Job 33 (BOYCB)
1 “Ǹjẹ́ nítorí náà, Jobu, èmí bẹ̀ ọ,gbọ́ ọ̀rọ̀ mi kí o sì fetísí ọ̀rọ̀ mi! 2 Kíyèsi i nísinsin yìí, èmí ya ẹnu mi,ahọ́n mi sì sọ̀rọ̀ ní ẹnu mi. 3 Ọ̀rọ̀ mi yóò sì jásí ìdúró ṣinṣin ọkàn mi,ètè mi yóò sì sọ ìmọ̀ mi jáde dájúdájú. 4 Ẹ̀mí Ọlọ́run ni ó tí dá mi,àti ìmísí Olódùmarè ni ó ti fún mi ní ìyè. 5 Bí ìwọ bá le dá mi lóhùn,tò ọ̀rọ̀ rẹ̀ lẹ́sẹẹsẹ níwájú mi; 6 kíyèsi i, bí ìwọ ṣe jẹ́ ti Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ ni èmi náà;láti amọ̀ wá ni a sì ti dá mi pẹ̀lú. 7 Kíyèsi i, ẹ̀rù ńlá mi kì yóò bà ọ;bẹ́ẹ̀ ni ọwọ́ mi kì yóò wúwo sí ọ lára. 8 “Nítòótọ́ ìwọ sọ ní etí mi,èmí sì gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀ wí pé, 9 ‘Èmi mọ́, láìní ìrékọjá, aláìṣẹ̀ ní èmi;bẹ́ẹ̀ àìṣedéédéé kò sí ní ọwọ́ mi. 10 Kíyèsi i, Ọlọ́run ti rí àìṣedéédéé pẹ̀lú mi;ó kà mí sì ọ̀tá rẹ̀. 11 Ó kan ẹ̀ṣẹ̀ mi sínú àbà;o kíyèsi ipa ọ̀nà mi gbogbo.’ 12 “Kíyèsi i, nínú èyí ìwọ ṣìnà!Èmi ó dá ọ lóhùn pé, Ọlọ́run tóbi jù ènìyàn lọ! 13 Nítorí kí ni ìwọ ṣe ń bá a jà, wí pé,òun kò ní sọ ọ̀rọ̀ kan nítorí iṣẹ́ rẹ̀? 14 Nítorí pe Ọlọ́run sọ̀rọ̀ lẹ́ẹ̀kan,àní, lẹ́ẹ̀kejì, ṣùgbọ́n ènìyàn kò róye rẹ̀. 15 Nínú àlá, ní ojúran òru,nígbà tí orun èjìká bá kùn ènìyàn lọ,ní sísùn lórí ibùsùn, 16 nígbà náà ni ó lè sọ̀rọ̀ ní etí wọn,yóò sì dẹ́rùbà wọ́n pẹ̀lú ìbáwí, 17 kí ó lè fa ènìyàn sẹ́yìn kúrò nínú ètè rẹ̀;kí ó sì pa ìgbéraga mọ́ kúrò lọ́dọ̀ ènìyàn; 18 Ó sì fa ọkàn rẹ̀ padà kúrò nínú isà òkú,àti ẹ̀mí rẹ̀ láti ṣègbé lọ́wọ́ idà. 19 “A sì nà án lórí ibùsùn ìrora rẹ̀;pẹ̀lúpẹ̀lú a fi ìjà egungun rẹ̀ ti ó dúró pẹ́ nà án, 20 bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀mí rẹ kọ oúnjẹ,ọkàn rẹ̀ sì kọ oúnjẹ dídùn. 21 Ẹran-ara rẹ̀ run, títí a kò sì fi lè rí i mọ́egungun rẹ̀ tí a kò tí rí sì ta jáde. 22 Àní, ọkàn rẹ̀ sì súnmọ́ isà òkú,ẹ̀mí rẹ̀ sì súnmọ́ ọ̀dọ̀ àwọn ìránṣẹ́ ikú. 23 Bí angẹli kan ba wà lọ́dọ̀ rẹ̀,ẹni tí ń ṣe alágbàwí,ọ̀kan nínú ẹgbẹ̀rún (1,000) láti fi ọ̀nà pípé hàn ni, 24 nígbà náà ni ó ṣe oore-ọ̀fẹ́ fún un ó sì wí pé,gbà á kúrò nínú lílọ sínú isà òkú;èmi ti rà á padà. 25 Ara rẹ̀ yóò sì di ọ̀tun bí i ti ọmọ kékeré,yóò sì tún padà sí ọjọ́ ìgbà èwe rẹ̀; 26 Ó gbàdúrà sọ́dọ̀ Ọlọ́run, òun sì ṣe ojúrere rẹ̀,o sì rí ojú rẹ̀ pẹ̀lú ayọ̀,òhun o san òdodo rẹ̀ padà fún ènìyàn. 27 Ó wá sọ́dọ̀ ènìyàn ó sì wí pé,‘Èmi ṣẹ̀, kò sì ṣí èyí tí o tọ́, mo sì ti yí èyí tí ó tọ́ po,a kò sì san ẹ̀san rẹ̀ fún mi; 28 Ọlọ́run ti gba ọkàn mi kúrò nínú lílọ sínú ihò,ẹ̀mí mi yóò wà láti jẹ adùn ìmọ́lẹ̀ ayé.’ 29 “Wò ó! Nǹkan wọ̀nyí ni Ọlọ́runmáa ń ṣe fún ènìyàn nígbà méjì àti nígbà mẹ́ta, 30 láti mú ọkàn rẹ padà kúrò nínú isà òkú,láti fi ìmọ́lẹ̀ alààyè han sí i. 31 “Jobu, kíyèsi i gidigidi, kí o sì fetí sí mi;pa ẹnu rẹ mọ́, èmi ó sì máa sọ ọ́. 32 Bí ìwọ bá sì ní ohun wí, dá mi lóhùn;máa sọ, nítorí pé èmi fẹ́ dá ọ láre. 33 Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, gbọ́ tèmi;pa ẹnu rẹ mọ́, èmi ó sì kọ́ ọ ní ọgbọ́n.”
