga wọn.Ìwọ kì yóò sì gbéraga mọ́ní òkè mímọ́ mi. 12 Ṣùgbọ́n Èmi yóò fi àwọn ọlọ́kàn tútùàti onírẹ̀lẹ̀ sílẹ̀ pẹ̀lú ni àárín rẹ̀,wọn yóò sì gbẹ́kẹ̀lé orúkọ OLÚWA. 13 Àwọn ìyókù Israẹli kì yóò hùwà ibi,wọn kì yóò sọ̀rọ̀ èké.Bẹ́ẹ̀ ni a kì yóò ríahọ́n àrékérekè ní ẹnu wọn.Àwọn yóò jẹun, wọn yóò sì dùbúlẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni ẹnikẹ́ni kì yóò dẹ́rùbà wọ́n.” 14 Kọrin, ìwọ ọmọbìnrin Sioni,kígbe sókè, ìwọ Israẹli!Fi gbogbo ọkàn yọ̀, kí inú rẹ kí ó sì dùn,ìwọ ọmọbìnrin Jerusalẹmu. 15 OLÚWA ti mú ìdájọ́ rẹ wọ̀n-ọn-nì kúrò,ó sì ti ti àwọn ọ̀tá rẹ padà sẹ́yìn. OLÚWA, ọba Israẹli wà pẹ̀lú rẹ;ìwọ kì yóò sì bẹ̀rù ibi kan mọ́. 16 Ní ọjọ́ náà, wọn yóò sọ fún Jerusalẹmu pé,“Má ṣe bẹ̀rù Sioni;má sì ṣe jẹ́ kí ọwọ́ rẹ kí ó dẹ̀. 17 OLÚWA Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ,Ó ní agbára láti gbà ọ là.Yóò yọ̀ ni orí rẹ fún ayọ̀;Yóò tún ọ ṣe nínú ìfẹ́ rẹ̀,Yóò sì fi orin yọ̀ ní orí rẹ.” 18 “Èmi ó kó àwọn tí ó ń banújẹ́ fún àjọ̀dún tí a yàn jọ,àwọn tí ó jẹ́ tirẹ̀;àwọn tí ẹ̀gàn rẹ̀ jásí ẹ̀rù. 19 Ní àkókò náàni èmi yóò dojúkọ àwọntí ń ni yín lára,èmi yóò gba àtiro là,èmi yóò sì ṣa àwọn tí ó ti fọ́nká jọ,èmi yóò fi ìyìn àti ọlá fún wọn nígbogbo ilẹ̀ tí a bá ti dójútì wọ́n. 20 Ní àkókò náà ni èmi yóò ṣà yín jọ;nígbà náà ni èmi yóò mú un yín padà wá sílé.Èmi yóò fi ọlá àti ìyìn fún un yínláàrín gbogbo ènìyàn àgbáyé,nígbà tí èmi yóò yí ìgbèkùn yínpadà bọ sípò ní ojú ara yín,”ni OLÚWA wí.
In Other Versions
Zephaniah 3 in the ANGEFD
Zephaniah 3 in the ANTPNG2D
Zephaniah 3 in the AS21
Zephaniah 3 in the BAGH
Zephaniah 3 in the BBPNG
Zephaniah 3 in the BBT1E
Zephaniah 3 in the BDS
Zephaniah 3 in the BEV
Zephaniah 3 in the BHAD
Zephaniah 3 in the BIB
Zephaniah 3 in the BLPT
Zephaniah 3 in the BNT
Zephaniah 3 in the BNTABOOT
Zephaniah 3 in the BNTLV
Zephaniah 3 in the BOATCB
Zephaniah 3 in the BOATCB2
Zephaniah 3 in the BOBCV
Zephaniah 3 in the BOCNT
Zephaniah 3 in the BOECS
Zephaniah 3 in the BOGWICC
Zephaniah 3 in the BOHCB
Zephaniah 3 in the BOHCV
Zephaniah 3 in the BOHLNT
Zephaniah 3 in the BOHNTLTAL
Zephaniah 3 in the BOICB
Zephaniah 3 in the BOILNTAP
Zephaniah 3 in the BOITCV
Zephaniah 3 in the BOKCV
Zephaniah 3 in the BOKCV2
Zephaniah 3 in the BOKHWOG
Zephaniah 3 in the BOKSSV
Zephaniah 3 in the BOLCB
Zephaniah 3 in the BOLCB2
Zephaniah 3 in the BOMCV
Zephaniah 3 in the BONAV
Zephaniah 3 in the BONCB
Zephaniah 3 in the BONLT
Zephaniah 3 in the BONUT2
Zephaniah 3 in the BOPLNT
Zephaniah 3 in the BOSCB
Zephaniah 3 in the BOSNC
Zephaniah 3 in the BOTLNT
Zephaniah 3 in the BOVCB
Zephaniah 3 in the BPBB
Zephaniah 3 in the BPH
Zephaniah 3 in the BSB
Zephaniah 3 in the CCB
Zephaniah 3 in the CUV
Zephaniah 3 in the CUVS
Zephaniah 3 in the DBT
Zephaniah 3 in the DGDNT