In Other Versions
Job 33 in the ANGEFD
Job 33 in the ANTPNG2D
Job 33 in the AS21
Job 33 in the BAGH
Job 33 in the BBPNG
Job 33 in the BBT1E
Job 33 in the BDS
Job 33 in the BEV
Job 33 in the BHAD
Job 33 in the BIB
Job 33 in the BLPT
Job 33 in the BNT
Job 33 in the BNTABOOT
Job 33 in the BNTLV
Job 33 in the BOATCB
Job 33 in the BOATCB2
Job 33 in the BOBCV
Job 33 in the BOCNT
Job 33 in the BOECS
Job 33 in the BOGWICC
Job 33 in the BOHCB
Job 33 in the BOHCV
Job 33 in the BOHLNT
Job 33 in the BOHNTLTAL
Job 33 in the BOICB
Job 33 in the BOILNTAP
Job 33 in the BOITCV
Job 33 in the BOKCV
Job 33 in the BOKCV2
Job 33 in the BOKHWOG
Job 33 in the BOKSSV
Job 33 in the BOLCB
Job 33 in the BOLCB2
Job 33 in the BOMCV
Job 33 in the BONAV
Job 33 in the BONCB
Job 33 in the BONLT
Job 33 in the BONUT2
Job 33 in the BOPLNT
Job 33 in the BOSCB
Job 33 in the BOSNC
Job 33 in the BOTLNT
Job 33 in the BOVCB
Job 33 in the BPBB
Job 33 in the BPH
Job 33 in the BSB
Job 33 in the CCB
Job 33 in the CUV
Job 33 in the CUVS
Job 33 in the DBT
Job 33 in the DGDNT
Job 33 in the DHNT
Job 33 in the DNT
Job 33 in the ELBE
Job 33 in the EMTV
Job 33 in the ESV
Job 33 in the FBV
Job 33 in the FEB
Job 33 in the GGMNT
Job 33 in the GNT
Job 33 in the HARY
Job 33 in the HNT
Job 33 in the IRVA
Job 33 in the IRVB
Job 33 in the IRVG
Job 33 in the IRVH
Job 33 in the IRVK
Job 33 in the IRVM
Job 33 in the IRVM2
Job 33 in the IRVO
Job 33 in the IRVP
Job 33 in the IRVT
Job 33 in the IRVT2
Job 33 in the IRVU
Job 33 in the ISVN
Job 33 in the JSNT
Job 33 in the KAPI
Job 33 in the KBT1ETNIK
Job 33 in the KBV
Job 33 in the KJV
Job 33 in the KNFD
Job 33 in the LBA
Job 33 in the LBLA
Job 33 in the LNT
Job 33 in the LSV
Job 33 in the MAAL
Job 33 in the MBV
Job 33 in the MBV2
Job 33 in the MHNT
Job 33 in the MKNFD
Job 33 in the MNG
Job 33 in the MNT
Job 33 in the MNT2
Job 33 in the MRS1T
Job 33 in the NAA
Job 33 in the NASB
Job 33 in the NBLA
Job 33 in the NBS
Job 33 in the NBVTP
Job 33 in the NET2
Job 33 in the NIV11
Job 33 in the NNT
Job 33 in the NNT2
Job 33 in the NNT3
Job 33 in the PDDPT
Job 33 in the PFNT
Job 33 in the RMNT
Job 33 in the SBIAS
Job 33 in the SBIBS
Job 33 in the SBIBS2
Job 33 in the SBICS
Job 33 in the SBIDS
Job 33 in the SBIGS
Job 33 in the SBIHS
Job 33 in the SBIIS
Job 33 in the SBIIS2
Job 33 in the SBIIS3
Job 33 in the SBIKS
Job 33 in the SBIKS2
Job 33 in the SBIMS
Job 33 in the SBIOS
Job 33 in the SBIPS
Job 33 in the SBISS
Job 33 in the SBITS
Job 33 in the SBITS2
Job 33 in the SBITS3
Job 33 in the SBITS4
Job 33 in the SBIUS
Job 33 in the SBIVS
Job 33 in the SBT
Job 33 in the SBT1E
Job 33 in the SCHL
Job 33 in the SNT
Job 33 in the SUSU
Job 33 in the SUSU2
Job 33 in the SYNO
Job 33 in the TBIAOTANT
Job 33 in the TBT1E
Job 33 in the TBT1E2
Job 33 in the TFTIP
Job 33 in the TFTU
Job 33 in the TGNTATF3T
Job 33 in the THAI
Job 33 in the TNFD
Job 33 in the TNT
Job 33 in the TNTIK
Job 33 in the TNTIL
Job 33 in the TNTIN
Job 33 in the TNTIP
Job 33 in the TNTIZ
Job 33 in the TOMA
Job 33 in the TTENT
Job 33 in the UBG
Job 33 in the UGV
Job 33 in the UGV2
Job 33 in the UGV3
Job 33 in the VBL
Job 33 in the VDCC
Job 33 in the YALU
Job 33 in the YAPE
Job 33 in the YBVTP
Job 33 in the ZBP