Zephaniah 3 in the DHNT
Zephaniah 3 in the DNT
Zephaniah 3 in the ELBE
Zephaniah 3 in the EMTV
Zephaniah 3 in the ESV
Zephaniah 3 in the FBV
Zephaniah 3 in the FEB
Zephaniah 3 in the GGMNT
Zephaniah 3 in the GNT
Zephaniah 3 in the HARY
Zephaniah 3 in the HNT
Zephaniah 3 in the IRVA
Zephaniah 3 in the IRVB
Zephaniah 3 in the IRVG
Zephaniah 3 in the IRVH
Zephaniah 3 in the IRVK
Zephaniah 3 in the IRVM
Zephaniah 3 in the IRVM2
Zephaniah 3 in the IRVO
Zephaniah 3 in the IRVP
Zephaniah 3 in the IRVT
Zephaniah 3 in the IRVT2
Zephaniah 3 in the IRVU
Zephaniah 3 in the ISVN
Zephaniah 3 in the JSNT
Zephaniah 3 in the KAPI
Zephaniah 3 in the KBT1ETNIK
Zephaniah 3 in the KBV
Zephaniah 3 in the KJV
Zephaniah 3 in the KNFD
Zephaniah 3 in the LBA
Zephaniah 3 in the LBLA
Zephaniah 3 in the LNT
Zephaniah 3 in the LSV
Zephaniah 3 in the MAAL
Zephaniah 3 in the MBV
Zephaniah 3 in the MBV2
Zephaniah 3 in the MHNT
Zephaniah 3 in the MKNFD
Zephaniah 3 in the MNG
Zephaniah 3 in the MNT
Zephaniah 3 in the MNT2
Zephaniah 3 in the MRS1T
Zephaniah 3 in the NAA
Zephaniah 3 in the NASB
Zephaniah 3 in the NBLA
Zephaniah 3 in the NBS
Zephaniah 3 in the NBVTP
Zephaniah 3 in the NET2
Zephaniah 3 in the NIV11
Zephaniah 3 in the NNT
Zephaniah 3 in the NNT2
Zephaniah 3 in the NNT3
Zephaniah 3 in the PDDPT
Zephaniah 3 in the PFNT
Zephaniah 3 in the RMNT
Zephaniah 3 in the SBIAS
Zephaniah 3 in the SBIBS
Zephaniah 3 in the SBIBS2
Zephaniah 3 in the SBICS
Zephaniah 3 in the SBIDS
Zephaniah 3 in the SBIGS
Zephaniah 3 in the SBIHS
Zephaniah 3 in the SBIIS
Zephaniah 3 in the SBIIS2
Zephaniah 3 in the SBIIS3
Zephaniah 3 in the SBIKS
Zephaniah 3 in the SBIKS2
Zephaniah 3 in the SBIMS
Zephaniah 3 in the SBIOS
Zephaniah 3 in the SBIPS
Zephaniah 3 in the SBISS
Zephaniah 3 in the SBITS
Zephaniah 3 in the SBITS2
Zephaniah 3 in the SBITS3
Zephaniah 3 in the SBITS4
Zephaniah 3 in the SBIUS
Zephaniah 3 in the SBIVS
Zephaniah 3 in the SBT
Zephaniah 3 in the SBT1E
Zephaniah 3 in the SCHL
Zephaniah 3 in the SNT
Zephaniah 3 in the SUSU
Zephaniah 3 in the SUSU2
Zephaniah 3 in the SYNO
Zephaniah 3 in the TBIAOTANT
Zephaniah 3 in the TBT1E
Zephaniah 3 in the TBT1E2
Zephaniah 3 in the TFTIP
Zephaniah 3 in the TFTU
Zephaniah 3 in the TGNTATF3T
Zephaniah 3 in the THAI
Zephaniah 3 in the TNFD
Zephaniah 3 in the TNT
Zephaniah 3 in the TNTIK
Zephaniah 3 in the TNTIL
Zephaniah 3 in the TNTIN
Zephaniah 3 in the TNTIP
Zephaniah 3 in the TNTIZ
Zephaniah 3 in the TOMA
Zephaniah 3 in the TTENT
Zephaniah 3 in the UBG
Zephaniah 3 in the UGV
Zephaniah 3 in the UGV2
Zephaniah 3 in the UGV3
Zephaniah 3 in the VBL
Zephaniah 3 in the VDCC
Zephaniah 3 in the YALU
Zephaniah 3 in the YAPE
Zephaniah 3 in the YBVTP
Zephaniah 3 in the ZBP